1 Corinthians 5 (BOYCB)

1 Ìròyìn rẹ ń tàn kalẹ̀ pé ìwà àgbèrè wa láàrín yín, irú àgbèrè tí a kò tilẹ̀ gbúròó rẹ̀ láàrín àwọn aláìkọlà pé, ẹnìkan nínú yín ń fẹ́ ìyàwó baba rẹ̀. 2 Ẹ̀yin ń ṣe ìgbéraga! Ẹ̀yin kò kúkú káàánú kí a lè mú ẹni tí ó hu ìwà yìí kúrò láàrín yín? 3 Lóòtítọ́ èmi kò sí láàrín yín nípa ti ara, ṣùgbọ́n mo wà lọ́dọ̀ yín nínú ẹ̀mí àti pé, ní orúkọ Olúwa Jesu Kristi, mo tí ṣe ìdájọ́ lórí irú ẹni bẹ́ẹ̀, bí ẹni pé mo wá láàrín yín. 4 Ní orúkọ Jesu Kristi. Nígbà tí ẹ̀yin bá péjọ, àti ẹ̀mí mi si wa pẹ̀lú yin nínú ẹ̀mí mi àti pẹ̀lú agbára Jesu Kristi Olúwa wa. 5 Kí ẹ fi irú ẹni bẹ́ẹ̀ lé Satani lọ́wọ́ fún ìparun ara, kí ó ba à le gba ẹ̀mí rẹ là ní ọjọ́ Olúwa wa Jesu Kristi. 6 Ìṣeféfé yín kò dára. Ẹ̀yin kò mọ̀ pé ìwúkàrà díẹ̀ ní mú gbogbo ìyẹ̀fun di wíwú? 7 Nítorí náà ẹ mú ìwúkàrà àtijọ́ kúrò nínú yín, kí ẹ̀yin kí ó lè jẹ ìyẹ̀fun tuntun, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí jẹ àkàrà ti kò ní ìwúkàrà. Nítorí à ti fi ìrékọjá wa, àní Kristi ni a ti pa láti fi ṣe ẹbọ fún ẹ̀ṣẹ̀ wa. 8 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á pa àjọ náà mọ́, kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà àtijọ́ bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà àrankàn àti ìwà búburú, ṣùgbọ́n pẹ̀lú àkàrà tí kò ní ìwúkàrà, àkàrà òtítọ́ àti òdodo. 9 Nígbà tí mo kọ̀wé ṣáájú sí i yín, mo sọ fún yín pé, kí ẹ má ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn alágbèrè ènìyàn. 10 Nígbà tí mo sọ bẹ́ẹ̀ ń kò sọ̀rọ̀ nípa àwọn tí ayé yìí, tí wọ́n ń gbé ìgbé ayé wọn nínú ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè, àti àwọn olójúkòkòrò tí ń rẹ́ ni jẹ, àwọn olè àti àwọn abọ̀rìṣà. Nítorí ó dájú pé ẹ̀yin gbọdọ̀ kúrò nínú ayé yìí láti yẹra fún wọn. 11 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí mo kọ̀wé sí i yín pé, bí ẹnikẹ́ni tí a pe rẹ̀ ni arákùnrin bá jẹ́ àgbèrè, tàbí wọ̀bìà, tàbí abọ̀rìṣà, àti ẹlẹ́gàn, tàbí ọ̀mùtípara, tàbí alọ́nilọ́wọ́gbà. Kí ẹ tilẹ̀ bá irú ẹni bẹ́ẹ̀ jẹun. 12 Nítorí èwo ni tèmi láti máa ṣe ìdájọ́ àwọn tí ń bẹ lóde? Kì í ha ṣe àwọn tí ó wà nínú ni ẹ̀yin ṣe ìdájọ́ wọn? 13 Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ àwọn tí ó ń bẹ lóde. “Ẹ lé àwọn ènìyàn búburú náà kúrò láàrín yín.”

