Jonah 1 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀ OLÚWA sì tọ Jona ọmọ Amittai wá, wí pé: 2 “Dìde lọ sí ìlú ńlá Ninefe kí o sì wàásù sí i, nítorí ìwà búburú rẹ̀ gòkè wá iwájú mi.” 3 Ṣùgbọ́n Jona dìde kúrò láti sálọ sí Tarṣiṣi kúrò níwájú OLÚWA, ó sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí Joppa, ìbí ti ó tí rí ọkọ̀ kan tí ń lọ sí Tarṣiṣi: lẹ́yìn ti ó sanwó ọkọ̀, ó wọlé sínú rẹ̀, láti bá wọn lọ sí Tarṣiṣi kúrò níwájú OLÚWA. 4 Nígbà náà ni OLÚWA rán ìjì ńlá jáde sí ojú Òkun, ìjì líle sì wà nínú Òkun tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ náà dàbí ẹni pé yóò fọ́. 5 Nígbà náà ni àwọn atukọ̀ bẹ̀rù, olúkúlùkù sì ń kígbe sí ọlọ́run rẹ̀, wọ́n kó ẹrù tí ó wà nínú ọkọ̀ dà sínú Òkun, kí ó bá à lè fúyẹ́.Ṣùgbọ́n Jona sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ ọkọ̀ ó sì dùbúlẹ̀, ó sùn wọra. 6 Bẹ́ẹ̀ ni olórí ọkọ̀ tọ̀ ọ́ wá, ó sì wí fún un pé, “Èéṣe tí ìwọ fi sùn, ìwọ olóòórùn? Dìde kí o ké pe Ọlọ́run rẹ! Bóyá yóò ro tiwa, kí àwa má ba à ṣègbé.” 7 Nígbà náà ni àwọn atukọ̀ sọ fún ara wọn pé, “Wá, ẹ jẹ́ kí a sẹ́ kèké, kí àwa kí o le mọ̀ nítorí ta ni búburú yìí ṣe wá sórí wa.” Wọ́n ṣẹ́ kèké, kèké sì mú Jona. 8 Nígbà náà ni wọn wí fún un pé, “Sọ fún wa, àwa bẹ̀ ọ́, nítorí ta ni búburú yìí ṣe wá sórí wa? Kí ni iṣẹ́ rẹ? Níbo ni ìwọ ti wá? Kí ni orúkọ ìlú rẹ? Ẹ̀yà orílẹ̀-èdè wo sì ni ìwọ sì í ṣe?” 9 Òun sì dá wọn lóhùn pé, “Heberu ni èmi, mo sì bẹ̀rù OLÚWA, Ọlọ́run ọ̀run ẹni tí ó dá Òkun àti ìyàngbẹ ilẹ̀.” 10 Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin náà bẹ̀rù gidigidi, wọn sì wí fún un pé, “Èéṣe tí ìwọ fi ṣe èyí?” (Nítorí àwọn ọkùnrin náà mọ̀ pé ó ń sá kúrò ní iwájú OLÚWA ni, nítorí òun ti sọ fun wọn bẹ́ẹ̀). 11 Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Kí ni kí àwa ó ṣe sí ọ kí Òkun lè dákẹ́ fún wa?” Nítorí Òkun ru, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle. 12 Òun sì wí fún wọn pé, “Ẹ gbé mi, kí ẹ sì sọ mi sínú Òkun, bẹ́ẹ̀ ni okun yóò sì dákẹ́ fún un yin. Nítorí èmi mọ̀ pé, nítorí mi ni ẹ̀fúùfù líle yìí ṣe dé bá a yín.” 13 Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin náà gbìyànjú gidigidi láti mú ọkọ̀ wà sí ilẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kò lè ṣe é: nítorí tí Òkun túbọ̀ ru sí i, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle sí wọn. 14 Nítorí náà wọ́n kígbe sí OLÚWA, wọ́n sì wí pé, “OLÚWA àwa bẹ̀ ọ́, má ṣe jẹ́ kí àwa ṣègbé nítorí ẹ̀mí ọkùnrin yìí. Má sì ka ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sí wa ní ọrùn, nítorí ìwọ, OLÚWA, ti ṣe bí ó ti wù ọ́.” 15 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbé Jona, tí wọ́n sì sọ ọ́ sínú Òkun, Òkun sì dẹ́kun ríru rẹ̀. 16 Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin náà bẹ̀rù OLÚWA gidigidi, wọn si rú ẹbọ sí OLÚWA, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀jẹ́. 17 Ṣùgbọ́n OLÚWA ti pèsè ẹja ńlá kan láti gbé Jona mì. Jona sì wà nínú ẹja náà ni ọ̀sán mẹ́ta àti òru mẹ́ta.
