1 Corinthians 6 (BOYCB)
1 Bí ẹnikẹ́ni nínú yín bá ni èdè-àìyedè sí ẹnìkejì rẹ̀, ó ha gbọdọ̀ lọ pè é lẹ́jọ́ níwájú àwọn aláìṣòótọ́ bí, bí kò ṣe níwájú àwọn ènìyàn mímọ́? 2 Ṣé ẹ̀yin kò mọ̀ pé àwọn ẹni mímọ́ ni yóò ṣe ìdájọ́ ayé? Ǹjẹ́ bí ó ba ṣe ìpàṣẹ yín ni a o ti ṣe ìdájọ́ ayé, kín ni ìdí tí ẹ kò fi yanjú àwọn ọ̀rọ̀ kéékèèké wọ̀nyí láàrín ara yín. 3 Ẹ kò mọ̀ pé àwa ni a ó ṣe ìdájọ́ àwọn angẹli ní? Mélòó mélòó àwọn nǹkan tó wà nínú ayé yìí. 4 Nítorí náà, bí ẹ̀yin bá ni aáwọ̀ lórí ọ̀rọ̀ yìí, ǹjẹ́ ẹ ó yàn láti gba ìdájọ́ lọ́dọ̀ àwọn tí ìgbé ayé wọn ń di gígàn nínú ìjọ. 5 Mo sọ èyí kí ojú lè tì yín. Ṣé ó ṣe é ṣe kí a máa rín ẹnìkan láàrín yín tí ó gbọ́n níwọ̀n láti ṣe ìdájọ́ èdè-àìyedè láàrín àwọn onígbàgbọ́? 6 Ṣùgbọ́n dípò èyí, arákùnrin kan ń pe arákùnrin kejì lẹ́jọ́ sí ilé ẹjọ́ níwájú àwọn aláìgbàgbọ́. 7 Ǹjẹ́ nísinsin yìí, àbùkù ni fún un yín pátápátá pé ẹ̀yin ń bá ara yín ṣe ẹjọ́. Kín ní ṣe tí ẹ kò kúkú gba ìyà? Kín ló dé tí ẹ kò kúkú gba ìrẹ́jẹ kí ẹ sì fi i sílẹ̀ bẹ́ẹ̀? 8 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ń jẹ ni ní ìyà, ẹ sì ń rẹ́ ni jẹ. Ẹ̀yin si ń ṣe èyí sí àwọn arákùnrin yín. 9 Ẹ̀yin kò mọ̀ pé àwọn aláìṣòótọ́ kì í yóò jogún ìjọba Ọlọ́run? Kí a máa tàn yín jẹ; kì í ṣe àwọn àgbèrè, tàbí àwọn abọ̀rìṣà, tàbí àwọn panṣágà, tàbí àwọn ọkùnrin tí ń ṣe ìṣe obìnrin tàbí àwọn ọkùnrin tí ń ba ara wọn lòpọ̀ 10 tàbí àwọn olè, tàbí àwọn wọ̀bìà, tàbí àwọn ọ̀mùtí, tàbí àwọn apẹ̀gàn, tàbí àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà ni yóò jogún ìjọba Ọlọ́run. 11 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn nínú yín sì tí jẹ́ rí; ṣùgbọ́n a ti sọ yín di mímọ́, ṣùgbọ́n a ti dá yín láre ni orúkọ Jesu Kristi Olúwa, àti nípa Ẹ̀mí Mímọ́ Ọlọ́run wa. 12 “Ohun gbogbo ní ó tọ́ fún mi,” ṣùgbọ́n kì í ṣe ohun gbogbo ni ó ní èrè. “Ohun gbogbo ni ó yẹ fún mi,” ṣùgbọ́n èmi kì yóò jẹ́ kí ohunkóhun ṣe olórí fun mi. 13 “Oúnjẹ fún inú àti inú fún oúnjẹ,” ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò fi òpin sí méjèèjì, ara kì í ṣe fún ìwà àgbèrè ṣíṣe, ṣùgbọ́n fún Olúwa, àti Olúwa fún ara náà. 14 Nínú agbára rẹ̀, Ọlọ́run jí Olúwa dìde kúrò nínú òkú bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò jí àwa náà dìde. 15 Ṣé ẹ kò tilẹ̀ mọ̀ pé ara yín gan an jẹ́ ẹ̀yà ara Kristi fún ara rẹ̀? Ǹjẹ́ tí ó ba jẹ́ bẹ́ẹ̀, ǹjẹ́ ó yẹ kí ń mú ẹ̀yà ara Kristi kí ń fi ṣe ẹ̀yà ara àgbèrè bí? Kí a má rí i! 16 Tàbí ẹ kò mọ̀ pé bí ẹnìkan bá so ara rẹ̀ pọ̀ mọ́ àgbèrè ó jẹ́ ara kan pẹ̀lú rẹ̀? Nítorí a tí kọ ọ́ wí pé, “Àwọn méjèèjì yóò sì di ara kan.” 17 Ṣùgbọ́n ẹni ti ó dàpọ̀ mọ́ Olúwa di ẹ̀mí kan náà pẹ̀lú rẹ̀. 