1 Chronicles 18 (BOYCB)
1 Ní àkókò kan, Dafidi kọlu àwọn ará Filistini, ó sì ṣẹ́gun wọn. Ó sì mú Gati àti àwọn ìletò agbègbè rẹ̀ kúrò lábẹ́ ìdarí àwọn ará Filistini. 2 Dafidi borí àwọn ará Moabu, wọ́n sì di ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì mú owó òde wá. 3 Síbẹ̀, Dafidi sì kọlu Hadadeseri ọba Soba ní Hamati, bí ó ti ń lọ láti fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ létí odò Eufurate. 4 Dafidi fi agbára gba ẹgbẹ̀rún (1,000) kẹ̀kẹ́ rẹ̀, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin (7,000) agun-kẹ̀kẹ́ àti ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) ológun ilẹ̀. Ó sì já gbogbo ọgọ́rùn-ún iṣan ẹsẹ̀ àwọn kẹ̀kẹ́-ẹṣin náà. 5 Nígbà ti àwọn ará Siria ti Damasku wá láti ran Hadadeseri ọba Soba lọ́wọ́, Dafidi lu ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) wọn bọ lẹ̀. 6 Ó sì fi àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun rẹ sínú ìjọba Siria ti Damasku, àwọn ará Siria sì ń sìn ní abẹ́ rẹ̀, wọ́n sì mú owó ìṣákọ́lẹ̀ wá. OLÚWA sì ń fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní ibi gbogbo tí ó bá lọ. 7 Dafidi mú àpáta wúrà tí àwọn ìjòyè Hadadeseri gbé, ó sì gbé wọn wá sí Jerusalẹmu. 8 Láti Tibhati àti Kuni, àwọn ìlú Hadadeseri, Dafidi kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ idẹ tí Solomoni lò láti fi ṣe okùn idẹ, àwọn òpó àti oríṣìí ohun èlò idẹ. 9 Nígbà tí Tou ọba Hamati gbọ́ pé Dafidi ti borí gbogbo ọmọ-ogun Hadadeseri ọba Soba. 10 Ó rán ọmọ rẹ̀ Hadoramu sí ọba Dafidi láti kí i àti láti lọ bá a yọ̀ lórí ìṣẹ́gun rẹ̀ nínú ogun lórí Hadadeseri, tí ó wà lójú ogun pẹ̀lú Tou. Hadoramu mú oríṣìíríṣìí ohun èlò ti wúrà àti fàdákà àti idẹ wá. 11 Ọba Dafidi ya ohun èlò wọ́n yí sí mímọ́ fún OLÚWA, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe pẹ̀lú fàdákà àti wúrà tí ó ti mú láti gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí: Edomu àti Moabu, ará Ammoni àti àwọn ará Filistini àti Amaleki. 12 Abiṣai ọmọ Seruiah lu ẹgbàá mẹ́sàn (18,000) ará Edomu bolẹ̀ ní àfonífojì Iyọ̀. 13 Ó fi ẹgbẹ́ ogun sí Edomu, gbogbo àwọn ará Edomu sì ń sìn ní abẹ́ Dafidi. OLÚWA fún Dafidi ní ìṣẹ́gun ní gbogbo ibí tí ó bá lọ. 14 Dafidi jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli, ó sì ṣe òdodo àti ohun tí ó yẹ fún gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀. 15 Joabu ọmọ Seruiah jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ-ogun;Jehoṣafati ọmọ Ahiludi jẹ́ akọ̀wé ìrántí; 16 Sadoku ọmọ Ahitubu àti Abimeleki ọmọ Abiatari jẹ́ àwọn àlùfáà;Ṣafṣa jẹ́ akọ̀wé; 17 Benaiah ọmọ Jehoiada jẹ́ olórí àwọn Kereti àti Peleti;àwọn ọmọ Dafidi sì ni àwọn olóyè oníṣẹ́ ní ọ̀dọ̀ ọba.
