1 John 5 (BOYCB)
1 Olúkúlùkù ẹni tí ó bá gbàgbọ́ pé Jesu ni Kristi, a bí i nípa ti Ọlọ́run: àti olúkúlùkù ẹni tí ó fẹ́ràn. Ẹni tí ó bi nì, ó fẹ́ràn ẹni tí a bí nípasẹ̀ rẹ̀ pẹ̀lú. 2 Nípa èyí ni àwa mọ̀ pé àwa fẹ́ràn àwọn ọmọ Ọlọ́run, nígbà tí a bá fẹ́ràn Ọlọ́run, tí a sì ń pa òfin rẹ̀ mọ́. 3 Nítorí èyí ni ìfẹ́ Ọlọ́run, pé kí àwa pa òfin rẹ̀ mọ́: òfin rẹ̀ kò sì nira, 4 nítorí olúkúlùkù ẹni tí a bí nípa tí Ọlọ́run, ó ṣẹ́gun ayé. Èyí sì ni ìṣẹ́gun tí ó ṣẹ́gun ayé, àní ìgbàgbọ́ wa. 5 Ta ni ẹni tí ó ṣẹ́gun ayé, bí kò ṣe ẹni tí ó gbàgbọ́ pé Ọmọ Ọlọ́run ni Jesu jẹ́? 6 Èyí ni ẹni tí ó wá nípa omi àti ẹ̀jẹ̀, Jesu Kristi, kì í ṣe nípa omi nìkan, bí kò ṣe nípa omi àti ẹ̀jẹ̀. Àti pé Ẹ̀mí ni ó sì ń jẹ́rìí, nítorí pé òtítọ́ ni Ẹ̀mí. 7 Nítorí pé àwọn mẹ́ta ni ó ń jẹ́rìí. 8 Ẹ̀mí, omi, àti ẹ̀jẹ̀: àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì wà ni ìṣọ̀kan. 9 Bí àwa ba ń gba ẹ̀rí ènìyàn, ẹ̀rí Ọlọ́run tóbi jù: nítorí ẹ̀rí Ọlọ́run ni èyí pé, Ó tí jẹ́rìí ní ti Ọmọ rẹ̀. 10 Ẹni tí ó bá gba Ọmọ Ọlọ́run gbọ́, ó ni ẹ̀rí nínú ara rẹ̀; ẹni tí kò bá gba Ọlọ́run gbọ́, ó ti mú un ni èké; nítorí kò gba ẹ̀rí náà gbọ́ tí Ọlọ́run jẹ́ ní ti Ọmọ rẹ̀. 11 Ẹ̀rí náà sì ni èyí pé Ọlọ́run fún wa ní ìyè àìnípẹ̀kun, ìyè yìí sì ń bẹ nínú Ọmọ rẹ̀. 12 Ẹni tí ó bá ni Ọmọ, ó ni ìyè; ẹni tí kò bá sì ni Ọmọ Ọlọ́run, kò ní ìyè. 13 Nǹkan wọ̀nyí ni mo kọ̀wé rẹ̀ sí yín, àní sí ẹ̀yin tí ó gba orúkọ Ọmọ Ọlọ́run gbọ́; kí ẹ̀yin lè mọ̀ pé ẹ̀yin ní ìyè àìnípẹ̀kun, àní fún ẹ̀yin tí ó gba orúkọ Ọmọ Ọlọ́run gbọ́. 14 Èyí sì ni ìgboyà tí àwa ní níwájú rẹ̀, pé bí àwa bá béèrè ohunkóhun gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, ó ń gbọ́ tí wa. 15 Bí àwa bá sì mọ̀ pé ó ń gbọ́ tí wa, ohunkóhun tí àwa bá béèrè, àwa mọ̀ pé àwa rí ìbéèrè tí àwa ti béèrè lọ́dọ̀ rẹ̀ gbà. 16 Bí ẹnikẹ́ni bá rí arákùnrin rẹ̀ tí ń dẹ́ṣẹ̀ tí kì í ṣe sí ikú, òun yóò béèrè, Ọlọ́run yóò sì fún un ni ìyè, àní, fún àwọn tí ń dẹ́ṣẹ̀ tí kì í ṣe sí ikú. Ẹ̀ṣẹ̀ kan ń bẹ sì ikú, èmi kò wí pé ki òun gbàdúrà fún èyí. 17 Gbogbo àìṣòdodo ni ẹ̀ṣẹ̀, ẹ̀ṣẹ̀ kan ń bẹ tí kì í ṣe sí ikú. 18 Àwa mọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí a bí nípa ti Ọlọ́run kì í dẹ́ṣẹ̀: ṣùgbọ́n ẹni tí a bí nípa tí Ọlọ́run a pa ara rẹ̀ mọ́, ẹni búburú kò ní lè fọwọ́ kàn án. 19 Àwa mọ̀ pé tí Ọlọ́run ni wá, àti gbogbo ayé ni ó wà lábẹ́ agbára ẹni búburú náà. 20 Àwa sì mọ̀ pé Ọmọ Ọlọ́run dé, ó sì tí fi òye fún wa, kí àwa lè mọ ẹni tí í ṣe òtítọ́, àwa sì ń bẹ nínú ẹni tí í ṣe òtítọ́, àní, nínú Ọmọ rẹ̀, Jesu Kristi. Èyí ni Ọlọ́run òtítọ́, àti ìyè àìnípẹ̀kun. 21 Ẹ̀yin ọmọ mi, ẹ pa ara yín mọ́ kúrò nínú òrìṣà.
