2 Kings 12 (BOYCB)
1 Ní ọdún keje tí Jehu, Jehoaṣi di ọba, ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ogójì ọdún. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Sibia: Ó wá láti Beerṣeba. 2 Jehoaṣi ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú OLÚWA ní gbogbo ọdún tí Jehoiada àlùfáà fi àṣẹ fún un. 3 Àwọn ibi gíga, bí ó ti wù kí ó rí, a kò sí wọn ní ìdí, àwọn ènìyàn sì tẹ̀síwájú láti máa rú ẹbọ àti sísun tùràrí níbẹ̀. 4 Jehoaṣi sọ fún àwọn àlùfáà pé, “Gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ mímọ́ sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA owó tí a gbà ní ìgbà kíka àwọn ènìyàn ìlú, owó tí a gbà láti ọwọ́ olúkúlùkù bí wọ́n ti ṣe jẹ́ ẹ̀yà àti owó tí ó ti ọkàn olúkúlùkù wá tí a mú wá sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. 5 Jẹ́ kí gbogbo àlùfáà gba owó náà lọ́wọ́ ọ̀kan nínú àwọn akápò. Kí a sì lò ó fún tuntun ohunkóhun tí ó bá bàjẹ́ nínú ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe.” 6 Ṣùgbọ́n ní ọdún kẹtàlélógún ọba Jehoaṣi, àwọn àlùfáà kò ì tí ì tún ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe. 7 Nígbà náà, ọba Jehoaṣi pe Jehoiada àlùfáà àti àwọn àlùfáà yòókù, ó sì bi wọ́n pé, “Kí ni ó dé tí ẹ̀yin kò fi tún ìbàjẹ́ tí a ṣe sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe? Ẹ má ṣe gba owó mọ́ lọ́wọ́ àwọn afowópamọ́, ṣùgbọ́n ẹ gbé e kalẹ̀ fún títún ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe.” 8 Àwọn àlùfáà fi ara mọ́ pé wọn kò nígbà owó kankan mọ́ lọ́wọ́ àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀ sì ni, wọn kò sì ní tún ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe mọ́ fúnra wọn. 9 Jehoiada àlùfáà mú àpótí kan, ó sì lu ihò sí ìdérí rẹ̀. Ó gbé e sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ ní apá ọ̀tún bí ẹnìkan ti wọlé tí a kọ́ fún OLÚWA. Àwọn àlùfáà tí ó ṣọ́ ẹnu-ọ̀nà àbáwọlé fi sínú àpótí náà gbogbo owó tí a mú wá sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. 10 Ìgbàkígbà tí wọ́n bá ti rí wí pé owó púpọ̀ wà nínú àpótí, akọ̀wé ọba àti olórí àlùfáà yóò wá, wọ́n á ka owó náà tí wọ́n ti mú wá sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. Wọn a sì kó o sínú àwọn àpò. 11 Nígbà tí wọ́n bá ti pinnu iye rẹ̀, wọn a kó owó náà fún àwọn tí a ti yàn láti bojútó iṣẹ́ náà lórí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. Pẹ̀lú u rẹ̀, wọ́n sọ fún àwọn tí ó ń ṣiṣẹ́ lórí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA; àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà àti àwọn olùkọ́lé. 12 Àwọn ilé ńlá àti àwọn agékúta. Wọ́n ra igi gẹdú àti òkúta tí wọ́n tọ́jú fún tuntun ilé tí a kọ́ fún OLÚWA ṣe. Wọ́n tún ohun gbogbo tí wọ́n ná fún títún tẹmpili ṣe. 13 Owó tí a mú wá sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA kò jẹ́ níná fún ṣíṣe òpó fàdákà, ohun èlò ta fi ń fa ẹnu fìtílà, àwokòtò, ìpè, ohun èlò wúrà tàbí ohun èlò fàdákà kan fún ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. 