Ezekiel 31 (BOYCB)
1 Ní ọjọ́ kìn-ín-ní, oṣù kẹta ọdún kọkànlá, ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ̀ mí wá: 2 “Ọmọ ènìyàn, sọ fún Farao ọba Ejibiti àti sí ìjọ rẹ̀:“ ‘Ta ní a le fiwé ọ ní ọláńlá? 3 Kíyèsi Asiria, tí ó jẹ́ igi kedari niLebanoni ní ìgbà kan rí,pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka dáradára tí ó ṣẹ́ ìji bo igbó náà;tí ó ga sókè,òkè rẹ̀ lókè ni ewé tí ó nípọn wà. 4 Omi mú un dàgbàsókè:orísun omi tí ó jinlẹ̀ mú kí o dàgbàsókè;àwọn odo rẹ̀ ń sàn yí ìdí rẹ̀ ká,ó sì rán ìṣàn omi rẹ̀ sí gbogbo igi orí pápá. 5 Nítorí náà ó ga sí òkè fíofíoju gbogbo igi orí pápá lọ;ẹ̀ka rẹ̀ pọ̀ sí iàwọn ẹ̀ka rẹ̀ sì gùn,wọn tẹ́ rẹrẹ nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi. 6 Ẹyẹ ojú ọ̀runkọ ilé sí ẹ̀ka rẹ̀gbogbo ẹranko igbóń bímọ ní abẹ́ ẹ̀ka rẹ̀;gbogbo orílẹ̀-èdè ńláń gbé abẹ́ ìji rẹ̀. 7 Ọláńlá ní ẹwà rẹ̀ jẹ́,pẹ̀lú títẹ́ rẹrẹ ẹ̀ka rẹ̀,nítorí gbòǹgbò rẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀sí ibi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi wà. 8 Àwọn igi kedari nínú ọgbà Ọlọ́runkò lè è bò ó mọ́lẹ̀;tàbí kí àwọn igi junifaṣe déédé pẹ̀lú ẹ̀ka rẹ̀,tàbí kí a fi igi títẹ́ rẹrẹ wé ẹ̀ka rẹ̀,kò sí igi nínú ọgbà Ọlọ́runtí ó dà bí rẹ̀ ní ẹwà rẹ̀. 9 Mo mú kí ó ní ẹwàpẹ̀lú ẹ̀ka lọ́pọ̀lọ́pọ̀tó fi jẹ́ ìlara àwọn igi gbogbo ní Edenití í ṣe ọgbà Ọlọ́run. 10 “ ‘Nítorí náà, èyí yìí ní OLÚWA Olódùmarè wí: Nítorí pé ó ga lọ sókè fíofío, tí ó sì gbé òkè rẹ̀ ga ju ewé tí ó nípọn lọ, àti nítorí pé gíga rẹ mú kí ó gbéraga, 11 mo fi lé alákòóso àwọn orílẹ̀-èdè náà lọ́wọ́, fún un láti fi ṣe ẹ̀tọ́ fún un gẹ́gẹ́ bí ìwà búburú rẹ̀. Mo pa á tì sí ẹ̀gbẹ́ kan, 12 àwọn orílẹ̀-èdè àjèjì aláìláàánú jùlọ ké e lulẹ̀, wọn sì fi kalẹ̀. Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ṣubú sórí òkè àti sí gbogbo àárín àwọn òkè; àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tí ó ṣẹ nà sílẹ̀ ní gbogbo àlàfo jíjìn ilẹ̀. Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ilẹ̀ ayé jáde kúrò ní abẹ́ ìji rẹ̀ wọn sì fi sílẹ̀. 13 Gbogbo àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ṣe àtìpó ni orí igi tí ó ṣubú lulẹ̀ náà, gbogbo àwọn ẹranko igbó wà ní àárín ẹ̀ka rẹ̀. 14 Nítorí náà kò sí igi mìíràn lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi tí ó lè fi ìgbéraga ga sókè fíofío, tí yóò sì gbé sókè rẹ̀ ga ju ewé tí ó nípọn lọ. Kò sí igi mìíràn tí ó ní omi tó bẹ́ẹ̀ tí ó lè ga tó bẹ́ẹ̀; gbogbo wọn ni a kádàrá ikú fún, fún ìsàlẹ̀ ilẹ̀, ní àárín àwọn alààyè ènìyàn, pẹ̀lú àwọn tí o lọ sí ọ̀gbun ní ìsàlẹ̀. 