Psalms 31 (BOYCB)

undefined Fún adarí orin. Saamu ti Dafidi. 1 Nínú rẹ̀, OLÚWA ni mo ti rí ààbò;má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí;gbà mí nínú òdodo rẹ. 2 Tẹ́ etí rẹ sí mi,gbà mí kíákíá;jẹ́ àpáta ààbò mi,jẹ́ odi alágbára láti gbà mí. 3 Ìwọ pàápàá ni àpáta àti ààbò mi,nítorí orúkọ rẹ, máa ṣe olùtọ́ mi, kí o sì ṣe amọ̀nà mi. 4 Yọ mí jáde kúrò nínú àwọ̀n tí wọ́n dẹ pamọ́ fún mi,nítorí ìwọ ni ìsádi mi. 5 Ní ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé;ìwọ ni o ti rà mí padà, OLÚWA, Ọlọ́run òtítọ́. 6 Èmi ti kórìíra àwọn ẹni tí ń fiyèsí òrìṣà tí kò níye lórí;ṣùgbọ́n èmi gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA. 7 Èmi yóò yọ̀, inú mi yóò dùn nínú ìfẹ́ ńlá rẹ,nítorí ìwọ ti rí ìbìnújẹ́ miìwọ ti mọ̀ ọkàn mi nínú ìpọ́njú. 8 Pẹ̀lú, ìwọ kò sì fà mi lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́ìwọ ti fi ẹsẹ̀ mi lé ibi ààyè ńlá. 9 Ṣàánú fún mi, ìwọ OLÚWA, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú;ojú mi fi ìbìnújẹ́ sùn,ọkàn àti ara mi pẹ̀lú. 10 Èmi fi ìbànújẹ́ lo ọjọ́ miàti àwọn ọdún mi pẹ̀lú ìmí ẹ̀dùn;agbára mi ti kùnà nítorí òsì mi,egungun mi sì ti rún dànù. 11 Èmi di ẹni ẹ̀gàn láàrín àwọn ọ̀tá mi gbogbo,pẹ̀lúpẹ̀lú láàrín àwọn aládùúgbò mi,mo sì di ẹ̀rù fún àwọn ojúlùmọ̀ mi;àwọn tí ó rí mi ní òde ń yẹra fún mi. 12 Èmi ti di ẹni ìgbàgbé kúrò ní ọkàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ti kú;èmi sì dàbí ohun èlò tí ó ti fọ́. 13 Nítorí mo gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpayà tí ó yí mi ká;tí wọn gbìmọ̀ pọ̀ sí mi,wọ́n sì ṣọ̀tẹ̀ sí miláti gba ẹ̀mí mi. 14 Ṣùgbọ́n èmí gbẹ́kẹ̀lé ọ, ìwọ OLÚWA;mo sọ wí pé, “Ìwọ ní Ọlọ́run mi.” 15 Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ;gbà mí kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá miàti àwọn onínúnibíni. 16 Jẹ́ kí ojú rẹ kí ó tan ìmọ́lẹ̀ sí ìránṣẹ́ rẹ lára;gbà mí nínú ìfẹ́ rẹ tí ó dúró ṣinṣin. 17 Má ṣe jẹ́ kí ojú ki ó tì mí, OLÚWA;nítorí pé mo ké pè ọ́;jẹ́ kí ojú kí ó ti ènìyàn búburú;jẹ́ kí wọ́n lọ pẹ̀lú ìdààmú sí isà òkú. 18 Jẹ́ kí àwọn ètè irọ́ kí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́,pẹ̀lú ìgbéraga àti ìkẹ́gàn,wọ́n sọ̀rọ̀ àfojúdi sí olódodo. 19 Báwo ni títóbi oore rẹ̀ ti pọ̀ tó,èyí tí ìwọ ti ní ní ìpamọ́ fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ,èyí tí ìwọ rọ̀jò rẹ̀ níwájú àwọn ènìyàntí wọ́n fi ọ́ ṣe ibi ìsádi wọn. 20 Ní abẹ́ ìbòòji iwájú rẹ ni ìwọ pa wọ́n mọ́ síkúrò nínú ìdìmọ̀lù àwọn ènìyàn;ní ibùgbé rẹ, o mú wọn kúrò nínú ewukúrò nínú ìjà ahọ́n. 21 Olùbùkún ni OLÚWA,nítorí pé ó ti fi àgbà ìyanu ìfẹ́ tí ó ní sí mi hàn,nígbà tí mo wà ní ìlú tí wọ́n rọ̀gbà yíká. 22 Èmí ti sọ nínú ìdágìrì mi,“A gé mi kúrò ní ojú rẹ!”Síbẹ̀ ìwọ ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún àánúnígbà tí mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. 23 Ẹ fẹ́ OLÚWA, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn rẹ̀ mímọ́! OLÚWA pa olódodo mọ́,ó sì san án padà fún agbéraga ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. 24 Jẹ́ alágbára, yóò sì mú yín ní àyà legbogbo ẹ̀yin tí ó dúró de OLÚWA.

