Deuteronomy 18 (BOYCB)

1 Àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Lefi, àní gbogbo ẹ̀yà Lefi, wọn kì yóò ní ìpín tàbí ogún láàrín Israẹli, wọn yóò máa jẹ nínú ọrẹ ẹbọ tí a fi iná ṣe sí OLÚWA, nítorí òun ni ogún un tiwọn. 2 Wọn kì yóò ní ìní láàrín àwọn arákùnrin wọn; OLÚWA ni yóò jẹ́ ìní i tiwọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí fún wọn. 3 Gbogbo èyí ni yóò jẹ́ ìpín àwọn àlùfáà láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn tí ó fi akọ màlúù tàbí àgùntàn rú ẹbọ; wọn yóò fi èjìká àti ẹ̀rẹ̀kẹ́ méjèèjì àti gbogbo inú fún àlùfáà. 4 Àkọ́so irúgbìn ọkà rẹ, ti wáìnì àti ti òróró rẹ, àti àkọ́rẹ́ irun àgùntàn rẹ ni ìwọ yóò fi fún wọn. 5 Nítorí OLÚWA Ọlọ́run rẹ ti yàn wọ́n àti àwọn ọmọ wọn láti inú gbogbo ẹ̀yà láti dúró àti láti ṣe ìránṣẹ́ ní orúkọ OLÚWA títí láé. 6 Tí ọmọ Lefi kan bá sì wá láti ibikíbi nínú àwọn ìlú u yín ní Israẹli, níbi tí ó ń gbé ṣe àtìpó, tí ó sì wá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀ sí ibi tí OLÚWA yóò yàn. 7 Nígbà náà ni ó lè máa ṣe ìránṣẹ́ ní orúkọ OLÚWA Ọlọ́run rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Lefi arákùnrin rẹ̀ ti ń dúró ṣe iṣẹ́ ìsìn níwájú OLÚWA níbẹ̀. 8 Wọn yóò ní ìpín kan láti jẹ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti gba owó nípa títa ogún baba rẹ̀. 9 Nígbà tí o bá wọ ilẹ̀ tí OLÚWA Ọlọ́run rẹ yóò fi fún ọ, ìwọ kò gbọdọ̀ kọ́ láti tẹ̀lé àwọn ọ̀nà ìríra àwọn orílẹ̀-èdè náà tí ó wà níbẹ̀. 10 Má ṣe jẹ́ kí a rí ẹnikẹ́ni láàrín yín tí ó fi ọmọ rẹ̀ ọkùnrin tàbí ọmọ rẹ̀ obìnrin la iná já (fi ọmọ rẹ rú ẹbọ) kí ẹnikẹ́ni má ṣe lọ fọ àfọ̀ṣẹ, tàbí ṣẹ́ oṣó, tàbí túmọ̀ àwọn àmì nǹkan tí ń bọ̀, tàbí àjẹ́, 11 tàbí afògèdè, tàbí jẹ́ a bá iwin gbìmọ̀ tàbí oṣó tàbí abókùúsọ̀rọ̀. 12 Ẹnikẹ́ni tó bá ṣe nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ìríra sí OLÚWA, àti nítorí àwọn ìwà ìríra wọ̀nyí ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ yóò fi lé àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí jáde kúrò níwájú rẹ. 13 O ní láti jẹ́ aláìlẹ́gàn níwájú OLÚWA Ọlọ́run rẹ. 14 Àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ yóò gba ilẹ̀ tí wọ́n ń gbé, wọ́n fetí sí tí àwọn tí ó ń ṣe oṣó tàbí ṣe àfọ̀ṣẹ. Ṣùgbọ́n, ní ti ìwọ, OLÚWA Ọlọ́run rẹ kò fi ààyè gbà ọ́ láti ṣe bẹ́ẹ̀. 15 OLÚWA Ọlọ́run rẹ yóò gbé wòlíì kan dìde gẹ́gẹ́ bí èmi láàrín àwọn arákùnrin rẹ. Tìrẹ ni kí o gbọ́. 16 Nítorí èyí ni ohun tí ìwọ béèrè lọ́wọ́ OLÚWA Ọlọ́run rẹ ní Horebu ní ọjọ́ àjọ, nígbà tí ìwọ wí pé, “Kí àwa má ṣe gbọ́ ohùn OLÚWA Ọlọ́run wa tàbí rí iná ńlá yìí mọ́. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́ àwa yóò kú.” 17 OLÚWA sì wí fún mi pé, “Ohun tí wọ́n sọ dára. 18 Èmi yóò gbé wòlíì kan dìde fún wọn láàrín àwọn arákùnrin wọn bí ìwọ, Èmi yóò fi ọ̀rọ̀ mi sí i ní ẹnu, yóò sì sọ fún wọn gbogbo ohun tí mo ti paláṣẹ fún un. 19 Ẹnikẹ́ni tí kò bá sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ mi tí wòlíì náà yóò sọ ní orúkọ mi, èmi fúnra à mi yóò sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀. 20 Ṣùgbọ́n bí wòlíì kan bá kùgbù sọ ọ̀rọ̀ kan tí èmi kò paláṣẹ fún un láti sọ ní orúkọ mi tàbí wòlíì tí ó sọ̀rọ̀ ní orúkọ ọlọ́run mìíràn, irú wòlíì bẹ́ẹ̀ ní láti kú.” 21 Ṣùgbọ́n ìwọ lè wí ní ọkàn rẹ pé, “Báwo ni àwa yóò ṣe mọ ọ̀rọ̀ tí OLÚWA kò sọ?” 22 Nígbà tí ohun tí wòlíì bá sọ ní orúkọ OLÚWA kò bá wá sí ìmúṣẹ tàbí jẹ́ òtítọ́, ìyẹn ni ọ̀rọ̀ tí OLÚWA kò sọ, irú wòlíì bẹ́ẹ̀ tí sọ láìwádìí. Kí ẹ má ṣe bẹ̀rù rẹ̀.