15 “ ‘Èyí ni OLÚWA Olódùmarè wí: Ní ọjọ́ ti a mú u wá sí isà òkú mo fi ọ̀fọ̀ ṣíṣe bo orísun omi jíjìn náà, mo dá àwọn ìṣàn omi rẹ̀ dúró, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi rẹ̀ ní a dí lọ́nà. Nítorí rẹ̀ mo fi ìwúwo ọkàn wọ Lebanoni ní aṣọ, gbogbo igi igbó gbẹ dànù. 16 Mo mú kí orílẹ̀-èdè wárìrì sì ìró ìṣubú rẹ̀ nígbà tí mo mú un wá sí ìsàlẹ̀ isà òkú pẹ̀lú àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbun ìsàlẹ̀. Nígbà náà gbogbo igi Edeni, àṣàyàn àti èyí tí ó dára jùlọ nínú Lebanoni, gbogbo igi tí ó ní omi dáradára ni a tù nínú ni ayé ìsàlẹ̀. 17 Àwọn tí ó ń gbé ní abẹ́ òjìji rẹ̀, àwọn àjèjì rẹ ní àárín àwọn orílẹ̀-èdè náà, ti lọ sí ìsàlẹ̀ isà òkú pẹ̀lú rẹ̀, ní dídárapọ̀ mọ́ àwọn tí a fi idà pa. 18 “ ‘Èwo lára igi Edeni ní a lè fiwé ọ ní dídán àti ọláńlá? Síbẹ̀ ìwọ, gan an wá sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn igi Edeni lọ sí ìsàlẹ̀ ilẹ̀; ìwọ yóò sùn ni àárín àwọn aláìkọlà, pẹ̀lú àwọn tí a fi idà pa.“ ‘Èyí yìí ní Farao àti ìjọ rẹ̀, ní OLÚWA Olódùmarè wí.’ ”
In Other Versions
Ezekiel 31 in the ANGEFD
Ezekiel 31 in the ANTPNG2D
Ezekiel 31 in the AS21
Ezekiel 31 in the BAGH
Ezekiel 31 in the BBPNG
Ezekiel 31 in the BBT1E
Ezekiel 31 in the BDS
Ezekiel 31 in the BEV
Ezekiel 31 in the BHAD
Ezekiel 31 in the BIB
Ezekiel 31 in the BLPT
Ezekiel 31 in the BNT
Ezekiel 31 in the BNTABOOT
Ezekiel 31 in the BNTLV
Ezekiel 31 in the BOATCB
Ezekiel 31 in the BOATCB2
Ezekiel 31 in the BOBCV
Ezekiel 31 in the BOCNT
Ezekiel 31 in the BOECS
Ezekiel 31 in the BOGWICC
Ezekiel 31 in the BOHCB
Ezekiel 31 in the BOHCV
Ezekiel 31 in the BOHLNT
Ezekiel 31 in the BOHNTLTAL
Ezekiel 31 in the BOICB
Ezekiel 31 in the BOILNTAP
Ezekiel 31 in the BOITCV
Ezekiel 31 in the BOKCV
Ezekiel 31 in the BOKCV2
Ezekiel 31 in the BOKHWOG
Ezekiel 31 in the BOKSSV
Ezekiel 31 in the BOLCB
Ezekiel 31 in the BOLCB2
Ezekiel 31 in the BOMCV
Ezekiel 31 in the BONAV
Ezekiel 31 in the BONCB
Ezekiel 31 in the BONLT
Ezekiel 31 in the BONUT2
Ezekiel 31 in the BOPLNT
Ezekiel 31 in the BOSCB
Ezekiel 31 in the BOSNC
Ezekiel 31 in the BOTLNT
Ezekiel 31 in the BOVCB
Ezekiel 31 in the BPBB
Ezekiel 31 in the BPH
Ezekiel 31 in the BSB
Ezekiel 31 in the CCB
Ezekiel 31 in the CUV
Ezekiel 31 in the CUVS
Ezekiel 31 in the DBT
Ezekiel 31 in the DGDNT
Ezekiel 31 in the DHNT
Ezekiel 31 in the DNT
Ezekiel 31 in the ELBE
Ezekiel 31 in the EMTV
Ezekiel 31 in the ESV
Ezekiel 31 in the FBV
