Ezekiel 9 (BOYCB)

1 Mo gbọ́ ti ó kígbe ní ohùn rara pé, “Mú àwọn olùṣọ́ ìlú súnmọ́ itòsí, kí olúkúlùkù wọn mú ohun ìjà olóró lọ́wọ́.” 2 Lójú ẹsẹ̀ ni ọkùnrin mẹ́fà jáde láti ẹnu-ọ̀nà òkè tó kọjú sí ìhà àríwá, olúkúlùkù pẹ̀lú ohun ìjà olóró lọ́wọ́ wọn. Ọkùnrin kan tó wọ aṣọ funfun gbòò wa láàrín wọn, pẹ̀lú ohun ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀. Gbogbo wọn sì dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ idẹ. 3 Ògo Ọlọ́run Israẹli sì gòkè kúrò lórí kérúbù, níbi tó wà tẹ́lẹ̀ lọ sí ibi ìloro tẹmpili. Nígbà náà ni OLÚWA pe ọkùnrin tó wọ aṣọ funfun náà tí ó sì ní ohun ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀. 4 Ó sì sọ fún un pé, “La àárín ìlú Jerusalẹmu já, kí ìwọ sì fi àmì síwájú orí gbogbo àwọn tó ń kẹ́dùn, tó sì ń sọkún nítorí ohun ìríra tí wọn ń ṣe láàrín rẹ̀.” 5 Bí mo ṣe ń fetí sí èyí, O tún sọ fún àwọn yòókù pé, “Tẹ̀lé ọkùnrin náà lọ sí àárín ìlú láti pa láì dá sí àti láì ṣàánú rárá. 6 Ẹ pa arúgbó àti ọ̀dọ́mọkùnrin, ẹ pa ọlọ́mọge, obìnrin àti ọmọ kéékèèké, ṣùgbọ́n ẹ má ṣe fi ọwọ́ kan àwọn tó ní àmì. Ẹ bẹ̀rẹ̀ láti ibi mímọ́.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn àgbàgbà tó wà níwájú tẹmpili. 7 Nígbà náà lo sọ fún wọn pé, “Ẹ sọ tẹmpili náà di àìmọ́, kí òkú sì kún àgbàlá náà. Ẹ lọ!” Wọ́n jáde síta, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í pa ènìyàn láàrín ìlú. 8 Èmi nìkan ló ṣẹ́kù nígbà tí wọ́n lọ pa àwọn ènìyàn, mo dójú mi bolẹ̀, mo kígbe pé, “Háà! OLÚWA Olódùmarè! Ìwọ yóò ha pa ìyókù Israẹli nípa dída ìbínú gbígbóná rẹ sórí Jerusalẹmu?” 9 Ó dá mi lóhùn pé, “Ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli àti Juda pọ gidigidi; ilé wọn kún fún ìtàjẹ̀ sílẹ̀ àti àìṣòótọ́. Wọ́n ní, ‘OLÚWA tí kọ ilẹ̀ náà sílẹ̀; OLÚWA kò sì rí wa.’ 10 Nítorí náà, èmi kò ní wò wọ́n pẹ̀lú àánú, èmi kò sì ní dá wọn sí, ṣùgbọ́n Èmi yóò dá ohun tí wọ́n ti ṣe padà sórí wọn.” 11 Ọkùnrin tí ó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀, tí ó ní ìwo tàdáwà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ròyìn pé, “Mo ti ṣe gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti pàṣẹ fún mi.”