In Other Versions
Jonah 1 in the ANGEFD
Jonah 1 in the ANTPNG2D
Jonah 1 in the AS21
Jonah 1 in the BAGH
Jonah 1 in the BBPNG
Jonah 1 in the BBT1E
Jonah 1 in the BDS
Jonah 1 in the BEV
Jonah 1 in the BHAD
Jonah 1 in the BIB
Jonah 1 in the BLPT
Jonah 1 in the BNT
Jonah 1 in the BNTABOOT
Jonah 1 in the BNTLV
Jonah 1 in the BOATCB
Jonah 1 in the BOATCB2
Jonah 1 in the BOBCV
Jonah 1 in the BOCNT
Jonah 1 in the BOECS
Jonah 1 in the BOGWICC
Jonah 1 in the BOHCB
Jonah 1 in the BOHCV
Jonah 1 in the BOHLNT
Jonah 1 in the BOHNTLTAL
Jonah 1 in the BOICB
Jonah 1 in the BOILNTAP
Jonah 1 in the BOITCV
Jonah 1 in the BOKCV
Jonah 1 in the BOKCV2
Jonah 1 in the BOKHWOG
Jonah 1 in the BOKSSV
Jonah 1 in the BOLCB
Jonah 1 in the BOLCB2
Jonah 1 in the BOMCV
Jonah 1 in the BONAV
Jonah 1 in the BONCB
Jonah 1 in the BONLT
Jonah 1 in the BONUT2
Jonah 1 in the BOPLNT
Jonah 1 in the BOSCB
Jonah 1 in the BOSNC
Jonah 1 in the BOTLNT
Jonah 1 in the BOVCB
Jonah 1 in the BPBB
Jonah 1 in the BPH
Jonah 1 in the BSB
Jonah 1 in the CCB
Jonah 1 in the CUV
Jonah 1 in the CUVS
Jonah 1 in the DBT
Jonah 1 in the DGDNT
Jonah 1 in the DHNT
Jonah 1 in the DNT
Jonah 1 in the ELBE
Jonah 1 in the EMTV
Jonah 1 in the ESV
Jonah 1 in the FBV
Jonah 1 in the FEB
Jonah 1 in the GGMNT
Jonah 1 in the GNT
Jonah 1 in the HARY
Jonah 1 in the HNT
Jonah 1 in the IRVA
Jonah 1 in the IRVB
Jonah 1 in the IRVG
Jonah 1 in the IRVH
Jonah 1 in the IRVK
Jonah 1 in the IRVM
Jonah 1 in the IRVM2
Jonah 1 in the IRVO
Jonah 1 in the IRVP
Jonah 1 in the IRVT
Jonah 1 in the IRVT2
Jonah 1 in the IRVU
Jonah 1 in the ISVN
Jonah 1 in the JSNT
Jonah 1 in the KAPI
Jonah 1 in the KBT1ETNIK
Jonah 1 in the KBV
Jonah 1 in the KJV
Jonah 1 in the KNFD
Jonah 1 in the LBA
Jonah 1 in the LBLA
Jonah 1 in the LNT
Jonah 1 in the LSV
Jonah 1 in the MAAL
Jonah 1 in the MBV
Jonah 1 in the MBV2
Jonah 1 in the MHNT
Jonah 1 in the MKNFD
Jonah 1 in the MNG
Jonah 1 in the MNT
Jonah 1 in the MNT2
Jonah 1 in the MRS1T
Jonah 1 in the NAA
Jonah 1 in the NASB
Jonah 1 in the NBLA
Jonah 1 in the NBS
Jonah 1 in the NBVTP
Jonah 1 in the NET2
Jonah 1 in the NIV11
Jonah 1 in the NNT
Jonah 1 in the NNT2
Jonah 1 in the NNT3
Jonah 1 in the PDDPT
Jonah 1 in the PFNT
Jonah 1 in the RMNT
Jonah 1 in the SBIAS
Jonah 1 in the SBIBS
Jonah 1 in the SBIBS2
Jonah 1 in the SBICS
Jonah 1 in the SBIDS
Jonah 1 in the SBIGS
Jonah 1 in the SBIHS
Jonah 1 in the SBIIS
Jonah 1 in the SBIIS2
Jonah 1 in the SBIIS3
Jonah 1 in the SBIKS
Jonah 1 in the SBIKS2
Jonah 1 in the SBIMS
Jonah 1 in the SBIOS
Jonah 1 in the SBIPS
Jonah 1 in the SBISS
Jonah 1 in the SBITS
Jonah 1 in the SBITS2
Jonah 1 in the SBITS3
Jonah 1 in the SBITS4
Jonah 1 in the SBIUS
Jonah 1 in the SBIVS
Jonah 1 in the SBT
Jonah 1 in the SBT1E
Jonah 1 in the SCHL
Jonah 1 in the SNT
Jonah 1 in the SUSU
Jonah 1 in the SUSU2
Jonah 1 in the SYNO
Jonah 1 in the TBIAOTANT
Jonah 1 in the TBT1E
Jonah 1 in the TBT1E2
Jonah 1 in the TFTIP
Jonah 1 in the TFTU
Jonah 1 in the TGNTATF3T
Jonah 1 in the THAI
Jonah 1 in the TNFD
Jonah 1 in the TNT
Jonah 1 in the TNTIK
Jonah 1 in the TNTIL
Jonah 1 in the TNTIN
Jonah 1 in the TNTIP
Jonah 1 in the TNTIZ
Jonah 1 in the TOMA
Jonah 1 in the TTENT
Jonah 1 in the UBG
Jonah 1 in the UGV
Jonah 1 in the UGV2
Jonah 1 in the UGV3
Jonah 1 in the VBL
Jonah 1 in the VDCC
Jonah 1 in the YALU
Jonah 1 in the YAPE
Jonah 1 in the YBVTP
Jonah 1 in the ZBP