In Other Versions

Deuteronomy 18 in the ANGEFD

Deuteronomy 18 in the ANTPNG2D

Deuteronomy 18 in the AS21

Deuteronomy 18 in the BAGH

Deuteronomy 18 in the BBPNG

Deuteronomy 18 in the BBT1E

Deuteronomy 18 in the BDS

Deuteronomy 18 in the BEV

Deuteronomy 18 in the BHAD

Deuteronomy 18 in the BIB

Deuteronomy 18 in the BLPT

Deuteronomy 18 in the BNT

Deuteronomy 18 in the BNTABOOT

Deuteronomy 18 in the BNTLV

Deuteronomy 18 in the BOATCB

Deuteronomy 18 in the BOATCB2

Deuteronomy 18 in the BOBCV

Deuteronomy 18 in the BOCNT

Deuteronomy 18 in the BOECS

Deuteronomy 18 in the BOGWICC

Deuteronomy 18 in the BOHCB

Deuteronomy 18 in the BOHCV

Deuteronomy 18 in the BOHLNT

Deuteronomy 18 in the BOHNTLTAL

Deuteronomy 18 in the BOICB

Deuteronomy 18 in the BOILNTAP

Deuteronomy 18 in the BOITCV

Deuteronomy 18 in the BOKCV

Deuteronomy 18 in the BOKCV2

Deuteronomy 18 in the BOKHWOG

Deuteronomy 18 in the BOKSSV

Deuteronomy 18 in the BOLCB

Deuteronomy 18 in the BOLCB2

Deuteronomy 18 in the BOMCV

Deuteronomy 18 in the BONAV

Deuteronomy 18 in the BONCB

Deuteronomy 18 in the BONLT

Deuteronomy 18 in the BONUT2

Deuteronomy 18 in the BOPLNT

Deuteronomy 18 in the BOSCB

Deuteronomy 18 in the BOSNC

Deuteronomy 18 in the BOTLNT

Deuteronomy 18 in the BOVCB

Deuteronomy 18 in the BPBB

Deuteronomy 18 in the BPH

Deuteronomy 18 in the BSB

Deuteronomy 18 in the CCB

Deuteronomy 18 in the CUV

Deuteronomy 18 in the CUVS

Deuteronomy 18 in the DBT

Deuteronomy 18 in the DGDNT

Deuteronomy 18 in the DHNT

Deuteronomy 18 in the DNT

Deuteronomy 18 in the ELBE

Deuteronomy 18 in the EMTV

Deuteronomy 18 in the ESV

Deuteronomy 18 in the FBV

Deuteronomy 18 in the FEB

Deuteronomy 18 in the GGMNT

Deuteronomy 18 in the GNT

Deuteronomy 18 in the HARY

Deuteronomy 18 in the HNT

Deuteronomy 18 in the IRVA

Deuteronomy 18 in the IRVB

Deuteronomy 18 in the IRVG

Deuteronomy 18 in the IRVH

Deuteronomy 18 in the IRVK

Deuteronomy 18 in the IRVM

Deuteronomy 18 in the IRVM2

Deuteronomy 18 in the IRVO

Deuteronomy 18 in the IRVP

Deuteronomy 18 in the IRVT

Deuteronomy 18 in the IRVT2

Deuteronomy 18 in the IRVU

Deuteronomy 18 in the ISVN

Deuteronomy 18 in the JSNT

Deuteronomy 18 in the KAPI

Deuteronomy 18 in the KBT1ETNIK

Deuteronomy 18 in the KBV

Deuteronomy 18 in the KJV

