Proverbs 5 (BOYCB)

1 Ọmọ mi, fiyèsí ọgbọ́n mi,kí o sì dẹtí rẹ sí òye mi, 2 kí ìwọ sì lè ní ìṣọ́rakí ètè rẹ sì le pa ìmọ̀ mọ́. 3 Nítorí ètè àwọn àjèjì obìnrin a máa sun bi oyin,ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì kúnná ju òróró lọ. 4 Ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, ó korò ju òróǹró lọ,ó mú bí idà olójú méjì. 5 Ẹsẹ̀ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí ọ̀nà ikúìgbésẹ̀ rẹ̀ lọ tààrà sí ibojì òkú. 6 Kí ìwọ má ba à já ipa ọ̀nà ìyè;ọ̀nà rẹ̀ rí pálapàla, ṣùgbọ́n kò tilẹ̀ mọ́. 7 Nítorí náà, ẹ̀yin ọmọ mi, ẹ dẹtí sí mi,kí ẹ̀yin kí ó má ṣe yàgò kúrò nínú ọ̀rọ̀ tí mo sọ. 8 Rìn ní ọ̀nà tí ó jìnnà sí ti rẹ̀,má ṣe súnmọ́ ẹnu-ọ̀nà ilé rẹ̀, 9 àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò gbé gbogbo ọlá rẹ lé ẹlòmíràn lọ́wọ́àti ọjọ́ ayé rẹ fún ìkà ènìyàn. 10 Kí a má ba à fi ọrọ̀ rẹ fún àjèjì ènìyàn,kí làálàá rẹ sì sọ ilé ẹlòmíràn di ọlọ́rọ̀. 11 Ní ìgbẹ̀yìn ayé rẹ ìwọ yóò kérora,nígbà tí agbára rẹ àti ara rẹ bá ti joro tán. 12 Ìwọ yóò wí pé, “Mo ti kórìíra ẹ̀kọ́ tó!Ọkàn mi ṣe wá kórìíra ìbáwí! 13 N kò gbọ́rọ̀ sí àwọn olùkọ́ mi lẹ́nu,tàbí kí n fetí sí àwọn tí ń kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́. 14 Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátání àárín gbogbo àwùjọ ènìyàn.” 15 Mu omi láti inú kànga tìrẹ,omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ. 16 Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nààti odò tí ń sàn lọ sí àárín ọjà? 17 Jẹ́ kí wọn jẹ́ tìrẹ nìkan,má ṣe ṣe àjọpín wọn pẹ̀lú àjèjì láéláé. 18 Jẹ́ kí orísun rẹ kí ó ní ìbùkún;kí ìwọ ó sì máa yọ nínú aya ìgbà èwe rẹ. 19 Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọ,jẹ́ kí ọmú rẹ̀ kí ó máa fi ayọ̀ fún ọ nígbà gbogbo,kí o sì máa yọ̀ nínú ìfẹ́ rẹ̀ nígbàkígbà. 20 Ọmọ mi, èéṣe tí ìwọ ó fi máa yọ̀ nínú ìfẹ́ obìnrin panṣágà,tí ìwọ ó sì fi dì mọ́ ìyàwó ẹlòmíràn? 21 Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún OLÚWAÓ sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀ wò. 22 Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn;okùn ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀ yóò sì dìímú. 23 Yóò kú ní àìgba ẹ̀kọ́ìwà òmùgọ̀ ara rẹ̀ yóò sì mú kí ó máa ṣìnà kiri.

