1 Corinthians 8 (BOYCB)
1 Ní ìsinsin yìí, nípa tí oúnjẹ ti a fi rú ẹbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé gbogbo wa ni a ní ìmọ̀. Imọ̀ a máa fẹ́ mu ní gbéraga, ṣùgbọ́n ìfẹ́ ní gbé ni ró. 2 Bí ẹnikẹ́ni bá ró pé òun mọ ohun kan, kò tí ì mọ̀ bí ó ti yẹ kí ó mọ̀. 3 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó fẹ́ràn Ọlọ́run nítòótọ́, òun ni ẹni tí Ọlọ́run mọ. 4 Nítorí náà, ǹjẹ́ ó yẹ kí a jẹ àwọn oúnjẹ ti a fi rú ẹbọ sí àwọn òrìṣà bí? Láìṣe àní àní, gbogbo wá mọ̀ pé àwọn ère òrìṣà kì í ṣe Ọlọ́run rárá, ohun asán ni wọn ni ayé. A sì mọ̀ dájúdájú pé Ọlọ́run kan ṣoṣo ní ń bẹ, kò sì ṣí ọlọ́run mìíràn bí kò ṣe ọ̀kan ṣoṣo. 5 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, à ní ọ̀pọ̀ ọlọ́run kéékèèké mìíràn ní ọ̀run àti ní ayé (gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ “ọlọ́run” ṣe wa náà ní ọ̀pọ̀ “olúwa” wa). 6 Ṣùgbọ́n fún àwa Ọlọ́run kan ní ó wa, Baba, lọ́wọ́ ẹni tí ó dá ohun gbogbo, àti ti ẹni tí gbogbo wa í ṣe, àti Olúwa kan ṣoṣo Jesu Kristi, nípasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo wà, àti àwa nípasẹ̀ rẹ̀. 7 Ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo ènìyàn lo mọ èyí. Ṣùgbọ́n àwọn ẹlòmíràn tí ó ti ń bọ̀rìṣà lọ́jọ́ tó ti pẹ́ títí di ìsinsin yìí jẹ ẹ́ bí ohun tí a fi rú ẹbọ sí òrìṣà, àti ẹ̀rí ọkàn wọn tí ó ṣe àìlera sì di aláìmọ́. 8 Ṣùgbọ́n oúnjẹ kò mú wa súnmọ́ Ọlọ́run, nítorí pé kì í ṣe bí àwa bá jẹun ni àwa burú jùlọ tàbí nígbà tí a kò jẹ ni àwa dára jùlọ. 9 Ṣùgbọ́n ẹ máa kíyèsi ara gidigidi nípa ìlò òmìnira yín kí ẹ má ba à mú kí àwọn arákùnrin mìíràn tí í ṣe onígbàgbọ́, tí ọkàn wọn ṣe aláìlera, ṣubú sínú ẹ̀ṣẹ̀. 10 Ẹ kíyèsára, nítorí bi ẹnìkan ba rí i ti ìwọ ti o ni ìmọ̀ bá jókòó ti oúnjẹ ní ilé òrìṣà, ǹjẹ́ òun kò ha ni mú ọkàn le, bi ẹ̀rí ọkàn rẹ̀ bá ṣe aláìlera, láti jẹ oúnjẹ tí a fi rú ẹbọ sí òrìṣà? 11 Nítorí náà, nípa ìmọ̀ rẹ ni arákùnrin aláìlera náà yóò ṣe ṣègbé, arákùnrin ẹni tí Kristi kú fún. 12 Bí ẹ bá dẹ́ṣẹ̀ sí arákùnrin rẹ̀ tí ẹ sì ń pa ọkàn àìlera wọn lára, ẹ̀yìn ǹ dẹ́ṣẹ̀ sí Kristi jùlọ. 13 Nítorí nà án, bí oúnjẹ bá mú arákùnrin mi kọsẹ̀, èmi kì yóò sì jẹ ẹran mọ́ títí láé, kí èmi má ba à mú arákùnrin mi kọsẹ̀.