In Other Versions
1 Chronicles 18 in the ANGEFD
1 Chronicles 18 in the ANTPNG2D
1 Chronicles 18 in the AS21
1 Chronicles 18 in the BAGH
1 Chronicles 18 in the BBPNG
1 Chronicles 18 in the BBT1E
1 Chronicles 18 in the BDS
1 Chronicles 18 in the BEV
1 Chronicles 18 in the BHAD
1 Chronicles 18 in the BIB
1 Chronicles 18 in the BLPT
1 Chronicles 18 in the BNT
1 Chronicles 18 in the BNTABOOT
1 Chronicles 18 in the BNTLV
1 Chronicles 18 in the BOATCB
1 Chronicles 18 in the BOATCB2
1 Chronicles 18 in the BOBCV
1 Chronicles 18 in the BOCNT
1 Chronicles 18 in the BOECS
1 Chronicles 18 in the BOGWICC
1 Chronicles 18 in the BOHCB
1 Chronicles 18 in the BOHCV
1 Chronicles 18 in the BOHLNT
1 Chronicles 18 in the BOHNTLTAL
1 Chronicles 18 in the BOICB
1 Chronicles 18 in the BOILNTAP
1 Chronicles 18 in the BOITCV
1 Chronicles 18 in the BOKCV
1 Chronicles 18 in the BOKCV2
1 Chronicles 18 in the BOKHWOG
1 Chronicles 18 in the BOKSSV
1 Chronicles 18 in the BOLCB
1 Chronicles 18 in the BOLCB2
1 Chronicles 18 in the BOMCV
1 Chronicles 18 in the BONAV
1 Chronicles 18 in the BONCB
1 Chronicles 18 in the BONLT
1 Chronicles 18 in the BONUT2
1 Chronicles 18 in the BOPLNT
1 Chronicles 18 in the BOSCB
1 Chronicles 18 in the BOSNC
1 Chronicles 18 in the BOTLNT
1 Chronicles 18 in the BOVCB
1 Chronicles 18 in the BPBB
1 Chronicles 18 in the BPH
1 Chronicles 18 in the BSB
1 Chronicles 18 in the CCB
1 Chronicles 18 in the CUV
1 Chronicles 18 in the CUVS
1 Chronicles 18 in the DBT
1 Chronicles 18 in the DGDNT
1 Chronicles 18 in the DHNT
1 Chronicles 18 in the DNT
1 Chronicles 18 in the ELBE
1 Chronicles 18 in the EMTV
1 Chronicles 18 in the ESV
1 Chronicles 18 in the FBV
1 Chronicles 18 in the FEB
1 Chronicles 18 in the GGMNT
1 Chronicles 18 in the GNT
1 Chronicles 18 in the HARY
1 Chronicles 18 in the HNT
1 Chronicles 18 in the IRVA
1 Chronicles 18 in the IRVB
1 Chronicles 18 in the IRVG
1 Chronicles 18 in the IRVH
1 Chronicles 18 in the IRVK
1 Chronicles 18 in the IRVM
1 Chronicles 18 in the IRVM2
1 Chronicles 18 in the IRVO
1 Chronicles 18 in the IRVP
1 Chronicles 18 in the IRVT
1 Chronicles 18 in the IRVT2
1 Chronicles 18 in the IRVU
1 Chronicles 18 in the ISVN
1 Chronicles 18 in the JSNT
1 Chronicles 18 in the KAPI
1 Chronicles 18 in the KBT1ETNIK
1 Chronicles 18 in the KBV
1 Chronicles 18 in the KJV
1 Chronicles 18 in the KNFD
1 Chronicles 18 in the LBA
1 Chronicles 18 in the LBLA
1 Chronicles 18 in the LNT
1 Chronicles 18 in the LSV
1 Chronicles 18 in the MAAL
1 Chronicles 18 in the MBV
1 Chronicles 18 in the MBV2
1 Chronicles 18 in the MHNT
1 Chronicles 18 in the MKNFD
1 Chronicles 18 in the MNG
1 Chronicles 18 in the MNT
1 Chronicles 18 in the MNT2
1 Chronicles 18 in the MRS1T
1 Chronicles 18 in the NAA
1 Chronicles 18 in the NASB
1 Chronicles 18 in the NBLA
1 Chronicles 18 in the NBS
1 Chronicles 18 in the NBVTP
1 Chronicles 18 in the NET2
1 Chronicles 18 in the NIV11
1 Chronicles 18 in the NNT
1 Chronicles 18 in the NNT2
1 Chronicles 18 in the NNT3
1 Chronicles 18 in the PDDPT
1 Chronicles 18 in the PFNT
1 Chronicles 18 in the RMNT
1 Chronicles 18 in the SBIAS
1 Chronicles 18 in the SBIBS
1 Chronicles 18 in the SBIBS2
1 Chronicles 18 in the SBICS
1 Chronicles 18 in the SBIDS
1 Chronicles 18 in the SBIGS
1 Chronicles 18 in the SBIHS
1 Chronicles 18 in the SBIIS
1 Chronicles 18 in the SBIIS2
1 Chronicles 18 in the SBIIS3
1 Chronicles 18 in the SBIKS
1 Chronicles 18 in the SBIKS2
1 Chronicles 18 in the SBIMS
1 Chronicles 18 in the SBIOS
1 Chronicles 18 in the SBIPS
1 Chronicles 18 in the SBISS
1 Chronicles 18 in the SBITS
1 Chronicles 18 in the SBITS2
1 Chronicles 18 in the SBITS3
1 Chronicles 18 in the SBITS4
1 Chronicles 18 in the SBIUS
1 Chronicles 18 in the SBIVS
1 Chronicles 18 in the SBT
1 Chronicles 18 in the SBT1E
1 Chronicles 18 in the SCHL
1 Chronicles 18 in the SNT
1 Chronicles 18 in the SUSU
1 Chronicles 18 in the SUSU2
1 Chronicles 18 in the SYNO
1 Chronicles 18 in the TBIAOTANT
1 Chronicles 18 in the TBT1E
1 Chronicles 18 in the TBT1E2
1 Chronicles 18 in the TFTIP
1 Chronicles 18 in the TFTU
1 Chronicles 18 in the TGNTATF3T
1 Chronicles 18 in the THAI
1 Chronicles 18 in the TNFD
1 Chronicles 18 in the TNT
1 Chronicles 18 in the TNTIK
1 Chronicles 18 in the TNTIL
1 Chronicles 18 in the TNTIN
1 Chronicles 18 in the TNTIP
1 Chronicles 18 in the TNTIZ
1 Chronicles 18 in the TOMA
1 Chronicles 18 in the TTENT
1 Chronicles 18 in the UBG
1 Chronicles 18 in the UGV
1 Chronicles 18 in the UGV2
1 Chronicles 18 in the UGV3
1 Chronicles 18 in the VBL
1 Chronicles 18 in the VDCC
1 Chronicles 18 in the YALU
1 Chronicles 18 in the YAPE
1 Chronicles 18 in the YBVTP
1 Chronicles 18 in the ZBP