Proverbs 4 (BOYCB)

1 Tẹ́tí, ẹ̀yin ọmọ mi, sí ẹ̀kọ́ baba; fetísílẹ̀ kí o sì ní òye sí i. 2 Mo fún ọ ní ẹ̀kọ́ tí ó yè kooro,nítorí náà, má ṣe kọ ẹ̀kọ́ mi sílẹ̀. 3 Nígbà tí mo jẹ́ ọ̀dọ́mọkùnrin ní ilé baba à mí,mo jẹ́ èwe, tí mo sì jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo lọ́wọ́ ìyá mi. 4 Ó kọ́ mi ó sì wí pé,“Jẹ́ kí àyà rẹ kí ó gba ọ̀rọ̀ mi dúró,pa òfin mi mọ́, kí ìwọ kí ó sì yè. 5 Gba ọgbọ́n, gba òye,má ṣe gbàgbé ọ̀rọ̀ mi tàbí kí o yẹsẹ̀ kúrò nínú rẹ̀. 6 Má ṣe kọ ọgbọ́n sílẹ̀, yóò sì dáàbò bò ọ́,fẹ́ràn rẹ̀, yóò sì bojútó ọ. 7 Ọgbọ́n ni ó ga jù; nítorí náà gba ọgbọ́n.Bí ó tilẹ̀ ná gbogbo ohun tí o ní, gba òye. 8 Gbé e ga, yóò sì gbé ọ gadìrọ̀ mọ́ ọn, yóò sì bu iyì fún ọ. 9 Yóò fi òdòdó ọ̀ṣọ́ ẹwà sí orí rẹyóò sì fi adé ẹlẹ́wà fún ọ.” 10 Tẹ́tí, ọmọ mi, gba ohun tí mo sọ,ọjọ́ ayé è rẹ yóò sì gùn. 11 Mo tọ́ ọ ṣọ́nà ní ọ̀nà ti ọgbọ́nmo sì mú ọ lọ ní ọ̀nà ti tààrà. 12 Nígbà tí o rìn, ìgbésẹ̀ rẹ kò ní ní ìdíwọ́nígbà tí o bá sáré, ìwọ kì yóò kọsẹ̀. 13 Di ẹ̀kọ́ mú, má ṣe jẹ́ kí ó lọ;tọ́jú u rẹ̀ dáradára nítorí òun ni ìyè rẹ. 14 Má ṣe gbé ẹsẹ̀ rẹ sí ojú ọnà àwọn ènìyàn búburútàbí kí o rìn ní ọ̀nà àwọn ẹni ibi. 15 Yẹra fún un, má ṣe rìn níbẹ̀;yàgò fún un kí o sì bá ọ̀nà tìrẹ lọ. 16 Nítorí wọn kò le sùn àyàfi tí wọ́n bá ṣe ibi,wọn kò ní tòògbé àyàfi tí wọ́n bá gbé ẹlòmíràn ṣubú. 17 Wọ́n ń jẹ oúnjẹ ìwà búburúwọ́n sì ń mu wáìnì ìwà ìkà. 18 Ipa ọ̀nà olódodo dàbí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ oòrùntí ń tànmọ́lẹ̀ sí i títí ọjọ́ fi kanrí 19 ṣùgbọ́n ọ̀nà ènìyàn búburú dàbí òkùnkùn biribiri;wọn kò mọ ohun tí ó ń mú wọn kọsẹ̀. 20 Ọmọ mi, tẹ́tí sí ohun tí mo sọ;fetísílẹ̀ dáradára sí ọ̀rọ̀ mi. 21 Má ṣe jẹ́ kí wọ́n rá mọ́ ọ lójúpa wọ́n mọ́ sínú ọkàn rẹ, 22 nítorí ìyè ni wọ́n jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó rí wọnàti ìlera fún gbogbo ara ènìyàn. 23 Ju gbogbo nǹkan tókù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́,nítorí òun ni orísun ìyè. 24 Mú àrékérekè kúrò ní ẹnu rẹ;sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ jìnnà réré sí ẹnu rẹ. 25 Jẹ́ kí ojú rẹ máa wo iwájú,jẹ́ kí ìwo ojú rẹ máa wo ọ̀kánkán iwájú rẹ sá á. 26 Kíyèsi ìrìn ẹsẹ̀ rẹsì rìn ní àwọn ọ̀nà tí ó dára nìkan. 27 Má ṣe yà sọ́tùn ún tàbí sósì;pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú ibi.

