Lamentations 5 (BOYCB)
1 Rántí, OLÚWA, ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wa;wò ó, kí o sì rí ìtìjú wa. 2 Àwọn ohun ìní wa ti di ti àlejò,ilé wa ti di ti àjèjì. 3 Àwa ti di aláìní òbí àti aláìní baba,àwọn ìyá wa ti di opó. 4 A gbọdọ̀ ra omi tí à ń mu;igi wa di títà fún wa. 5 Àwọn tí ó ń lé wa súnmọ́ wa;àárẹ̀ mú wa àwa kò sì rí ìsinmi. 6 Àwa jọ̀wọ́ ara wa fún Ejibiti àti Asirialáti rí oúnjẹ tó tó jẹ. 7 Àwọn baba wa ti ṣẹ̀, wọn kò sì ṣí mọ́,àwa sì ń ru ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 8 Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa,kò sì ṣí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ wọn. 9 Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wanítorí idà tí ó wà ní aginjù. 10 Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò,ebi sì yó wa bí àárẹ̀. 11 Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni,àti àwọn wúńdíá ti o wa ní ìlú Juda. 12 Àwọn ọmọ ọbakùnrin ti di síso sókè ní ọwọ́ wọn;kò sí ìbọ̀wọ̀ fún àgbàgbà mọ́. 13 Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wa ru òkúta;àwọn ọmọkùnrin sì ń ṣàárẹ̀ lábẹ́ ẹrù igi. 14 Àwọn àgbàgbà ti lọ kúrò ní ẹnu-bodè ìlú;àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì dákẹ́ orin wọn. 15 Ayọ̀ ti ṣáko ní ọkàn wa;ọ̀fọ̀ sì ti dúró bí ijó fún wa. 16 Adé ti ṣí kúrò ní orí waègbé ni fún wa, nítorí a ti ṣẹ̀. 17 Nítorí èyí, àárẹ̀ mú ọkàn wa,nítorí èyí, ojú wa sì ṣú. 18 Fún òkè Sioni tí ó ti di ahorolórí rẹ̀ àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ sì ń rìn kiri. 19 Ìwọ, OLÚWA, jẹ ọba títí láé;ìjọba rẹ dúró láti ìran kan dé ìran mìíràn. 20 Kí ló dé tí o ń gbàgbé wa ní gbogbo ìgbà?Kí ló dé tí o fi kọ̀ wá sílẹ̀ fún ọjọ́ pípẹ́? 21 Mú wa padà sí ọ̀dọ̀ rẹ, OLÚWA, kí àwa kí ó le padà;mú ọjọ́ wa di tuntun bí ìgbàanì, 22 àyàfi tí o bá ti kọ̀ wá sílẹ̀ pátápátátí ìbínú rẹ sí wa sì kọjá ìwọ̀n.
In Other Versions
Lamentations 5 in the ANGEFD
Lamentations 5 in the ANTPNG2D
Lamentations 5 in the AS21
Lamentations 5 in the BAGH
Lamentations 5 in the BBPNG
Lamentations 5 in the BBT1E
Lamentations 5 in the BDS
Lamentations 5 in the BEV
Lamentations 5 in the BHAD
Lamentations 5 in the BIB
Lamentations 5 in the BLPT
Lamentations 5 in the BNT
Lamentations 5 in the BNTABOOT
Lamentations 5 in the BNTLV
Lamentations 5 in the BOATCB
Lamentations 5 in the BOATCB2
Lamentations 5 in the BOBCV
Lamentations 5 in the BOCNT
Lamentations 5 in the BOECS
Lamentations 5 in the BOGWICC
Lamentations 5 in the BOHCB
Lamentations 5 in the BOHCV
Lamentations 5 in the BOHLNT
Lamentations 5 in the BOHNTLTAL
Lamentations 5 in the BOICB
Lamentations 5 in the BOILNTAP
Lamentations 5 in the BOITCV
Lamentations 5 in the BOKCV
Lamentations 5 in the BOKCV2
Lamentations 5 in the BOKHWOG
Lamentations 5 in the BOKSSV
Lamentations 5 in the BOLCB
Lamentations 5 in the BOLCB2
Lamentations 5 in the BOMCV
Lamentations 5 in the BONAV
Lamentations 5 in the BONCB
Lamentations 5 in the BONLT
Lamentations 5 in the BONUT2
Lamentations 5 in the BOPLNT
Lamentations 5 in the BOSCB
Lamentations 5 in the BOSNC
Lamentations 5 in the BOTLNT
Lamentations 5 in the BOVCB
Lamentations 5 in the BPBB
Lamentations 5 in the BPH
Lamentations 5 in the BSB
