Micah 4 (BOYCB)

1 Ní ọjọ́ ìkẹyìna ó fi òkè ilé OLÚWA lélẹ̀ lórí àwọn òkè ńlá,a ó sì gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,àwọn ènìyàn yóò sì máa wọ̀ sínú rẹ̀. 2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè yóò wá,wọn yóò sì wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á gòkè ńlá OLÚWA,àti sí ilé Ọlọ́run Jakọbu.Òun yóò sì kọ́ wa ní ọ̀nà rẹ̀,kí àwa kí ó lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀.”Òfin yóò jáde láti Sioni wá,àti ọ̀rọ̀ OLÚWA láti Jerusalẹmu. 3 Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ láàrín ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn,yóò sì parí aáwọ̀ fún orílẹ̀-èdè alágbára jíjìn réré.Wọn yóò sì fi idà wọn rọ ohun èlò ìtulẹ̀àti ọ̀kọ̀ wọn di dòjéorílẹ̀-èdè kì yóò gbé idà sókè sí orílẹ̀-èdè mọ́,bẹ́ẹ̀ ni wọn kì yóò kọ́ ogun jíjà mọ́. 4 Ṣùgbọ́n olúkúlùkù yóò jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,ẹnìkan kì yóò sì dẹ́rùbà wọ́n,nítorí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ti sọ̀rọ̀. 5 Gbogbo àwọn ènìyàn ń rìn,olúkúlùkù ni orúkọ ọlọ́run tirẹ̀,ṣùgbọ́n àwa yóò máa rìn ní orúkọ OLÚWA.Ọlọ́run wa láé àti láéláé. 6 “Ní ọjọ́ náà,” ni OLÚWA wí,“Èmi yóò kó àwọn arọ jọ;èmi yóò sì ṣà àwọn tí a lé kúrò ní ìlú jọ,àti àwọn ẹni tí èmi ti pọ́n lójú. 7 Èmi yóò dá àwọn arọ sí fún èyí tókù,èmi yóò sì sọ àwọn tí a lé kúrò ní ìlú di orílẹ̀-èdè alágbára. OLÚWA yóò sì jẹ ọba lórí wọn ní òkè ńlá Sioniláti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé. 8 Ní ti ìwọ, ilé ìṣọ́ agbo àgùntàn,odi alágbára ọmọbìnrin Sioni,a ó mú ìjọba ìṣáájú padà bọ̀ sípò fún un yín;ìjọba yóò sì wà sí ọ̀dọ̀ ọmọbìnrin Jerusalẹmu.” 9 Kí ni ìwọ ha ń kígbe sókè sí nísinsin yìí?Ǹjẹ́ ìwọ kò ní ọba bí?Àwọn ìgbìmọ̀ rẹ ṣègbé bí?Nítorí ìrora ti dì ọ́ mú bí obìnrin tí ń rọbí. 10 Máa yí síyìn-ín sọ́hùn-ún nínú ìrora,ìwọ obìnrin Sioni,bí ẹni tí ń rọbí,nítorí nísinsin yìí ìwọ yóò jáde lọ kúrò ní ìlú,ìwọ yóò sì máa gbé inú igbó.Ìwọ yóò lọ sí Babeli;níbẹ̀ ni ìwọ yóò sì ti rí ìgbàlà.Níbẹ̀ ni OLÚWA yóò ti rà ọ́ padà kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ. 11 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ọ̀pọ̀lọpọ̀ Orílẹ̀-èdè kó ara wọn jọ sí ọ.Wọ́n sì wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a sọ ọ́ di àìmọ́,ẹ jẹ́ kí ojú wa kí ó wo Sioni!” 12 Ṣùgbọ́n wọn kò mọèrò inú OLÚWA;bẹ́ẹ̀ ni òye ìmọ̀ rẹ̀ kò yé wọn,nítorí ó ti kó wọn jọ bí i ìtí sínú ìpakà. 13 “Dìde, kí ó sì máa pa ọkà ìwọ ọmọbìnrin Sioni,nítorí èmi yóò sọ ìwo rẹ̀ di irin,èmi yóò sì sọ pátákò rẹ̀ di idẹìwọ yóò run ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè pátápátá.”Èmi yóò sì ya èrè wọn sọ́tọ̀ fún OLÚWAàti ọrọ̀ wọn sí Olúwa gbogbo ayé.

