Amos 1 (BOYCB)

1 Àwọn ọ̀rọ̀ Amosi, ọ̀kan lára àwọn olùṣọ́-àgùntàn Tekoa; ohun tí o rí nípa Israẹli ní ọdún méjì ṣáájú ilẹ̀-rírì, nígbà tí Ussiah ọba Juda àti Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli. 2 Ó wí pé,“OLÚWA yóò bú jáde láti Sioni,ohùn rẹ̀ yóò sì sán bí àrá láti Jerusalẹmu wá;ibùgbé àwọn olùṣọ́-àgùntàn yóò sì ṣọ̀fọ̀,orí òkè Karmeli yóò sì rọ.” 3 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí Damasku,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Nítorí wọn fi ohun èlò ìpakà pa Gileadi.Pẹ̀lú ohun èlò irin tí ó ní eyín mímú, 4 Èmi yóò rán iná sí ilé Hasaeli,èyí ti yóò jó àwọn ààfin Beni-Hadadi run. 5 Èmi yóò ṣẹ́ ọ̀pá ìdábùú Damasku;Èmi yóò sì pa ọba tí ó wà ní àfonífojì Afeni runàti ẹni tí ó di ọ̀pá aládé mú ní Beti-Edeni.Àwọn ará a Aramu yóò lọ sí ìgbèkùn sí Kiri,”ni OLÚWA wí. 6 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta Gasa,àní nítorí mẹ́rin,Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Gẹ́gẹ́ bí í oníṣòwò ẹrú,ó kó gbogbo àwọn ènìyàn mi ní ìgbèkùn.Ó sì tà wọ́n fún Edomu, 7 Èmi yóò rán iná sí ara odi Gasatí yóò jó gbogbo ààfin rẹ̀ run. 8 Èmi yóò ké àwọn olùgbé Aṣdodu kúrò,ti ẹni tí ó di ọ̀pá aládé ní Aṣkeloni mú.Èmi yóò yí ọwọ́ mi sí Ekronitítí tí ìyókù Filistini yóò fi ṣègbé,”ni OLÚWA Olódùmarè wí. 9 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Tireàní nítorí mẹ́rin, Èmi kì yóò yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Nítorí wọ́n ta gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà ní ìgbèkùn fún Edomu.Wọn kò sì náání májẹ̀mú ọbàkan, 10 Èmi yóò rán iná sí ara odi Tire,tí yóò jó gbogbo àwọn ààfin rẹ̀ run.” 11 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí Edomu,àní nítorí mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Nítorí òhun fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,Ó sì gbé gbogbo àánú sọnù,ìbínú rẹ̀ sì ń faniya títí,ó sì pa ìbínú rẹ̀ bí èéfín mọ́, 12 Èmi yóò rán iná sí orí Temani,tí yóò jó gbogbo ààfin Bosra run.” 13 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Ammoni,àní mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Nítorí wọn ti la inú àwọn aboyún Gileadikí wọ́n ba à lè fẹ ilẹ̀ wọn sẹ́yìn. 14 Èmi yóò rán iná sí ara odi Rabbaèyí tí yóò jó àwọn ààfin rẹ̀ runpẹ̀lú ìhó ayọ̀ ní ọjọ́ ogun,pẹ̀lú ìjì líle ni ọjọ́ àjà. 15 Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùn,òun àti àwọn ọmọ-aládé rẹ̀ lápapọ̀,”ni OLÚWA wí.

