Proverbs 24 (BOYCB)
1 Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburúmá ṣe jẹ́ kí àwùjọ wọn wù ọ́; 2 nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ohun búburú,ètè wọn sì ń sọ̀rọ̀ nípa dídá rúgúdù sílẹ̀. 3 Nípa ọgbọ́n ni ilé di kíkọ́nípa òye sì ni ó ti fìdímúlẹ̀; 4 nípa ìmọ̀ ni àwọn yàrá rẹ̀ kúnpẹ̀lú àwọn ohun ọ̀ṣọ́ tí ó lẹ́wà tí ó sì ṣọ̀wọ́n. 5 Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára púpọ̀,ènìyàn tí ó ní ìmọ̀ sì ń ní agbára sí i. 6 Láti jagun, ó nílò ìtọ́sọ́nà:nínú ìṣẹ́gun ni ọ̀pọ̀ onígbìmọ̀. 7 Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrèàti gbọ̀ngàn ìlú níbi ibodè kò ní ohun tí yóò wí. 8 Ẹni tí ń pète ibini a ó mọ̀ bí ènìyàn ibi. 9 Ète òmùgọ̀ ènìyàn jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,àwọn ènìyàn sì kórìíra ẹlẹ́gàn. 10 Bí ìwọ bá dákú lásìkò ìdààmúbáwo ni agbára rẹ ha ti kéré tó! 11 Gba àwọn tí a ń wọ́ lọ sí ibi ikú là;fa àwọn tó ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lọ sí ibi ìparun padà. 12 Bí ìwọ bá wí pé, “Ṣùgbọ́n a kò mọ nǹkan kan nípa èyí,”ǹjẹ́ ẹni tí ń díwọ̀n ọkàn kò kíyèsi i? Ǹjẹ́ ẹni tí ń ṣọ́ ẹ̀mí rẹ kò mọ̀ ọ́n?Ǹjẹ́ kò ní san án fún ẹnìkọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó ti ṣe? 13 Jẹ oyin, ìwọ ọmọ mi, nítorí tí ó dára,oyin láti inú afárá oyin dùn lẹ́nu. 14 Mọ̀ pẹ̀lú pé ọgbọ́n pẹ̀lú dùn fún ọkàn rẹbí ìwọ bá rí i ìrètí ọjọ́ iwájú wà fún ọìrètí rẹ kì yóò sì já ṣófo. 15 Má ṣe ba ní ibùba bí ènìyàn búburúláti gba ibùjókòó olódodo,má ṣe fi ibi ìsinmi rẹ̀ ṣe ìjẹ; 16 nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbà méje, yóò tún padà dìde sá á ni,ṣùgbọ́n ìdààmú yóò fa ènìyàn búburú lulẹ̀. 17 Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú;nígbà tí ó bá kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yọ̀. 18 Àìṣe bẹ́ẹ̀ OLÚWA yóò rí i yóò sì bínúyóò sì yí ìbínú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀. 19 Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibitàbí jowú àwọn ènìyàn búburú, 20 nítorí ẹni ibi kò ní ìrètí ọjọ́ iwájúa ó sì pa fìtílà àwọn ènìyàn búburú kú. 21 Bẹ̀rù OLÚWA àti ọba, ọmọ mi,má sì ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí kunkun. 22 Nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn,ta ni ó sì mọ irú ìyọnu tí wọ́n lè mú wá? 23 Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú tún jẹ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n:láti ṣe ojúsàájú níbi ìdájọ́ kò dára rárá. 24 Ẹnikẹ́ni tí ó wí fún ẹlẹ́bi pé, “Ìwọ lo jàre,”àwọn ènìyàn yóò ṣẹ́ èpè fún un àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kọ̀ ọ́. 25 Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi,ọ̀pọ̀ ìbùkún yóò sì wá sórí wọn. 26 Ìdáhùn òtítọ́dàbí ìfẹnukoni ní ẹnu. 27 Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹsì rí i pé oko rẹ ti ṣe dáradára;lẹ́yìn náà kọ́ ilé rẹ. 28 Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí,tàbí kí o fi ètè rẹ tannijẹ. 29 Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi;Èmi yóò san ohun tí ó ṣe fún mi padà fún un.” 30 Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ,mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn; 31 ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo,koríko ti gba gbogbo oko náà. 32 Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsimo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí; 33 oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀,ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi, 34 òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalèàti àìní bí olè.
