Hosea 13 (BOYCB)
1 Nígbà ti Efraimu bá ń sọ̀rọ̀, àwọn ènìyàn máa ń wárìrì,a gbé e ga ní Israẹliṣùgbọ́n ó jẹ̀bi ẹ̀sùn pé ó ń sin òrìṣà Baali, ó sì kú. 2 Báyìí, wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀;wọn fi fàdákà ṣe ère òrìṣà fúnra wọn;ère tí a fi ọgbọ́n dá àrà sí,gbogbo wọn jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ oníṣọ̀nà.Wọn ń sọ nípa àwọn ènìyàn wọ̀nyí.Pé, “Jẹ́ kí àwọn ènìyàn tí ń rú ẹbọ fi ẹnu,ko àwọn ẹgbọrọ màlúù ni ẹnu.” 3 Nítorí náà wọn yóò dàbí ìkùùkuu òwúrọ̀,bí ìrì òwúrọ̀ kùtùkùtù tó máa ń parẹ́,bí i èèpo ìyẹ̀fun tí afẹ́fẹ́ gbé láti ibi ìpakàbí èéfín tó rú jáde gba ojú fèrèsé. 4 “Ṣùgbọ́n Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ̀,ẹni tó mú ọ jáde láti ilẹ̀ Ejibiti wá.Ìwọ̀ kì yóò sì mọ ọlọ́run mìíràn àfi èmikò sí olùgbàlà mìíràn lẹ́yìn mi. 5 Mo ṣe ìtọ́jú rẹ ní aginjù,ní ilẹ̀ tí ó gbẹ tí kò ní omi. 6 Wọn ni ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí mo fún wọn ní oúnjẹ,Nígbà tí wọ́n ní ìtẹ́lọ́rùn tan wọ́n di agbéraga.Nígbà náà ni wọ́n sì gbàgbé mi. 7 Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún,Èmi yóò fi ara pamọ́ dè wọ́n lọ́nà bí i ẹkùn. 8 Beari igbó tí a já ọmọ rẹ̀ gbà,Èmi yóò bá wọn jà bí?Èmi yóò sì fà wọ́n yabí ìgbà tí ẹkùn bá fa ara wọn yabi ẹranko búburú ni èmi yóò fa wọn ya. 9 “A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli,nítorí pé ìwọ lòdì sí mi, ìwọ lòdì sí olùrànlọ́wọ́ rẹ. 10 Níbo ni ọba rẹ gbé wà nísinsin yìí kí ó bá à le gbà ọ là?Níbo ni àwọn olórí ìlú yín wà,àwọn tí ẹ sọ pé,‘Fún wa ní ọba àti ọmọ-aládé’? 11 Nítorí èyí nínú ìbínú mi ni mo fún un yín ní ọba,nínú ìbínú gbígbóná mi, mo sì mú un kúrò. 12 Ẹ̀bi Efraimu ni a tí ko jọgbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ wà nínú àkọsílẹ̀. 13 Ìrora bí obìnrin tó fẹ́ bímọ ti dé bá a,ṣùgbọ́n ó jẹ́ ọmọ tí kò lọ́gbọ́n,nígbà tí àsìkò tó,ó kọ̀ láti jáde síta láti inú. 14 “Èmi yóò rà wọ́n padà kúrò lọ́wọ́ agbára isà òkú.Èmi yóò rà wọ́n padà lọ́wọ́ ikú,ikú, àjàkálẹ̀-ààrùn rẹ dà?Isà òkú, ìparun rẹ dà? “Èmi kò ní ṣàánú mọ́. 15 Bí ó tilẹ̀ gbilẹ̀ láàrín àwọn arákùnrin rẹ̀afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn láti ọ̀dọ̀ OLÚWA yóò wá,yóò fẹ́ wá láti inú aginjùorísun omi rẹ̀ yóò gbẹkànga rẹ̀ yóò gbẹpẹ̀lú olè yóò fọ́ ilé ẹrùàti gbogbo ilé ìṣúra rẹ̀. 16 Ará Samaria gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn,nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí Ọlọ́run wọn.Wọn ó ti ipa idà ṣubú;a ó fọ́ àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀,a ó sì la àwọn aboyún wọn nínú.”
