2 Thessalonians 3 (BOYCB)

1 Ní àkótán, ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa, kí ọ̀rọ̀ Olúwa lè máa tàn káàkiri, kí ó sì jẹ́ èyí tí a bu ọlá fún, gẹ́gẹ́ bí ó ti rí ní ọ̀dọ̀ yín. 2 Kí ẹ sì máa gbàdúrà fún wa kí a lè bọ́ lọ́wọ́ àwọn ìkà àti àwọn ènìyàn búburú, nítorí pé kì í ṣe gbogbo ènìyàn ló ní ìgbàgbọ́. 3 Ṣùgbọ́n olódodo ni Olúwa, ẹni tí yóò fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóò sì pa yín mọ́ kúrò nínú ibi. 4 Àwa sì ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa ní ti ohun tí ẹ ń ṣe, àti pé àwọn nǹkan wọ̀n-ọn-nì tí a pàṣẹ fún un yín ni ẹ̀yin ń ṣe. 5 Kí Olúwa máa tọ́ ọkàn yín ṣọ́nà sí ìfẹ́ Ọlọ́run àti sínú sùúrù Kristi. 6 Ní orúkọ Jesu Kristi Olúwa wa, àwa pàṣẹ fún un yín ará, pé kí ẹ yẹra fún gbogbo àwọn arákùnrin yín tí ń ṣe ìmẹ́lẹ́, tí kò sì gbé ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀kọ́ tí ẹ gbà ní ọ̀dọ̀ wa. 7 Nítorí ẹ̀yin náà mọ̀ bí ó ṣe yẹ kí ẹ máa fi ara wé wa. Àwa kì í ṣe ìmẹ́lẹ́ nígbà tí a wà ní ọ̀dọ̀ yín. 8 Bẹ́ẹ̀ ni àwa kò sì jẹ oúnjẹ ẹnikẹ́ni lọ́fẹ̀ẹ́. Ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀, àwa ń ṣiṣẹ́ tọ̀sán tòru kí a má ba à di àjàgà sí ẹnikẹ́ni nínú yín lọ́rùn. 9 Àwa ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, kì í ṣe nítorí pé àwa kò ní ẹ̀tọ́ láti béèrè fún un, ṣùgbọ́n àwa ń fi ara wa ṣe àpẹẹrẹ tí ẹ ó tẹ̀lé. 10 Nítorí nígbà tí àwa wà lọ́dọ̀ yín, a ṣe àwọn òfin wọ̀nyí fún un yín pé, “Bí ẹnikẹ́ni kò bá fẹ́ ṣiṣẹ́, kí ó má ṣe jẹun.” 11 A gbọ́ pé àwọn kan wà láàrín yín tí wọn jẹ́ ìmẹ́lẹ́. Wọ́n jẹ́ atọjúlékiri. 12 Ǹjẹ́ irú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ ni àwa ń pàṣẹ fún, tí a sì ń rọ̀ nínú Jesu Kristi Olúwa pé kí wọn ó máa ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tí wọ́n ń jẹ. 13 Ṣùgbọ́n ní tiyín ará, ẹ má ṣe jẹ́ kí agara dá yín ní rere ṣíṣe. 14 Bí ẹnikẹ́ni kò bá sì pa òfin wa nínú lẹ́tà yìí mọ́, ẹ sàmì sí ẹni náà. Ẹ má ṣe bá a kẹ́gbẹ́ kí ojú bà á le tì í. 15 Síbẹ̀, ẹ má ṣe kà á sí ọ̀tá, ṣùgbọ́n ẹ máa kìlọ̀ fún un gẹ́gẹ́ bí arákùnrin yín. 16 Ǹjẹ́ kí Olúwa àlàáfíà, fúnra rẹ̀ máa fún yín ní àlàáfíà nígbà gbogbo. Kí Olúwa kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín. 17 Èmi Paulu fi ọwọ́ ara mi kọ lẹ́tà ìkíni yìí, èyí ṣe àmì ìdámọ̀ nínú gbogbo lẹ́tà. Bí mo ṣe máa ń kọ̀wé nìyìí. 18 Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú yín.