In Other Versions

1 Corinthians 5 in the ANGEFD

1 Corinthians 5 in the ANTPNG2D

1 Corinthians 5 in the AS21

1 Corinthians 5 in the BAGH

1 Corinthians 5 in the BBPNG

1 Corinthians 5 in the BBT1E

1 Corinthians 5 in the BDS

1 Corinthians 5 in the BEV

1 Corinthians 5 in the BHAD

1 Corinthians 5 in the BIB

1 Corinthians 5 in the BLPT

1 Corinthians 5 in the BNT

1 Corinthians 5 in the BNTABOOT

1 Corinthians 5 in the BNTLV

1 Corinthians 5 in the BOATCB

1 Corinthians 5 in the BOATCB2

1 Corinthians 5 in the BOBCV

1 Corinthians 5 in the BOCNT

1 Corinthians 5 in the BOECS

1 Corinthians 5 in the BOGWICC

1 Corinthians 5 in the BOHCB

1 Corinthians 5 in the BOHCV

1 Corinthians 5 in the BOHLNT

1 Corinthians 5 in the BOHNTLTAL

1 Corinthians 5 in the BOICB

1 Corinthians 5 in the BOILNTAP

1 Corinthians 5 in the BOITCV

1 Corinthians 5 in the BOKCV

1 Corinthians 5 in the BOKCV2

1 Corinthians 5 in the BOKHWOG

1 Corinthians 5 in the BOKSSV

1 Corinthians 5 in the BOLCB

1 Corinthians 5 in the BOLCB2

1 Corinthians 5 in the BOMCV

1 Corinthians 5 in the BONAV

1 Corinthians 5 in the BONCB

1 Corinthians 5 in the BONLT

1 Corinthians 5 in the BONUT2

1 Corinthians 5 in the BOPLNT

1 Corinthians 5 in the BOSCB

1 Corinthians 5 in the BOSNC

1 Corinthians 5 in the BOTLNT

1 Corinthians 5 in the BOVCB

1 Corinthians 5 in the BPBB

1 Corinthians 5 in the BPH

1 Corinthians 5 in the BSB

1 Corinthians 5 in the CCB

1 Corinthians 5 in the CUV

1 Corinthians 5 in the CUVS

1 Corinthians 5 in the DBT

1 Corinthians 5 in the DGDNT

1 Corinthians 5 in the DHNT

1 Corinthians 5 in the DNT

1 Corinthians 5 in the ELBE

1 Corinthians 5 in the EMTV

1 Corinthians 5 in the ESV

1 Corinthians 5 in the FBV

1 Corinthians 5 in the FEB

1 Corinthians 5 in the GGMNT

1 Corinthians 5 in the GNT

1 Corinthians 5 in the HARY

1 Corinthians 5 in the HNT

1 Corinthians 5 in the IRVA

1 Corinthians 5 in the IRVB

1 Corinthians 5 in the IRVG

1 Corinthians 5 in the IRVH

1 Corinthians 5 in the IRVK

1 Corinthians 5 in the IRVM

1 Corinthians 5 in the IRVM2

1 Corinthians 5 in the IRVO

1 Corinthians 5 in the IRVP

1 Corinthians 5 in the IRVT

1 Corinthians 5 in the IRVT2

1 Corinthians 5 in the IRVU

1 Corinthians 5 in the ISVN

1 Corinthians 5 in the JSNT

1 Corinthians 5 in the KAPI

1 Corinthians 5 in the KBT1ETNIK

1 Corinthians 5 in the KBV

1 Corinthians 5 in the KJV

1 Corinthians 5 in the KNFD

1 Corinthians 5 in the LBA

1 Corinthians 5 in the LBLA

1 Corinthians 5 in the LNT

1 Corinthians 5 in the LSV

1 Corinthians 5 in the MAAL

1 Corinthians 5 in the MBV

1 Corinthians 5 in the MBV2

1 Corinthians 5 in the MHNT

1 Corinthians 5 in the MKNFD

1 Corinthians 5 in the MNG

1 Corinthians 5 in the MNT

1 Corinthians 5 in the MNT2

1 Corinthians 5 in the MRS1T

1 Corinthians 5 in the NAA

1 Corinthians 5 in the NASB

1 Corinthians 5 in the NBLA

1 Corinthians 5 in the NBS

1 Corinthians 5 in the NBVTP

1 Corinthians 5 in the NET2

1 Corinthians 5 in the NIV11

1 Corinthians 5 in the NNT

1 Corinthians 5 in the NNT2

1 Corinthians 5 in the NNT3

1 Corinthians 5 in the PDDPT

1 Corinthians 5 in the PFNT

1 Corinthians 5 in the RMNT

1 Corinthians 5 in the SBIAS

1 Corinthians 5 in the SBIBS

1 Corinthians 5 in the SBIBS2

1 Corinthians 5 in the SBICS

1 Corinthians 5 in the SBIDS

1 Corinthians 5 in the SBIGS

1 Corinthians 5 in the SBIHS

1 Corinthians 5 in the SBIIS

1 Corinthians 5 in the SBIIS2

1 Corinthians 5 in the SBIIS3

1 Corinthians 5 in the SBIKS

1 Corinthians 5 in the SBIKS2

1 Corinthians 5 in the SBIMS

1 Corinthians 5 in the SBIOS

1 Corinthians 5 in the SBIPS

1 Corinthians 5 in the SBISS

1 Corinthians 5 in the SBITS

1 Corinthians 5 in the SBITS2

1 Corinthians 5 in the SBITS3

1 Corinthians 5 in the SBITS4

1 Corinthians 5 in the SBIUS

1 Corinthians 5 in the SBIVS

1 Corinthians 5 in the SBT

1 Corinthians 5 in the SBT1E

1 Corinthians 5 in the SCHL

1 Corinthians 5 in the SNT

1 Corinthians 5 in the SUSU

1 Corinthians 5 in the SUSU2

1 Corinthians 5 in the SYNO

1 Corinthians 5 in the TBIAOTANT

1 Corinthians 5 in the TBT1E

1 Corinthians 5 in the TBT1E2

1 Corinthians 5 in the TFTIP

1 Corinthians 5 in the TFTU

1 Corinthians 5 in the TGNTATF3T

1 Corinthians 5 in the THAI

1 Corinthians 5 in the TNFD

1 Corinthians 5 in the TNT

1 Corinthians 5 in the TNTIK

1 Corinthians 5 in the TNTIL

1 Corinthians 5 in the TNTIN

1 Corinthians 5 in the TNTIP

1 Corinthians 5 in the TNTIZ

1 Corinthians 5 in the TOMA

1 Corinthians 5 in the TTENT

1 Corinthians 5 in the UBG

1 Corinthians 5 in the UGV

1 Corinthians 5 in the UGV2

1 Corinthians 5 in the UGV3

1 Corinthians 5 in the VBL

1 Corinthians 5 in the VDCC

1 Corinthians 5 in the YALU

1 Corinthians 5 in the YAPE

1 Corinthians 5 in the YBVTP

1 Corinthians 5 in the ZBP