2 Chronicles 3 (BOYCB)
1 Nígbà náà, Solomoni bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé OLÚWA ní Jerusalẹmu lórí òkè Moria, níbi tí OLÚWA ti farahan baba a rẹ̀ Dafidi. Ní orí ilẹ̀ ìpakà Arauna ará Jebusi, ibi tí Dafidi pèsè. 2 Ó bẹ̀rẹ̀ sí kíkọ́ rẹ̀ ní ọjọ́ kejì oṣù kejì ní ọdún kẹrin ìjọba rẹ̀. 3 Ìpìlẹ̀ tí Solomoni gbé kalẹ̀ fún kíkọ́ ilé Ọlọ́run jẹ́ ọgọ́ta gígùn ìgbọ̀nwọ́ àti ogún fífẹ̀ ìgbọ̀nwọ́. 4 Ìloro tí ó wà níwájú ilé OLÚWA náà jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn rékọjá fífẹ̀ ilé náà àti gíga rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn rékọjá fífẹ̀ ilé náà àti gíga rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́.Ó tẹ́ inú rẹ̀ pẹ̀lú kìkì wúrà. 5 Ó fi igi firi bo ilé yàrá ńlá náà ó sì bò ó pẹ̀lú kìkì wúrà, ó sì ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú igi ọ̀pẹ àti àwòrán ẹ̀wọ̀n. 6 Ó ṣe ilé OLÚWA náà lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú òkúta iyebíye. Wúrà tí ó lò jẹ́ wúrà parifaimu. 7 Ó tẹ́ àjà ilé náà pẹ̀lú ìtí igi àti ìlẹ̀kùn ògiri àti àwọn ìlẹ̀kùn ilé OLÚWA pẹ̀lú wúrà, ó sì gbẹ́ àwòrán kérúbù sára ògiri. 8 Ó kọ́ Ibi Mímọ́ Jùlọ, gígùn rẹ̀ bá fífẹ̀ ilé OLÚWA mu, ogún ìgbọ̀nwọ́ fún gígùn, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́, ó tẹ́ inú rẹ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ̀ta (600) tálẹ́ǹtì ti wúrà dáradára. 9 Ìwọ̀n àwọn ìṣó náà jẹ́ àádọ́ta ṣékélì. Ó tẹ́ àwọn apẹ òkè pẹ̀lú wúrà. 10 Ní Ibi Mímọ́ Jùlọ, ó gbẹ́ àwòrán igi kérúbù kan, ó sì tẹ́ wọn pẹ̀lú wúrà. 11 Iye ìyẹ́ apá ìbú àtẹ́lẹwọ́ lápapọ̀ ní ti kérúbù, jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ ọ̀kan nínú ìyẹ́ apá ti kérúbù àkọ́kọ́ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní gígùn, ó sì farakan ògiri ilé OLÚWA. Nígbà tí ìyẹ́ apá kejì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní gígùn ó sì, farakan ìyẹ́ apá kérúbù mìíràn. 12 Ní ìjọra, ìyẹ́ apá kan ti kérúbù kejì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní gígùn, ó sì farakan ògiri ilé OLÚWA mìíràn; ìyẹ́ apá rẹ̀ mìíràn sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn ní gígùn pẹ̀lú tí ó farakan ìyẹ́ apá kérúbù àkọ́kọ́. 13 Ìyẹ́ apá àwọn kérúbù wọ̀nyí gbà tó ogún ìgbọ̀nwọ́. Wọ́n dúró ní ẹsẹ̀ wọn, wọ́n kọjú sí yàrá pàtàkì ńlá náà. 14 Ó ṣe aṣọ títa ní àwọ̀ ojú ọ̀run, àwọ̀ àlùkò àti àwọ̀ pupa fòò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ pẹ̀lú kérúbù tí a ṣe sórí i rẹ̀. 15 Níwájú ilé OLÚWA náà ó ṣe òpó méjì tí lápapọ̀ jẹ́ márùn-ún dín lógójì ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, olúkúlùkù pẹ̀lú olórí lórí rẹ̀ tí o ń wọn ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún. 16 Ó ṣe ẹ̀wọ̀n tí a hun wọ inú ara wọn, ó gbé wọn ká orí òpó náà. Ó ṣe ọgọ́rùn-ún pomegiranate (orúkọ èso igi) ó sì so wọ́n mọ́ àwọn ẹ̀wọ̀n náà 17 Ó gbe òpó náà dúró níwájú ilé OLÚWA, ọ̀kan sí gúúsù, pẹ̀lú ọ̀kan sí àríwá. Èyí ti gúúsù, ó sọ ní Jakini àti èyí ti àríwá, ó sọ ní Boasi.
