2 Chronicles 12 (BOYCB)

1 Lẹ́yìn ìgbà tí a fi ìjọba Rehoboamu múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba, tí ó sì ti di alágbára, òun àti gbogbo Israẹli, pẹ̀lú rẹ̀ ni wọ́n pa òfin OLÚWA tì. 2 Nítorí tí wọn kò ṣọ òtítọ́ sí OLÚWA. Ṣiṣaki ọba Ejibiti dojúkọ Jerusalẹmu ní ọdún karùn-ún ti ọba Rehoboamu. 3 Pẹ̀lú ẹgbàá mẹ́fà (12,000) kẹ̀kẹ́ àti ọ̀kẹ́ mẹ́ta (60,000) àwọn ọkùnrin ẹlẹ́ṣin àti àìníye ọ̀wọ́ ogun ti Libia, Sukki àti Kuṣi, tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ láti Ejibiti. 4 Ó fi agbára mú àwọn ìlú ààbò ti Juda, pẹ̀lú wá sí Jerusalẹmu bí ó ti jìnnà tó. 5 Nígbà náà, wòlíì Ṣemaiah wá sí ọ̀dọ̀ Rehoboamu àti sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí Juda tí wọ́n ti péjọ ní Jerusalẹmu nítorí ìbẹ̀rù Ṣiṣaki, ó sì wí fún wọn pé, “Èyí ni ohun tí OLÚWA wí: ìwọ ti pa mí tì; nítorí náà èmi náà ti pa yín tì sí ọ̀dọ̀ Ṣiṣaki.” 6 Àwọn olórí Israẹli àti ọba rẹ̀ ará wọn sílẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Olódodo ni OLÚWA.” 7 Nígbà tí OLÚWA rí i pé, wọ́n ti rẹ̀ ara wọn sílẹ̀ ọ̀rọ̀ OLÚWA yí tọ Ṣemaiah lọ pé, “Níwọ́n ìgbà tí wọ́n ti rẹ ara wọn sílẹ̀, Èmi kì yóò pa wọ́n ṣùgbọ́n, yóò fún wọn ní ìtúsílẹ̀ tó bá yá. Ìbínú mi kì yóò dà sórí Jerusalẹmu ní ipasẹ̀ Ṣiṣaki. 8 Bí ó ti wù kí ó rí, wọn yóò sìn ní abẹ́ rẹ̀, kí wọn kí ó lè mọ̀ ìyàtọ̀ láàrín sí sìn mí àti sí sin àwọn ọba ilẹ̀ mìíràn.” 9 Nígbà tí Ṣiṣaki ọba Ejibiti dojúkọ Jerusalẹmu, ó gbé àwọn ìṣúra ilé OLÚWA, àti àwọn ìṣúra ààfin ọba. Ó gbé gbogbo rẹ̀, pẹ̀lú àwọn àpáta wúrà tí Solomoni dá. 10 Bẹ́ẹ̀ ni, ọba Rehoboamu dá àwọn àpáta idẹ láti fi dípò wọn, ó sì fi èyí lé àwọn alákòóso àti olùṣọ́ tí ó wà ní ẹnu iṣẹ́ ní àbáwọlé ẹnu-ọ̀nà ààfin ọba lọ́wọ́. 11 Ìgbàkígbà tí ọba bá lọ sí ilé OLÚWA, àwọn olùṣọ́ n lọ pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n ń gbé àwọn àpáta náà àti lẹ́yìn, wọ́n dá wọn padà sí yàrá ìṣọ́. 12 Nítorí ti Rehoboamu rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ìbínú OLÚWA yí padà kúrò lórí rẹ̀, a kò sì pa á run pátápátá. Nítòótọ́, ìre díẹ̀ wà ní Juda. 13 Ọba Rehoboamu fi ara rẹ̀ lélẹ̀ gidigidi ní Jerusalẹmu, ó sì tẹ̀síwájú gẹ́gẹ́ bí ọba. Ó jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélógójì nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ní Jerusalẹmu, ìlú ńlá tí OLÚWA ti yàn jáde kúrò nínú gbogbo àwọn ẹ̀yà Israẹli ní èyí tí ó fẹ́ fi orúkọ rẹ̀ síbẹ̀. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Naama, ará Ammoni. 14 O sì ṣe búburú, nítorí tí kò múra nínú ọkàn rẹ̀ láti wá OLÚWA. 15 Fún tí iṣẹ́ ìjọba Rehoboamu láti ìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìrántí ti Ṣemaiah wòlíì àti ti Iddo, aríran tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá? Ìtẹ̀síwájú ogun jíjà sì wà láàrín Rehoboamu àti Jeroboamu. 16 Rehoboamu sun pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sin ín sínú ìlú ńlá ti Dafidi. Abijah ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