Lamentations 5 in the CCB
Lamentations 5 in the CUV
Lamentations 5 in the CUVS
Lamentations 5 in the DBT
Lamentations 5 in the DGDNT
Lamentations 5 in the DHNT
Lamentations 5 in the DNT
Lamentations 5 in the ELBE
Lamentations 5 in the EMTV
Lamentations 5 in the ESV
Lamentations 5 in the FBV
Lamentations 5 in the FEB
Lamentations 5 in the GGMNT
Lamentations 5 in the GNT
Lamentations 5 in the HARY
Lamentations 5 in the HNT
Lamentations 5 in the IRVA
Lamentations 5 in the IRVB
Lamentations 5 in the IRVG
Lamentations 5 in the IRVH
Lamentations 5 in the IRVK
Lamentations 5 in the IRVM
Lamentations 5 in the IRVM2
Lamentations 5 in the IRVO
Lamentations 5 in the IRVP
Lamentations 5 in the IRVT
Lamentations 5 in the IRVT2
Lamentations 5 in the IRVU
Lamentations 5 in the ISVN
Lamentations 5 in the JSNT
Lamentations 5 in the KAPI
Lamentations 5 in the KBT1ETNIK
Lamentations 5 in the KBV
Lamentations 5 in the KJV
Lamentations 5 in the KNFD
Lamentations 5 in the LBA
Lamentations 5 in the LBLA
Lamentations 5 in the LNT
Lamentations 5 in the LSV
Lamentations 5 in the MAAL
Lamentations 5 in the MBV
Lamentations 5 in the MBV2
Lamentations 5 in the MHNT
Lamentations 5 in the MKNFD
Lamentations 5 in the MNG
Lamentations 5 in the MNT
Lamentations 5 in the MNT2
Lamentations 5 in the MRS1T
Lamentations 5 in the NAA
Lamentations 5 in the NASB
Lamentations 5 in the NBLA
Lamentations 5 in the NBS
Lamentations 5 in the NBVTP
Lamentations 5 in the NET2
Lamentations 5 in the NIV11
Lamentations 5 in the NNT
Lamentations 5 in the NNT2
Lamentations 5 in the NNT3
Lamentations 5 in the PDDPT
Lamentations 5 in the PFNT
Lamentations 5 in the RMNT
Lamentations 5 in the SBIAS
Lamentations 5 in the SBIBS
Lamentations 5 in the SBIBS2
Lamentations 5 in the SBICS
Lamentations 5 in the SBIDS
Lamentations 5 in the SBIGS
Lamentations 5 in the SBIHS
Lamentations 5 in the SBIIS
Lamentations 5 in the SBIIS2
Lamentations 5 in the SBIIS3
Lamentations 5 in the SBIKS
Lamentations 5 in the SBIKS2
Lamentations 5 in the SBIMS
Lamentations 5 in the SBIOS
Lamentations 5 in the SBIPS
Lamentations 5 in the SBISS
Lamentations 5 in the SBITS
Lamentations 5 in the SBITS2
Lamentations 5 in the SBITS3
Lamentations 5 in the SBITS4
Lamentations 5 in the SBIUS
Lamentations 5 in the SBIVS
Lamentations 5 in the SBT
Lamentations 5 in the SBT1E
Lamentations 5 in the SCHL
Lamentations 5 in the SNT
Lamentations 5 in the SUSU
Lamentations 5 in the SUSU2
Lamentations 5 in the SYNO
Lamentations 5 in the TBIAOTANT
Lamentations 5 in the TBT1E
Lamentations 5 in the TBT1E2
Lamentations 5 in the TFTIP
Lamentations 5 in the TFTU
Lamentations 5 in the TGNTATF3T
Lamentations 5 in the THAI
Lamentations 5 in the TNFD
Lamentations 5 in the TNT
Lamentations 5 in the TNTIK
Lamentations 5 in the TNTIL
Lamentations 5 in the TNTIN
Lamentations 5 in the TNTIP
Lamentations 5 in the TNTIZ
Lamentations 5 in the TOMA
Lamentations 5 in the TTENT
Lamentations 5 in the UBG
Lamentations 5 in the UGV
Lamentations 5 in the UGV2
Lamentations 5 in the UGV3
Lamentations 5 in the VBL
Lamentations 5 in the VDCC
Lamentations 5 in the YALU
Lamentations 5 in the YAPE
Lamentations 5 in the YBVTP
Lamentations 5 in the ZBP