Job 5 (BOYCB)
1 “Ó jẹ́ pé nísinsin yìí bí ẹnìkan bá wà tí yóò dá wa lóhùn?Tàbí ta ni nínú àwọn ènìyàn mímọ́ tí ìwọ ó yípadà sí? 2 Nítorí pé ìbínú pa aláìmòye,ìrunú a sì pa òpè ènìyàn. 3 Èmi ti rí aláìmòye ti ó ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lulẹ̀,ṣùgbọ́n lójúkan náà mo fi ibùjókòó rẹ̀ bú. 4 Àwọn ọmọ rẹ̀ kò jìnnà sí ewu,a sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ lójú ibodè,bẹ́ẹ̀ ni kò sí aláàbò kan. 5 Ìkórè oko ẹni tí àwọn tí ebi ń pa sọ̀ di jíjẹ,tí wọ́n sì wọ inú ẹ̀gún lọ kó,àwọn ìgárá ọlọ́ṣà sì gbé ohun ìní wọn mì. 6 Bí ìpọ́njú kò bá ti inú erùpẹ̀ jáde wá ni,tí ìyọnu kò ti ilẹ̀ jáde wá. 7 Ṣùgbọ́n a bí ènìyàn sínú wàhálà,gẹ́gẹ́ bí ìpẹ́pẹ́ iná ti máa ń ta sókè. 8 “Ṣùgbọ́n bí ó ṣe tèmi, ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ní èmi yóò ti ṣìpẹ̀,ní ọwọ́ Ọlọ́run ní èmi yóò máa fi ọ̀rọ̀ mi lé. 9 Ẹni tí ó ṣe ohun tí ó tóbi tí a kò lè ṣe àwárí,ohun ìyanu láìní iye. 10 Tí ń rọ̀jò sí orí ilẹ̀ ayétí ó sì ń rán omi sínú ilẹ̀kílẹ̀. 11 Láti gbé àwọn orílẹ̀-èdè lékèkí á lè gbé àwọn ẹni ìbànújẹ́ ga sí ibi aláìléwu. 12 Ó yí ìmọ̀ àwọn alárékérekè po,bẹ́ẹ̀ ní ọwọ́ wọn kò lè mú ìdáwọ́lé wọn ṣẹ. 13 Ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n nínú àrékérekè ara wọn,àti ìmọ̀ àwọn òǹrorò ní ó tì ṣubú ní ògèdèǹgbé. 14 Wọ́n sáré wọ inú òkùnkùn ní ọ̀sán;wọ́n sì fọwọ́ tálẹ̀ ní ọ̀sán gangan bí ẹni pé ní òru ni. 15 Ṣùgbọ́n ó gba tálákà là ní ọwọ́ idà,lọ́wọ́ ẹnu wọn àti lọ́wọ́ àwọn alágbára. 16 Bẹ́ẹ̀ ni ìrètí wà fún tálákà,àìṣòótọ́ sì pa ẹnu rẹ̀ mọ́. 17 “Kíyèsi i, ìbùkún ni fún ẹni tí Ọlọ́run bá wí,nítorí náà, má ṣe gan ìbáwí Olódùmarè. 18 Nítorí pé òun a máa pa ni lára, síbẹ̀ òun a sì tún dì í ní ìdì ìtura,ó sá lọ́gbẹ́, a sì fi ọwọ́ rẹ̀ di ojú ọgbẹ̀ náà jiná. 19 Yóò gbà ọ́ nínú ìpọ́njú mẹ́fà,àní nínú méje, ibi kan kì yóò bá ọ. 20 Nínú ìyanu yóò gbà ọ́ lọ́wọ́ ikúàti nínú ogun, yóò gbà ọ́ lọ́wọ́ idà. 21 A ó pa ọ́ mọ́ kúrò lọ́wọ́ iná ahọ́n,bẹ́ẹ̀ ní ìwọ kì yóò bẹ̀rù ìparun tí ó bá dé. 22 Ìwọ yóò rẹ́rìn-ín nínú ìparun àti ìyàn,bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kì yóò bẹ̀rù ẹranko ilẹ̀ ayé. 23 Nítorí pé ìwọ ti bá òkúta igbó mulẹ̀,àwọn ẹranko igbó yóò wà pẹ̀lú rẹ ní àlàáfíà. 24 Ìwọ ó sì mọ̀ pé àlàáfíà ni ibùjókòó rẹ wà,ìwọ yóò sì máa ṣe ìbẹ̀wò ibùjókòó rẹ, ìwọ kì yóò ṣìnà. 25 Ìwọ ó sì mọ̀ pẹ̀lú pé irú-ọmọ rẹ ó sì pọ̀àti àwọn ọmọ ọmọ rẹ yóò rí bí koríko igbó. 26 Ìwọ yóò wọ isà òkú rẹ ní ògbólógbòó ọjọ́,bí síírí ọkà tí ó gbó tí á sì kó ní ìgbà ìkórè rẹ̀. 27 “Kíyèsi i, àwa ti wádìí rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ní ó rí!Gbà á gbọ́, kí o sì mọ̀ pé fún ìre ara rẹ ni.”