In Other Versions

2 Chronicles 12 in the ANGEFD

2 Chronicles 12 in the ANTPNG2D

2 Chronicles 12 in the AS21

2 Chronicles 12 in the BAGH

2 Chronicles 12 in the BBPNG

2 Chronicles 12 in the BBT1E

2 Chronicles 12 in the BDS

2 Chronicles 12 in the BEV

2 Chronicles 12 in the BHAD

2 Chronicles 12 in the BIB

2 Chronicles 12 in the BLPT

2 Chronicles 12 in the BNT

2 Chronicles 12 in the BNTABOOT

2 Chronicles 12 in the BNTLV

2 Chronicles 12 in the BOATCB

2 Chronicles 12 in the BOATCB2

2 Chronicles 12 in the BOBCV

2 Chronicles 12 in the BOCNT

2 Chronicles 12 in the BOECS

2 Chronicles 12 in the BOGWICC

2 Chronicles 12 in the BOHCB

2 Chronicles 12 in the BOHCV

2 Chronicles 12 in the BOHLNT

2 Chronicles 12 in the BOHNTLTAL

2 Chronicles 12 in the BOICB

2 Chronicles 12 in the BOILNTAP

2 Chronicles 12 in the BOITCV

2 Chronicles 12 in the BOKCV

2 Chronicles 12 in the BOKCV2

2 Chronicles 12 in the BOKHWOG

2 Chronicles 12 in the BOKSSV

2 Chronicles 12 in the BOLCB

2 Chronicles 12 in the BOLCB2

2 Chronicles 12 in the BOMCV

2 Chronicles 12 in the BONAV

2 Chronicles 12 in the BONCB

2 Chronicles 12 in the BONLT

2 Chronicles 12 in the BONUT2

2 Chronicles 12 in the BOPLNT

2 Chronicles 12 in the BOSCB

2 Chronicles 12 in the BOSNC

2 Chronicles 12 in the BOTLNT

2 Chronicles 12 in the BOVCB

2 Chronicles 12 in the BPBB

2 Chronicles 12 in the BPH

2 Chronicles 12 in the BSB

2 Chronicles 12 in the CCB

2 Chronicles 12 in the CUV

2 Chronicles 12 in the CUVS

2 Chronicles 12 in the DBT

2 Chronicles 12 in the DGDNT

2 Chronicles 12 in the DHNT

2 Chronicles 12 in the DNT

2 Chronicles 12 in the ELBE

2 Chronicles 12 in the EMTV

2 Chronicles 12 in the ESV

2 Chronicles 12 in the FBV

2 Chronicles 12 in the FEB

2 Chronicles 12 in the GGMNT

2 Chronicles 12 in the GNT

2 Chronicles 12 in the HARY

2 Chronicles 12 in the HNT

2 Chronicles 12 in the IRVA

2 Chronicles 12 in the IRVB

2 Chronicles 12 in the IRVG

2 Chronicles 12 in the IRVH

2 Chronicles 12 in the IRVK

2 Chronicles 12 in the IRVM

2 Chronicles 12 in the IRVM2

2 Chronicles 12 in the IRVO

2 Chronicles 12 in the IRVP

2 Chronicles 12 in the IRVT

2 Chronicles 12 in the IRVT2

2 Chronicles 12 in the IRVU

2 Chronicles 12 in the ISVN

2 Chronicles 12 in the JSNT

2 Chronicles 12 in the KAPI

2 Chronicles 12 in the KBT1ETNIK

2 Chronicles 12 in the KBV

2 Chronicles 12 in the KJV