In Other Versions
2 Chronicles 3 in the ANGEFD
2 Chronicles 3 in the ANTPNG2D
2 Chronicles 3 in the AS21
2 Chronicles 3 in the BAGH
2 Chronicles 3 in the BBPNG
2 Chronicles 3 in the BBT1E
2 Chronicles 3 in the BDS
2 Chronicles 3 in the BEV
2 Chronicles 3 in the BHAD
2 Chronicles 3 in the BIB
2 Chronicles 3 in the BLPT
2 Chronicles 3 in the BNT
2 Chronicles 3 in the BNTABOOT
2 Chronicles 3 in the BNTLV
2 Chronicles 3 in the BOATCB
2 Chronicles 3 in the BOATCB2
2 Chronicles 3 in the BOBCV
2 Chronicles 3 in the BOCNT
2 Chronicles 3 in the BOECS
2 Chronicles 3 in the BOGWICC
2 Chronicles 3 in the BOHCB
2 Chronicles 3 in the BOHCV
2 Chronicles 3 in the BOHLNT
2 Chronicles 3 in the BOHNTLTAL
2 Chronicles 3 in the BOICB
2 Chronicles 3 in the BOILNTAP
2 Chronicles 3 in the BOITCV
2 Chronicles 3 in the BOKCV
2 Chronicles 3 in the BOKCV2
2 Chronicles 3 in the BOKHWOG
2 Chronicles 3 in the BOKSSV
2 Chronicles 3 in the BOLCB
2 Chronicles 3 in the BOLCB2
2 Chronicles 3 in the BOMCV
2 Chronicles 3 in the BONAV
2 Chronicles 3 in the BONCB
2 Chronicles 3 in the BONLT
2 Chronicles 3 in the BONUT2
2 Chronicles 3 in the BOPLNT
2 Chronicles 3 in the BOSCB
2 Chronicles 3 in the BOSNC
2 Chronicles 3 in the BOTLNT
2 Chronicles 3 in the BOVCB
2 Chronicles 3 in the BPBB
2 Chronicles 3 in the BPH
2 Chronicles 3 in the BSB
2 Chronicles 3 in the CCB
2 Chronicles 3 in the CUV
2 Chronicles 3 in the CUVS
2 Chronicles 3 in the DBT
2 Chronicles 3 in the DGDNT
2 Chronicles 3 in the DHNT
2 Chronicles 3 in the DNT
2 Chronicles 3 in the ELBE
2 Chronicles 3 in the EMTV
2 Chronicles 3 in the ESV
2 Chronicles 3 in the FBV
2 Chronicles 3 in the FEB
2 Chronicles 3 in the GGMNT
2 Chronicles 3 in the GNT
2 Chronicles 3 in the HARY
2 Chronicles 3 in the HNT
2 Chronicles 3 in the IRVA
2 Chronicles 3 in the IRVB
2 Chronicles 3 in the IRVG
2 Chronicles 3 in the IRVH
2 Chronicles 3 in the IRVK
2 Chronicles 3 in the IRVM
2 Chronicles 3 in the IRVM2
2 Chronicles 3 in the IRVO
2 Chronicles 3 in the IRVP
2 Chronicles 3 in the IRVT
2 Chronicles 3 in the IRVT2
2 Chronicles 3 in the IRVU
2 Chronicles 3 in the ISVN
2 Chronicles 3 in the JSNT
2 Chronicles 3 in the KAPI
2 Chronicles 3 in the KBT1ETNIK
2 Chronicles 3 in the KBV
2 Chronicles 3 in the KJV
