Revelation 13 (BOYCB)
1 Mo sì rí ẹranko kan ń ti inú Òkun jáde wá, ó ní ìwo mẹ́wàá àti orí méje, lórí àwọn ìwo náà ni adé méje wà, ni orí kọ̀ọ̀kan ni orúkọ ọ̀rọ̀-òdì wà. 2 Ẹranko tí mo rí náà sì dàbí ẹkùn, ẹsẹ̀ rẹ̀ sì dàbí tí beari ẹnu rẹ̀ sì dàbí tí kìnnìún: dragoni náà sì fún un ni agbára rẹ̀, àti ìtẹ́ rẹ̀, àti àṣẹ ńlá. 3 Mo sì rí ọ̀kan nínú àwọn orí rẹ̀ bí ẹni pé a sá a pa, a sì tí wo ọgbẹ́ àṣápa rẹ̀ náà sàn, gbogbo ayé sì fi ìyanu tẹ̀lé ẹranko náà. 4 Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún dragoni náà, nítorí tí o fún ẹranko náà ní àṣẹ, wọn sì foríbalẹ̀ fún ẹranko náà, wí pé, “Ta ni o dàbí ẹranko yìí? Ta ni ó sì lè bá a jagun?” 5 A sì fún un ni ẹnu láti má sọ ohun ńlá àti ọ̀rọ̀-òdì, a sì fi agbára fún un láti ṣe bẹ́ẹ̀ ni oṣù méjìlélógójì. 6 Ó sì ya ẹnu rẹ̀ ni ọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run, láti sọ ọ̀rọ̀-òdì sí orúkọ rẹ̀, àti sí àgọ́ rẹ̀, àti sí àwọn tí ń gbé ọ̀run. 7 A sì fún un láti máa bá àwọn ènìyàn mímọ́ jagun, àti láti ṣẹ́gun wọn, a sì fi agbára fún un lórí gbogbo ẹ̀yà, àti ènìyàn, àti èdè, àti orílẹ̀. 8 Gbogbo àwọn tí ń gbé orí ilẹ̀ ayé yóò sì máa sìn ín, olúkúlùkù ẹni tí a kò kọ orúkọ rẹ̀, sínú ìwé ìyè Ọ̀dọ́-Àgùntàn tí a tí pa láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé. 9 Bí ẹnikẹ́ni bá létí kí o gbọ́. 10 Ẹni tí a ti pinnu rẹ̀ fún ìgbèkùn,ìgbèkùn ni yóò lọ;ẹni tí a sì ti pinnu rẹ̀ fún idà,ni a ó sì fi idà pa.Níhìn-ín ni sùúrù àti ìgbàgbọ́ àwọn ènìyàn mímọ́ wà. 11 Mo sì rí ẹranko mìíràn gòkè láti inú ilẹ̀ wá; ó sì ní ìwo méjì bí ọ̀dọ́-àgùntàn, ó sì ń sọ̀rọ̀ bí dragoni. 12 Ó sì ń lo gbogbo agbára ẹranko èkínní níwájú rẹ̀, ó sì mú ilẹ̀ ayé àti àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ foríbalẹ̀ fún ẹranko èkínní tí a ti wo ọgbẹ́ àṣápa rẹ̀ sàn. 13 Ó sì ń ṣe ohun ìyanu ńlá, àní tí ó fi ń mú iná sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá sì ilẹ̀ ayé níwájú àwọn ènìyàn. 14 Ó sì ń tán àwọn tí ń gbé orí ilẹ̀ ayé jẹ nípa àwọn ohun ìyanu tí a fi fún un láti ṣe níwájú ẹranko náà; ó wí fún àwọn tí ń gbé orí ilẹ̀ ayé láti ya àwòrán fún ẹranko náà tí o tí gbá ọgbẹ́ idà, tí ó sì yè. 15 A sì fi fún un, láti fi ẹ̀mí fún àwòrán ẹranko náà kí ó máa sọ̀rọ̀ kí ó sì mu kí a pa gbogbo àwọn tí kò foríbalẹ̀ fún àwòrán ẹranko náà. 16 Ó sì mu gbogbo wọn, àti kékeré àti ńlá, ọlọ́rọ̀ àti tálákà, olómìnira àti ẹrú, láti gba àmì kan sí ọwọ́ ọ̀tún wọn, tàbí ní iwájú orí wọn; 17 àti kí ẹnikẹ́ni má lè rà tàbí tà, bí kò ṣe ẹni tí o bá ní àmì náà, èyí ni orúkọ ẹranko náà, tàbí àmì orúkọ rẹ̀. 18 Níhìn-ín ni ọgbọ́n gbé wà. Ẹni tí o bá ní òye, kí o ka òǹkà tí ń bẹ̀ lára ẹranko náà, nítorí pé òǹkà ènìyàn ni, òǹkà rẹ̀ náà sì jẹ́ ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́fà (666).