2 Chronicles 12 in the KNFD

2 Chronicles 12 in the LBA

2 Chronicles 12 in the LBLA

2 Chronicles 12 in the LNT

2 Chronicles 12 in the LSV

2 Chronicles 12 in the MAAL

2 Chronicles 12 in the MBV

2 Chronicles 12 in the MBV2

2 Chronicles 12 in the MHNT

2 Chronicles 12 in the MKNFD

2 Chronicles 12 in the MNG

2 Chronicles 12 in the MNT

2 Chronicles 12 in the MNT2

2 Chronicles 12 in the MRS1T

2 Chronicles 12 in the NAA

2 Chronicles 12 in the NASB

2 Chronicles 12 in the NBLA

2 Chronicles 12 in the NBS

2 Chronicles 12 in the NBVTP

2 Chronicles 12 in the NET2

2 Chronicles 12 in the NIV11

2 Chronicles 12 in the NNT

2 Chronicles 12 in the NNT2

2 Chronicles 12 in the NNT3

2 Chronicles 12 in the PDDPT

2 Chronicles 12 in the PFNT

2 Chronicles 12 in the RMNT

2 Chronicles 12 in the SBIAS

2 Chronicles 12 in the SBIBS

2 Chronicles 12 in the SBIBS2

2 Chronicles 12 in the SBICS

2 Chronicles 12 in the SBIDS

2 Chronicles 12 in the SBIGS

2 Chronicles 12 in the SBIHS

2 Chronicles 12 in the SBIIS

2 Chronicles 12 in the SBIIS2

2 Chronicles 12 in the SBIIS3

2 Chronicles 12 in the SBIKS

2 Chronicles 12 in the SBIKS2

2 Chronicles 12 in the SBIMS

2 Chronicles 12 in the SBIOS

2 Chronicles 12 in the SBIPS

2 Chronicles 12 in the SBISS

2 Chronicles 12 in the SBITS

2 Chronicles 12 in the SBITS2

2 Chronicles 12 in the SBITS3

2 Chronicles 12 in the SBITS4

2 Chronicles 12 in the SBIUS

2 Chronicles 12 in the SBIVS

2 Chronicles 12 in the SBT

2 Chronicles 12 in the SBT1E

2 Chronicles 12 in the SCHL

2 Chronicles 12 in the SNT

2 Chronicles 12 in the SUSU

2 Chronicles 12 in the SUSU2

2 Chronicles 12 in the SYNO

2 Chronicles 12 in the TBIAOTANT

2 Chronicles 12 in the TBT1E

2 Chronicles 12 in the TBT1E2

2 Chronicles 12 in the TFTIP

2 Chronicles 12 in the TFTU

2 Chronicles 12 in the TGNTATF3T

2 Chronicles 12 in the THAI

2 Chronicles 12 in the TNFD

2 Chronicles 12 in the TNT

2 Chronicles 12 in the TNTIK

2 Chronicles 12 in the TNTIL

2 Chronicles 12 in the TNTIN

2 Chronicles 12 in the TNTIP

2 Chronicles 12 in the TNTIZ

2 Chronicles 12 in the TOMA

2 Chronicles 12 in the TTENT

2 Chronicles 12 in the UBG

2 Chronicles 12 in the UGV

2 Chronicles 12 in the UGV2

2 Chronicles 12 in the UGV3

2 Chronicles 12 in the VBL

2 Chronicles 12 in the VDCC

2 Chronicles 12 in the YALU

2 Chronicles 12 in the YAPE

2 Chronicles 12 in the YBVTP

2 Chronicles 12 in the ZBP