Deuteronomy 18 in the KNFD

Deuteronomy 18 in the LBA

Deuteronomy 18 in the LBLA

Deuteronomy 18 in the LNT

Deuteronomy 18 in the LSV

Deuteronomy 18 in the MAAL

Deuteronomy 18 in the MBV

Deuteronomy 18 in the MBV2

Deuteronomy 18 in the MHNT

Deuteronomy 18 in the MKNFD

Deuteronomy 18 in the MNG

Deuteronomy 18 in the MNT

Deuteronomy 18 in the MNT2

Deuteronomy 18 in the MRS1T

Deuteronomy 18 in the NAA

Deuteronomy 18 in the NASB

Deuteronomy 18 in the NBLA

Deuteronomy 18 in the NBS

Deuteronomy 18 in the NBVTP

Deuteronomy 18 in the NET2

Deuteronomy 18 in the NIV11

Deuteronomy 18 in the NNT

Deuteronomy 18 in the NNT2

Deuteronomy 18 in the NNT3

Deuteronomy 18 in the PDDPT

Deuteronomy 18 in the PFNT

Deuteronomy 18 in the RMNT

Deuteronomy 18 in the SBIAS

Deuteronomy 18 in the SBIBS

Deuteronomy 18 in the SBIBS2

Deuteronomy 18 in the SBICS

Deuteronomy 18 in the SBIDS

Deuteronomy 18 in the SBIGS

Deuteronomy 18 in the SBIHS

Deuteronomy 18 in the SBIIS

Deuteronomy 18 in the SBIIS2

Deuteronomy 18 in the SBIIS3

Deuteronomy 18 in the SBIKS

Deuteronomy 18 in the SBIKS2

Deuteronomy 18 in the SBIMS

Deuteronomy 18 in the SBIOS

Deuteronomy 18 in the SBIPS

Deuteronomy 18 in the SBISS

Deuteronomy 18 in the SBITS

Deuteronomy 18 in the SBITS2

Deuteronomy 18 in the SBITS3

Deuteronomy 18 in the SBITS4

Deuteronomy 18 in the SBIUS

Deuteronomy 18 in the SBIVS

Deuteronomy 18 in the SBT

Deuteronomy 18 in the SBT1E

Deuteronomy 18 in the SCHL

Deuteronomy 18 in the SNT

Deuteronomy 18 in the SUSU

Deuteronomy 18 in the SUSU2

Deuteronomy 18 in the SYNO

Deuteronomy 18 in the TBIAOTANT

Deuteronomy 18 in the TBT1E

Deuteronomy 18 in the TBT1E2

Deuteronomy 18 in the TFTIP

Deuteronomy 18 in the TFTU

Deuteronomy 18 in the TGNTATF3T

Deuteronomy 18 in the THAI

Deuteronomy 18 in the TNFD

Deuteronomy 18 in the TNT

Deuteronomy 18 in the TNTIK

Deuteronomy 18 in the TNTIL

Deuteronomy 18 in the TNTIN

Deuteronomy 18 in the TNTIP

Deuteronomy 18 in the TNTIZ

Deuteronomy 18 in the TOMA

Deuteronomy 18 in the TTENT

Deuteronomy 18 in the UBG

Deuteronomy 18 in the UGV

Deuteronomy 18 in the UGV2

Deuteronomy 18 in the UGV3

Deuteronomy 18 in the VBL

Deuteronomy 18 in the VDCC

Deuteronomy 18 in the YALU

Deuteronomy 18 in the YAPE

Deuteronomy 18 in the YBVTP

Deuteronomy 18 in the ZBP