In Other Versions

Amos 1 in the ANGEFD

Amos 1 in the ANTPNG2D

Amos 1 in the AS21

Amos 1 in the BAGH

Amos 1 in the BBPNG

Amos 1 in the BBT1E

Amos 1 in the BDS

Amos 1 in the BEV

Amos 1 in the BHAD

Amos 1 in the BIB

Amos 1 in the BLPT

Amos 1 in the BNT

Amos 1 in the BNTABOOT

Amos 1 in the BNTLV

Amos 1 in the BOATCB

Amos 1 in the BOATCB2

Amos 1 in the BOBCV

Amos 1 in the BOCNT

Amos 1 in the BOECS

Amos 1 in the BOGWICC

Amos 1 in the BOHCB

Amos 1 in the BOHCV

Amos 1 in the BOHLNT

Amos 1 in the BOHNTLTAL

Amos 1 in the BOICB

Amos 1 in the BOILNTAP

Amos 1 in the BOITCV

Amos 1 in the BOKCV

Amos 1 in the BOKCV2

Amos 1 in the BOKHWOG

Amos 1 in the BOKSSV

Amos 1 in the BOLCB

Amos 1 in the BOLCB2

Amos 1 in the BOMCV

Amos 1 in the BONAV

Amos 1 in the BONCB

Amos 1 in the BONLT

Amos 1 in the BONUT2

Amos 1 in the BOPLNT

Amos 1 in the BOSCB

Amos 1 in the BOSNC

Amos 1 in the BOTLNT

Amos 1 in the BOVCB

Amos 1 in the BPBB

Amos 1 in the BPH

Amos 1 in the BSB

Amos 1 in the CCB

Amos 1 in the CUV

Amos 1 in the CUVS

Amos 1 in the DBT

Amos 1 in the DGDNT

Amos 1 in the DHNT

Amos 1 in the DNT

Amos 1 in the ELBE

Amos 1 in the EMTV

Amos 1 in the ESV

Amos 1 in the FBV

Amos 1 in the FEB

Amos 1 in the GGMNT

Amos 1 in the GNT

Amos 1 in the HARY

Amos 1 in the HNT

Amos 1 in the IRVA

Amos 1 in the IRVB

Amos 1 in the IRVG

Amos 1 in the IRVH

Amos 1 in the IRVK

Amos 1 in the IRVM

Amos 1 in the IRVM2

Amos 1 in the IRVO

Amos 1 in the IRVP

Amos 1 in the IRVT

Amos 1 in the IRVT2

Amos 1 in the IRVU

Amos 1 in the ISVN

Amos 1 in the JSNT

Amos 1 in the KAPI

Amos 1 in the KBT1ETNIK

Amos 1 in the KBV

Amos 1 in the KJV

Amos 1 in the KNFD

Amos 1 in the LBA

Amos 1 in the LBLA

Amos 1 in the LNT

Amos 1 in the LSV

Amos 1 in the MAAL

Amos 1 in the MBV

Amos 1 in the MBV2

Amos 1 in the MHNT

Amos 1 in the MKNFD

Amos 1 in the MNG

Amos 1 in the MNT

Amos 1 in the MNT2

Amos 1 in the MRS1T

Amos 1 in the NAA

Amos 1 in the NASB

Amos 1 in the NBLA

Amos 1 in the NBS

Amos 1 in the NBVTP

Amos 1 in the NET2

Amos 1 in the NIV11

Amos 1 in the NNT

Amos 1 in the NNT2

Amos 1 in the NNT3

Amos 1 in the PDDPT

Amos 1 in the PFNT

Amos 1 in the RMNT

Amos 1 in the SBIAS

Amos 1 in the SBIBS

Amos 1 in the SBIBS2

Amos 1 in the SBICS

Amos 1 in the SBIDS

Amos 1 in the SBIGS

Amos 1 in the SBIHS

Amos 1 in the SBIIS

Amos 1 in the SBIIS2

Amos 1 in the SBIIS3

Amos 1 in the SBIKS

Amos 1 in the SBIKS2

Amos 1 in the SBIMS

Amos 1 in the SBIOS

Amos 1 in the SBIPS

Amos 1 in the SBISS

Amos 1 in the SBITS

Amos 1 in the SBITS2

Amos 1 in the SBITS3

Amos 1 in the SBITS4

Amos 1 in the SBIUS

Amos 1 in the SBIVS

Amos 1 in the SBT

Amos 1 in the SBT1E

Amos 1 in the SCHL

Amos 1 in the SNT

Amos 1 in the SUSU

Amos 1 in the SUSU2

Amos 1 in the SYNO

Amos 1 in the TBIAOTANT

Amos 1 in the TBT1E

Amos 1 in the TBT1E2

Amos 1 in the TFTIP

Amos 1 in the TFTU

Amos 1 in the TGNTATF3T

Amos 1 in the THAI

Amos 1 in the TNFD

Amos 1 in the TNT

Amos 1 in the TNTIK

Amos 1 in the TNTIL

Amos 1 in the TNTIN

Amos 1 in the TNTIP

Amos 1 in the TNTIZ

Amos 1 in the TOMA

Amos 1 in the TTENT

Amos 1 in the UBG

Amos 1 in the UGV

Amos 1 in the UGV2

Amos 1 in the UGV3

Amos 1 in the VBL

Amos 1 in the VDCC

Amos 1 in the YALU

Amos 1 in the YAPE

Amos 1 in the YBVTP

Amos 1 in the ZBP