Job 19 (BOYCB)
1 Ìgbà náà ni Jobu dáhùn, ó sì wí pé: 2 “Yóò ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin ó fi máa fi ìyà jẹ mí,tí ẹ̀yin ó fi máa fi ọ̀rọ̀ yìí? 3 Ìgbà mẹ́wàá ní yin yọ mi lénu ẹ̀yin ti ń gàn mí;ojú kò tì yín tí ẹ fi jẹ mí ní yà. 4 Kí a sì wí bẹ́ẹ̀ pé, mo ṣìnà nítòótọ́,ìṣìnà mi wà lára èmi tìkára mi. 5 Bí ó tilẹ̀ ṣe pé ẹ̀yin ó ṣògo si mi lórí nítòótọ́,tí ẹ ó sì máa fi ẹ̀gàn mi gún mí lójú, 6 kí ẹ mọ̀ nísinsin yìí pé, Ọlọ́run ni ó bì mí ṣubú,ó sì nà àwọ̀n rẹ̀ yí mi ká. 7 “Kíyèsi, èmi ń kígbe pe, ‘Ọwọ́ alágbára!’ Ṣùgbọ́n a kò gbọ́ ti èmi;mo kígbe fún ìrànlọ́wọ́, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ìdájọ́. 8 Ó ṣọgbà dí ọ̀nà mi tí èmi kò le è kọjá,Ó sì mú òkùnkùn ṣú sí ipa ọ̀nà mi. 9 Ó ti bọ́ ògo mi,ó sì ṣí adé kúrò ní orí mi. 10 Ó ti bà mí jẹ́ ní ìhà gbogbo,ẹ̀mí sì pin; ìrètí mi ni a ó sì fàtu bí igi. 11 Ó sì tiná bọ ìbínú rẹ̀ sí mi,ó sì kà mí sí bí ọ̀kan nínú àwọn ọ̀tá rẹ̀. 12 Ẹgbẹ́ ogun rẹ̀ sì dàpọ̀ sí mi,wọ́n sì mọ odi yí mi ká,wọ́n sì yí àgọ́ mi ká. 13 “Ó mú àwọn arákùnrin mi jìnà sí mi réré,àti àwọn ojúlùmọ̀ mi di àjèjì sí mi pátápátá. 14 Àwọn alájọbí mi fàsẹ́yìn,àwọn ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ mi sì di onígbàgbé mi. 15 Àwọn ará inú ilé mi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi kà mí sí àjèjì;èmi jásí àjèjì ènìyàn ní ojú wọn. 16 Mo pe ìránṣẹ́ mi, òun kò sì dá mi lóhùn;mo fi ẹnu mi bẹ̀ ẹ́. 17 Ẹ̀mí mi ṣú àyà mi, àti òórùn miṣú àwọn ọmọ inú ìyá mi. 18 Àní àwọn ọmọdékùnrin fi mí ṣẹ̀sín,mo dìde, wọ́n sì sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí mi. 19 Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi kórìíra mi,àwọn olùfẹ́ mi sì kẹ̀yìndà mí. 20 Egungun mi lẹ̀ mọ́ ara mi àti mọ́ ẹran-ara mi,mo sì yọ́ pẹ̀lú awọ eyín mi. 21 “Ẹ ṣàánú fún mi, ẹ ṣàánú fún mi,ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi, nítorí ọwọ́ Ọlọ́run ti bà mí. 22 Nítorí kí ni ẹ̀yin ṣe lépa mi bíỌlọ́run, tí ẹran-ara mi kò tẹ́ yín lọ́rùn? 23 “Háà! Ìbá ṣe pé a le kọ̀wé ọ̀rọ̀ mi nísinsin yìí,ìbá ṣe pé a le kọ ọ sínú ìwé! 24 Kí a fi kálámù irin àti ti òjé kọwọ́n sínú àpáta fún láéláé. 25 Nítorí èmi mọ̀ pé olùdáǹdè mi ń bẹ láààyèàti pe òun ni yóò dìde dúró lórí ilẹ̀ ní ìkẹyìn; 26 àti lẹ́yìn ìgbà tí a pa àwọ̀ ara mi run,síbẹ̀ láìsí ẹran-ara mi ni èmi ó rí Ọlọ́run, 27 ẹni tí èmi ó rí fún ara mi,tí ojú mi ó sì wo, kì sì í ṣe ti ẹlòmíràn;ọkàn mi sì dákú ní inú mi. 28 “Bí ẹ̀yin bá wí pé, ‘Àwa ó ti lépa rẹ̀ tó!Àti pé, gbogbo ọ̀rọ̀ náà ni a sá à rí ní ọwọ́ rẹ̀,’ 29 kí ẹ̀yin kí ó bẹ̀rù,nítorí ìbínú ní í mú ìjìyà wá nípa idà,kí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ pé ìdájọ́ kan ń bẹ.”