In Other Versions

2 Thessalonians 3 in the ANGEFD

2 Thessalonians 3 in the ANTPNG2D

2 Thessalonians 3 in the AS21

2 Thessalonians 3 in the BAGH

2 Thessalonians 3 in the BBPNG

2 Thessalonians 3 in the BBT1E

2 Thessalonians 3 in the BDS

2 Thessalonians 3 in the BEV

2 Thessalonians 3 in the BHAD

2 Thessalonians 3 in the BIB

2 Thessalonians 3 in the BLPT

2 Thessalonians 3 in the BNT

2 Thessalonians 3 in the BNTABOOT

2 Thessalonians 3 in the BNTLV

2 Thessalonians 3 in the BOATCB

2 Thessalonians 3 in the BOATCB2

2 Thessalonians 3 in the BOBCV

2 Thessalonians 3 in the BOCNT

2 Thessalonians 3 in the BOECS

2 Thessalonians 3 in the BOGWICC

2 Thessalonians 3 in the BOHCB

2 Thessalonians 3 in the BOHCV

2 Thessalonians 3 in the BOHLNT

2 Thessalonians 3 in the BOHNTLTAL

2 Thessalonians 3 in the BOICB

2 Thessalonians 3 in the BOILNTAP

2 Thessalonians 3 in the BOITCV

2 Thessalonians 3 in the BOKCV

2 Thessalonians 3 in the BOKCV2

2 Thessalonians 3 in the BOKHWOG

2 Thessalonians 3 in the BOKSSV

2 Thessalonians 3 in the BOLCB

2 Thessalonians 3 in the BOLCB2

2 Thessalonians 3 in the BOMCV

2 Thessalonians 3 in the BONAV

2 Thessalonians 3 in the BONCB

2 Thessalonians 3 in the BONLT

2 Thessalonians 3 in the BONUT2

2 Thessalonians 3 in the BOPLNT

2 Thessalonians 3 in the BOSCB

2 Thessalonians 3 in the BOSNC

2 Thessalonians 3 in the BOTLNT

2 Thessalonians 3 in the BOVCB

2 Thessalonians 3 in the BPBB

2 Thessalonians 3 in the BPH

2 Thessalonians 3 in the BSB

2 Thessalonians 3 in the CCB

2 Thessalonians 3 in the CUV

2 Thessalonians 3 in the CUVS

2 Thessalonians 3 in the DBT

2 Thessalonians 3 in the DGDNT

2 Thessalonians 3 in the DHNT

2 Thessalonians 3 in the DNT

2 Thessalonians 3 in the ELBE

2 Thessalonians 3 in the EMTV

2 Thessalonians 3 in the ESV

2 Thessalonians 3 in the FBV

2 Thessalonians 3 in the FEB

2 Thessalonians 3 in the GGMNT

2 Thessalonians 3 in the GNT

2 Thessalonians 3 in the HARY

2 Thessalonians 3 in the HNT

2 Thessalonians 3 in the IRVA

2 Thessalonians 3 in the IRVB

2 Thessalonians 3 in the IRVG

2 Thessalonians 3 in the IRVH

2 Thessalonians 3 in the IRVK

2 Thessalonians 3 in the IRVM

2 Thessalonians 3 in the IRVM2

2 Thessalonians 3 in the IRVO

2 Thessalonians 3 in the IRVP

2 Thessalonians 3 in the IRVT

2 Thessalonians 3 in the IRVT2

2 Thessalonians 3 in the IRVU

2 Thessalonians 3 in the ISVN

2 Thessalonians 3 in the JSNT

2 Thessalonians 3 in the KAPI

2 Thessalonians 3 in the KBT1ETNIK

2 Thessalonians 3 in the KBV

2 Thessalonians 3 in the KJV