14 A sì san án fún àwọn ọkùnrin tí ó ń ṣiṣẹ́, tí wọ́n ń tọ́jú ilé tí a kọ́ fún OLÚWA. 15 Wọn kò sì bá àwọn ọkùnrin náà ṣírò, ní ọwọ́ ẹni tí wọ́n fún ní owó láti san fún àwọn òṣìṣẹ́. Torí wọ́n ṣe é pẹ̀lú òdodo tí ó pé. 16 Owó láti ibi ọrẹ ẹ̀bi àti ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀ ní a kò mú wá sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA, ó jẹ́ ti àwọn àlùfáà. 17 Ní déédé àkókò yìí, Hasaeli ọba Siria gòkè lọ láti dojúkọ Gati àti láti fi agbára mú un. Nígbà náà, ó yípadà láti dojúkọ Jerusalẹmu. 18 Ṣùgbọ́n Jehoaṣi ọba Juda mú gbogbo ohun mímọ́ tí a gbé ka iwájú tí a yà sọ́tọ̀ nípasẹ̀ baba rẹ̀ Jehoṣafati, Jehoramu àti Ahasiah, àwọn ọba Juda, àti àwọn ẹ̀bùn tí òun tìkára rẹ̀ ti yà sọ́tọ̀ àti gbogbo wúrà, tí ó rí nínú ibi ìfowópamọ́ sí ilé tí a kọ́ fún OLÚWA àti ní ti ààfin ọba, ó sì fi wọ́n ránṣẹ́ sí Hasaeli; ọba Siria, tí ó sì fà padà kúrò ní Jerusalẹmu. 19 Pẹ̀lú ìyókù ìṣe Joaṣi, àti ohun gbogbo tí ó ṣe, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Juda? 20 Àwọn oníṣẹ́ rẹ̀ dìtẹ̀ sí i wọ́n sì lù ú pa ní Beti-Milo ní ọ̀nà sí Silla. 21 Àwọn oníṣẹ́ tí ó pa á jẹ́ Josabadi ọmọ Ṣimeati àti Jehosabadi ọmọ Ṣomeri. Ó kú, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú baba rẹ̀ ní ìlú ńlá ti Dafidi. Amasiah ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.
In Other Versions
2 Kings 12 in the ANGEFD
2 Kings 12 in the ANTPNG2D
2 Kings 12 in the AS21
2 Kings 12 in the BAGH
2 Kings 12 in the BBPNG
2 Kings 12 in the BBT1E
2 Kings 12 in the BDS
2 Kings 12 in the BEV
2 Kings 12 in the BHAD
2 Kings 12 in the BIB
2 Kings 12 in the BLPT
2 Kings 12 in the BNT
2 Kings 12 in the BNTABOOT
2 Kings 12 in the BNTLV
2 Kings 12 in the BOATCB
2 Kings 12 in the BOATCB2
2 Kings 12 in the BOBCV
2 Kings 12 in the BOCNT
2 Kings 12 in the BOECS
2 Kings 12 in the BOGWICC
2 Kings 12 in the BOHCB
2 Kings 12 in the BOHCV
2 Kings 12 in the BOHLNT
2 Kings 12 in the BOHNTLTAL
2 Kings 12 in the BOICB
2 Kings 12 in the BOILNTAP
2 Kings 12 in the BOITCV
2 Kings 12 in the BOKCV
2 Kings 12 in the BOKCV2
2 Kings 12 in the BOKHWOG
2 Kings 12 in the BOKSSV
2 Kings 12 in the BOLCB
2 Kings 12 in the BOLCB2
2 Kings 12 in the BOMCV
2 Kings 12 in the BONAV
2 Kings 12 in the BONCB
2 Kings 12 in the BONLT
2 Kings 12 in the BONUT2
2 Kings 12 in the BOPLNT
2 Kings 12 in the BOSCB
2 Kings 12 in the BOSNC
2 Kings 12 in the BOTLNT
2 Kings 12 in the BOVCB
2 Kings 12 in the BPBB
2 Kings 12 in the BPH
2 Kings 12 in the BSB
2 Kings 12 in the CCB