In Other Versions
Job 5 in the ANGEFD
Job 5 in the ANTPNG2D
Job 5 in the AS21
Job 5 in the BAGH
Job 5 in the BBPNG
Job 5 in the BBT1E
Job 5 in the BDS
Job 5 in the BEV
Job 5 in the BHAD
Job 5 in the BIB
Job 5 in the BLPT
Job 5 in the BNT
Job 5 in the BNTABOOT
Job 5 in the BNTLV
Job 5 in the BOATCB
Job 5 in the BOATCB2
Job 5 in the BOBCV
Job 5 in the BOCNT
Job 5 in the BOECS
Job 5 in the BOGWICC
Job 5 in the BOHCB
Job 5 in the BOHCV
Job 5 in the BOHLNT
Job 5 in the BOHNTLTAL
Job 5 in the BOICB
Job 5 in the BOILNTAP
Job 5 in the BOITCV
Job 5 in the BOKCV
Job 5 in the BOKCV2
Job 5 in the BOKHWOG
Job 5 in the BOKSSV
Job 5 in the BOLCB
Job 5 in the BOLCB2
Job 5 in the BOMCV
Job 5 in the BONAV
Job 5 in the BONCB
Job 5 in the BONLT
Job 5 in the BONUT2
Job 5 in the BOPLNT
Job 5 in the BOSCB
Job 5 in the BOSNC
Job 5 in the BOTLNT
Job 5 in the BOVCB
Job 5 in the BPBB
Job 5 in the BPH
Job 5 in the BSB
Job 5 in the CCB
Job 5 in the CUV
Job 5 in the CUVS
Job 5 in the DBT
Job 5 in the DGDNT
Job 5 in the DHNT
Job 5 in the DNT
Job 5 in the ELBE
Job 5 in the EMTV
Job 5 in the ESV
Job 5 in the FBV
Job 5 in the FEB
Job 5 in the GGMNT
Job 5 in the GNT
Job 5 in the HARY
Job 5 in the HNT
Job 5 in the IRVA
Job 5 in the IRVB
Job 5 in the IRVG
Job 5 in the IRVH
Job 5 in the IRVK
Job 5 in the IRVM
Job 5 in the IRVM2
Job 5 in the IRVO
Job 5 in the IRVP
Job 5 in the IRVT
Job 5 in the IRVT2
Job 5 in the IRVU
Job 5 in the ISVN
Job 5 in the JSNT
Job 5 in the KAPI
Job 5 in the KBT1ETNIK
Job 5 in the KBV
Job 5 in the KJV
Job 5 in the KNFD
Job 5 in the LBA
Job 5 in the LBLA
Job 5 in the LNT
Job 5 in the LSV
Job 5 in the MAAL
Job 5 in the MBV
Job 5 in the MBV2
Job 5 in the MHNT
Job 5 in the MKNFD
Job 5 in the MNG
Job 5 in the MNT
Job 5 in the MNT2
Job 5 in the MRS1T
Job 5 in the NAA
Job 5 in the NASB
Job 5 in the NBLA
Job 5 in the NBS
Job 5 in the NBVTP
Job 5 in the NET2
Job 5 in the NIV11
Job 5 in the NNT
Job 5 in the NNT2
Job 5 in the NNT3
Job 5 in the PDDPT
Job 5 in the PFNT
Job 5 in the RMNT
Job 5 in the SBIAS
Job 5 in the SBIBS
Job 5 in the SBIBS2
Job 5 in the SBICS
Job 5 in the SBIDS
Job 5 in the SBIGS
Job 5 in the SBIHS
Job 5 in the SBIIS
Job 5 in the SBIIS2
Job 5 in the SBIIS3
Job 5 in the SBIKS
Job 5 in the SBIKS2
Job 5 in the SBIMS
Job 5 in the SBIOS
Job 5 in the SBIPS
Job 5 in the SBISS
Job 5 in the SBITS
Job 5 in the SBITS2
Job 5 in the SBITS3
Job 5 in the SBITS4
Job 5 in the SBIUS
Job 5 in the SBIVS
Job 5 in the SBT
Job 5 in the SBT1E
Job 5 in the SCHL
Job 5 in the SNT
Job 5 in the SUSU
Job 5 in the SUSU2
Job 5 in the SYNO
Job 5 in the TBIAOTANT
Job 5 in the TBT1E
Job 5 in the TBT1E2
Job 5 in the TFTIP
Job 5 in the TFTU
Job 5 in the TGNTATF3T
Job 5 in the THAI
Job 5 in the TNFD
Job 5 in the TNT
Job 5 in the TNTIK
Job 5 in the TNTIL
Job 5 in the TNTIN
Job 5 in the TNTIP
Job 5 in the TNTIZ
Job 5 in the TOMA
Job 5 in the TTENT
Job 5 in the UBG
Job 5 in the UGV
Job 5 in the UGV2
Job 5 in the UGV3
Job 5 in the VBL
Job 5 in the VDCC
Job 5 in the YALU
Job 5 in the YAPE
Job 5 in the YBVTP
Job 5 in the ZBP