Proverbs 28 (BOYCB)
1 Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé eṣùgbọ́n olódodo láyà bí i kìnnìún. 2 Nígbà tí orílẹ̀-èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀,ṣùgbọ́n olóye àti onímọ̀ a máa pa òfin mọ́. 3 Ọba tí ó ni àwọn tálákà láradàbí àgbàrá òjò tí ó ń gbá gbogbo ọ̀gbìn lọ. 4 Àwọn tí ó kọ òfin sílẹ̀ a máa gbóríyìn fún ènìyàn búburúṣùgbọ́n àwọn tí ó pa òfin mọ́ kọjú ìjà sí ènìyàn búburú. 5 Òye ìdájọ́ òdodo kò yé àwọn ẹni ibiṣùgbọ́n ó yé àwọn tí ń wá OLÚWA dáradára. 6 Ó sàn láti jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ jẹ́ aláìlábùkùju ọlọ́rọ̀ tí ọ̀nà rẹ̀ rí pálapàla. 7 Ẹni tí ó pa òfin mọ́ jẹ́ olóye ọmọṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ẹ́ jẹgúdújẹrá kẹ́gbẹ́ dójútì baba rẹ̀. 8 Ẹni tí ó mú ọrọ̀ rẹ̀ di púpọ̀ nípa èrè àjẹjùń kó jọ fún ẹlòmíràn, tí yóò ní àánú àwọn tálákà. 9 Bí ẹnikẹ́ni bá kọ etí ikún sí òfin,kódà àdúrà rẹ̀ jẹ́ ìríra. 10 Ẹni tí ó mú olódodo rìn ọ̀nà búburúyóò bọ́ sínú pàkúté ara rẹ̀ṣùgbọ́n aláìlẹ́gàn yóò gba ogún rere. 11 Ọlọ́rọ̀ ènìyàn le è gbọ́n lójú ara rẹ̀ṣùgbọ́n tálákà tí ó ní òye rí ìdí, rẹ̀. 12 Nígbà tí olódodo ń lékè ariwo ayọ̀ ta;ṣùgbọ́n nígbà tí ènìyàn búburú gorí òye, àwọn ènìyàn a na pápá bora. 13 Ẹni tí ó bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kì yóò ṣe rere,ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá jẹ́wọ́ tí ó sì kọ̀ wọ́n sílẹ̀ máa ń rí àánú gbà. 14 Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run nígbà gbogboṣùgbọ́n ẹni tí ó sé ọkàn rẹ̀ le bọ́ sínú wàhálà. 15 Bí kìnnìún tí ń ké tàbí Beari tí ń halẹ̀ni ènìyàn búburú tí ń jẹ ọba lórí àwọn aláìlágbára. 16 Ọmọ-aládé tí ó ṣe aláìmòye púpọ̀ ní ń ṣe ìwà ìkà púpọ̀ pẹ̀lú,ṣùgbọ́n èyí tí ó kórìíra ojúkòkòrò yóò mú ọjọ́ rẹ̀ pẹ́. 17 Ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò balẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ìpànìyànyóò máa joró rẹ̀ títí ikúmá ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ràn án lọ́wọ́. 18 Ẹni tí ń rìn déédéé ní yóò là,ṣùgbọ́n ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ àyídáyidà ni yóò ṣubú lójijì. 19 Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọ́pọ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ń lé ohun asán yóò kún fún òsì. 20 Olóòtítọ́ ènìyàn yóò rí ìbùkún gbà gan anṣùgbọ́n ẹni tí ojú ń kán láti di ọlọ́rọ̀ kì yóò lọ láìjìyà. 21 Ojúsàájú ṣíṣe kò dára,síbẹ̀ ènìyàn kan ń ṣẹ̀ nítorí òkèlè oúnjẹ kan. 22 Ahun ń sáré àti làkò sì funra pé òsì dúró de òun. 23 Ẹni tí ó bá ènìyàn kan wí yóò rí ojúrere ni nígbẹ̀yìnju ẹni tí ó ní ètè ẹ̀tàn lọ. 24 Ẹni tí ó ja baba tàbí ìyá rẹ̀ lólètí ó sì wí pé, “Kì í ṣe ẹ̀ṣẹ̀,”irú kan ni òun àti ẹni tí ń pa ni run. 25 Ọ̀kánjúwà ènìyàn a máa dá ìjà sílẹ̀,ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA yóò gbilẹ̀. 26 Ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé ara rẹ̀ jẹ́ aláìgbọ́nṣùgbọ́n ẹni tí ń rìn nínú ọgbọ́n wà láìléwu. 27 Ẹni tí ó ń fi fún tálákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhun,ṣùgbọ́n ẹni tí ó di ojú rẹ̀ sí wọn gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ègún. 28 Nígbà tí ènìyàn búburú bá dórí ìjọba, àwọn ènìyàn a na pápá bora;ṣùgbọ́n nígbà tí ènìyàn búburú bá ṣègbé,àwọn olódodo ń gbilẹ̀ sí i.