2 Kings 12 in the CUV
2 Kings 12 in the CUVS
2 Kings 12 in the DBT
2 Kings 12 in the DGDNT
2 Kings 12 in the DHNT
2 Kings 12 in the DNT
2 Kings 12 in the ELBE
2 Kings 12 in the EMTV
2 Kings 12 in the ESV
2 Kings 12 in the FBV
2 Kings 12 in the FEB
2 Kings 12 in the GGMNT
2 Kings 12 in the GNT
2 Kings 12 in the HARY
2 Kings 12 in the HNT
2 Kings 12 in the IRVA
2 Kings 12 in the IRVB
2 Kings 12 in the IRVG
2 Kings 12 in the IRVH
2 Kings 12 in the IRVK
2 Kings 12 in the IRVM
2 Kings 12 in the IRVM2
2 Kings 12 in the IRVO
2 Kings 12 in the IRVP
2 Kings 12 in the IRVT
2 Kings 12 in the IRVT2
2 Kings 12 in the IRVU
2 Kings 12 in the ISVN
2 Kings 12 in the JSNT
2 Kings 12 in the KAPI
2 Kings 12 in the KBT1ETNIK
2 Kings 12 in the KBV
2 Kings 12 in the KJV
2 Kings 12 in the KNFD
2 Kings 12 in the LBA
2 Kings 12 in the LBLA
2 Kings 12 in the LNT
2 Kings 12 in the LSV
2 Kings 12 in the MAAL
2 Kings 12 in the MBV
2 Kings 12 in the MBV2
2 Kings 12 in the MHNT
2 Kings 12 in the MKNFD
2 Kings 12 in the MNG
2 Kings 12 in the MNT
2 Kings 12 in the MNT2
2 Kings 12 in the MRS1T
2 Kings 12 in the NAA
2 Kings 12 in the NASB
2 Kings 12 in the NBLA
2 Kings 12 in the NBS
2 Kings 12 in the NBVTP
2 Kings 12 in the NET2
2 Kings 12 in the NIV11
2 Kings 12 in the NNT
2 Kings 12 in the NNT2
2 Kings 12 in the NNT3
2 Kings 12 in the PDDPT
2 Kings 12 in the PFNT
2 Kings 12 in the RMNT
2 Kings 12 in the SBIAS
2 Kings 12 in the SBIBS
2 Kings 12 in the SBIBS2
2 Kings 12 in the SBICS
2 Kings 12 in the SBIDS
2 Kings 12 in the SBIGS
2 Kings 12 in the SBIHS
2 Kings 12 in the SBIIS
2 Kings 12 in the SBIIS2
2 Kings 12 in the SBIIS3
2 Kings 12 in the SBIKS
2 Kings 12 in the SBIKS2
2 Kings 12 in the SBIMS
2 Kings 12 in the SBIOS
2 Kings 12 in the SBIPS
2 Kings 12 in the SBISS
2 Kings 12 in the SBITS
2 Kings 12 in the SBITS2
2 Kings 12 in the SBITS3
2 Kings 12 in the SBITS4
2 Kings 12 in the SBIUS
2 Kings 12 in the SBIVS
2 Kings 12 in the SBT
2 Kings 12 in the SBT1E
2 Kings 12 in the SCHL
2 Kings 12 in the SNT
2 Kings 12 in the SUSU
2 Kings 12 in the SUSU2
2 Kings 12 in the SYNO
2 Kings 12 in the TBIAOTANT
2 Kings 12 in the TBT1E
2 Kings 12 in the TBT1E2
2 Kings 12 in the TFTIP
2 Kings 12 in the TFTU
2 Kings 12 in the TGNTATF3T
2 Kings 12 in the THAI
2 Kings 12 in the TNFD
2 Kings 12 in the TNT
2 Kings 12 in the TNTIK
2 Kings 12 in the TNTIL
2 Kings 12 in the TNTIN
2 Kings 12 in the TNTIP
2 Kings 12 in the TNTIZ
2 Kings 12 in the TOMA
2 Kings 12 in the TTENT
2 Kings 12 in the UBG
2 Kings 12 in the UGV
2 Kings 12 in the UGV2
2 Kings 12 in the UGV3
2 Kings 12 in the VBL
2 Kings 12 in the VDCC
2 Kings 12 in the YALU
2 Kings 12 in the YAPE
2 Kings 12 in the YBVTP
2 Kings 12 in the ZBP