In Other Versions
1 Corinthians 8 in the ANGEFD
1 Corinthians 8 in the ANTPNG2D
1 Corinthians 8 in the AS21
1 Corinthians 8 in the BAGH
1 Corinthians 8 in the BBPNG
1 Corinthians 8 in the BBT1E
1 Corinthians 8 in the BDS
1 Corinthians 8 in the BEV
1 Corinthians 8 in the BHAD
1 Corinthians 8 in the BIB
1 Corinthians 8 in the BLPT
1 Corinthians 8 in the BNT
1 Corinthians 8 in the BNTABOOT
1 Corinthians 8 in the BNTLV
1 Corinthians 8 in the BOATCB
1 Corinthians 8 in the BOATCB2
1 Corinthians 8 in the BOBCV
1 Corinthians 8 in the BOCNT
1 Corinthians 8 in the BOECS
1 Corinthians 8 in the BOGWICC
1 Corinthians 8 in the BOHCB
1 Corinthians 8 in the BOHCV
1 Corinthians 8 in the BOHLNT
1 Corinthians 8 in the BOHNTLTAL
1 Corinthians 8 in the BOICB
1 Corinthians 8 in the BOILNTAP
1 Corinthians 8 in the BOITCV
1 Corinthians 8 in the BOKCV
1 Corinthians 8 in the BOKCV2
1 Corinthians 8 in the BOKHWOG
1 Corinthians 8 in the BOKSSV
1 Corinthians 8 in the BOLCB
1 Corinthians 8 in the BOLCB2
1 Corinthians 8 in the BOMCV
1 Corinthians 8 in the BONAV
1 Corinthians 8 in the BONCB
1 Corinthians 8 in the BONLT
1 Corinthians 8 in the BONUT2
1 Corinthians 8 in the BOPLNT
1 Corinthians 8 in the BOSCB
1 Corinthians 8 in the BOSNC
1 Corinthians 8 in the BOTLNT
1 Corinthians 8 in the BOVCB
1 Corinthians 8 in the BPBB
1 Corinthians 8 in the BPH
1 Corinthians 8 in the BSB
1 Corinthians 8 in the CCB
1 Corinthians 8 in the CUV
1 Corinthians 8 in the CUVS
1 Corinthians 8 in the DBT
1 Corinthians 8 in the DGDNT
1 Corinthians 8 in the DHNT
1 Corinthians 8 in the DNT
1 Corinthians 8 in the ELBE
1 Corinthians 8 in the EMTV
1 Corinthians 8 in the ESV
1 Corinthians 8 in the FBV
1 Corinthians 8 in the FEB
1 Corinthians 8 in the GGMNT
1 Corinthians 8 in the GNT
1 Corinthians 8 in the HARY
1 Corinthians 8 in the HNT
1 Corinthians 8 in the IRVA
1 Corinthians 8 in the IRVB
1 Corinthians 8 in the IRVG
1 Corinthians 8 in the IRVH
1 Corinthians 8 in the IRVK
1 Corinthians 8 in the IRVM
1 Corinthians 8 in the IRVM2
1 Corinthians 8 in the IRVO
1 Corinthians 8 in the IRVP
1 Corinthians 8 in the IRVT
1 Corinthians 8 in the IRVT2
1 Corinthians 8 in the IRVU
1 Corinthians 8 in the ISVN
1 Corinthians 8 in the JSNT
1 Corinthians 8 in the KAPI
1 Corinthians 8 in the KBT1ETNIK
1 Corinthians 8 in the KBV
1 Corinthians 8 in the KJV
1 Corinthians 8 in the KNFD
1 Corinthians 8 in the LBA
1 Corinthians 8 in the LBLA
1 Corinthians 8 in the LNT
1 Corinthians 8 in the LSV
1 Corinthians 8 in the MAAL
1 Corinthians 8 in the MBV
1 Corinthians 8 in the MBV2
1 Corinthians 8 in the MHNT
1 Corinthians 8 in the MKNFD
1 Corinthians 8 in the MNG
1 Corinthians 8 in the MNT
1 Corinthians 8 in the MNT2
1 Corinthians 8 in the MRS1T
1 Corinthians 8 in the NAA
1 Corinthians 8 in the NASB
1 Corinthians 8 in the NBLA
1 Corinthians 8 in the NBS
1 Corinthians 8 in the NBVTP
1 Corinthians 8 in the NET2
1 Corinthians 8 in the NIV11
1 Corinthians 8 in the NNT
1 Corinthians 8 in the NNT2
1 Corinthians 8 in the NNT3
1 Corinthians 8 in the PDDPT
1 Corinthians 8 in the PFNT
1 Corinthians 8 in the RMNT
1 Corinthians 8 in the SBIAS
1 Corinthians 8 in the SBIBS
1 Corinthians 8 in the SBIBS2
1 Corinthians 8 in the SBICS
1 Corinthians 8 in the SBIDS
1 Corinthians 8 in the SBIGS
1 Corinthians 8 in the SBIHS
1 Corinthians 8 in the SBIIS
1 Corinthians 8 in the SBIIS2
1 Corinthians 8 in the SBIIS3
1 Corinthians 8 in the SBIKS
1 Corinthians 8 in the SBIKS2
1 Corinthians 8 in the SBIMS
1 Corinthians 8 in the SBIOS
1 Corinthians 8 in the SBIPS
1 Corinthians 8 in the SBISS
1 Corinthians 8 in the SBITS
1 Corinthians 8 in the SBITS2
1 Corinthians 8 in the SBITS3
1 Corinthians 8 in the SBITS4
1 Corinthians 8 in the SBIUS
1 Corinthians 8 in the SBIVS
1 Corinthians 8 in the SBT
1 Corinthians 8 in the SBT1E
1 Corinthians 8 in the SCHL
1 Corinthians 8 in the SNT
1 Corinthians 8 in the SUSU
1 Corinthians 8 in the SUSU2
1 Corinthians 8 in the SYNO
1 Corinthians 8 in the TBIAOTANT
1 Corinthians 8 in the TBT1E
1 Corinthians 8 in the TBT1E2
1 Corinthians 8 in the TFTIP
1 Corinthians 8 in the TFTU
1 Corinthians 8 in the TGNTATF3T
1 Corinthians 8 in the THAI
1 Corinthians 8 in the TNFD
1 Corinthians 8 in the TNT
1 Corinthians 8 in the TNTIK
1 Corinthians 8 in the TNTIL
1 Corinthians 8 in the TNTIN
1 Corinthians 8 in the TNTIP
1 Corinthians 8 in the TNTIZ
1 Corinthians 8 in the TOMA
1 Corinthians 8 in the TTENT
1 Corinthians 8 in the UBG
1 Corinthians 8 in the UGV
1 Corinthians 8 in the UGV2
1 Corinthians 8 in the UGV3
1 Corinthians 8 in the VBL
1 Corinthians 8 in the VDCC
1 Corinthians 8 in the YALU
1 Corinthians 8 in the YAPE
1 Corinthians 8 in the YBVTP
1 Corinthians 8 in the ZBP