2 Chronicles 14 (BOYCB)
1 Abijah sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú Dafidi. Asa ọmọ rẹ̀ sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Ní àwọn ọjọ́ rẹ̀, orílẹ̀-èdè wà ní àlàáfíà fún ọdún mẹ́wàá. 2 Asa ṣe ohun tí ó dára, tí ó sì tọ́ ní ojú OLÚWA Ọlọ́run rẹ̀. 3 Ó gbé àwọn pẹpẹ àjèjì kúrò àti àwọn ibi gíga. Ó fọ́ àwọn òkúta tí a yà sọ́tọ̀, ó sì gé àwọn ère Aṣerah bolẹ̀. 4 Ó pa á láṣẹ fún Juda láti wá OLÚWA Ọlọ́run àwọn baba a wọn àti láti tẹ̀lé àwọn òfin rẹ̀ àti àṣẹ. 5 Ó gbé àwọn ibi gíga kúrò àti àwọn pẹpẹ tùràrí ní gbogbo ìlú ní Juda. Ìjọba sì wà ní àlàáfíà ní abẹ́ rẹ̀. 6 Ó mọ àwọn ìlú ààbò ti Juda, níwọ̀n ìgbà tí ìlú ti wà ní àlàáfíà. Kò sí ẹnikẹ́ni ti o jagun pẹ̀lú rẹ̀ nígbà náà, nítorí OLÚWA fún un ní ìsinmi. 7 “Ẹ jẹ́ kí a kọ́ àwọn ìlú wọ̀nyí,” ó wí fún Juda, “kí ẹ sì mọ odi yí wọn ká pẹ̀lú àwọn ilé ìṣọ́ gíga, àwọn ẹnu-ọ̀nà òde, àti àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀. Ilé náà ti wà, nítorí a ti béèrè lọ́wọ́ OLÚWA Ọlọ́run wa; a béèrè lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì ti fún wa ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kọ́ ọ, wọn sì ṣe rere. 8 Asa ní àwọn ọmọ-ogun ti ó jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000) àwọn ọkùnrin láti Juda. Pẹ̀lú àwọn ohun èlò àwọn àpáta ńlá àti ọ̀kọ̀ àti ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlá (280,000) láti Benjamini wọ́n dira pẹ̀lú àwọn àpáta kéékèèké àti àwọn ọrun. Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ ògbójú jagunjagun ọkùnrin. 9 Sera ará Etiopia yàn láti dojúkọ wọ́n, pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ọmọ-ogun pẹ̀lú ọ̀ọ́dúnrún (300) kẹ̀kẹ́, wọ́n sì wá láti jìnnà réré bí Meraṣa. 10 Asa jáde lọ láti lọ bá a. Wọ́n sì mú ibi ogun ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Sefata lẹ́bàá Meraṣa. 11 Nígbà náà, Asa ké pe OLÚWA Ọlọ́run baba a rẹ̀, ó sì wí pé “OLÚWA kò sí ẹnìkan bí rẹ láti rán aláìlágbára lọ́wọ́ láti dójú kọ alágbára. Ràn wá lọ́wọ́, OLÚWA Ọlọ́run wa, nítorí tí àwa gbẹ́kẹ̀lé ọ àti ní orúkọ rẹ ni àwa fi wá láti dojúkọ àwọn ọ̀pọ̀ ọmọ-ogun yìí. OLÚWA, ìwọ ni Ọlọ́run wa; má ṣe jẹ́ kí ènìyàn kó ṣẹ́gun rẹ.” 12 OLÚWA lu àwọn ará Kuṣi bolẹ̀ níwájú Asa àti Juda. Àwọn ará Kuṣi sálọ. 13 Asa àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ sá tẹ̀lé wọn ní jìnnà réré sí Gerari. Ọ̀pọ̀lọpọ̀, àwọn ará Kuṣi ṣubú, wọn kò sì le sán padà mọ́. Wọn rún wọn mọ́lẹ̀ níwájú OLÚWA àti ọmọ-ogun rẹ̀. Àwọn ọkùnrin Juda kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkógun. 14 Wọ́n pa gbogbo àwọn ìletò tí ó wà ní ẹ̀bá Gerari, nítorí tí ìpayà OLÚWA ti sọ̀kalẹ̀ sórí wọn. Wọ́n kó gbogbo ìkógun àwọn ìletò yìí lọ, níwọ̀n ìgbà tí ọ̀pọ̀ ìkógun ti wà níbẹ̀. 15 Wọ́n kọlu àwọn ibùdó àwọn darandaran, wọ́n sì gbé àwọn ọ̀wọ́ ẹran àgùntàn àti àwọn ewúrẹ́ àti àwọn ìbákasẹ. Nígbà náà wọ́n padà sí Jerusalẹmu.