In Other Versions

Proverbs 5 in the ANGEFD

Proverbs 5 in the ANTPNG2D

Proverbs 5 in the AS21

Proverbs 5 in the BAGH

Proverbs 5 in the BBPNG

Proverbs 5 in the BBT1E

Proverbs 5 in the BDS

Proverbs 5 in the BEV

Proverbs 5 in the BHAD

Proverbs 5 in the BIB

Proverbs 5 in the BLPT

Proverbs 5 in the BNT

Proverbs 5 in the BNTABOOT

Proverbs 5 in the BNTLV

Proverbs 5 in the BOATCB

Proverbs 5 in the BOATCB2

Proverbs 5 in the BOBCV

Proverbs 5 in the BOCNT

Proverbs 5 in the BOECS

Proverbs 5 in the BOGWICC

Proverbs 5 in the BOHCB

Proverbs 5 in the BOHCV

Proverbs 5 in the BOHLNT

Proverbs 5 in the BOHNTLTAL

Proverbs 5 in the BOICB

Proverbs 5 in the BOILNTAP

Proverbs 5 in the BOITCV

Proverbs 5 in the BOKCV

Proverbs 5 in the BOKCV2

Proverbs 5 in the BOKHWOG

Proverbs 5 in the BOKSSV

Proverbs 5 in the BOLCB

Proverbs 5 in the BOLCB2

Proverbs 5 in the BOMCV

Proverbs 5 in the BONAV

Proverbs 5 in the BONCB

Proverbs 5 in the BONLT

Proverbs 5 in the BONUT2

Proverbs 5 in the BOPLNT

Proverbs 5 in the BOSCB

Proverbs 5 in the BOSNC

Proverbs 5 in the BOTLNT

Proverbs 5 in the BOVCB

Proverbs 5 in the BPBB

Proverbs 5 in the BPH

Proverbs 5 in the BSB

Proverbs 5 in the CCB

Proverbs 5 in the CUV

Proverbs 5 in the CUVS

Proverbs 5 in the DBT

Proverbs 5 in the DGDNT

Proverbs 5 in the DHNT

Proverbs 5 in the DNT

Proverbs 5 in the ELBE

Proverbs 5 in the EMTV

Proverbs 5 in the ESV

Proverbs 5 in the FBV

Proverbs 5 in the FEB

Proverbs 5 in the GGMNT

Proverbs 5 in the GNT

Proverbs 5 in the HARY

Proverbs 5 in the HNT

Proverbs 5 in the IRVA

Proverbs 5 in the IRVB

Proverbs 5 in the IRVG

Proverbs 5 in the IRVH

Proverbs 5 in the IRVK

Proverbs 5 in the IRVM

Proverbs 5 in the IRVM2

Proverbs 5 in the IRVO

Proverbs 5 in the IRVP

Proverbs 5 in the IRVT

Proverbs 5 in the IRVT2

Proverbs 5 in the IRVU

Proverbs 5 in the ISVN

Proverbs 5 in the JSNT

Proverbs 5 in the KAPI

Proverbs 5 in the KBT1ETNIK

Proverbs 5 in the KBV

Proverbs 5 in the KJV

Proverbs 5 in the KNFD

Proverbs 5 in the LBA

Proverbs 5 in the LBLA

Proverbs 5 in the LNT

Proverbs 5 in the LSV

Proverbs 5 in the MAAL

Proverbs 5 in the MBV

Proverbs 5 in the MBV2

Proverbs 5 in the MHNT

Proverbs 5 in the MKNFD

Proverbs 5 in the MNG

Proverbs 5 in the MNT

Proverbs 5 in the MNT2

Proverbs 5 in the MRS1T

Proverbs 5 in the NAA

Proverbs 5 in the NASB

Proverbs 5 in the NBLA

Proverbs 5 in the NBS

Proverbs 5 in the NBVTP

Proverbs 5 in the NET2

Proverbs 5 in the NIV11

Proverbs 5 in the NNT

Proverbs 5 in the NNT2

Proverbs 5 in the NNT3

Proverbs 5 in the PDDPT

Proverbs 5 in the PFNT

Proverbs 5 in the RMNT

Proverbs 5 in the SBIAS

Proverbs 5 in the SBIBS

Proverbs 5 in the SBIBS2

Proverbs 5 in the SBICS

Proverbs 5 in the SBIDS

Proverbs 5 in the SBIGS

Proverbs 5 in the SBIHS

Proverbs 5 in the SBIIS

Proverbs 5 in the SBIIS2

Proverbs 5 in the SBIIS3

Proverbs 5 in the SBIKS

Proverbs 5 in the SBIKS2

Proverbs 5 in the SBIMS

Proverbs 5 in the SBIOS

Proverbs 5 in the SBIPS

Proverbs 5 in the SBISS

Proverbs 5 in the SBITS

Proverbs 5 in the SBITS2

Proverbs 5 in the SBITS3

Proverbs 5 in the SBITS4

Proverbs 5 in the SBIUS

Proverbs 5 in the SBIVS

Proverbs 5 in the SBT

Proverbs 5 in the SBT1E

Proverbs 5 in the SCHL

Proverbs 5 in the SNT

Proverbs 5 in the SUSU

Proverbs 5 in the SUSU2

Proverbs 5 in the SYNO

Proverbs 5 in the TBIAOTANT

Proverbs 5 in the TBT1E

Proverbs 5 in the TBT1E2

Proverbs 5 in the TFTIP

Proverbs 5 in the TFTU

Proverbs 5 in the TGNTATF3T

Proverbs 5 in the THAI

Proverbs 5 in the TNFD

Proverbs 5 in the TNT

Proverbs 5 in the TNTIK

Proverbs 5 in the TNTIL

Proverbs 5 in the TNTIN

Proverbs 5 in the TNTIP

Proverbs 5 in the TNTIZ

Proverbs 5 in the TOMA

Proverbs 5 in the TTENT

Proverbs 5 in the UBG

Proverbs 5 in the UGV

Proverbs 5 in the UGV2

Proverbs 5 in the UGV3

Proverbs 5 in the VBL

Proverbs 5 in the VDCC

Proverbs 5 in the YALU

Proverbs 5 in the YAPE

Proverbs 5 in the YBVTP

Proverbs 5 in the ZBP