2 Corinthians 4 (BOYCB)

1 Nítorí náà, níwọ̀n bí ó ti jẹ́ pé nípa àánú Ọlọ́run ni a rí iṣẹ́ ìránṣẹ́ yìí gba, àárẹ̀ kò mú ọkàn wa rara, 2 ṣùgbọ́n àwa tí kọ gbogbo ohun ìkọ̀kọ̀ tí ó ní ìtìjú sílẹ̀, àwa kò rìn ní ẹ̀tàn, bẹ́ẹ̀ ni àwa kò fi ọwọ́ ẹ̀tàn mú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run; ṣùgbọ́n nípa fífi òtítọ́ hàn, àwa ń fi ara wa le ẹ̀rí ọkàn olúkúlùkù ènìyàn lọ́wọ́ níwájú Ọlọ́run. 3 Ṣùgbọ́n báyìí, bí ìyìnrere wa bá sí fi ara sin, ó fi ara sin fún àwọn tí ó ń ṣègbé. 4 Nínú àwọn ẹni tí ọlọ́run ayé yìí ti sọ ọkàn àwọn aláìgbàgbọ́ dí afọ́jú, kí ìmọ́lẹ̀ ìyìnrere Kristi tí ó lógo, ẹni tí í ṣe àwòrán Ọlọ́run, má ṣe mọ́lẹ̀ nínú wọn. 5 Nítorí àwa kò wàásù àwa tìkára wa, bí kò ṣe Kristi Jesu Olúwa; àwa tìkára wa sì jẹ́ ẹrú yín nítorí Jesu. 6 Nítorí Ọlọ́run ni ẹni tí ó wí pé, “Kí ìmọ́lẹ̀ ó tan láti inú òkùnkùn jáde,” òun ní ó ti ń tan mọ́lẹ̀ lọ́kàn wa, láti fún wa ní ìmọ́lẹ̀ ìmọ̀ ògo Ọlọ́run ní ojú Jesu Kristi. 7 Ṣùgbọ́n àwa ní ìṣúra yìí nínú ohun èlò amọ̀, kí ọláńlá agbára náà lè jẹ́ ti Ọlọ́run, kí ó má ṣe ti ọ̀dọ̀ wa wá. 8 A ń pọ́n wa lójú níhà gbogbo, ṣùgbọ́n ara kò ni wá: a ń dààmú wa, ṣùgbọ́n a kò sọ ìrètí nù. 9 A ń ṣe inúnibíni sí wa, ṣùgbọ́n a kò kọ̀ wá sílẹ̀; a ń rẹ̀ wá sílẹ̀ ṣùgbọ́n a kò pa wá run. 10 Nígbà gbogbo àwa ń ru ikú Jesu Olúwa kiri ni ará wa, kí a lè fi ìyè Jesu hàn pẹ̀lú lára wa. 11 Nítorí pé nígbà gbogbo ní a ń fi àwa tí ó wà láààyè fún ikú nítorí Jesu, kí a lè fi ìyè hàn nínú ara kíkú wa pẹ̀lú. 12 Bẹ́ẹ̀ ni ikú ń ṣiṣẹ́ nínú wa, ṣùgbọ́n ìyè ṣiṣẹ́ nínú yín. 13 Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ pé, “Èmi gbàgbọ́, nítorí náà ni èmi ṣe sọ,” pẹ̀lú ẹ̀mí ìgbàgbọ́ kan náà, a tún gbàgbọ́ àti nítorí náà ni àwa sì ṣe ń sọ. 14 Àwa mọ̀ pé, ẹni tí o jí Jesu Olúwa dìde yóò sì jí wa dìde pẹ̀lú nípa Jesu, yóò sì mú wa wà níwájú rẹ̀ pẹ̀lú yín, 15 Nítorí tiyín ní gbogbo rẹ̀, ki ọ̀pẹ lè dí púpọ̀ fún ògo Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí oore-ọ̀fẹ́ ti ń gbòòrò sí i fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn. 16 Nítorí èyí ni àárẹ̀ kò ṣe mú wa; ṣùgbọ́n bí ọkùnrin ti òde wa bá ń parun, síbẹ̀ ọkùnrin tí inú wa ń di tuntun lójoojúmọ́. 17 Nítorí ìpọ́njú díẹ̀ yìí ń pèsè ògo tí ó ní ìwọ̀n ayérayé tí ó pọ̀ rékọjá sílẹ̀ fún wa. 18 Níwọ́n bí kò ti wo ohun tí a ń rí, bí kò ṣé ohun tí a kò rí; nítorí ohun tí a ń rí ni ti ìgbà ìsinsin yìí; ṣùgbọ́n ohun tí a kò rí ni ti ayérayé.

