Amos 2 (BOYCB)

1 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí,“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Moabu,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà,nítorí ó ti sun ún, di eérú,egungun ọba Edomu, 2 Èmi yóò rán iná sí orí Moabuèyí tí yóò jó àwọn ààfin Kerioti run.Moabu yóò sì kú pẹ̀lú ariwopẹ̀lú igbe àti pẹ̀lú ìró ìpè. 3 Èmi yóò ké onídàájọ́ rẹ̀ kúrò,Èmi yóò sì pa gbogbo àwọn ọmọ-aládé rẹ́ nínú rẹ̀,”ni OLÚWA wí. 4 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí,“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Juda,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Nítorí wọn ti kọ òfin OLÚWA sílẹ̀,wọn kò sì pa àwọn ìlànà rẹ̀ mọ́.Nítorí àwọn òrìṣà ti sì wọ́n lọ́nà,òrìṣà tí àwọn Baba ńlá wọn ń tẹ̀lé, 5 Èmi yóò rán iná sí orí Judaèyí tí yóò jó àwọn ààfin Jerusalẹmu run.” 6 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta Israẹliàní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà.Wọ́n ta olódodo fún fàdákààti aláìní fún bàtà ẹsẹ̀ méjèèjì. 7 Wọ́n fi ẹsẹ̀ tẹ orí àwọn tálákà mọ́lẹ̀,bí wọ́n ti ń tẹ erùpẹ̀ ilẹ̀tí wọ́n ko sì ṣe òtítọ́ si àwọn tí a ni lára.Baba àti ọmọ ń wọlé tọ wúńdíá kan náà,láti ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́. 8 Wọ́n dùbúlẹ̀ lẹ́bàá a pẹpẹ,lórí aṣọ tí wọ́n fi jẹ́ ẹ̀jẹ́ní ilé òrìṣà wọnwọ́n sì mu ọtí tí wọ́n san fún ìtánràn. 9 “Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọngíga ẹni tí ó dàbí igi kedari.Òun sì le koko bí igi óákùmo pa èso rẹ̀ run láti òkè wáàti egbò rẹ̀ láti ìsàlẹ̀ wá. 10 Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá,mo sì sìn yín la aginjù já ní ogójì ọdúnláti fi ilẹ̀ àwọn ará Amori fún un yín. 11 “Èmi sì tún gbé àwọn wòlíì dìde láàrín àwọn ọmọ yínàti láàrín àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín láti jẹ Nasirièyí kò ha jẹ́ òtítọ́ bí ará Israẹli?”ni OLÚWA wí. 12 “Ṣùgbọ́n ẹ̀yin fún àwọn Nasiri ní ọtí mue sì pàṣẹ fún àwọn wòlíì kí wọ́n má ṣe sọtẹ́lẹ̀. 13 “Ní báyìí, èmi yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀bí kẹ̀kẹ́ tí ó kún fún ìtí ti í tẹ̀. 14 Ẹni tí ó yára bí àṣá kò ní rí ọ̀nà àbáyọalágbára kò ní le è dúró lé agbára rẹ̀jagunjagun kì yóò le gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là. 15 Tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó gún ẹṣinkì yóò gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là. 16 Àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọyóò sálọ ní ìhòhò ní ọjọ́ náà,”ni OLÚWA wí.