In Other Versions
2 Chronicles 14 in the ANGEFD
2 Chronicles 14 in the ANTPNG2D
2 Chronicles 14 in the AS21
2 Chronicles 14 in the BAGH
2 Chronicles 14 in the BBPNG
2 Chronicles 14 in the BBT1E
2 Chronicles 14 in the BDS
2 Chronicles 14 in the BEV
2 Chronicles 14 in the BHAD
2 Chronicles 14 in the BIB
2 Chronicles 14 in the BLPT
2 Chronicles 14 in the BNT
2 Chronicles 14 in the BNTABOOT
2 Chronicles 14 in the BNTLV
2 Chronicles 14 in the BOATCB
2 Chronicles 14 in the BOATCB2
2 Chronicles 14 in the BOBCV
2 Chronicles 14 in the BOCNT
2 Chronicles 14 in the BOECS
2 Chronicles 14 in the BOGWICC
2 Chronicles 14 in the BOHCB
2 Chronicles 14 in the BOHCV
2 Chronicles 14 in the BOHLNT
2 Chronicles 14 in the BOHNTLTAL
2 Chronicles 14 in the BOICB
2 Chronicles 14 in the BOILNTAP
2 Chronicles 14 in the BOITCV
2 Chronicles 14 in the BOKCV
2 Chronicles 14 in the BOKCV2
2 Chronicles 14 in the BOKHWOG
2 Chronicles 14 in the BOKSSV
2 Chronicles 14 in the BOLCB
2 Chronicles 14 in the BOLCB2
2 Chronicles 14 in the BOMCV
2 Chronicles 14 in the BONAV
2 Chronicles 14 in the BONCB
2 Chronicles 14 in the BONLT
2 Chronicles 14 in the BONUT2
2 Chronicles 14 in the BOPLNT
2 Chronicles 14 in the BOSCB
2 Chronicles 14 in the BOSNC
2 Chronicles 14 in the BOTLNT
2 Chronicles 14 in the BOVCB
2 Chronicles 14 in the BPBB
2 Chronicles 14 in the BPH
2 Chronicles 14 in the BSB
2 Chronicles 14 in the CCB
2 Chronicles 14 in the CUV
2 Chronicles 14 in the CUVS
2 Chronicles 14 in the DBT
2 Chronicles 14 in the DGDNT
2 Chronicles 14 in the DHNT
2 Chronicles 14 in the DNT
2 Chronicles 14 in the ELBE
2 Chronicles 14 in the EMTV
2 Chronicles 14 in the ESV
2 Chronicles 14 in the FBV
2 Chronicles 14 in the FEB
2 Chronicles 14 in the GGMNT
2 Chronicles 14 in the GNT
2 Chronicles 14 in the HARY
2 Chronicles 14 in the HNT
2 Chronicles 14 in the IRVA
2 Chronicles 14 in the IRVB
2 Chronicles 14 in the IRVG
2 Chronicles 14 in the IRVH
2 Chronicles 14 in the IRVK
2 Chronicles 14 in the IRVM
2 Chronicles 14 in the IRVM2
2 Chronicles 14 in the IRVO
2 Chronicles 14 in the IRVP
2 Chronicles 14 in the IRVT
2 Chronicles 14 in the IRVT2
2 Chronicles 14 in the IRVU
2 Chronicles 14 in the ISVN
2 Chronicles 14 in the JSNT
2 Chronicles 14 in the KAPI
2 Chronicles 14 in the KBT1ETNIK
2 Chronicles 14 in the KBV
2 Chronicles 14 in the KJV