In Other Versions
Hosea 13 in the ANGEFD
Hosea 13 in the ANTPNG2D
Hosea 13 in the AS21
Hosea 13 in the BAGH
Hosea 13 in the BBPNG
Hosea 13 in the BBT1E
Hosea 13 in the BDS
Hosea 13 in the BEV
Hosea 13 in the BHAD
Hosea 13 in the BIB
Hosea 13 in the BLPT
Hosea 13 in the BNT
Hosea 13 in the BNTABOOT
Hosea 13 in the BNTLV
Hosea 13 in the BOATCB
Hosea 13 in the BOATCB2
Hosea 13 in the BOBCV
Hosea 13 in the BOCNT
Hosea 13 in the BOECS
Hosea 13 in the BOGWICC
Hosea 13 in the BOHCB
Hosea 13 in the BOHCV
Hosea 13 in the BOHLNT
Hosea 13 in the BOHNTLTAL
Hosea 13 in the BOICB
Hosea 13 in the BOILNTAP
Hosea 13 in the BOITCV
Hosea 13 in the BOKCV
Hosea 13 in the BOKCV2
Hosea 13 in the BOKHWOG
Hosea 13 in the BOKSSV
Hosea 13 in the BOLCB
Hosea 13 in the BOLCB2
Hosea 13 in the BOMCV
Hosea 13 in the BONAV
Hosea 13 in the BONCB
Hosea 13 in the BONLT
Hosea 13 in the BONUT2
Hosea 13 in the BOPLNT
Hosea 13 in the BOSCB
Hosea 13 in the BOSNC
Hosea 13 in the BOTLNT
Hosea 13 in the BOVCB
Hosea 13 in the BPBB
Hosea 13 in the BPH
Hosea 13 in the BSB
Hosea 13 in the CCB
Hosea 13 in the CUV
Hosea 13 in the CUVS
Hosea 13 in the DBT
Hosea 13 in the DGDNT
Hosea 13 in the DHNT
Hosea 13 in the DNT
Hosea 13 in the ELBE
Hosea 13 in the EMTV
Hosea 13 in the ESV
Hosea 13 in the FBV
Hosea 13 in the FEB
Hosea 13 in the GGMNT
Hosea 13 in the GNT
Hosea 13 in the HARY
Hosea 13 in the HNT
Hosea 13 in the IRVA
Hosea 13 in the IRVB
Hosea 13 in the IRVG
Hosea 13 in the IRVH
Hosea 13 in the IRVK
Hosea 13 in the IRVM
Hosea 13 in the IRVM2
Hosea 13 in the IRVO
Hosea 13 in the IRVP
Hosea 13 in the IRVT
Hosea 13 in the IRVT2
Hosea 13 in the IRVU
Hosea 13 in the ISVN
Hosea 13 in the JSNT
Hosea 13 in the KAPI
Hosea 13 in the KBT1ETNIK
Hosea 13 in the KBV
Hosea 13 in the KJV
Hosea 13 in the KNFD
Hosea 13 in the LBA
Hosea 13 in the LBLA
Hosea 13 in the LNT
Hosea 13 in the LSV
Hosea 13 in the MAAL
Hosea 13 in the MBV
Hosea 13 in the MBV2
Hosea 13 in the MHNT
Hosea 13 in the MKNFD
Hosea 13 in the MNG
Hosea 13 in the MNT
Hosea 13 in the MNT2
Hosea 13 in the MRS1T
Hosea 13 in the NAA
Hosea 13 in the NASB
Hosea 13 in the NBLA
Hosea 13 in the NBS
Hosea 13 in the NBVTP
Hosea 13 in the NET2
Hosea 13 in the NIV11
Hosea 13 in the NNT
Hosea 13 in the NNT2
Hosea 13 in the NNT3
Hosea 13 in the PDDPT
Hosea 13 in the PFNT
Hosea 13 in the RMNT
Hosea 13 in the SBIAS
Hosea 13 in the SBIBS
Hosea 13 in the SBIBS2
Hosea 13 in the SBICS
Hosea 13 in the SBIDS
Hosea 13 in the SBIGS
Hosea 13 in the SBIHS
Hosea 13 in the SBIIS
Hosea 13 in the SBIIS2
Hosea 13 in the SBIIS3
Hosea 13 in the SBIKS
Hosea 13 in the SBIKS2
Hosea 13 in the SBIMS
Hosea 13 in the SBIOS
Hosea 13 in the SBIPS
Hosea 13 in the SBISS
Hosea 13 in the SBITS
Hosea 13 in the SBITS2
Hosea 13 in the SBITS3
Hosea 13 in the SBITS4
Hosea 13 in the SBIUS
Hosea 13 in the SBIVS
Hosea 13 in the SBT
Hosea 13 in the SBT1E
Hosea 13 in the SCHL
Hosea 13 in the SNT
Hosea 13 in the SUSU
Hosea 13 in the SUSU2
Hosea 13 in the SYNO
Hosea 13 in the TBIAOTANT
Hosea 13 in the TBT1E
Hosea 13 in the TBT1E2
Hosea 13 in the TFTIP
Hosea 13 in the TFTU
Hosea 13 in the TGNTATF3T
Hosea 13 in the THAI
Hosea 13 in the TNFD
Hosea 13 in the TNT
Hosea 13 in the TNTIK
Hosea 13 in the TNTIL
Hosea 13 in the TNTIN
Hosea 13 in the TNTIP
Hosea 13 in the TNTIZ
Hosea 13 in the TOMA
Hosea 13 in the TTENT
Hosea 13 in the UBG
Hosea 13 in the UGV
Hosea 13 in the UGV2
Hosea 13 in the UGV3
Hosea 13 in the VBL
Hosea 13 in the VDCC
Hosea 13 in the YALU
Hosea 13 in the YAPE
Hosea 13 in the YBVTP
Hosea 13 in the ZBP