In Other Versions
Revelation 13 in the ANGEFD
Revelation 13 in the ANTPNG2D
Revelation 13 in the AS21
Revelation 13 in the BAGH
Revelation 13 in the BBPNG
Revelation 13 in the BBT1E
Revelation 13 in the BDS
Revelation 13 in the BEV
Revelation 13 in the BHAD
Revelation 13 in the BIB
Revelation 13 in the BLPT
Revelation 13 in the BNT
Revelation 13 in the BNTABOOT
Revelation 13 in the BNTLV
Revelation 13 in the BOATCB
Revelation 13 in the BOATCB2
Revelation 13 in the BOBCV
Revelation 13 in the BOCNT
Revelation 13 in the BOECS
Revelation 13 in the BOGWICC
Revelation 13 in the BOHCB
Revelation 13 in the BOHCV
Revelation 13 in the BOHLNT
Revelation 13 in the BOHNTLTAL
Revelation 13 in the BOICB
Revelation 13 in the BOILNTAP
Revelation 13 in the BOITCV
Revelation 13 in the BOKCV
Revelation 13 in the BOKCV2
Revelation 13 in the BOKHWOG
Revelation 13 in the BOKSSV
Revelation 13 in the BOLCB
Revelation 13 in the BOLCB2
Revelation 13 in the BOMCV
Revelation 13 in the BONAV
Revelation 13 in the BONCB
Revelation 13 in the BONLT
Revelation 13 in the BONUT2
Revelation 13 in the BOPLNT
Revelation 13 in the BOSCB
Revelation 13 in the BOSNC
Revelation 13 in the BOTLNT
Revelation 13 in the BOVCB
Revelation 13 in the BPBB
Revelation 13 in the BPH
Revelation 13 in the BSB
Revelation 13 in the CCB
Revelation 13 in the CUV
Revelation 13 in the CUVS
Revelation 13 in the DBT
Revelation 13 in the DGDNT
Revelation 13 in the DHNT
Revelation 13 in the DNT
Revelation 13 in the ELBE
Revelation 13 in the EMTV
Revelation 13 in the ESV
Revelation 13 in the FBV
Revelation 13 in the FEB
Revelation 13 in the GGMNT
Revelation 13 in the GNT
Revelation 13 in the HARY
Revelation 13 in the HNT
Revelation 13 in the IRVA
Revelation 13 in the IRVB
Revelation 13 in the IRVG
Revelation 13 in the IRVH
Revelation 13 in the IRVK
Revelation 13 in the IRVM
Revelation 13 in the IRVM2
Revelation 13 in the IRVO
Revelation 13 in the IRVP
Revelation 13 in the IRVT
Revelation 13 in the IRVT2
Revelation 13 in the IRVU
Revelation 13 in the ISVN
Revelation 13 in the JSNT
Revelation 13 in the KAPI
Revelation 13 in the KBT1ETNIK
Revelation 13 in the KBV
Revelation 13 in the KJV
Revelation 13 in the KNFD
Revelation 13 in the LBA
Revelation 13 in the LBLA
Revelation 13 in the LNT
Revelation 13 in the LSV
Revelation 13 in the MAAL
Revelation 13 in the MBV
Revelation 13 in the MBV2
Revelation 13 in the MHNT
Revelation 13 in the MKNFD
Revelation 13 in the MNG
Revelation 13 in the MNT
Revelation 13 in the MNT2
Revelation 13 in the MRS1T
Revelation 13 in the NAA
Revelation 13 in the NASB
Revelation 13 in the NBLA
Revelation 13 in the NBS
Revelation 13 in the NBVTP
Revelation 13 in the NET2
Revelation 13 in the NIV11
Revelation 13 in the NNT
Revelation 13 in the NNT2
Revelation 13 in the NNT3
Revelation 13 in the PDDPT
Revelation 13 in the PFNT
Revelation 13 in the RMNT
Revelation 13 in the SBIAS
Revelation 13 in the SBIBS
Revelation 13 in the SBIBS2
Revelation 13 in the SBICS
Revelation 13 in the SBIDS
Revelation 13 in the SBIGS
Revelation 13 in the SBIHS
Revelation 13 in the SBIIS
Revelation 13 in the SBIIS2
Revelation 13 in the SBIIS3
Revelation 13 in the SBIKS
Revelation 13 in the SBIKS2
Revelation 13 in the SBIMS
Revelation 13 in the SBIOS
Revelation 13 in the SBIPS
Revelation 13 in the SBISS
Revelation 13 in the SBITS
Revelation 13 in the SBITS2
Revelation 13 in the SBITS3
Revelation 13 in the SBITS4
Revelation 13 in the SBIUS
Revelation 13 in the SBIVS
Revelation 13 in the SBT
Revelation 13 in the SBT1E
Revelation 13 in the SCHL
Revelation 13 in the SNT
Revelation 13 in the SUSU
Revelation 13 in the SUSU2
Revelation 13 in the SYNO
Revelation 13 in the TBIAOTANT
Revelation 13 in the TBT1E
Revelation 13 in the TBT1E2
Revelation 13 in the TFTIP
Revelation 13 in the TFTU
Revelation 13 in the TGNTATF3T
Revelation 13 in the THAI
Revelation 13 in the TNFD
Revelation 13 in the TNT
Revelation 13 in the TNTIK
Revelation 13 in the TNTIL
Revelation 13 in the TNTIN
Revelation 13 in the TNTIP
Revelation 13 in the TNTIZ
Revelation 13 in the TOMA
Revelation 13 in the TTENT
Revelation 13 in the UBG
Revelation 13 in the UGV
Revelation 13 in the UGV2
Revelation 13 in the UGV3
Revelation 13 in the VBL
Revelation 13 in the VDCC
Revelation 13 in the YALU
Revelation 13 in the YAPE
Revelation 13 in the YBVTP
Revelation 13 in the ZBP