Ephesians 2 (BOYCB)
1 Ní ti ẹ̀yin, ẹ̀yin ni ó sì ti sọ di ààyè, nígbà ti ẹ̀yin ti kú nítorí ìrékọjá àti àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín, 2 nínú èyí tí ẹ̀yin ti gbé rí, àní bí ìlànà ti ayé yìí, gẹ́gẹ́ bí aláṣẹ agbára ojú ọ̀run, ẹ̀mí tí n ṣiṣẹ́ ni ìsinsin yìí nínú àwọn ọmọ aláìgbọ́ràn. 3 Nínú àwọn ẹni tí gbogbo wa pẹ̀lú ti wà rí nínú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wa, a ń mú ìfẹ́ ara àti ti inú ṣẹ, àti nípa ìṣẹ̀dá àwa sì ti jẹ́ ọmọ ìbínú, gẹ́gẹ́ bí àwọn ìyókù pẹ̀lú. 4 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run, ẹni tí í ṣe ọlọ́rọ̀ ni àánú, nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó fi fẹ́ wa, 5 nígbà tí àwa tilẹ̀ ti kú nítorí ìrékọjá wa, ó sọ wá di ààyè pẹ̀lú Kristi, oore-ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là. 6 Ọlọ́run sì ti jí wa dìde pẹ̀lú Kristi, ó sì ti mú wa jókòó pẹ̀lú rẹ̀ nínú àwọn ọ̀run nínú Kristi Jesu. 7 Pé ni gbogbo ìgbà tí ń bọ̀ kí ó bà á lè fi ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí o pọ̀ rékọjá hàn fún wa nínú ìṣeun rẹ̀ sì wà nínú Kristi Jesu. 8 Nítorí oore-ọ̀fẹ́ ní a fi gbà yín là nípa ìgbàgbọ́. Èyí kì í ṣe nípa agbára ẹ̀yin fúnra yín: ẹ̀bùn Ọlọ́run ni, 9 kì í ṣe nípa àwọn iṣẹ́, kí ẹnikẹ́ni má ba à ṣògo. 10 Nítorí àwa ni iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ tí a ti dá nínú Kristi Jesu fún àwọn iṣẹ́ rere, èyí tí Ọlọ́run ti pèsè tẹ́lẹ̀, fún wa láti ṣe. 11 Nítorí náà ẹ rántí pé, nígbà àtijọ́ rí, ẹ̀yin tí ẹ ti jẹ́ Kèfèrí nípa ti ìbí, tí àwọn tí a ń pè ní “aláìkọlà” láti ọwọ́ àwọn tí ń pe ara wọn “akọlà” (èyí ti a fi ọwọ́ ènìyàn ṣe sí ni ní ara). 12 Ẹ rántí pé ni àkókò náà ẹ̀yin wà láìní Kristi, ẹ jẹ́ àjèjì sí Israẹli, àti àjèjì sí àwọn májẹ̀mú ìlérí náà, láìní ìrètí, àti láìní Ọlọ́run ni ayé. 13 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí nínú Kristi Jesu ẹ̀yin tí ó ti jìnà réré nígbà àtijọ́ rí ni a mú súnmọ́ tòsí, nípa ẹ̀jẹ̀ Kristi. 14 Nítorí òun ni àlàáfíà wa, ẹni tí o ti ṣe méjèèjì ni ọ̀kan, tí ó sì ti wó ògiri ìkélé ti ìkórìíra èyí tí ń bẹ láàrín yín. 15 Ó sì ti fi òpin sí ọ̀tá náà nínú ara rẹ̀, àní sí òfin àti àṣẹ wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ nínú ìlànà, kí ó lè sọ àwọn méjèèjì di ẹni tuntun kan nínú ara rẹ̀, kí ó sì ṣe ìlàjà 16 àti kí ó lè mú àwọn méjèèjì bá Ọlọ́run làjà nínú ara kan nípa àgbélébùú; nípa èyí tí yóò fi pa ìṣọ̀tá náà run. 17 Ó sì ti wá, ó sì ti wàásù àlàáfíà fún ẹ̀yin tí o jìnnà réré, àti àlàáfíà fún àwọn tí o súnmọ́ tòsí. 18 Nítorí nípa rẹ̀ ni àwa méjèèjì ti ni àǹfààní sọ́dọ̀ baba nípa Ẹ̀mí kan. 19 Ǹjẹ́ nítorí náà ẹ̀yin kì í ṣe àlejò àti àjèjì mọ́, ṣùgbọ́n àjùmọ̀jogún ọmọ ìbílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ́, àti àwọn ará ilé Ọlọ́run; 20 a sì ń gbé yín ró lórí ìpìlẹ̀ àwọn aposteli, àti àwọn wòlíì, pẹ̀lú Jesu Kristi fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí pàtàkì òkúta igun ilé. 21 Nínú rẹ ni gbogbo ilé náà, tí a ń kọ wà papọ̀ ṣọ̀kan tí ó sì ń dàgbàsókè láti di tẹmpili mímọ́ kan nínú Olúwa. 22 Nínú rẹ̀ ni a ń gbé ẹ̀yin pẹ̀lú ró pẹ̀lú fún ibùjókòó Ọlọ́run nínú Ẹ̀mí rẹ̀.