In Other Versions

Ezekiel 9 in the ANGEFD

Ezekiel 9 in the ANTPNG2D

Ezekiel 9 in the AS21

Ezekiel 9 in the BAGH

Ezekiel 9 in the BBPNG

Ezekiel 9 in the BBT1E

Ezekiel 9 in the BDS

Ezekiel 9 in the BEV

Ezekiel 9 in the BHAD

Ezekiel 9 in the BIB

Ezekiel 9 in the BLPT

Ezekiel 9 in the BNT

Ezekiel 9 in the BNTABOOT

Ezekiel 9 in the BNTLV

Ezekiel 9 in the BOATCB

Ezekiel 9 in the BOATCB2

Ezekiel 9 in the BOBCV

Ezekiel 9 in the BOCNT

Ezekiel 9 in the BOECS

Ezekiel 9 in the BOGWICC

Ezekiel 9 in the BOHCB

Ezekiel 9 in the BOHCV

Ezekiel 9 in the BOHLNT

Ezekiel 9 in the BOHNTLTAL

Ezekiel 9 in the BOICB

Ezekiel 9 in the BOILNTAP

Ezekiel 9 in the BOITCV

Ezekiel 9 in the BOKCV

Ezekiel 9 in the BOKCV2

Ezekiel 9 in the BOKHWOG

Ezekiel 9 in the BOKSSV

Ezekiel 9 in the BOLCB

Ezekiel 9 in the BOLCB2

Ezekiel 9 in the BOMCV

Ezekiel 9 in the BONAV

Ezekiel 9 in the BONCB

Ezekiel 9 in the BONLT

Ezekiel 9 in the BONUT2

Ezekiel 9 in the BOPLNT

Ezekiel 9 in the BOSCB

Ezekiel 9 in the BOSNC

Ezekiel 9 in the BOTLNT

Ezekiel 9 in the BOVCB

Ezekiel 9 in the BPBB

Ezekiel 9 in the BPH

Ezekiel 9 in the BSB

Ezekiel 9 in the CCB

Ezekiel 9 in the CUV

Ezekiel 9 in the CUVS

Ezekiel 9 in the DBT

Ezekiel 9 in the DGDNT

Ezekiel 9 in the DHNT

Ezekiel 9 in the DNT

Ezekiel 9 in the ELBE

Ezekiel 9 in the EMTV

Ezekiel 9 in the ESV

Ezekiel 9 in the FBV

Ezekiel 9 in the FEB

Ezekiel 9 in the GGMNT

Ezekiel 9 in the GNT

Ezekiel 9 in the HARY

Ezekiel 9 in the HNT

Ezekiel 9 in the IRVA

Ezekiel 9 in the IRVB

Ezekiel 9 in the IRVG

Ezekiel 9 in the IRVH

Ezekiel 9 in the IRVK

Ezekiel 9 in the IRVM

Ezekiel 9 in the IRVM2

Ezekiel 9 in the IRVO

Ezekiel 9 in the IRVP

Ezekiel 9 in the IRVT

Ezekiel 9 in the IRVT2

Ezekiel 9 in the IRVU

Ezekiel 9 in the ISVN

Ezekiel 9 in the JSNT

Ezekiel 9 in the KAPI

Ezekiel 9 in the KBT1ETNIK

Ezekiel 9 in the KBV

Ezekiel 9 in the KJV

Ezekiel 9 in the KNFD

Ezekiel 9 in the LBA

Ezekiel 9 in the LBLA

Ezekiel 9 in the LNT

Ezekiel 9 in the LSV

Ezekiel 9 in the MAAL

Ezekiel 9 in the MBV

Ezekiel 9 in the MBV2

Ezekiel 9 in the MHNT

Ezekiel 9 in the MKNFD

Ezekiel 9 in the MNG

Ezekiel 9 in the MNT

Ezekiel 9 in the MNT2

Ezekiel 9 in the MRS1T

Ezekiel 9 in the NAA

Ezekiel 9 in the NASB

Ezekiel 9 in the NBLA

Ezekiel 9 in the NBS

Ezekiel 9 in the NBVTP

Ezekiel 9 in the NET2

Ezekiel 9 in the NIV11

Ezekiel 9 in the NNT

Ezekiel 9 in the NNT2

Ezekiel 9 in the NNT3

Ezekiel 9 in the PDDPT

Ezekiel 9 in the PFNT

Ezekiel 9 in the RMNT

Ezekiel 9 in the SBIAS

Ezekiel 9 in the SBIBS

Ezekiel 9 in the SBIBS2

Ezekiel 9 in the SBICS

Ezekiel 9 in the SBIDS

Ezekiel 9 in the SBIGS

Ezekiel 9 in the SBIHS

Ezekiel 9 in the SBIIS

Ezekiel 9 in the SBIIS2

Ezekiel 9 in the SBIIS3

Ezekiel 9 in the SBIKS

Ezekiel 9 in the SBIKS2

Ezekiel 9 in the SBIMS

Ezekiel 9 in the SBIOS

Ezekiel 9 in the SBIPS

Ezekiel 9 in the SBISS

Ezekiel 9 in the SBITS

Ezekiel 9 in the SBITS2

Ezekiel 9 in the SBITS3

Ezekiel 9 in the SBITS4

Ezekiel 9 in the SBIUS

Ezekiel 9 in the SBIVS

Ezekiel 9 in the SBT

Ezekiel 9 in the SBT1E

Ezekiel 9 in the SCHL

Ezekiel 9 in the SNT

Ezekiel 9 in the SUSU

Ezekiel 9 in the SUSU2

Ezekiel 9 in the SYNO

Ezekiel 9 in the TBIAOTANT

Ezekiel 9 in the TBT1E

Ezekiel 9 in the TBT1E2

Ezekiel 9 in the TFTIP

Ezekiel 9 in the TFTU

Ezekiel 9 in the TGNTATF3T

Ezekiel 9 in the THAI

Ezekiel 9 in the TNFD

Ezekiel 9 in the TNT

Ezekiel 9 in the TNTIK

Ezekiel 9 in the TNTIL

Ezekiel 9 in the TNTIN

Ezekiel 9 in the TNTIP

Ezekiel 9 in the TNTIZ

Ezekiel 9 in the TOMA

Ezekiel 9 in the TTENT

Ezekiel 9 in the UBG

Ezekiel 9 in the UGV

Ezekiel 9 in the UGV2

Ezekiel 9 in the UGV3

Ezekiel 9 in the VBL

Ezekiel 9 in the VDCC

Ezekiel 9 in the YALU

Ezekiel 9 in the YAPE

Ezekiel 9 in the YBVTP

Ezekiel 9 in the ZBP