Revelation 12 (BOYCB)
1 Àmì ńlá kan sì hàn ni ọ̀run; obìnrin kan tí a fi oòrùn wọ̀ ní aṣọ, òṣùpá sì ń bẹ lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá sì ń bẹ lórí rẹ̀. 2 Ó sì lóyún, ó sì kígbe ni ìrọbí, ó sì wà ni ìrora àti bímọ. 3 Àmì mìíràn sì hàn ní ọ̀run; sì kíyèsi i, dragoni pupa ńlá kan, tí ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, àti adé méje ní orí rẹ̀. 4 Ìrù rẹ̀ sì wọ́ ìdámẹ́ta àwọn ìràwọ̀ ní ojú ọ̀run, ó sì jù wọ́n sí ilẹ̀ ayé, dragoni náà sì dúró níwájú obìnrin náà tí ó fẹ́ bímọ, pé nígbà tí o bá bí i, kí òun lè pa ọmọ rẹ̀ jẹ. 5 Ó sì bi ọmọkùnrin kan tí yóò fi ọ̀pá irin ṣe àkóso gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè, a sì gba ọmọ rẹ̀ lọ sókè sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, àti sí orí ìtẹ́ rẹ̀. 6 Obìnrin náà sì sálọ sí aginjù, níbi tí a gbé ti pèsè ààyè sílẹ̀ dè é láti ọwọ́ Ọlọ́run wá, pé kí wọ́n máa bọ́ ọ níbẹ̀ ní ẹgbẹ̀fà ọjọ́ ó lé ọgọ́ta (1,260). 7 Ogun sì ń bẹ ní ọ̀run: Mikaeli àti àwọn angẹli rẹ̀ bá dragoni náà jagun; dragoni sì jagun àti àwọn angẹli rẹ̀. 8 Wọ́n kò sì lè ṣẹ́gun; bẹ́ẹ̀ ni a kò sì rí ipò wọn mọ́ ni ọ̀run. 9 A sì lé dragoni ńlá náà jáde, ejò láéláé nì, tí a ń pè ni Èṣù, àti Satani, tí ń tan gbogbo ayé jẹ: a sì lé e jù sí ilẹ̀ ayé, a sì lé àwọn angẹli rẹ̀ jáde pẹ̀lú rẹ̀. 10 Mo sì gbọ́ ohùn ńlá ní ọ̀run, wí pè:“Nígbà yìí ni ìgbàlà dé, àti agbára, àti ìjọba Ọlọ́run wá,àti ọlá àti Kristi rẹ̀.Nítorí a tí le olùfisùn àwọn arákùnrin wa jáde,tí o ń fi wọ́n sùn níwájú Ọlọ́run wa lọ́sàn án àti lóru. 11 Wọ́n sì ti ṣẹ́gun rẹ̀nítorí ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-àgùntàn náà,àti nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀rí wọn,wọn kò sì fẹ́ràn ẹ̀mí wọnàní títí dé ikú. 12 Nítorí náà ẹ máa yọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,àti ẹ̀yin tí ń gbé inú wọn.Ègbé ni fún ayé àti Òkun;nítorí èṣù sọ̀kalẹ̀ tọ̀ yín wá ní ìbínú ńlá,nítorí ó mọ̀ pé ìgbà kúkúrú sá ni òun ní.” 13 Nígbà tí dragoni náà rí pé a lé òun lọ sí ilẹ̀ ayé, ó ṣe inúnibíni sì obìnrin tí ó bí ọmọkùnrin náà. 14 A sì fi apá ìyẹ́ méjì tí idì ńlá náà fún obìnrin náà, pé kí ó fò lọ sí aginjù, sí ipò rẹ̀, níbi tí a ó gbe bọ ọ fún àkókò kan àti fún àwọn àkókò, àti fún ìdajì àkókò kúrò lọ́dọ̀ ejò náà. 15 Ejò náà sì tu omi jáde láti ẹnu rẹ̀ wá bí odò ńlá sẹ́yìn obìnrin náà, kí ó lè fi ìṣàn omi náà gbà á lọ. 16 Ilẹ̀ sì ran obìnrin náà lọ́wọ́, ilẹ̀ sì ya ẹnu rẹ̀, ó sì fi ìṣàn omi náà mú, tí dragoni náà tu jáde láti ẹnu rẹ̀ wá. 17 Dragoni náà sì bínú gidigidi sí obìnrin náà, ó sì lọ bá àwọn irú-ọmọ rẹ̀ ìyókù jagun, tí wọ́n ń pa òfin Ọlọ́run mọ̀, tí wọn sì di ẹ̀rí Jesu mú, Ó sì dúró lórí iyanrìn Òkun.