In Other Versions

Micah 4 in the ANGEFD

Micah 4 in the ANTPNG2D

Micah 4 in the AS21

Micah 4 in the BAGH

Micah 4 in the BBPNG

Micah 4 in the BBT1E

Micah 4 in the BDS

Micah 4 in the BEV

Micah 4 in the BHAD

Micah 4 in the BIB

Micah 4 in the BLPT

Micah 4 in the BNT

Micah 4 in the BNTABOOT

Micah 4 in the BNTLV

Micah 4 in the BOATCB

Micah 4 in the BOATCB2

Micah 4 in the BOBCV

Micah 4 in the BOCNT

Micah 4 in the BOECS

Micah 4 in the BOGWICC

Micah 4 in the BOHCB

Micah 4 in the BOHCV

Micah 4 in the BOHLNT

Micah 4 in the BOHNTLTAL

Micah 4 in the BOICB

Micah 4 in the BOILNTAP

Micah 4 in the BOITCV

Micah 4 in the BOKCV

Micah 4 in the BOKCV2

Micah 4 in the BOKHWOG

Micah 4 in the BOKSSV

Micah 4 in the BOLCB

Micah 4 in the BOLCB2

Micah 4 in the BOMCV

Micah 4 in the BONAV

Micah 4 in the BONCB

Micah 4 in the BONLT

Micah 4 in the BONUT2

Micah 4 in the BOPLNT

Micah 4 in the BOSCB

Micah 4 in the BOSNC

Micah 4 in the BOTLNT

Micah 4 in the BOVCB

Micah 4 in the BPBB

Micah 4 in the BPH

Micah 4 in the BSB

Micah 4 in the CCB

Micah 4 in the CUV

Micah 4 in the CUVS

Micah 4 in the DBT

Micah 4 in the DGDNT

Micah 4 in the DHNT

Micah 4 in the DNT

Micah 4 in the ELBE

Micah 4 in the EMTV

Micah 4 in the ESV

Micah 4 in the FBV

Micah 4 in the FEB

Micah 4 in the GGMNT

Micah 4 in the GNT

Micah 4 in the HARY

Micah 4 in the HNT

Micah 4 in the IRVA

Micah 4 in the IRVB

Micah 4 in the IRVG

Micah 4 in the IRVH

Micah 4 in the IRVK

Micah 4 in the IRVM

Micah 4 in the IRVM2

Micah 4 in the IRVO

Micah 4 in the IRVP

Micah 4 in the IRVT

Micah 4 in the IRVT2

Micah 4 in the IRVU

Micah 4 in the ISVN

Micah 4 in the JSNT

Micah 4 in the KAPI

Micah 4 in the KBT1ETNIK

Micah 4 in the KBV

Micah 4 in the KJV

Micah 4 in the KNFD

Micah 4 in the LBA

Micah 4 in the LBLA

Micah 4 in the LNT

Micah 4 in the LSV

Micah 4 in the MAAL

Micah 4 in the MBV

Micah 4 in the MBV2

Micah 4 in the MHNT

Micah 4 in the MKNFD

Micah 4 in the MNG

Micah 4 in the MNT

Micah 4 in the MNT2

Micah 4 in the MRS1T

Micah 4 in the NAA

Micah 4 in the NASB

Micah 4 in the NBLA

Micah 4 in the NBS

Micah 4 in the NBVTP

Micah 4 in the NET2

Micah 4 in the NIV11

Micah 4 in the NNT

Micah 4 in the NNT2

Micah 4 in the NNT3

Micah 4 in the PDDPT

Micah 4 in the PFNT

Micah 4 in the RMNT

Micah 4 in the SBIAS

Micah 4 in the SBIBS

Micah 4 in the SBIBS2

Micah 4 in the SBICS

Micah 4 in the SBIDS

Micah 4 in the SBIGS

Micah 4 in the SBIHS

Micah 4 in the SBIIS

Micah 4 in the SBIIS2

Micah 4 in the SBIIS3

Micah 4 in the SBIKS

Micah 4 in the SBIKS2

Micah 4 in the SBIMS

Micah 4 in the SBIOS

Micah 4 in the SBIPS

Micah 4 in the SBISS

Micah 4 in the SBITS

Micah 4 in the SBITS2

Micah 4 in the SBITS3

Micah 4 in the SBITS4

Micah 4 in the SBIUS

Micah 4 in the SBIVS

Micah 4 in the SBT

Micah 4 in the SBT1E

Micah 4 in the SCHL

Micah 4 in the SNT

Micah 4 in the SUSU

Micah 4 in the SUSU2

Micah 4 in the SYNO

Micah 4 in the TBIAOTANT

Micah 4 in the TBT1E

Micah 4 in the TBT1E2

Micah 4 in the TFTIP

Micah 4 in the TFTU

Micah 4 in the TGNTATF3T

Micah 4 in the THAI

Micah 4 in the TNFD

Micah 4 in the TNT

Micah 4 in the TNTIK

Micah 4 in the TNTIL

Micah 4 in the TNTIN

Micah 4 in the TNTIP

Micah 4 in the TNTIZ

Micah 4 in the TOMA

Micah 4 in the TTENT

Micah 4 in the UBG

Micah 4 in the UGV

Micah 4 in the UGV2

Micah 4 in the UGV3

Micah 4 in the VBL

Micah 4 in the VDCC

Micah 4 in the YALU

Micah 4 in the YAPE

Micah 4 in the YBVTP

Micah 4 in the ZBP