In Other Versions
Proverbs 28 in the ANGEFD
Proverbs 28 in the ANTPNG2D
Proverbs 28 in the AS21
Proverbs 28 in the BAGH
Proverbs 28 in the BBPNG
Proverbs 28 in the BBT1E
Proverbs 28 in the BDS
Proverbs 28 in the BEV
Proverbs 28 in the BHAD
Proverbs 28 in the BIB
Proverbs 28 in the BLPT
Proverbs 28 in the BNT
Proverbs 28 in the BNTABOOT
Proverbs 28 in the BNTLV
Proverbs 28 in the BOATCB
Proverbs 28 in the BOATCB2
Proverbs 28 in the BOBCV
Proverbs 28 in the BOCNT
Proverbs 28 in the BOECS
Proverbs 28 in the BOGWICC
Proverbs 28 in the BOHCB
Proverbs 28 in the BOHCV
Proverbs 28 in the BOHLNT
Proverbs 28 in the BOHNTLTAL
Proverbs 28 in the BOICB
Proverbs 28 in the BOILNTAP
Proverbs 28 in the BOITCV
Proverbs 28 in the BOKCV
Proverbs 28 in the BOKCV2
Proverbs 28 in the BOKHWOG
Proverbs 28 in the BOKSSV
Proverbs 28 in the BOLCB
Proverbs 28 in the BOLCB2
Proverbs 28 in the BOMCV
Proverbs 28 in the BONAV
Proverbs 28 in the BONCB
Proverbs 28 in the BONLT
Proverbs 28 in the BONUT2
Proverbs 28 in the BOPLNT
Proverbs 28 in the BOSCB
Proverbs 28 in the BOSNC
Proverbs 28 in the BOTLNT
Proverbs 28 in the BOVCB
Proverbs 28 in the BPBB
Proverbs 28 in the BPH
Proverbs 28 in the BSB
Proverbs 28 in the CCB
Proverbs 28 in the CUV
Proverbs 28 in the CUVS
Proverbs 28 in the DBT
Proverbs 28 in the DGDNT
Proverbs 28 in the DHNT
Proverbs 28 in the DNT
Proverbs 28 in the ELBE
Proverbs 28 in the EMTV
Proverbs 28 in the ESV
Proverbs 28 in the FBV
Proverbs 28 in the FEB
Proverbs 28 in the GGMNT
Proverbs 28 in the GNT
Proverbs 28 in the HARY
Proverbs 28 in the HNT
Proverbs 28 in the IRVA
Proverbs 28 in the IRVB
Proverbs 28 in the IRVG
Proverbs 28 in the IRVH
Proverbs 28 in the IRVK
Proverbs 28 in the IRVM
Proverbs 28 in the IRVM2
Proverbs 28 in the IRVO
Proverbs 28 in the IRVP
Proverbs 28 in the IRVT
Proverbs 28 in the IRVT2
Proverbs 28 in the IRVU
Proverbs 28 in the ISVN
Proverbs 28 in the JSNT
Proverbs 28 in the KAPI
Proverbs 28 in the KBT1ETNIK
Proverbs 28 in the KBV
Proverbs 28 in the KJV
Proverbs 28 in the KNFD
Proverbs 28 in the LBA
Proverbs 28 in the LBLA
Proverbs 28 in the LNT
Proverbs 28 in the LSV
Proverbs 28 in the MAAL
Proverbs 28 in the MBV
Proverbs 28 in the MBV2
Proverbs 28 in the MHNT
Proverbs 28 in the MKNFD
Proverbs 28 in the MNG
Proverbs 28 in the MNT
Proverbs 28 in the MNT2
Proverbs 28 in the MRS1T
Proverbs 28 in the NAA
Proverbs 28 in the NASB
Proverbs 28 in the NBLA
Proverbs 28 in the NBS
Proverbs 28 in the NBVTP
Proverbs 28 in the NET2
Proverbs 28 in the NIV11
Proverbs 28 in the NNT
Proverbs 28 in the NNT2
Proverbs 28 in the NNT3
Proverbs 28 in the PDDPT
Proverbs 28 in the PFNT
Proverbs 28 in the RMNT
Proverbs 28 in the SBIAS
Proverbs 28 in the SBIBS
Proverbs 28 in the SBIBS2
Proverbs 28 in the SBICS
Proverbs 28 in the SBIDS
Proverbs 28 in the SBIGS
Proverbs 28 in the SBIHS
Proverbs 28 in the SBIIS
Proverbs 28 in the SBIIS2
Proverbs 28 in the SBIIS3
Proverbs 28 in the SBIKS
Proverbs 28 in the SBIKS2
Proverbs 28 in the SBIMS
Proverbs 28 in the SBIOS
Proverbs 28 in the SBIPS
Proverbs 28 in the SBISS
Proverbs 28 in the SBITS
Proverbs 28 in the SBITS2
Proverbs 28 in the SBITS3
Proverbs 28 in the SBITS4
Proverbs 28 in the SBIUS
Proverbs 28 in the SBIVS
Proverbs 28 in the SBT
Proverbs 28 in the SBT1E
Proverbs 28 in the SCHL
Proverbs 28 in the SNT
Proverbs 28 in the SUSU
Proverbs 28 in the SUSU2
Proverbs 28 in the SYNO
Proverbs 28 in the TBIAOTANT
Proverbs 28 in the TBT1E
Proverbs 28 in the TBT1E2
Proverbs 28 in the TFTIP
Proverbs 28 in the TFTU
Proverbs 28 in the TGNTATF3T
Proverbs 28 in the THAI
Proverbs 28 in the TNFD
Proverbs 28 in the TNT
Proverbs 28 in the TNTIK
Proverbs 28 in the TNTIL
Proverbs 28 in the TNTIN
Proverbs 28 in the TNTIP
Proverbs 28 in the TNTIZ
Proverbs 28 in the TOMA
Proverbs 28 in the TTENT
Proverbs 28 in the UBG
Proverbs 28 in the UGV
Proverbs 28 in the UGV2
Proverbs 28 in the UGV3
Proverbs 28 in the VBL
Proverbs 28 in the VDCC
Proverbs 28 in the YALU
Proverbs 28 in the YAPE
Proverbs 28 in the YBVTP
Proverbs 28 in the ZBP