In Other Versions

Amos 2 in the ANGEFD

Amos 2 in the ANTPNG2D

Amos 2 in the AS21

Amos 2 in the BAGH

Amos 2 in the BBPNG

Amos 2 in the BBT1E

Amos 2 in the BDS

Amos 2 in the BEV

Amos 2 in the BHAD

Amos 2 in the BIB

Amos 2 in the BLPT

Amos 2 in the BNT

Amos 2 in the BNTABOOT

Amos 2 in the BNTLV

Amos 2 in the BOATCB

Amos 2 in the BOATCB2

Amos 2 in the BOBCV

Amos 2 in the BOCNT

Amos 2 in the BOECS

Amos 2 in the BOGWICC

Amos 2 in the BOHCB

Amos 2 in the BOHCV

Amos 2 in the BOHLNT

Amos 2 in the BOHNTLTAL

Amos 2 in the BOICB

Amos 2 in the BOILNTAP

Amos 2 in the BOITCV

Amos 2 in the BOKCV

Amos 2 in the BOKCV2

Amos 2 in the BOKHWOG

Amos 2 in the BOKSSV

Amos 2 in the BOLCB

Amos 2 in the BOLCB2

Amos 2 in the BOMCV

Amos 2 in the BONAV

Amos 2 in the BONCB

Amos 2 in the BONLT

Amos 2 in the BONUT2

Amos 2 in the BOPLNT

Amos 2 in the BOSCB

Amos 2 in the BOSNC

Amos 2 in the BOTLNT

Amos 2 in the BOVCB

Amos 2 in the BPBB

Amos 2 in the BPH

Amos 2 in the BSB

Amos 2 in the CCB

Amos 2 in the CUV

Amos 2 in the CUVS

Amos 2 in the DBT

Amos 2 in the DGDNT

Amos 2 in the DHNT

Amos 2 in the DNT

Amos 2 in the ELBE

Amos 2 in the EMTV

Amos 2 in the ESV

Amos 2 in the FBV

Amos 2 in the FEB

Amos 2 in the GGMNT

Amos 2 in the GNT

Amos 2 in the HARY

Amos 2 in the HNT

Amos 2 in the IRVA

Amos 2 in the IRVB

Amos 2 in the IRVG

Amos 2 in the IRVH

Amos 2 in the IRVK

Amos 2 in the IRVM

Amos 2 in the IRVM2

Amos 2 in the IRVO

Amos 2 in the IRVP

Amos 2 in the IRVT

Amos 2 in the IRVT2

Amos 2 in the IRVU

Amos 2 in the ISVN

Amos 2 in the JSNT

Amos 2 in the KAPI

Amos 2 in the KBT1ETNIK

Amos 2 in the KBV

Amos 2 in the KJV

Amos 2 in the KNFD

Amos 2 in the LBA

Amos 2 in the LBLA

Amos 2 in the LNT

Amos 2 in the LSV

Amos 2 in the MAAL

Amos 2 in the MBV

Amos 2 in the MBV2

Amos 2 in the MHNT

Amos 2 in the MKNFD

Amos 2 in the MNG

Amos 2 in the MNT

Amos 2 in the MNT2

Amos 2 in the MRS1T

Amos 2 in the NAA

Amos 2 in the NASB

Amos 2 in the NBLA

Amos 2 in the NBS

Amos 2 in the NBVTP

Amos 2 in the NET2

Amos 2 in the NIV11

Amos 2 in the NNT

Amos 2 in the NNT2

Amos 2 in the NNT3

Amos 2 in the PDDPT

Amos 2 in the PFNT

Amos 2 in the RMNT

Amos 2 in the SBIAS

Amos 2 in the SBIBS

Amos 2 in the SBIBS2

Amos 2 in the SBICS

Amos 2 in the SBIDS

Amos 2 in the SBIGS

Amos 2 in the SBIHS

Amos 2 in the SBIIS

Amos 2 in the SBIIS2

Amos 2 in the SBIIS3

Amos 2 in the SBIKS

Amos 2 in the SBIKS2

Amos 2 in the SBIMS

Amos 2 in the SBIOS

Amos 2 in the SBIPS

Amos 2 in the SBISS

Amos 2 in the SBITS

Amos 2 in the SBITS2

Amos 2 in the SBITS3

Amos 2 in the SBITS4

Amos 2 in the SBIUS

Amos 2 in the SBIVS

Amos 2 in the SBT

Amos 2 in the SBT1E

Amos 2 in the SCHL

Amos 2 in the SNT

Amos 2 in the SUSU

Amos 2 in the SUSU2

Amos 2 in the SYNO

Amos 2 in the TBIAOTANT

Amos 2 in the TBT1E

Amos 2 in the TBT1E2

Amos 2 in the TFTIP

Amos 2 in the TFTU

Amos 2 in the TGNTATF3T

Amos 2 in the THAI

Amos 2 in the TNFD

Amos 2 in the TNT

Amos 2 in the TNTIK

Amos 2 in the TNTIL

Amos 2 in the TNTIN

Amos 2 in the TNTIP

Amos 2 in the TNTIZ

Amos 2 in the TOMA

Amos 2 in the TTENT

Amos 2 in the UBG

Amos 2 in the UGV

Amos 2 in the UGV2

Amos 2 in the UGV3

Amos 2 in the VBL

Amos 2 in the VDCC

Amos 2 in the YALU

Amos 2 in the YAPE

Amos 2 in the YBVTP

Amos 2 in the ZBP