In Other Versions
Job 19 in the ANGEFD
Job 19 in the ANTPNG2D
Job 19 in the AS21
Job 19 in the BAGH
Job 19 in the BBPNG
Job 19 in the BBT1E
Job 19 in the BDS
Job 19 in the BEV
Job 19 in the BHAD
Job 19 in the BIB
Job 19 in the BLPT
Job 19 in the BNT
Job 19 in the BNTABOOT
Job 19 in the BNTLV
Job 19 in the BOATCB
Job 19 in the BOATCB2
Job 19 in the BOBCV
Job 19 in the BOCNT
Job 19 in the BOECS
Job 19 in the BOGWICC
Job 19 in the BOHCB
Job 19 in the BOHCV
Job 19 in the BOHLNT
Job 19 in the BOHNTLTAL
Job 19 in the BOICB
Job 19 in the BOILNTAP
Job 19 in the BOITCV
Job 19 in the BOKCV
Job 19 in the BOKCV2
Job 19 in the BOKHWOG
Job 19 in the BOKSSV
Job 19 in the BOLCB
Job 19 in the BOLCB2
Job 19 in the BOMCV
Job 19 in the BONAV
Job 19 in the BONCB
Job 19 in the BONLT
Job 19 in the BONUT2
Job 19 in the BOPLNT
Job 19 in the BOSCB
Job 19 in the BOSNC
Job 19 in the BOTLNT
Job 19 in the BOVCB
Job 19 in the BPBB
Job 19 in the BPH
Job 19 in the BSB
Job 19 in the CCB
Job 19 in the CUV
Job 19 in the CUVS
Job 19 in the DBT
Job 19 in the DGDNT
Job 19 in the DHNT
Job 19 in the DNT
Job 19 in the ELBE
Job 19 in the EMTV
Job 19 in the ESV
Job 19 in the FBV
Job 19 in the FEB
Job 19 in the GGMNT
Job 19 in the GNT
Job 19 in the HARY
Job 19 in the HNT
Job 19 in the IRVA
Job 19 in the IRVB
Job 19 in the IRVG
Job 19 in the IRVH
Job 19 in the IRVK
Job 19 in the IRVM
Job 19 in the IRVM2
Job 19 in the IRVO
Job 19 in the IRVP
Job 19 in the IRVT
Job 19 in the IRVT2
Job 19 in the IRVU
Job 19 in the ISVN
Job 19 in the JSNT
Job 19 in the KAPI
Job 19 in the KBT1ETNIK
Job 19 in the KBV
Job 19 in the KJV
Job 19 in the KNFD
Job 19 in the LBA
Job 19 in the LBLA
Job 19 in the LNT
Job 19 in the LSV
Job 19 in the MAAL
Job 19 in the MBV
Job 19 in the MBV2
Job 19 in the MHNT
Job 19 in the MKNFD
Job 19 in the MNG
Job 19 in the MNT
Job 19 in the MNT2
Job 19 in the MRS1T
Job 19 in the NAA
Job 19 in the NASB
Job 19 in the NBLA
Job 19 in the NBS
Job 19 in the NBVTP
Job 19 in the NET2
Job 19 in the NIV11
Job 19 in the NNT
Job 19 in the NNT2
Job 19 in the NNT3
Job 19 in the PDDPT
Job 19 in the PFNT
Job 19 in the RMNT
Job 19 in the SBIAS
Job 19 in the SBIBS
Job 19 in the SBIBS2
Job 19 in the SBICS
Job 19 in the SBIDS
Job 19 in the SBIGS
Job 19 in the SBIHS
Job 19 in the SBIIS
Job 19 in the SBIIS2
Job 19 in the SBIIS3
Job 19 in the SBIKS
Job 19 in the SBIKS2
Job 19 in the SBIMS
Job 19 in the SBIOS
Job 19 in the SBIPS
Job 19 in the SBISS
Job 19 in the SBITS
Job 19 in the SBITS2
Job 19 in the SBITS3
Job 19 in the SBITS4
Job 19 in the SBIUS
Job 19 in the SBIVS
Job 19 in the SBT
Job 19 in the SBT1E
Job 19 in the SCHL
Job 19 in the SNT
Job 19 in the SUSU
Job 19 in the SUSU2
Job 19 in the SYNO
Job 19 in the TBIAOTANT
Job 19 in the TBT1E
Job 19 in the TBT1E2
Job 19 in the TFTIP
Job 19 in the TFTU
Job 19 in the TGNTATF3T
Job 19 in the THAI
Job 19 in the TNFD
Job 19 in the TNT
Job 19 in the TNTIK
Job 19 in the TNTIL
Job 19 in the TNTIN
Job 19 in the TNTIP
Job 19 in the TNTIZ
Job 19 in the TOMA
Job 19 in the TTENT
Job 19 in the UBG
Job 19 in the UGV
Job 19 in the UGV2
Job 19 in the UGV3
Job 19 in the VBL
Job 19 in the VDCC
Job 19 in the YALU
Job 19 in the YAPE
Job 19 in the YBVTP
Job 19 in the ZBP