Revelation 17 (BOYCB)
1 Ọ̀kan nínú àwọn angẹli méje náà tí ó ní ìgò méje wọ̀n-ọn-nì sì wá, ó sì ba mi sọ̀rọ̀ wí pé, “Wá níhìn-ín; èmi ó sì fi ìdájọ́ àgbèrè ńlá ní tí ó jókòó lórí omi púpọ̀ han ọ, 2 ẹni tí àwọn ọba ayé bá ṣe àgbèrè, tí a sì fi ọtí wáìnì àgbèrè rẹ̀ pa àwọn tí ń gbé inú ayé.” 3 Ó sì gbé mi nínú ẹ̀mí lọ sí aginjù: mo sì rí obìnrin kan ó jókòó lórí ẹranko aláwọ̀ òdòdó kan tí ó kún fún orúkọ ọ̀rọ̀-òdì, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá. 4 A sì fi aṣọ elése àlùkò àti aṣọ òdòdó wọ obìnrin náà, a sì fi wúrà àti òkúta iyebíye àti perli ṣe é ní ọ̀ṣọ́, ó ní ago wúrà kan ní ọwọ́ rẹ̀, tí ó kún fún ìríra àti fún ẹ̀gbin àgbèrè rẹ̀; 5 àti níwájú rẹ̀ ni orúkọ kan tí a kọ:Ohun ìjìnlẹ̀ Babeli ńláìyá àwọn panṣágààti àwọn ohun ìríra ayé. 6 Mo sì rí obìnrin náà mu ẹ̀jẹ̀ àwọn ènìyàn mímọ́, àti ẹ̀jẹ̀ àwọn ajẹ́rìí ikú Jesu ní àmuyó.Nígbà tí mo sì rí i, ẹnu yà mi gidigidi. 7 Angẹli sì wí fún mi pé, “Nítorí kí ni ẹnu ṣe yà ọ́? Èmi ó sọ ti ìjìnlẹ̀ obìnrin náà fún ọ, àti ti ẹranko tí ó gùn, ti ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá. 8 Ẹranko tí ìwọ ri nì, o ti wà, kò sì ṣí mọ́, yóò sì ti inú ọ̀gbun gòkè wá, yóò sì lọ sínú ìparun rẹ. Àwọn olùgbé ayé ti a kọ orúkọ wọn sínú ìwé iye láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé, nígbà tí wọn ń wò ẹranko tí o ti wà, tí kò sì ṣí mọ́, tí ó sì ń bọ̀ wá, ẹnu si ya wọn. 9 “Níhìn-ín ni ìtumọ̀ tí o ní ọgbọ́n wà. Orí méje ni òkè ńlá méje ni, lórí èyí tí obìnrin náà jókòó. 10 Ọba méje sì ní wọn: àwọn márùn-ún ṣubú, ọ̀kan ń bẹ, ọ̀kan ìyókù kò sì tí ì dé; nígbà tí ó bá sì dé, yóò dúró fún ìgbà kúkúrú. 11 Ẹranko tí ó sì ti wà, tí kò sì ṣí, òun náà sì ni ẹ̀kẹjọ, ó sì ti inú àwọn méje náà wá, ó sì lọ sí ìparun. 12 “Ìwo mẹ́wàá tí ìwọ sì rí ni ọba mẹ́wàá ni wọn, tí wọn kò ì ti gba ìjọba; ṣùgbọ́n wọn gba àṣẹ bí ọba pẹ̀lú ẹranko náà fún wákàtí kan. 13 Àwọn wọ̀nyí ní inú kan, wọ́n yóò sì fi agbára àti ọlá wọn fún ẹranko náà. 14 Àwọn wọ̀nyí ni yóò si máa bá Ọ̀dọ́-Àgùntàn jagun, Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà yóò sì ṣẹ́gun wọn: nítorí òun ni Olúwa àwọn Olúwa, àti ọba àwọn ọba: àwọn tí ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀, tí a pè, tí a yàn, tí wọ́n sì jẹ́ olóòtítọ́ yóò sì ṣẹ́gun pẹ̀lú.” 15 Ó sì wí fún mi pé, “Àwọn omi tí ìwọ ti rí ni, níbi tí àgbèrè náà jókòó, àwọn ènìyàn àti ẹ̀yà àti orílẹ̀ àti onírúurú èdè ni wọ́n. 16 Àti ìwo mẹ́wàá tí ìwọ rí, àti ẹranko náà, àwọn wọ̀nyí ni yóò kórìíra àgbèrè náà, wọn ó sì sọ ọ́ di ahoro àti ẹni ìhòhò, wọn ó sì jẹ ẹran-ara rẹ̀, wọn ó sì fi iná sun ún pátápátá. 17 Nítorí Ọlọ́run ti fi sínú ọkàn wọn láti mú ìfẹ́ rẹ̀ ṣẹ, láti ní inú kan, àti láti fi ìjọba wọn fún ẹranko náà, títí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run yóò fi ṣẹ. 18 Obìnrin tí ìwọ rí ní ìlú ńlá ni, tí ń jẹ ọba lórí àwọn ọba ilẹ̀ ayé.”