In Other Versions
Proverbs 24 in the ANGEFD
Proverbs 24 in the ANTPNG2D
Proverbs 24 in the AS21
Proverbs 24 in the BAGH
Proverbs 24 in the BBPNG
Proverbs 24 in the BBT1E
Proverbs 24 in the BDS
Proverbs 24 in the BEV
Proverbs 24 in the BHAD
Proverbs 24 in the BIB
Proverbs 24 in the BLPT
Proverbs 24 in the BNT
Proverbs 24 in the BNTABOOT
Proverbs 24 in the BNTLV
Proverbs 24 in the BOATCB
Proverbs 24 in the BOATCB2
Proverbs 24 in the BOBCV
Proverbs 24 in the BOCNT
Proverbs 24 in the BOECS
Proverbs 24 in the BOGWICC
Proverbs 24 in the BOHCB
Proverbs 24 in the BOHCV
Proverbs 24 in the BOHLNT
Proverbs 24 in the BOHNTLTAL
Proverbs 24 in the BOICB
Proverbs 24 in the BOILNTAP
Proverbs 24 in the BOITCV
Proverbs 24 in the BOKCV
Proverbs 24 in the BOKCV2
Proverbs 24 in the BOKHWOG
Proverbs 24 in the BOKSSV
Proverbs 24 in the BOLCB
Proverbs 24 in the BOLCB2
Proverbs 24 in the BOMCV
Proverbs 24 in the BONAV
Proverbs 24 in the BONCB
Proverbs 24 in the BONLT
Proverbs 24 in the BONUT2
Proverbs 24 in the BOPLNT
Proverbs 24 in the BOSCB
Proverbs 24 in the BOSNC
Proverbs 24 in the BOTLNT
Proverbs 24 in the BOVCB
Proverbs 24 in the BPBB
Proverbs 24 in the BPH
Proverbs 24 in the BSB
Proverbs 24 in the CCB
Proverbs 24 in the CUV
Proverbs 24 in the CUVS
Proverbs 24 in the DBT
Proverbs 24 in the DGDNT
Proverbs 24 in the DHNT
Proverbs 24 in the DNT
Proverbs 24 in the ELBE
Proverbs 24 in the EMTV
Proverbs 24 in the ESV
Proverbs 24 in the FBV
Proverbs 24 in the FEB
Proverbs 24 in the GGMNT
Proverbs 24 in the GNT
Proverbs 24 in the HARY
Proverbs 24 in the HNT
Proverbs 24 in the IRVA
Proverbs 24 in the IRVB
Proverbs 24 in the IRVG
Proverbs 24 in the IRVH
Proverbs 24 in the IRVK
Proverbs 24 in the IRVM
Proverbs 24 in the IRVM2
Proverbs 24 in the IRVO
Proverbs 24 in the IRVP
Proverbs 24 in the IRVT
Proverbs 24 in the IRVT2
Proverbs 24 in the IRVU
Proverbs 24 in the ISVN
Proverbs 24 in the JSNT
Proverbs 24 in the KAPI
Proverbs 24 in the KBT1ETNIK
Proverbs 24 in the KBV
Proverbs 24 in the KJV
Proverbs 24 in the KNFD
Proverbs 24 in the LBA
Proverbs 24 in the LBLA
Proverbs 24 in the LNT
Proverbs 24 in the LSV
Proverbs 24 in the MAAL
Proverbs 24 in the MBV
Proverbs 24 in the MBV2
Proverbs 24 in the MHNT
Proverbs 24 in the MKNFD
Proverbs 24 in the MNG
Proverbs 24 in the MNT
Proverbs 24 in the MNT2
Proverbs 24 in the MRS1T
Proverbs 24 in the NAA
Proverbs 24 in the NASB
Proverbs 24 in the NBLA
Proverbs 24 in the NBS
Proverbs 24 in the NBVTP
Proverbs 24 in the NET2
Proverbs 24 in the NIV11
Proverbs 24 in the NNT
Proverbs 24 in the NNT2
Proverbs 24 in the NNT3
Proverbs 24 in the PDDPT
Proverbs 24 in the PFNT
Proverbs 24 in the RMNT
Proverbs 24 in the SBIAS
Proverbs 24 in the SBIBS
Proverbs 24 in the SBIBS2
Proverbs 24 in the SBICS
Proverbs 24 in the SBIDS
Proverbs 24 in the SBIGS
Proverbs 24 in the SBIHS
Proverbs 24 in the SBIIS
Proverbs 24 in the SBIIS2
Proverbs 24 in the SBIIS3
Proverbs 24 in the SBIKS
Proverbs 24 in the SBIKS2
Proverbs 24 in the SBIMS
Proverbs 24 in the SBIOS
Proverbs 24 in the SBIPS
Proverbs 24 in the SBISS
Proverbs 24 in the SBITS
Proverbs 24 in the SBITS2
Proverbs 24 in the SBITS3
Proverbs 24 in the SBITS4
Proverbs 24 in the SBIUS
Proverbs 24 in the SBIVS
Proverbs 24 in the SBT
Proverbs 24 in the SBT1E
Proverbs 24 in the SCHL
Proverbs 24 in the SNT
Proverbs 24 in the SUSU
Proverbs 24 in the SUSU2
Proverbs 24 in the SYNO
Proverbs 24 in the TBIAOTANT
Proverbs 24 in the TBT1E
Proverbs 24 in the TBT1E2
Proverbs 24 in the TFTIP
Proverbs 24 in the TFTU
Proverbs 24 in the TGNTATF3T
Proverbs 24 in the THAI
Proverbs 24 in the TNFD
Proverbs 24 in the TNT
Proverbs 24 in the TNTIK
Proverbs 24 in the TNTIL
Proverbs 24 in the TNTIN
Proverbs 24 in the TNTIP
Proverbs 24 in the TNTIZ
Proverbs 24 in the TOMA
Proverbs 24 in the TTENT
Proverbs 24 in the UBG
Proverbs 24 in the UGV
Proverbs 24 in the UGV2
Proverbs 24 in the UGV3
Proverbs 24 in the VBL
Proverbs 24 in the VDCC
Proverbs 24 in the YALU
Proverbs 24 in the YAPE
Proverbs 24 in the YBVTP
Proverbs 24 in the ZBP