In Other Versions

Proverbs 4 in the ANGEFD

Proverbs 4 in the ANTPNG2D

Proverbs 4 in the AS21

Proverbs 4 in the BAGH

Proverbs 4 in the BBPNG

Proverbs 4 in the BBT1E

Proverbs 4 in the BDS

Proverbs 4 in the BEV

Proverbs 4 in the BHAD

Proverbs 4 in the BIB

Proverbs 4 in the BLPT

Proverbs 4 in the BNT

Proverbs 4 in the BNTABOOT

Proverbs 4 in the BNTLV

Proverbs 4 in the BOATCB

Proverbs 4 in the BOATCB2

Proverbs 4 in the BOBCV

Proverbs 4 in the BOCNT

Proverbs 4 in the BOECS

Proverbs 4 in the BOGWICC

Proverbs 4 in the BOHCB

Proverbs 4 in the BOHCV

Proverbs 4 in the BOHLNT

Proverbs 4 in the BOHNTLTAL

Proverbs 4 in the BOICB

Proverbs 4 in the BOILNTAP

Proverbs 4 in the BOITCV

Proverbs 4 in the BOKCV

Proverbs 4 in the BOKCV2

Proverbs 4 in the BOKHWOG

Proverbs 4 in the BOKSSV

Proverbs 4 in the BOLCB

Proverbs 4 in the BOLCB2

Proverbs 4 in the BOMCV

Proverbs 4 in the BONAV

Proverbs 4 in the BONCB

Proverbs 4 in the BONLT

Proverbs 4 in the BONUT2

Proverbs 4 in the BOPLNT

Proverbs 4 in the BOSCB

Proverbs 4 in the BOSNC

Proverbs 4 in the BOTLNT

Proverbs 4 in the BOVCB

Proverbs 4 in the BPBB

Proverbs 4 in the BPH

Proverbs 4 in the BSB

Proverbs 4 in the CCB

Proverbs 4 in the CUV

Proverbs 4 in the CUVS

Proverbs 4 in the DBT

Proverbs 4 in the DGDNT

Proverbs 4 in the DHNT

Proverbs 4 in the DNT

Proverbs 4 in the ELBE

Proverbs 4 in the EMTV

Proverbs 4 in the ESV

Proverbs 4 in the FBV

Proverbs 4 in the FEB

Proverbs 4 in the GGMNT

Proverbs 4 in the GNT

Proverbs 4 in the HARY

Proverbs 4 in the HNT

Proverbs 4 in the IRVA

Proverbs 4 in the IRVB

Proverbs 4 in the IRVG

Proverbs 4 in the IRVH

Proverbs 4 in the IRVK

Proverbs 4 in the IRVM

Proverbs 4 in the IRVM2

Proverbs 4 in the IRVO

Proverbs 4 in the IRVP

Proverbs 4 in the IRVT

Proverbs 4 in the IRVT2

Proverbs 4 in the IRVU

Proverbs 4 in the ISVN

Proverbs 4 in the JSNT

Proverbs 4 in the KAPI

Proverbs 4 in the KBT1ETNIK

Proverbs 4 in the KBV

Proverbs 4 in the KJV

Proverbs 4 in the KNFD

Proverbs 4 in the LBA

Proverbs 4 in the LBLA

Proverbs 4 in the LNT

Proverbs 4 in the LSV

Proverbs 4 in the MAAL

Proverbs 4 in the MBV

Proverbs 4 in the MBV2

Proverbs 4 in the MHNT

Proverbs 4 in the MKNFD

Proverbs 4 in the MNG

Proverbs 4 in the MNT

Proverbs 4 in the MNT2

Proverbs 4 in the MRS1T

Proverbs 4 in the NAA

Proverbs 4 in the NASB

Proverbs 4 in the NBLA

Proverbs 4 in the NBS

Proverbs 4 in the NBVTP

Proverbs 4 in the NET2

Proverbs 4 in the NIV11

Proverbs 4 in the NNT

Proverbs 4 in the NNT2

Proverbs 4 in the NNT3

Proverbs 4 in the PDDPT

Proverbs 4 in the PFNT

Proverbs 4 in the RMNT

Proverbs 4 in the SBIAS

Proverbs 4 in the SBIBS

Proverbs 4 in the SBIBS2

Proverbs 4 in the SBICS

Proverbs 4 in the SBIDS

Proverbs 4 in the SBIGS

Proverbs 4 in the SBIHS

Proverbs 4 in the SBIIS

Proverbs 4 in the SBIIS2

Proverbs 4 in the SBIIS3

Proverbs 4 in the SBIKS

Proverbs 4 in the SBIKS2

Proverbs 4 in the SBIMS

Proverbs 4 in the SBIOS

Proverbs 4 in the SBIPS

Proverbs 4 in the SBISS

Proverbs 4 in the SBITS

Proverbs 4 in the SBITS2

Proverbs 4 in the SBITS3

Proverbs 4 in the SBITS4

Proverbs 4 in the SBIUS

Proverbs 4 in the SBIVS

Proverbs 4 in the SBT

Proverbs 4 in the SBT1E

Proverbs 4 in the SCHL

Proverbs 4 in the SNT

Proverbs 4 in the SUSU

Proverbs 4 in the SUSU2

Proverbs 4 in the SYNO

Proverbs 4 in the TBIAOTANT

Proverbs 4 in the TBT1E

Proverbs 4 in the TBT1E2

Proverbs 4 in the TFTIP

Proverbs 4 in the TFTU

Proverbs 4 in the TGNTATF3T

Proverbs 4 in the THAI

Proverbs 4 in the TNFD

Proverbs 4 in the TNT

Proverbs 4 in the TNTIK

Proverbs 4 in the TNTIL

Proverbs 4 in the TNTIN

Proverbs 4 in the TNTIP

Proverbs 4 in the TNTIZ

Proverbs 4 in the TOMA

Proverbs 4 in the TTENT

Proverbs 4 in the UBG

Proverbs 4 in the UGV

Proverbs 4 in the UGV2

Proverbs 4 in the UGV3

Proverbs 4 in the VBL

Proverbs 4 in the VDCC

Proverbs 4 in the YALU

Proverbs 4 in the YAPE

Proverbs 4 in the YBVTP

Proverbs 4 in the ZBP