2 Thessalonians 3 in the KNFD

2 Thessalonians 3 in the LBA

2 Thessalonians 3 in the LBLA

2 Thessalonians 3 in the LNT

2 Thessalonians 3 in the LSV

2 Thessalonians 3 in the MAAL

2 Thessalonians 3 in the MBV

2 Thessalonians 3 in the MBV2

2 Thessalonians 3 in the MHNT

2 Thessalonians 3 in the MKNFD

2 Thessalonians 3 in the MNG

2 Thessalonians 3 in the MNT

2 Thessalonians 3 in the MNT2

2 Thessalonians 3 in the MRS1T

2 Thessalonians 3 in the NAA

2 Thessalonians 3 in the NASB

2 Thessalonians 3 in the NBLA

2 Thessalonians 3 in the NBS

2 Thessalonians 3 in the NBVTP

2 Thessalonians 3 in the NET2

2 Thessalonians 3 in the NIV11

2 Thessalonians 3 in the NNT

2 Thessalonians 3 in the NNT2

2 Thessalonians 3 in the NNT3

2 Thessalonians 3 in the PDDPT

2 Thessalonians 3 in the PFNT

2 Thessalonians 3 in the RMNT

2 Thessalonians 3 in the SBIAS

2 Thessalonians 3 in the SBIBS

2 Thessalonians 3 in the SBIBS2

2 Thessalonians 3 in the SBICS

2 Thessalonians 3 in the SBIDS

2 Thessalonians 3 in the SBIGS

2 Thessalonians 3 in the SBIHS

2 Thessalonians 3 in the SBIIS

2 Thessalonians 3 in the SBIIS2

2 Thessalonians 3 in the SBIIS3

2 Thessalonians 3 in the SBIKS

2 Thessalonians 3 in the SBIKS2

2 Thessalonians 3 in the SBIMS

2 Thessalonians 3 in the SBIOS

2 Thessalonians 3 in the SBIPS

2 Thessalonians 3 in the SBISS

2 Thessalonians 3 in the SBITS

2 Thessalonians 3 in the SBITS2

2 Thessalonians 3 in the SBITS3

2 Thessalonians 3 in the SBITS4

2 Thessalonians 3 in the SBIUS

2 Thessalonians 3 in the SBIVS

2 Thessalonians 3 in the SBT

2 Thessalonians 3 in the SBT1E

2 Thessalonians 3 in the SCHL

2 Thessalonians 3 in the SNT

2 Thessalonians 3 in the SUSU

2 Thessalonians 3 in the SUSU2

2 Thessalonians 3 in the SYNO

2 Thessalonians 3 in the TBIAOTANT

2 Thessalonians 3 in the TBT1E

2 Thessalonians 3 in the TBT1E2

2 Thessalonians 3 in the TFTIP

2 Thessalonians 3 in the TFTU

2 Thessalonians 3 in the TGNTATF3T

2 Thessalonians 3 in the THAI

2 Thessalonians 3 in the TNFD

2 Thessalonians 3 in the TNT

2 Thessalonians 3 in the TNTIK

2 Thessalonians 3 in the TNTIL

2 Thessalonians 3 in the TNTIN

2 Thessalonians 3 in the TNTIP

2 Thessalonians 3 in the TNTIZ

2 Thessalonians 3 in the TOMA

2 Thessalonians 3 in the TTENT

2 Thessalonians 3 in the UBG

2 Thessalonians 3 in the UGV

2 Thessalonians 3 in the UGV2

2 Thessalonians 3 in the UGV3

2 Thessalonians 3 in the VBL

2 Thessalonians 3 in the VDCC

2 Thessalonians 3 in the YALU

2 Thessalonians 3 in the YAPE

2 Thessalonians 3 in the YBVTP

2 Thessalonians 3 in the ZBP