In Other Versions

Psalms 31 in the ANGEFD

Psalms 31 in the ANTPNG2D

Psalms 31 in the AS21

Psalms 31 in the BAGH

Psalms 31 in the BBPNG

Psalms 31 in the BBT1E

Psalms 31 in the BDS

Psalms 31 in the BEV

Psalms 31 in the BHAD

Psalms 31 in the BIB

Psalms 31 in the BLPT

Psalms 31 in the BNT

Psalms 31 in the BNTABOOT

Psalms 31 in the BNTLV

Psalms 31 in the BOATCB

Psalms 31 in the BOATCB2

Psalms 31 in the BOBCV

Psalms 31 in the BOCNT

Psalms 31 in the BOECS

Psalms 31 in the BOGWICC

Psalms 31 in the BOHCB

Psalms 31 in the BOHCV

Psalms 31 in the BOHLNT

Psalms 31 in the BOHNTLTAL

Psalms 31 in the BOICB

Psalms 31 in the BOILNTAP

Psalms 31 in the BOITCV

Psalms 31 in the BOKCV

Psalms 31 in the BOKCV2

Psalms 31 in the BOKHWOG

Psalms 31 in the BOKSSV

Psalms 31 in the BOLCB

Psalms 31 in the BOLCB2

Psalms 31 in the BOMCV

Psalms 31 in the BONAV

Psalms 31 in the BONCB

Psalms 31 in the BONLT

Psalms 31 in the BONUT2

Psalms 31 in the BOPLNT

Psalms 31 in the BOSCB

Psalms 31 in the BOSNC

Psalms 31 in the BOTLNT

Psalms 31 in the BOVCB

Psalms 31 in the BPBB

Psalms 31 in the BPH

Psalms 31 in the BSB

Psalms 31 in the CCB

Psalms 31 in the CUV

Psalms 31 in the CUVS

Psalms 31 in the DBT

Psalms 31 in the DGDNT

Psalms 31 in the DHNT

Psalms 31 in the DNT

Psalms 31 in the ELBE

Psalms 31 in the EMTV

Psalms 31 in the ESV

Psalms 31 in the FBV

Psalms 31 in the FEB

Psalms 31 in the GGMNT

Psalms 31 in the GNT

Psalms 31 in the HARY

Psalms 31 in the HNT

Psalms 31 in the IRVA

Psalms 31 in the IRVB

Psalms 31 in the IRVG

Psalms 31 in the IRVH

Psalms 31 in the IRVK

Psalms 31 in the IRVM

Psalms 31 in the IRVM2

Psalms 31 in the IRVO

Psalms 31 in the IRVP

Psalms 31 in the IRVT

Psalms 31 in the IRVT2

Psalms 31 in the IRVU

Psalms 31 in the ISVN

Psalms 31 in the JSNT

Psalms 31 in the KAPI

Psalms 31 in the KBT1ETNIK

Psalms 31 in the KBV

Psalms 31 in the KJV

Psalms 31 in the KNFD

Psalms 31 in the LBA

Psalms 31 in the LBLA

Psalms 31 in the LNT

Psalms 31 in the LSV

Psalms 31 in the MAAL

Psalms 31 in the MBV

Psalms 31 in the MBV2

Psalms 31 in the MHNT

Psalms 31 in the MKNFD

Psalms 31 in the MNG

Psalms 31 in the MNT

Psalms 31 in the MNT2

Psalms 31 in the MRS1T

Psalms 31 in the NAA

Psalms 31 in the NASB

Psalms 31 in the NBLA

Psalms 31 in the NBS

Psalms 31 in the NBVTP

Psalms 31 in the NET2

Psalms 31 in the NIV11

Psalms 31 in the NNT

Psalms 31 in the NNT2

Psalms 31 in the NNT3

Psalms 31 in the PDDPT

Psalms 31 in the PFNT

Psalms 31 in the RMNT

Psalms 31 in the SBIAS

Psalms 31 in the SBIBS

Psalms 31 in the SBIBS2

Psalms 31 in the SBICS

Psalms 31 in the SBIDS

Psalms 31 in the SBIGS

Psalms 31 in the SBIHS

Psalms 31 in the SBIIS

Psalms 31 in the SBIIS2

Psalms 31 in the SBIIS3

Psalms 31 in the SBIKS

Psalms 31 in the SBIKS2

Psalms 31 in the SBIMS

Psalms 31 in the SBIOS

Psalms 31 in the SBIPS

Psalms 31 in the SBISS

Psalms 31 in the SBITS

Psalms 31 in the SBITS2

Psalms 31 in the SBITS3

Psalms 31 in the SBITS4

Psalms 31 in the SBIUS

Psalms 31 in the SBIVS

Psalms 31 in the SBT

Psalms 31 in the SBT1E

Psalms 31 in the SCHL

Psalms 31 in the SNT

Psalms 31 in the SUSU

Psalms 31 in the SUSU2

Psalms 31 in the SYNO

Psalms 31 in the TBIAOTANT

Psalms 31 in the TBT1E

Psalms 31 in the TBT1E2

Psalms 31 in the TFTIP

Psalms 31 in the TFTU

Psalms 31 in the TGNTATF3T

Psalms 31 in the THAI

Psalms 31 in the TNFD

Psalms 31 in the TNT

Psalms 31 in the TNTIK

Psalms 31 in the TNTIL

Psalms 31 in the TNTIN

Psalms 31 in the TNTIP

Psalms 31 in the TNTIZ

Psalms 31 in the TOMA

Psalms 31 in the TTENT

Psalms 31 in the UBG

Psalms 31 in the UGV

Psalms 31 in the UGV2

Psalms 31 in the UGV3

Psalms 31 in the VBL

Psalms 31 in the VDCC

Psalms 31 in the YALU

Psalms 31 in the YAPE

Psalms 31 in the YBVTP

Psalms 31 in the ZBP