In Other Versions

2 Corinthians 4 in the ANGEFD

2 Corinthians 4 in the ANTPNG2D

2 Corinthians 4 in the AS21

2 Corinthians 4 in the BAGH

2 Corinthians 4 in the BBPNG

2 Corinthians 4 in the BBT1E

2 Corinthians 4 in the BDS

2 Corinthians 4 in the BEV

2 Corinthians 4 in the BHAD

2 Corinthians 4 in the BIB

2 Corinthians 4 in the BLPT

2 Corinthians 4 in the BNT

2 Corinthians 4 in the BNTABOOT

2 Corinthians 4 in the BNTLV

2 Corinthians 4 in the BOATCB

2 Corinthians 4 in the BOATCB2

2 Corinthians 4 in the BOBCV

2 Corinthians 4 in the BOCNT

2 Corinthians 4 in the BOECS

2 Corinthians 4 in the BOGWICC

2 Corinthians 4 in the BOHCB

2 Corinthians 4 in the BOHCV

2 Corinthians 4 in the BOHLNT

2 Corinthians 4 in the BOHNTLTAL

2 Corinthians 4 in the BOICB

2 Corinthians 4 in the BOILNTAP

2 Corinthians 4 in the BOITCV

2 Corinthians 4 in the BOKCV

2 Corinthians 4 in the BOKCV2

2 Corinthians 4 in the BOKHWOG

2 Corinthians 4 in the BOKSSV

2 Corinthians 4 in the BOLCB

2 Corinthians 4 in the BOLCB2

2 Corinthians 4 in the BOMCV

2 Corinthians 4 in the BONAV

2 Corinthians 4 in the BONCB

2 Corinthians 4 in the BONLT

2 Corinthians 4 in the BONUT2

2 Corinthians 4 in the BOPLNT

2 Corinthians 4 in the BOSCB

2 Corinthians 4 in the BOSNC

2 Corinthians 4 in the BOTLNT

2 Corinthians 4 in the BOVCB

2 Corinthians 4 in the BPBB

2 Corinthians 4 in the BPH

2 Corinthians 4 in the BSB

2 Corinthians 4 in the CCB

2 Corinthians 4 in the CUV

2 Corinthians 4 in the CUVS

2 Corinthians 4 in the DBT

2 Corinthians 4 in the DGDNT

2 Corinthians 4 in the DHNT

2 Corinthians 4 in the DNT

2 Corinthians 4 in the ELBE

2 Corinthians 4 in the EMTV

2 Corinthians 4 in the ESV

2 Corinthians 4 in the FBV

2 Corinthians 4 in the FEB

2 Corinthians 4 in the GGMNT

2 Corinthians 4 in the GNT

2 Corinthians 4 in the HARY

2 Corinthians 4 in the HNT

2 Corinthians 4 in the IRVA

2 Corinthians 4 in the IRVB

2 Corinthians 4 in the IRVG

2 Corinthians 4 in the IRVH

2 Corinthians 4 in the IRVK

2 Corinthians 4 in the IRVM

2 Corinthians 4 in the IRVM2

2 Corinthians 4 in the IRVO

2 Corinthians 4 in the IRVP

2 Corinthians 4 in the IRVT

2 Corinthians 4 in the IRVT2

2 Corinthians 4 in the IRVU

2 Corinthians 4 in the ISVN

2 Corinthians 4 in the JSNT

2 Corinthians 4 in the KAPI

2 Corinthians 4 in the KBT1ETNIK

2 Corinthians 4 in the KBV

2 Corinthians 4 in the KJV