2 Chronicles 3 in the KNFD
2 Chronicles 3 in the LBA
2 Chronicles 3 in the LBLA
2 Chronicles 3 in the LNT
2 Chronicles 3 in the LSV
2 Chronicles 3 in the MAAL
2 Chronicles 3 in the MBV
2 Chronicles 3 in the MBV2
2 Chronicles 3 in the MHNT
2 Chronicles 3 in the MKNFD
2 Chronicles 3 in the MNG
2 Chronicles 3 in the MNT
2 Chronicles 3 in the MNT2
2 Chronicles 3 in the MRS1T
2 Chronicles 3 in the NAA
2 Chronicles 3 in the NASB
2 Chronicles 3 in the NBLA
2 Chronicles 3 in the NBS
2 Chronicles 3 in the NBVTP
2 Chronicles 3 in the NET2
2 Chronicles 3 in the NIV11
2 Chronicles 3 in the NNT
2 Chronicles 3 in the NNT2
2 Chronicles 3 in the NNT3
2 Chronicles 3 in the PDDPT
2 Chronicles 3 in the PFNT
2 Chronicles 3 in the RMNT
2 Chronicles 3 in the SBIAS
2 Chronicles 3 in the SBIBS
2 Chronicles 3 in the SBIBS2
2 Chronicles 3 in the SBICS
2 Chronicles 3 in the SBIDS
2 Chronicles 3 in the SBIGS
2 Chronicles 3 in the SBIHS
2 Chronicles 3 in the SBIIS
2 Chronicles 3 in the SBIIS2
2 Chronicles 3 in the SBIIS3
2 Chronicles 3 in the SBIKS
2 Chronicles 3 in the SBIKS2
2 Chronicles 3 in the SBIMS
2 Chronicles 3 in the SBIOS
2 Chronicles 3 in the SBIPS
2 Chronicles 3 in the SBISS
2 Chronicles 3 in the SBITS
2 Chronicles 3 in the SBITS2
2 Chronicles 3 in the SBITS3
2 Chronicles 3 in the SBITS4
2 Chronicles 3 in the SBIUS
2 Chronicles 3 in the SBIVS
2 Chronicles 3 in the SBT
2 Chronicles 3 in the SBT1E
2 Chronicles 3 in the SCHL
2 Chronicles 3 in the SNT
2 Chronicles 3 in the SUSU
2 Chronicles 3 in the SUSU2
2 Chronicles 3 in the SYNO
2 Chronicles 3 in the TBIAOTANT
2 Chronicles 3 in the TBT1E
2 Chronicles 3 in the TBT1E2
2 Chronicles 3 in the TFTIP
2 Chronicles 3 in the TFTU
2 Chronicles 3 in the TGNTATF3T
2 Chronicles 3 in the THAI
2 Chronicles 3 in the TNFD
2 Chronicles 3 in the TNT
2 Chronicles 3 in the TNTIK
2 Chronicles 3 in the TNTIL
2 Chronicles 3 in the TNTIN
2 Chronicles 3 in the TNTIP
2 Chronicles 3 in the TNTIZ
2 Chronicles 3 in the TOMA
2 Chronicles 3 in the TTENT
2 Chronicles 3 in the UBG
2 Chronicles 3 in the UGV
2 Chronicles 3 in the UGV2
2 Chronicles 3 in the UGV3
2 Chronicles 3 in the VBL
2 Chronicles 3 in the VDCC
2 Chronicles 3 in the YALU
2 Chronicles 3 in the YAPE
2 Chronicles 3 in the YBVTP
2 Chronicles 3 in the ZBP