In Other Versions
1 John 5 in the ANGEFD
1 John 5 in the ANTPNG2D
1 John 5 in the AS21
1 John 5 in the BAGH
1 John 5 in the BBPNG
1 John 5 in the BBT1E
1 John 5 in the BDS
1 John 5 in the BEV
1 John 5 in the BHAD
1 John 5 in the BIB
1 John 5 in the BLPT
1 John 5 in the BNT
1 John 5 in the BNTABOOT
1 John 5 in the BNTLV
1 John 5 in the BOATCB
1 John 5 in the BOATCB2
1 John 5 in the BOBCV
1 John 5 in the BOCNT
1 John 5 in the BOECS
1 John 5 in the BOGWICC
1 John 5 in the BOHCB
1 John 5 in the BOHCV
1 John 5 in the BOHLNT
1 John 5 in the BOHNTLTAL
1 John 5 in the BOICB
1 John 5 in the BOILNTAP
1 John 5 in the BOITCV
1 John 5 in the BOKCV
1 John 5 in the BOKCV2
1 John 5 in the BOKHWOG
1 John 5 in the BOKSSV
1 John 5 in the BOLCB
1 John 5 in the BOLCB2
1 John 5 in the BOMCV
1 John 5 in the BONAV
1 John 5 in the BONCB
1 John 5 in the BONLT
1 John 5 in the BONUT2
1 John 5 in the BOPLNT
1 John 5 in the BOSCB
1 John 5 in the BOSNC
1 John 5 in the BOTLNT
1 John 5 in the BOVCB
1 John 5 in the BPBB
1 John 5 in the BPH
1 John 5 in the BSB
1 John 5 in the CCB
1 John 5 in the CUV
1 John 5 in the CUVS
1 John 5 in the DBT
1 John 5 in the DGDNT
1 John 5 in the DHNT
1 John 5 in the DNT
1 John 5 in the ELBE
1 John 5 in the EMTV
1 John 5 in the ESV
1 John 5 in the FBV
1 John 5 in the FEB
1 John 5 in the GGMNT
1 John 5 in the GNT
1 John 5 in the HARY
1 John 5 in the HNT
1 John 5 in the IRVA
1 John 5 in the IRVB
1 John 5 in the IRVG
1 John 5 in the IRVH
1 John 5 in the IRVK
1 John 5 in the IRVM
1 John 5 in the IRVM2
1 John 5 in the IRVO
1 John 5 in the IRVP
1 John 5 in the IRVT
1 John 5 in the IRVT2
1 John 5 in the IRVU
1 John 5 in the ISVN
1 John 5 in the JSNT
1 John 5 in the KAPI
1 John 5 in the KBT1ETNIK
1 John 5 in the KBV
1 John 5 in the KJV
1 John 5 in the KNFD
1 John 5 in the LBA
1 John 5 in the LBLA
1 John 5 in the LNT
1 John 5 in the LSV
1 John 5 in the MAAL
1 John 5 in the MBV
1 John 5 in the MBV2
1 John 5 in the MHNT
1 John 5 in the MKNFD
1 John 5 in the MNG
1 John 5 in the MNT
1 John 5 in the MNT2
1 John 5 in the MRS1T
1 John 5 in the NAA
1 John 5 in the NASB
1 John 5 in the NBLA
1 John 5 in the NBS
1 John 5 in the NBVTP
1 John 5 in the NET2
1 John 5 in the NIV11
1 John 5 in the NNT
1 John 5 in the NNT2
1 John 5 in the NNT3
1 John 5 in the PDDPT
1 John 5 in the PFNT
1 John 5 in the RMNT
1 John 5 in the SBIAS
1 John 5 in the SBIBS
1 John 5 in the SBIBS2
1 John 5 in the SBICS
1 John 5 in the SBIDS
1 John 5 in the SBIGS
1 John 5 in the SBIHS
1 John 5 in the SBIIS
1 John 5 in the SBIIS2
1 John 5 in the SBIIS3
1 John 5 in the SBIKS
1 John 5 in the SBIKS2
1 John 5 in the SBIMS
1 John 5 in the SBIOS
1 John 5 in the SBIPS
1 John 5 in the SBISS
1 John 5 in the SBITS
1 John 5 in the SBITS2
1 John 5 in the SBITS3
1 John 5 in the SBITS4
1 John 5 in the SBIUS
1 John 5 in the SBIVS
1 John 5 in the SBT
1 John 5 in the SBT1E
1 John 5 in the SCHL
1 John 5 in the SNT
1 John 5 in the SUSU
1 John 5 in the SUSU2
1 John 5 in the SYNO
1 John 5 in the TBIAOTANT
1 John 5 in the TBT1E
1 John 5 in the TBT1E2
1 John 5 in the TFTIP
1 John 5 in the TFTU
1 John 5 in the TGNTATF3T
1 John 5 in the THAI
1 John 5 in the TNFD
1 John 5 in the TNT
1 John 5 in the TNTIK
1 John 5 in the TNTIL
1 John 5 in the TNTIN
1 John 5 in the TNTIP
1 John 5 in the TNTIZ
1 John 5 in the TOMA
1 John 5 in the TTENT
1 John 5 in the UBG
1 John 5 in the UGV
1 John 5 in the UGV2
1 John 5 in the UGV3
1 John 5 in the VBL
1 John 5 in the VDCC
1 John 5 in the YALU
1 John 5 in the YAPE
1 John 5 in the YBVTP
1 John 5 in the ZBP