2 Corinthians 4 in the KNFD

2 Corinthians 4 in the LBA

2 Corinthians 4 in the LBLA

2 Corinthians 4 in the LNT

2 Corinthians 4 in the LSV

2 Corinthians 4 in the MAAL

2 Corinthians 4 in the MBV

2 Corinthians 4 in the MBV2

2 Corinthians 4 in the MHNT

2 Corinthians 4 in the MKNFD

2 Corinthians 4 in the MNG

2 Corinthians 4 in the MNT

2 Corinthians 4 in the MNT2

2 Corinthians 4 in the MRS1T

2 Corinthians 4 in the NAA

2 Corinthians 4 in the NASB

2 Corinthians 4 in the NBLA

2 Corinthians 4 in the NBS

2 Corinthians 4 in the NBVTP

2 Corinthians 4 in the NET2

2 Corinthians 4 in the NIV11

2 Corinthians 4 in the NNT

2 Corinthians 4 in the NNT2

2 Corinthians 4 in the NNT3

2 Corinthians 4 in the PDDPT

2 Corinthians 4 in the PFNT

2 Corinthians 4 in the RMNT

2 Corinthians 4 in the SBIAS

2 Corinthians 4 in the SBIBS

2 Corinthians 4 in the SBIBS2

2 Corinthians 4 in the SBICS

2 Corinthians 4 in the SBIDS

2 Corinthians 4 in the SBIGS

2 Corinthians 4 in the SBIHS

2 Corinthians 4 in the SBIIS

2 Corinthians 4 in the SBIIS2

2 Corinthians 4 in the SBIIS3

2 Corinthians 4 in the SBIKS

2 Corinthians 4 in the SBIKS2

2 Corinthians 4 in the SBIMS

2 Corinthians 4 in the SBIOS

2 Corinthians 4 in the SBIPS

2 Corinthians 4 in the SBISS

2 Corinthians 4 in the SBITS

2 Corinthians 4 in the SBITS2

2 Corinthians 4 in the SBITS3

2 Corinthians 4 in the SBITS4

2 Corinthians 4 in the SBIUS

2 Corinthians 4 in the SBIVS

2 Corinthians 4 in the SBT

2 Corinthians 4 in the SBT1E

2 Corinthians 4 in the SCHL

2 Corinthians 4 in the SNT

2 Corinthians 4 in the SUSU

2 Corinthians 4 in the SUSU2

2 Corinthians 4 in the SYNO

2 Corinthians 4 in the TBIAOTANT

2 Corinthians 4 in the TBT1E

2 Corinthians 4 in the TBT1E2

2 Corinthians 4 in the TFTIP

2 Corinthians 4 in the TFTU

2 Corinthians 4 in the TGNTATF3T

2 Corinthians 4 in the THAI

2 Corinthians 4 in the TNFD

2 Corinthians 4 in the TNT

2 Corinthians 4 in the TNTIK

2 Corinthians 4 in the TNTIL

2 Corinthians 4 in the TNTIN

2 Corinthians 4 in the TNTIP

2 Corinthians 4 in the TNTIZ

2 Corinthians 4 in the TOMA

2 Corinthians 4 in the TTENT

2 Corinthians 4 in the UBG

2 Corinthians 4 in the UGV

2 Corinthians 4 in the UGV2

2 Corinthians 4 in the UGV3

2 Corinthians 4 in the VBL

2 Corinthians 4 in the VDCC

2 Corinthians 4 in the YALU

2 Corinthians 4 in the YAPE

2 Corinthians 4 in the YBVTP

2 Corinthians 4 in the ZBP