In Other Versions
Revelation 12 in the ANGEFD
Revelation 12 in the ANTPNG2D
Revelation 12 in the AS21
Revelation 12 in the BAGH
Revelation 12 in the BBPNG
Revelation 12 in the BBT1E
Revelation 12 in the BDS
Revelation 12 in the BEV
Revelation 12 in the BHAD
Revelation 12 in the BIB
Revelation 12 in the BLPT
Revelation 12 in the BNT
Revelation 12 in the BNTABOOT
Revelation 12 in the BNTLV
Revelation 12 in the BOATCB
Revelation 12 in the BOATCB2
Revelation 12 in the BOBCV
Revelation 12 in the BOCNT
Revelation 12 in the BOECS
Revelation 12 in the BOGWICC
Revelation 12 in the BOHCB
Revelation 12 in the BOHCV
Revelation 12 in the BOHLNT
Revelation 12 in the BOHNTLTAL
Revelation 12 in the BOICB
Revelation 12 in the BOILNTAP
Revelation 12 in the BOITCV
Revelation 12 in the BOKCV
Revelation 12 in the BOKCV2
Revelation 12 in the BOKHWOG
Revelation 12 in the BOKSSV
Revelation 12 in the BOLCB
Revelation 12 in the BOLCB2
Revelation 12 in the BOMCV
Revelation 12 in the BONAV
Revelation 12 in the BONCB
Revelation 12 in the BONLT
Revelation 12 in the BONUT2
Revelation 12 in the BOPLNT
Revelation 12 in the BOSCB
Revelation 12 in the BOSNC
Revelation 12 in the BOTLNT
Revelation 12 in the BOVCB
Revelation 12 in the BPBB
Revelation 12 in the BPH
Revelation 12 in the BSB
Revelation 12 in the CCB
Revelation 12 in the CUV
Revelation 12 in the CUVS
Revelation 12 in the DBT
Revelation 12 in the DGDNT
Revelation 12 in the DHNT
Revelation 12 in the DNT
Revelation 12 in the ELBE
Revelation 12 in the EMTV
Revelation 12 in the ESV
Revelation 12 in the FBV
Revelation 12 in the FEB
Revelation 12 in the GGMNT
Revelation 12 in the GNT
Revelation 12 in the HARY
Revelation 12 in the HNT
Revelation 12 in the IRVA
Revelation 12 in the IRVB
Revelation 12 in the IRVG
Revelation 12 in the IRVH
Revelation 12 in the IRVK
Revelation 12 in the IRVM
Revelation 12 in the IRVM2
Revelation 12 in the IRVO
Revelation 12 in the IRVP
Revelation 12 in the IRVT
Revelation 12 in the IRVT2
Revelation 12 in the IRVU
Revelation 12 in the ISVN
Revelation 12 in the JSNT
Revelation 12 in the KAPI
Revelation 12 in the KBT1ETNIK
Revelation 12 in the KBV
Revelation 12 in the KJV
Revelation 12 in the KNFD
Revelation 12 in the LBA
Revelation 12 in the LBLA
Revelation 12 in the LNT
Revelation 12 in the LSV
Revelation 12 in the MAAL
Revelation 12 in the MBV
Revelation 12 in the MBV2
Revelation 12 in the MHNT
Revelation 12 in the MKNFD
Revelation 12 in the MNG
Revelation 12 in the MNT
Revelation 12 in the MNT2
Revelation 12 in the MRS1T
Revelation 12 in the NAA
Revelation 12 in the NASB
Revelation 12 in the NBLA
Revelation 12 in the NBS
Revelation 12 in the NBVTP
Revelation 12 in the NET2
Revelation 12 in the NIV11
Revelation 12 in the NNT
Revelation 12 in the NNT2
Revelation 12 in the NNT3
Revelation 12 in the PDDPT
Revelation 12 in the PFNT
Revelation 12 in the RMNT
Revelation 12 in the SBIAS
Revelation 12 in the SBIBS
Revelation 12 in the SBIBS2
Revelation 12 in the SBICS
Revelation 12 in the SBIDS
Revelation 12 in the SBIGS
Revelation 12 in the SBIHS
Revelation 12 in the SBIIS
Revelation 12 in the SBIIS2
Revelation 12 in the SBIIS3
Revelation 12 in the SBIKS
Revelation 12 in the SBIKS2
Revelation 12 in the SBIMS
Revelation 12 in the SBIOS
Revelation 12 in the SBIPS
Revelation 12 in the SBISS
Revelation 12 in the SBITS
Revelation 12 in the SBITS2
Revelation 12 in the SBITS3
Revelation 12 in the SBITS4
Revelation 12 in the SBIUS
Revelation 12 in the SBIVS
Revelation 12 in the SBT
Revelation 12 in the SBT1E
Revelation 12 in the SCHL
Revelation 12 in the SNT
Revelation 12 in the SUSU
Revelation 12 in the SUSU2
Revelation 12 in the SYNO
Revelation 12 in the TBIAOTANT
Revelation 12 in the TBT1E
Revelation 12 in the TBT1E2
Revelation 12 in the TFTIP
Revelation 12 in the TFTU
Revelation 12 in the TGNTATF3T
Revelation 12 in the THAI
Revelation 12 in the TNFD
Revelation 12 in the TNT
Revelation 12 in the TNTIK
Revelation 12 in the TNTIL
Revelation 12 in the TNTIN
Revelation 12 in the TNTIP
Revelation 12 in the TNTIZ
Revelation 12 in the TOMA
Revelation 12 in the TTENT
Revelation 12 in the UBG
Revelation 12 in the UGV
Revelation 12 in the UGV2
Revelation 12 in the UGV3
Revelation 12 in the VBL
Revelation 12 in the VDCC
Revelation 12 in the YALU
Revelation 12 in the YAPE
Revelation 12 in the YBVTP
Revelation 12 in the ZBP