2 Chronicles 14 in the KNFD
2 Chronicles 14 in the LBA
2 Chronicles 14 in the LBLA
2 Chronicles 14 in the LNT
2 Chronicles 14 in the LSV
2 Chronicles 14 in the MAAL
2 Chronicles 14 in the MBV
2 Chronicles 14 in the MBV2
2 Chronicles 14 in the MHNT
2 Chronicles 14 in the MKNFD
2 Chronicles 14 in the MNG
2 Chronicles 14 in the MNT
2 Chronicles 14 in the MNT2
2 Chronicles 14 in the MRS1T
2 Chronicles 14 in the NAA
2 Chronicles 14 in the NASB
2 Chronicles 14 in the NBLA
2 Chronicles 14 in the NBS
2 Chronicles 14 in the NBVTP
2 Chronicles 14 in the NET2
2 Chronicles 14 in the NIV11
2 Chronicles 14 in the NNT
2 Chronicles 14 in the NNT2
2 Chronicles 14 in the NNT3
2 Chronicles 14 in the PDDPT
2 Chronicles 14 in the PFNT
2 Chronicles 14 in the RMNT
2 Chronicles 14 in the SBIAS
2 Chronicles 14 in the SBIBS
2 Chronicles 14 in the SBIBS2
2 Chronicles 14 in the SBICS
2 Chronicles 14 in the SBIDS
2 Chronicles 14 in the SBIGS
2 Chronicles 14 in the SBIHS
2 Chronicles 14 in the SBIIS
2 Chronicles 14 in the SBIIS2
2 Chronicles 14 in the SBIIS3
2 Chronicles 14 in the SBIKS
2 Chronicles 14 in the SBIKS2
2 Chronicles 14 in the SBIMS
2 Chronicles 14 in the SBIOS
2 Chronicles 14 in the SBIPS
2 Chronicles 14 in the SBISS
2 Chronicles 14 in the SBITS
2 Chronicles 14 in the SBITS2
2 Chronicles 14 in the SBITS3
2 Chronicles 14 in the SBITS4
2 Chronicles 14 in the SBIUS
2 Chronicles 14 in the SBIVS
2 Chronicles 14 in the SBT
2 Chronicles 14 in the SBT1E
2 Chronicles 14 in the SCHL
2 Chronicles 14 in the SNT
2 Chronicles 14 in the SUSU
2 Chronicles 14 in the SUSU2
2 Chronicles 14 in the SYNO
2 Chronicles 14 in the TBIAOTANT
2 Chronicles 14 in the TBT1E
2 Chronicles 14 in the TBT1E2
2 Chronicles 14 in the TFTIP
2 Chronicles 14 in the TFTU
2 Chronicles 14 in the TGNTATF3T
2 Chronicles 14 in the THAI
2 Chronicles 14 in the TNFD
2 Chronicles 14 in the TNT
2 Chronicles 14 in the TNTIK
2 Chronicles 14 in the TNTIL
2 Chronicles 14 in the TNTIN
2 Chronicles 14 in the TNTIP
2 Chronicles 14 in the TNTIZ
2 Chronicles 14 in the TOMA
2 Chronicles 14 in the TTENT
2 Chronicles 14 in the UBG
2 Chronicles 14 in the UGV
2 Chronicles 14 in the UGV2
2 Chronicles 14 in the UGV3
2 Chronicles 14 in the VBL
2 Chronicles 14 in the VDCC
2 Chronicles 14 in the YALU
2 Chronicles 14 in the YAPE
2 Chronicles 14 in the YBVTP
2 Chronicles 14 in the ZBP