Ephesians 6 (BOYCB)

1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa, nítorí pé èyí ní ó tọ́. 2 “Bọ̀wọ̀ fún baba àti ìyá rẹ,” èyí tí í ṣe òfin kìn-ín-ní pẹ̀lú ìlérí, 3 “ki ó lé dára fún ọ, àti kí ìwọ lè wà pẹ́ ní ayé.” 4 Àti ẹ̀yin baba, ẹ má ṣe mú àwọn ọmọ yín bínú, ṣùgbọ́n ẹ máa tọ́ wọn nínú ẹ̀kọ́ àti ìkìlọ̀ Olúwa. 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ máa gbọ́ ti àwọn olúwa yín nípá ti ara, pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, bí ẹni pé sí Kristi. 6 Gbọ́ ọ̀rọ̀ sí wọn lẹ́nu kì í ṣe láti rí ojúrere wọn nígbà tí ojú wọn bá ń bẹ lára rẹ, ṣùgbọ́n bí ẹrú Kristi, ní ṣíṣe ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ. 7 Ẹ máa fi gbogbo ọkàn yin ṣe iṣẹ́ ìsìn bí sí Olúwa, kì í sí ṣe sí ènìyàn. 8 Bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé ohun rere tí olúkúlùkù bá ṣe òun náà ní yóò sí gbà padà lọ́dọ̀ Olúwa, ìbá à ṣe ẹrú, tàbí òmìnira. 9 Àti ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ máa ṣe irú ìtọ́jú kan náà sí àwọn ẹrú yin, ẹ máa dín ìbẹ̀rù yín kù bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé Olúwa ẹ̀yin tìkára yín ń bẹ ní ọ̀run; kò sì ṣí ojúsàájú ènìyàn lọ́dọ̀ rẹ̀. 10 Ní àkótán, ara mí, ẹ jẹ́ alágbára nínú Olúwa, àti nínú agbára ipá rẹ̀. 11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin lè kọ ojú ìjà sí àrékérekè èṣù. 12 Nítorí pé kì í ṣe ẹ̀jẹ̀ àti ẹran-ara ní àwa ń bá jìjàkadì, ṣùgbọ́n àwọn ìjòyè, àwọn ọlọ́lá, àwọn aláṣẹ ìbí òkùnkùn ayé yìí, àti àwọn ẹ̀mí búburú ní ojú ọ̀run. 13 Nítorí náà, ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin lè dúró tiiri sí ọjọ́ ibi, nígbà tí ẹ̀yin bá sì ti ṣe ohun gbogbo tan kí ẹ sì dúró. 14 Ẹ dúró nítorí náà lẹ́yìn tí ẹ fi àmùrè òtítọ́ dì ẹ̀gbẹ́ yin, tí ẹ sì ti di ìgbàyà òdodo mọ́ra. 15 Tí ẹ sì ti fi ìmúra ìyìnrere àlàáfíà wọ ẹsẹ̀ yín ní bàtà. 16 Ní àfikún, ẹ mú àpáta ìgbàgbọ́, nípa èyí tí ẹ̀yin lè máa fi paná gbogbo ọfà iná ẹni ibi náà. 17 Kí ẹ sì mú àṣíborí ìgbàlà, àti idà ẹ̀mí, tí í ṣe ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. 18 Pẹ̀lú gbogbo àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ ni kí ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo nínú Ẹ̀mí, kí ẹ sì máa ṣọ́ra sí i nínú ìdúró ṣinṣin gbogbo àti ẹ̀bẹ̀ fún gbogbo ènìyàn mímọ́. 19 Kí ẹ sì máa gbàdúrà fún mí pẹ̀lú, kí Ọlọ́run lè fún mí ní ọ̀rọ̀ tí ó yẹ kí èmi lè máa fì ìgboyà sọ àwọn ohun ìjìnlẹ̀ ìyìnrere náà. 20 Nítorí èyí tí èmí jẹ́ ikọ̀ nínú ẹ̀wọ̀n, kí èmi lè máa fi ìgboyà sọ̀rọ̀ nínú rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ó ti tọ́ fún mí láti máa sọ. 21 Tikiku, arákùnrin olùfẹ́ àti ìránṣẹ́ olóòtítọ́ nínú Olúwa yóò sọ ohun gbogbo dí mí mọ̀ fún yín, kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè mọ̀ bí nǹkan ti rí fún mí àti bí mo tí ń ṣe sí. 22 Ẹni tí mo rán sí yín nítorí èyí náà, kí ẹ lè mọ̀ bí a tí wà, kì òun lè tu ọkàn yín nínú. 23 Àlàáfíà fún àwọn ará, àti ìfẹ́ pẹ̀lú ìgbàgbọ́, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wà, àti Olúwa wà Jesu Kristi. 24 Kí oore-ọ̀fẹ́ wà pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa wa Jesu Kristi ni àìṣẹ̀tàn.