In Other Versions
Revelation 17 in the ANGEFD
Revelation 17 in the ANTPNG2D
Revelation 17 in the AS21
Revelation 17 in the BAGH
Revelation 17 in the BBPNG
Revelation 17 in the BBT1E
Revelation 17 in the BDS
Revelation 17 in the BEV
Revelation 17 in the BHAD
Revelation 17 in the BIB
Revelation 17 in the BLPT
Revelation 17 in the BNT
Revelation 17 in the BNTABOOT
Revelation 17 in the BNTLV
Revelation 17 in the BOATCB
Revelation 17 in the BOATCB2
Revelation 17 in the BOBCV
Revelation 17 in the BOCNT
Revelation 17 in the BOECS
Revelation 17 in the BOGWICC
Revelation 17 in the BOHCB
Revelation 17 in the BOHCV
Revelation 17 in the BOHLNT
Revelation 17 in the BOHNTLTAL
Revelation 17 in the BOICB
Revelation 17 in the BOILNTAP
Revelation 17 in the BOITCV
Revelation 17 in the BOKCV
Revelation 17 in the BOKCV2
Revelation 17 in the BOKHWOG
Revelation 17 in the BOKSSV
Revelation 17 in the BOLCB
Revelation 17 in the BOLCB2
Revelation 17 in the BOMCV
Revelation 17 in the BONAV
Revelation 17 in the BONCB
Revelation 17 in the BONLT
Revelation 17 in the BONUT2
Revelation 17 in the BOPLNT
Revelation 17 in the BOSCB
Revelation 17 in the BOSNC
Revelation 17 in the BOTLNT
Revelation 17 in the BOVCB
Revelation 17 in the BPBB
Revelation 17 in the BPH
Revelation 17 in the BSB
Revelation 17 in the CCB
Revelation 17 in the CUV
Revelation 17 in the CUVS
Revelation 17 in the DBT
Revelation 17 in the DGDNT
Revelation 17 in the DHNT
Revelation 17 in the DNT
Revelation 17 in the ELBE
Revelation 17 in the EMTV
Revelation 17 in the ESV
Revelation 17 in the FBV
Revelation 17 in the FEB
Revelation 17 in the GGMNT
Revelation 17 in the GNT
Revelation 17 in the HARY
Revelation 17 in the HNT
Revelation 17 in the IRVA
Revelation 17 in the IRVB
Revelation 17 in the IRVG
Revelation 17 in the IRVH
Revelation 17 in the IRVK
Revelation 17 in the IRVM
Revelation 17 in the IRVM2
Revelation 17 in the IRVO
Revelation 17 in the IRVP
Revelation 17 in the IRVT
Revelation 17 in the IRVT2
Revelation 17 in the IRVU
Revelation 17 in the ISVN
Revelation 17 in the JSNT
Revelation 17 in the KAPI
Revelation 17 in the KBT1ETNIK
Revelation 17 in the KBV
Revelation 17 in the KJV
Revelation 17 in the KNFD
Revelation 17 in the LBA
Revelation 17 in the LBLA
Revelation 17 in the LNT
Revelation 17 in the LSV
Revelation 17 in the MAAL
Revelation 17 in the MBV
Revelation 17 in the MBV2
Revelation 17 in the MHNT
Revelation 17 in the MKNFD
Revelation 17 in the MNG
Revelation 17 in the MNT
Revelation 17 in the MNT2
Revelation 17 in the MRS1T
Revelation 17 in the NAA
Revelation 17 in the NASB
Revelation 17 in the NBLA
Revelation 17 in the NBS
Revelation 17 in the NBVTP
Revelation 17 in the NET2
Revelation 17 in the NIV11
Revelation 17 in the NNT
Revelation 17 in the NNT2
Revelation 17 in the NNT3
Revelation 17 in the PDDPT
Revelation 17 in the PFNT
Revelation 17 in the RMNT
Revelation 17 in the SBIAS
Revelation 17 in the SBIBS
Revelation 17 in the SBIBS2
Revelation 17 in the SBICS
Revelation 17 in the SBIDS
Revelation 17 in the SBIGS
Revelation 17 in the SBIHS
Revelation 17 in the SBIIS
Revelation 17 in the SBIIS2
Revelation 17 in the SBIIS3
Revelation 17 in the SBIKS
Revelation 17 in the SBIKS2
Revelation 17 in the SBIMS
Revelation 17 in the SBIOS
Revelation 17 in the SBIPS
Revelation 17 in the SBISS
Revelation 17 in the SBITS
Revelation 17 in the SBITS2
Revelation 17 in the SBITS3
Revelation 17 in the SBITS4
Revelation 17 in the SBIUS
Revelation 17 in the SBIVS
Revelation 17 in the SBT
Revelation 17 in the SBT1E
Revelation 17 in the SCHL
Revelation 17 in the SNT
Revelation 17 in the SUSU
Revelation 17 in the SUSU2
Revelation 17 in the SYNO
Revelation 17 in the TBIAOTANT
Revelation 17 in the TBT1E
Revelation 17 in the TBT1E2
Revelation 17 in the TFTIP
Revelation 17 in the TFTU
Revelation 17 in the TGNTATF3T
Revelation 17 in the THAI
Revelation 17 in the TNFD
Revelation 17 in the TNT
Revelation 17 in the TNTIK
Revelation 17 in the TNTIL
Revelation 17 in the TNTIN
Revelation 17 in the TNTIP
Revelation 17 in the TNTIZ
Revelation 17 in the TOMA
Revelation 17 in the TTENT
Revelation 17 in the UBG
Revelation 17 in the UGV
Revelation 17 in the UGV2
Revelation 17 in the UGV3
Revelation 17 in the VBL
Revelation 17 in the VDCC
Revelation 17 in the YALU
Revelation 17 in the YAPE
Revelation 17 in the YBVTP
Revelation 17 in the ZBP