18 Ẹ máa sá fún àgbèrè. Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí ènìyàn ń dá wà lóde ara, ṣùgbọ́n ẹni tí ń ṣe àgbèrè ń ṣe sí ara òun tìkára rẹ̀. 19 Tàbí, ẹ̀yin kò mọ̀ pé ara yín ni tẹmpili Ẹ̀mí Mímọ́, ti ń bẹ nínú yín, ti ẹ̀yin ti gbà lọ́wọ́ Ọlọ́run? Ẹ̀yin kì í ṣe ti ara yín, 20 nítorí a ti rà yín ni iye kan. Nítorí náà ẹ yìn Ọlọ́run lógo nínú ara yín, àti nínú ẹ̀mí yín, tì í ṣe ti Ọlọ́run.
In Other Versions
1 Corinthians 6 in the ANGEFD
1 Corinthians 6 in the ANTPNG2D
1 Corinthians 6 in the AS21
1 Corinthians 6 in the BAGH
1 Corinthians 6 in the BBPNG
1 Corinthians 6 in the BBT1E
1 Corinthians 6 in the BDS
1 Corinthians 6 in the BEV
1 Corinthians 6 in the BHAD
1 Corinthians 6 in the BIB
1 Corinthians 6 in the BLPT
1 Corinthians 6 in the BNT
1 Corinthians 6 in the BNTABOOT
1 Corinthians 6 in the BNTLV
1 Corinthians 6 in the BOATCB
1 Corinthians 6 in the BOATCB2
1 Corinthians 6 in the BOBCV
1 Corinthians 6 in the BOCNT
1 Corinthians 6 in the BOECS
1 Corinthians 6 in the BOGWICC
1 Corinthians 6 in the BOHCB
1 Corinthians 6 in the BOHCV
1 Corinthians 6 in the BOHLNT
1 Corinthians 6 in the BOHNTLTAL
1 Corinthians 6 in the BOICB
1 Corinthians 6 in the BOILNTAP
1 Corinthians 6 in the BOITCV
1 Corinthians 6 in the BOKCV
1 Corinthians 6 in the BOKCV2
1 Corinthians 6 in the BOKHWOG
1 Corinthians 6 in the BOKSSV
1 Corinthians 6 in the BOLCB
1 Corinthians 6 in the BOLCB2
1 Corinthians 6 in the BOMCV
1 Corinthians 6 in the BONAV
1 Corinthians 6 in the BONCB
1 Corinthians 6 in the BONLT
1 Corinthians 6 in the BONUT2
1 Corinthians 6 in the BOPLNT
1 Corinthians 6 in the BOSCB
1 Corinthians 6 in the BOSNC
1 Corinthians 6 in the BOTLNT
1 Corinthians 6 in the BOVCB
1 Corinthians 6 in the BPBB
1 Corinthians 6 in the BPH
1 Corinthians 6 in the BSB
1 Corinthians 6 in the CCB
1 Corinthians 6 in the CUV
1 Corinthians 6 in the CUVS
1 Corinthians 6 in the DBT
1 Corinthians 6 in the DGDNT
1 Corinthians 6 in the DHNT
1 Corinthians 6 in the DNT
1 Corinthians 6 in the ELBE
1 Corinthians 6 in the EMTV
1 Corinthians 6 in the ESV
1 Corinthians 6 in the FBV
1 Corinthians 6 in the FEB
1 Corinthians 6 in the GGMNT
1 Corinthians 6 in the GNT
1 Corinthians 6 in the HARY
1 Corinthians 6 in the HNT
1 Corinthians 6 in the IRVA
1 Corinthians 6 in the IRVB
1 Corinthians 6 in the IRVG
1 Corinthians 6 in the IRVH
1 Corinthians 6 in the IRVK
1 Corinthians 6 in the IRVM
1 Corinthians 6 in the IRVM2
1 Corinthians 6 in the IRVO
1 Corinthians 6 in the IRVP
1 Corinthians 6 in the IRVT
1 Corinthians 6 in the IRVT2