In Other Versions

Ephesians 6 in the ANGEFD

Ephesians 6 in the ANTPNG2D

Ephesians 6 in the AS21

Ephesians 6 in the BAGH

Ephesians 6 in the BBPNG

Ephesians 6 in the BBT1E

Ephesians 6 in the BDS

Ephesians 6 in the BEV

Ephesians 6 in the BHAD

Ephesians 6 in the BIB

Ephesians 6 in the BLPT

Ephesians 6 in the BNT

Ephesians 6 in the BNTABOOT

Ephesians 6 in the BNTLV

Ephesians 6 in the BOATCB

Ephesians 6 in the BOATCB2

Ephesians 6 in the BOBCV

Ephesians 6 in the BOCNT

Ephesians 6 in the BOECS

Ephesians 6 in the BOGWICC

Ephesians 6 in the BOHCB

Ephesians 6 in the BOHCV

Ephesians 6 in the BOHLNT

Ephesians 6 in the BOHNTLTAL

Ephesians 6 in the BOICB

Ephesians 6 in the BOILNTAP

Ephesians 6 in the BOITCV

Ephesians 6 in the BOKCV

Ephesians 6 in the BOKCV2

Ephesians 6 in the BOKHWOG

Ephesians 6 in the BOKSSV

Ephesians 6 in the BOLCB

Ephesians 6 in the BOLCB2

Ephesians 6 in the BOMCV

Ephesians 6 in the BONAV

Ephesians 6 in the BONCB

Ephesians 6 in the BONLT

Ephesians 6 in the BONUT2

Ephesians 6 in the BOPLNT

Ephesians 6 in the BOSCB

Ephesians 6 in the BOSNC

Ephesians 6 in the BOTLNT

Ephesians 6 in the BOVCB

Ephesians 6 in the BPBB

Ephesians 6 in the BPH

Ephesians 6 in the BSB

Ephesians 6 in the CCB

Ephesians 6 in the CUV

Ephesians 6 in the CUVS

Ephesians 6 in the DBT

Ephesians 6 in the DGDNT

Ephesians 6 in the DHNT

Ephesians 6 in the DNT

Ephesians 6 in the ELBE

Ephesians 6 in the EMTV

Ephesians 6 in the ESV

Ephesians 6 in the FBV

Ephesians 6 in the FEB

Ephesians 6 in the GGMNT

Ephesians 6 in the GNT

Ephesians 6 in the HARY

Ephesians 6 in the HNT

Ephesians 6 in the IRVA

Ephesians 6 in the IRVB

Ephesians 6 in the IRVG

Ephesians 6 in the IRVH

Ephesians 6 in the IRVK

Ephesians 6 in the IRVM

Ephesians 6 in the IRVM2

Ephesians 6 in the IRVO

Ephesians 6 in the IRVP

Ephesians 6 in the IRVT

Ephesians 6 in the IRVT2

Ephesians 6 in the IRVU

Ephesians 6 in the ISVN

Ephesians 6 in the JSNT

Ephesians 6 in the KAPI

Ephesians 6 in the KBT1ETNIK

Ephesians 6 in the KBV

Ephesians 6 in the KJV

Ephesians 6 in the KNFD

Ephesians 6 in the LBA

Ephesians 6 in the LBLA

Ephesians 6 in the LNT

Ephesians 6 in the LSV

Ephesians 6 in the MAAL

Ephesians 6 in the MBV

Ephesians 6 in the MBV2

Ephesians 6 in the MHNT

Ephesians 6 in the MKNFD

Ephesians 6 in the MNG

Ephesians 6 in the MNT

Ephesians 6 in the MNT2

Ephesians 6 in the MRS1T

Ephesians 6 in the NAA

Ephesians 6 in the NASB

Ephesians 6 in the NBLA

Ephesians 6 in the NBS

Ephesians 6 in the NBVTP

Ephesians 6 in the NET2

Ephesians 6 in the NIV11

Ephesians 6 in the NNT

Ephesians 6 in the NNT2

Ephesians 6 in the NNT3

Ephesians 6 in the PDDPT

Ephesians 6 in the PFNT

Ephesians 6 in the RMNT

Ephesians 6 in the SBIAS

Ephesians 6 in the SBIBS

Ephesians 6 in the SBIBS2

Ephesians 6 in the SBICS

Ephesians 6 in the SBIDS

Ephesians 6 in the SBIGS

Ephesians 6 in the SBIHS

Ephesians 6 in the SBIIS

Ephesians 6 in the SBIIS2

Ephesians 6 in the SBIIS3

Ephesians 6 in the SBIKS

Ephesians 6 in the SBIKS2

Ephesians 6 in the SBIMS

Ephesians 6 in the SBIOS

Ephesians 6 in the SBIPS

Ephesians 6 in the SBISS

Ephesians 6 in the SBITS

Ephesians 6 in the SBITS2

Ephesians 6 in the SBITS3

Ephesians 6 in the SBITS4

Ephesians 6 in the SBIUS

Ephesians 6 in the SBIVS

Ephesians 6 in the SBT

Ephesians 6 in the SBT1E

Ephesians 6 in the SCHL

Ephesians 6 in the SNT

Ephesians 6 in the SUSU

Ephesians 6 in the SUSU2

Ephesians 6 in the SYNO

Ephesians 6 in the TBIAOTANT

Ephesians 6 in the TBT1E

Ephesians 6 in the TBT1E2

Ephesians 6 in the TFTIP

Ephesians 6 in the TFTU

Ephesians 6 in the TGNTATF3T

Ephesians 6 in the THAI

Ephesians 6 in the TNFD

Ephesians 6 in the TNT

Ephesians 6 in the TNTIK

Ephesians 6 in the TNTIL

Ephesians 6 in the TNTIN

Ephesians 6 in the TNTIP

Ephesians 6 in the TNTIZ

Ephesians 6 in the TOMA

Ephesians 6 in the TTENT

Ephesians 6 in the UBG

Ephesians 6 in the UGV

Ephesians 6 in the UGV2

Ephesians 6 in the UGV3

Ephesians 6 in the VBL

Ephesians 6 in the VDCC

Ephesians 6 in the YALU

Ephesians 6 in the YAPE

Ephesians 6 in the YBVTP

Ephesians 6 in the ZBP