Ezekiel 31 in the FEB
Ezekiel 31 in the GGMNT
Ezekiel 31 in the GNT
Ezekiel 31 in the HARY
Ezekiel 31 in the HNT
Ezekiel 31 in the IRVA
Ezekiel 31 in the IRVB
Ezekiel 31 in the IRVG
Ezekiel 31 in the IRVH
Ezekiel 31 in the IRVK
Ezekiel 31 in the IRVM
Ezekiel 31 in the IRVM2
Ezekiel 31 in the IRVO
Ezekiel 31 in the IRVP
Ezekiel 31 in the IRVT
Ezekiel 31 in the IRVT2
Ezekiel 31 in the IRVU
Ezekiel 31 in the ISVN
Ezekiel 31 in the JSNT
Ezekiel 31 in the KAPI
Ezekiel 31 in the KBT1ETNIK
Ezekiel 31 in the KBV
Ezekiel 31 in the KJV
Ezekiel 31 in the KNFD
Ezekiel 31 in the LBA
Ezekiel 31 in the LBLA
Ezekiel 31 in the LNT
Ezekiel 31 in the LSV
Ezekiel 31 in the MAAL
Ezekiel 31 in the MBV
Ezekiel 31 in the MBV2
Ezekiel 31 in the MHNT
Ezekiel 31 in the MKNFD
Ezekiel 31 in the MNG
Ezekiel 31 in the MNT
Ezekiel 31 in the MNT2
Ezekiel 31 in the MRS1T
Ezekiel 31 in the NAA
Ezekiel 31 in the NASB
Ezekiel 31 in the NBLA
Ezekiel 31 in the NBS
Ezekiel 31 in the NBVTP
Ezekiel 31 in the NET2
Ezekiel 31 in the NIV11
Ezekiel 31 in the NNT
Ezekiel 31 in the NNT2
Ezekiel 31 in the NNT3
Ezekiel 31 in the PDDPT
Ezekiel 31 in the PFNT
Ezekiel 31 in the RMNT
Ezekiel 31 in the SBIAS
Ezekiel 31 in the SBIBS
Ezekiel 31 in the SBIBS2
Ezekiel 31 in the SBICS
Ezekiel 31 in the SBIDS
Ezekiel 31 in the SBIGS
Ezekiel 31 in the SBIHS
Ezekiel 31 in the SBIIS
Ezekiel 31 in the SBIIS2
Ezekiel 31 in the SBIIS3
Ezekiel 31 in the SBIKS
Ezekiel 31 in the SBIKS2
Ezekiel 31 in the SBIMS
Ezekiel 31 in the SBIOS
Ezekiel 31 in the SBIPS
Ezekiel 31 in the SBISS
Ezekiel 31 in the SBITS
Ezekiel 31 in the SBITS2
Ezekiel 31 in the SBITS3
Ezekiel 31 in the SBITS4
Ezekiel 31 in the SBIUS
Ezekiel 31 in the SBIVS
Ezekiel 31 in the SBT
Ezekiel 31 in the SBT1E
Ezekiel 31 in the SCHL
Ezekiel 31 in the SNT
Ezekiel 31 in the SUSU
Ezekiel 31 in the SUSU2
Ezekiel 31 in the SYNO
Ezekiel 31 in the TBIAOTANT
Ezekiel 31 in the TBT1E
Ezekiel 31 in the TBT1E2
Ezekiel 31 in the TFTIP
Ezekiel 31 in the TFTU
Ezekiel 31 in the TGNTATF3T
Ezekiel 31 in the THAI
Ezekiel 31 in the TNFD
Ezekiel 31 in the TNT
Ezekiel 31 in the TNTIK
Ezekiel 31 in the TNTIL
Ezekiel 31 in the TNTIN
Ezekiel 31 in the TNTIP
Ezekiel 31 in the TNTIZ
Ezekiel 31 in the TOMA
Ezekiel 31 in the TTENT
Ezekiel 31 in the UBG
Ezekiel 31 in the UGV
Ezekiel 31 in the UGV2
Ezekiel 31 in the UGV3
Ezekiel 31 in the VBL
Ezekiel 31 in the VDCC
Ezekiel 31 in the YALU
Ezekiel 31 in the YAPE
Ezekiel 31 in the YBVTP
Ezekiel 31 in the ZBP