In Other Versions
Ephesians 2 in the ANGEFD
Ephesians 2 in the ANTPNG2D
Ephesians 2 in the AS21
Ephesians 2 in the BAGH
Ephesians 2 in the BBPNG
Ephesians 2 in the BBT1E
Ephesians 2 in the BDS
Ephesians 2 in the BEV
Ephesians 2 in the BHAD
Ephesians 2 in the BIB
Ephesians 2 in the BLPT
Ephesians 2 in the BNT
Ephesians 2 in the BNTABOOT
Ephesians 2 in the BNTLV
Ephesians 2 in the BOATCB
Ephesians 2 in the BOATCB2
Ephesians 2 in the BOBCV
Ephesians 2 in the BOCNT
Ephesians 2 in the BOECS
Ephesians 2 in the BOGWICC
Ephesians 2 in the BOHCB
Ephesians 2 in the BOHCV
Ephesians 2 in the BOHLNT
Ephesians 2 in the BOHNTLTAL
Ephesians 2 in the BOICB
Ephesians 2 in the BOILNTAP
Ephesians 2 in the BOITCV
Ephesians 2 in the BOKCV
Ephesians 2 in the BOKCV2
Ephesians 2 in the BOKHWOG
Ephesians 2 in the BOKSSV
Ephesians 2 in the BOLCB
Ephesians 2 in the BOLCB2
Ephesians 2 in the BOMCV
Ephesians 2 in the BONAV
Ephesians 2 in the BONCB
Ephesians 2 in the BONLT
Ephesians 2 in the BONUT2
Ephesians 2 in the BOPLNT
Ephesians 2 in the BOSCB
Ephesians 2 in the BOSNC
Ephesians 2 in the BOTLNT
Ephesians 2 in the BOVCB
Ephesians 2 in the BPBB
Ephesians 2 in the BPH
Ephesians 2 in the BSB
Ephesians 2 in the CCB
Ephesians 2 in the CUV
Ephesians 2 in the CUVS
Ephesians 2 in the DBT
Ephesians 2 in the DGDNT
Ephesians 2 in the DHNT
Ephesians 2 in the DNT
Ephesians 2 in the ELBE
Ephesians 2 in the EMTV
Ephesians 2 in the ESV
Ephesians 2 in the FBV
Ephesians 2 in the FEB
Ephesians 2 in the GGMNT
Ephesians 2 in the GNT
Ephesians 2 in the HARY
Ephesians 2 in the HNT
Ephesians 2 in the IRVA
Ephesians 2 in the IRVB
Ephesians 2 in the IRVG
Ephesians 2 in the IRVH
Ephesians 2 in the IRVK
Ephesians 2 in the IRVM
Ephesians 2 in the IRVM2
Ephesians 2 in the IRVO
Ephesians 2 in the IRVP
Ephesians 2 in the IRVT
Ephesians 2 in the IRVT2
Ephesians 2 in the IRVU
Ephesians 2 in the ISVN
Ephesians 2 in the JSNT
Ephesians 2 in the KAPI
Ephesians 2 in the KBT1ETNIK
Ephesians 2 in the KBV
Ephesians 2 in the KJV
Ephesians 2 in the KNFD
Ephesians 2 in the LBA
Ephesians 2 in the LBLA
Ephesians 2 in the LNT
Ephesians 2 in the LSV
Ephesians 2 in the MAAL
Ephesians 2 in the MBV
Ephesians 2 in the MBV2
Ephesians 2 in the MHNT
Ephesians 2 in the MKNFD
Ephesians 2 in the MNG
Ephesians 2 in the MNT
Ephesians 2 in the MNT2
Ephesians 2 in the MRS1T
Ephesians 2 in the NAA
Ephesians 2 in the NASB
Ephesians 2 in the NBLA
Ephesians 2 in the NBS
Ephesians 2 in the NBVTP
Ephesians 2 in the NET2
Ephesians 2 in the NIV11
Ephesians 2 in the NNT
Ephesians 2 in the NNT2
Ephesians 2 in the NNT3
Ephesians 2 in the PDDPT
Ephesians 2 in the PFNT
Ephesians 2 in the RMNT
Ephesians 2 in the SBIAS
Ephesians 2 in the SBIBS
Ephesians 2 in the SBIBS2
Ephesians 2 in the SBICS
Ephesians 2 in the SBIDS
Ephesians 2 in the SBIGS
Ephesians 2 in the SBIHS
Ephesians 2 in the SBIIS
Ephesians 2 in the SBIIS2
Ephesians 2 in the SBIIS3
Ephesians 2 in the SBIKS
Ephesians 2 in the SBIKS2
Ephesians 2 in the SBIMS
Ephesians 2 in the SBIOS
Ephesians 2 in the SBIPS
Ephesians 2 in the SBISS
Ephesians 2 in the SBITS
Ephesians 2 in the SBITS2
Ephesians 2 in the SBITS3
Ephesians 2 in the SBITS4
Ephesians 2 in the SBIUS
Ephesians 2 in the SBIVS
Ephesians 2 in the SBT
Ephesians 2 in the SBT1E
Ephesians 2 in the SCHL
Ephesians 2 in the SNT
Ephesians 2 in the SUSU
Ephesians 2 in the SUSU2
Ephesians 2 in the SYNO
Ephesians 2 in the TBIAOTANT
Ephesians 2 in the TBT1E
Ephesians 2 in the TBT1E2
Ephesians 2 in the TFTIP
Ephesians 2 in the TFTU
Ephesians 2 in the TGNTATF3T
Ephesians 2 in the THAI
Ephesians 2 in the TNFD
Ephesians 2 in the TNT
Ephesians 2 in the TNTIK
Ephesians 2 in the TNTIL
Ephesians 2 in the TNTIN
Ephesians 2 in the TNTIP
Ephesians 2 in the TNTIZ
Ephesians 2 in the TOMA
Ephesians 2 in the TTENT
Ephesians 2 in the UBG
Ephesians 2 in the UGV
Ephesians 2 in the UGV2
Ephesians 2 in the UGV3
Ephesians 2 in the VBL
Ephesians 2 in the VDCC
Ephesians 2 in the YALU
Ephesians 2 in the YAPE
Ephesians 2 in the YBVTP
Ephesians 2 in the ZBP