1 Corinthians 6 in the IRVU
1 Corinthians 6 in the ISVN
1 Corinthians 6 in the JSNT
1 Corinthians 6 in the KAPI
1 Corinthians 6 in the KBT1ETNIK
1 Corinthians 6 in the KBV
1 Corinthians 6 in the KJV
1 Corinthians 6 in the KNFD
1 Corinthians 6 in the LBA
1 Corinthians 6 in the LBLA
1 Corinthians 6 in the LNT
1 Corinthians 6 in the LSV
1 Corinthians 6 in the MAAL
1 Corinthians 6 in the MBV
1 Corinthians 6 in the MBV2
1 Corinthians 6 in the MHNT
1 Corinthians 6 in the MKNFD
1 Corinthians 6 in the MNG
1 Corinthians 6 in the MNT
1 Corinthians 6 in the MNT2
1 Corinthians 6 in the MRS1T
1 Corinthians 6 in the NAA
1 Corinthians 6 in the NASB
1 Corinthians 6 in the NBLA
1 Corinthians 6 in the NBS
1 Corinthians 6 in the NBVTP
1 Corinthians 6 in the NET2
1 Corinthians 6 in the NIV11
1 Corinthians 6 in the NNT
1 Corinthians 6 in the NNT2
1 Corinthians 6 in the NNT3
1 Corinthians 6 in the PDDPT
1 Corinthians 6 in the PFNT
1 Corinthians 6 in the RMNT
1 Corinthians 6 in the SBIAS
1 Corinthians 6 in the SBIBS
1 Corinthians 6 in the SBIBS2
1 Corinthians 6 in the SBICS
1 Corinthians 6 in the SBIDS
1 Corinthians 6 in the SBIGS
1 Corinthians 6 in the SBIHS
1 Corinthians 6 in the SBIIS
1 Corinthians 6 in the SBIIS2
1 Corinthians 6 in the SBIIS3
1 Corinthians 6 in the SBIKS
1 Corinthians 6 in the SBIKS2
1 Corinthians 6 in the SBIMS
1 Corinthians 6 in the SBIOS
1 Corinthians 6 in the SBIPS
1 Corinthians 6 in the SBISS
1 Corinthians 6 in the SBITS
1 Corinthians 6 in the SBITS2
1 Corinthians 6 in the SBITS3
1 Corinthians 6 in the SBITS4
1 Corinthians 6 in the SBIUS
1 Corinthians 6 in the SBIVS
1 Corinthians 6 in the SBT
1 Corinthians 6 in the SBT1E
1 Corinthians 6 in the SCHL
1 Corinthians 6 in the SNT
1 Corinthians 6 in the SUSU
1 Corinthians 6 in the SUSU2
1 Corinthians 6 in the SYNO
1 Corinthians 6 in the TBIAOTANT
1 Corinthians 6 in the TBT1E
1 Corinthians 6 in the TBT1E2
1 Corinthians 6 in the TFTIP
1 Corinthians 6 in the TFTU
1 Corinthians 6 in the TGNTATF3T
1 Corinthians 6 in the THAI
1 Corinthians 6 in the TNFD
1 Corinthians 6 in the TNT
1 Corinthians 6 in the TNTIK
1 Corinthians 6 in the TNTIL
1 Corinthians 6 in the TNTIN
1 Corinthians 6 in the TNTIP
1 Corinthians 6 in the TNTIZ
1 Corinthians 6 in the TOMA
1 Corinthians 6 in the TTENT
1 Corinthians 6 in the UBG
1 Corinthians 6 in the UGV
1 Corinthians 6 in the UGV2
1 Corinthians 6 in the UGV3
1 Corinthians 6 in the VBL
1 Corinthians 6 in the VDCC
1 Corinthians 6 in the YALU
1 Corinthians 6 in the YAPE
1 Corinthians 6 in the YBVTP
1 Corinthians 6 in the ZBP