Amos 3 (BOYCB)
1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí OLÚWA ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Ejibiti: 2 “Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yànnínú gbogbo àwọn ìran ayé yìí;nígbà náà èmi ó jẹ ọ́ ní yàfún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.” 3 Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀láìjẹ́ pé wọ́n ti pinnu láti ṣe bẹ? 4 Ǹjẹ́ Kìnnìún yóò ha bú ramúramù nínú igbó,bí kò bá ní ohun ọdẹ?Ọmọ kìnnìún yóò ha ké jáde nínú ìhó rẹ̀bí kò bá rí ohun kan mú? 5 Ǹjẹ́ ẹyẹ ṣubú sínú okùn ọdẹ lórí ilẹ̀nígbà tí a kò dẹ okùn ọdẹ fún un?Okùn ọdẹ ha lè hù jáde lórí ilẹ̀nígbà tí kò sí ohun tí yóò mú? 6 Nígbà tí ìpè bá dún ní ìlú,àwọn ènìyàn kò ha bẹ̀rù?Tí ewu bá wa lórí ìlúkò ha ṣe OLÚWA ni ó fà á? 7 Nítòótọ́ OLÚWA Olódùmarè kò ṣe ohun kanláìfi èrò rẹ̀ hànfun àwọn wòlíì ìránṣẹ́ rẹ̀. 8 Kìnnìún ti bú ramúramùta ni kì yóò bẹ̀rù? OLÚWA Olódùmarè ti sọ̀rọ̀ta ni le ṣe àìsọ àsọtẹ́lẹ̀? 9 Ẹ kéde ní ààfin Aṣdoduàti ní ààfin ní ilẹ̀ Ejibiti.“Ẹ kó ara yín jọ sí orí òkè ńlá Samaria;kí ẹ sì wo ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ńlá láàrín rẹ̀àti ìnilára láàrín àwọn ènìyàn rẹ.” 10 “Wọn kò mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rere,” ni OLÚWA wí,“àwọn ẹni tí ó gba àwọn ìwà ipá àti olè sí ààfin rẹ̀.” 11 Nítorí náà, báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí:“Àwọn ọ̀tá yóò pa ilẹ̀ náà run;yóò wó ibi gíga yín palẹ̀a ó sì ba ààfin rẹ̀ jẹ́.” 12 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Bí olùṣọ́-àgùntàn ti ń gbà itan méjìkúrò ní ẹnu kìnnìún tàbí ẹ̀là etí kanbẹ́ẹ̀ ni a ó mú àwọn ọmọ Israẹli,tí ń gbé Samaria kúròní igun ibùsùn wọnní orí àga ìrọ̀gbọ̀kú wọn ní Damasku.” 13 “Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jakọbu,” ni Olúwa wí, OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun. 14 “Ní ọjọ́ tí mo fìyà jẹ Israẹli lórí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,Èmi yóò pa pẹpẹ Beteli run;ìwo pẹpẹ ni a ó ké kúròyóò sì wó lulẹ̀. 15 Èmi yóò wó ilé òtútùlulẹ̀ pẹ̀lú ilé ooru;ilé tí a fi eyín erin ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ yóò ṣègbéa ó sì pa ilé ńlá náà run,”ni OLÚWA wí.
In Other Versions
Amos 3 in the ANGEFD
Amos 3 in the ANTPNG2D
Amos 3 in the AS21
Amos 3 in the BAGH
Amos 3 in the BBPNG
Amos 3 in the BBT1E
Amos 3 in the BDS
Amos 3 in the BEV
Amos 3 in the BHAD
Amos 3 in the BIB
Amos 3 in the BLPT
Amos 3 in the BNT
Amos 3 in the BNTABOOT
Amos 3 in the BNTLV
Amos 3 in the BOATCB
Amos 3 in the BOATCB2
Amos 3 in the BOBCV
Amos 3 in the BOCNT
Amos 3 in the BOECS
Amos 3 in the BOGWICC
Amos 3 in the BOHCB
Amos 3 in the BOHCV
Amos 3 in the BOHLNT
Amos 3 in the BOHNTLTAL
Amos 3 in the BOICB
Amos 3 in the BOILNTAP
Amos 3 in the BOITCV
Amos 3 in the BOKCV
Amos 3 in the BOKCV2
Amos 3 in the BOKHWOG
Amos 3 in the BOKSSV
Amos 3 in the BOLCB
Amos 3 in the BOLCB2
Amos 3 in the BOMCV
Amos 3 in the BONAV
Amos 3 in the BONCB
Amos 3 in the BONLT
Amos 3 in the BONUT2
Amos 3 in the BOPLNT
Amos 3 in the BOSCB
Amos 3 in the BOSNC
Amos 3 in the BOTLNT
Amos 3 in the BOVCB
Amos 3 in the BPBB
Amos 3 in the BPH
Amos 3 in the BSB
Amos 3 in the CCB
Amos 3 in the CUV
Amos 3 in the CUVS
Amos 3 in the DBT
Amos 3 in the DGDNT
Amos 3 in the DHNT
Amos 3 in the DNT
Amos 3 in the ELBE
Amos 3 in the EMTV
Amos 3 in the ESV
Amos 3 in the FBV
Amos 3 in the FEB
Amos 3 in the GGMNT
Amos 3 in the GNT
Amos 3 in the HARY
Amos 3 in the HNT
Amos 3 in the IRVA
Amos 3 in the IRVB
Amos 3 in the IRVG
Amos 3 in the IRVH
Amos 3 in the IRVK
Amos 3 in the IRVM
Amos 3 in the IRVM2
Amos 3 in the IRVO
Amos 3 in the IRVP
Amos 3 in the IRVT
Amos 3 in the IRVT2
Amos 3 in the IRVU
Amos 3 in the ISVN
Amos 3 in the JSNT
Amos 3 in the KAPI
Amos 3 in the KBT1ETNIK
Amos 3 in the KBV
Amos 3 in the KJV
Amos 3 in the KNFD
Amos 3 in the LBA
Amos 3 in the LBLA
Amos 3 in the LNT
Amos 3 in the LSV
Amos 3 in the MAAL
Amos 3 in the MBV
Amos 3 in the MBV2
Amos 3 in the MHNT
Amos 3 in the MKNFD
Amos 3 in the MNG
Amos 3 in the MNT
Amos 3 in the MNT2
Amos 3 in the MRS1T
Amos 3 in the NAA
Amos 3 in the NASB
Amos 3 in the NBLA
Amos 3 in the NBS
Amos 3 in the NBVTP
Amos 3 in the NET2
Amos 3 in the NIV11
Amos 3 in the NNT
Amos 3 in the NNT2
Amos 3 in the NNT3
Amos 3 in the PDDPT
Amos 3 in the PFNT
Amos 3 in the RMNT
Amos 3 in the SBIAS
Amos 3 in the SBIBS
Amos 3 in the SBIBS2
Amos 3 in the SBICS
Amos 3 in the SBIDS
Amos 3 in the SBIGS
Amos 3 in the SBIHS
Amos 3 in the SBIIS
Amos 3 in the SBIIS2
Amos 3 in the SBIIS3
Amos 3 in the SBIKS
Amos 3 in the SBIKS2
Amos 3 in the SBIMS
Amos 3 in the SBIOS
Amos 3 in the SBIPS
Amos 3 in the SBISS
Amos 3 in the SBITS
Amos 3 in the SBITS2
Amos 3 in the SBITS3
Amos 3 in the SBITS4
Amos 3 in the SBIUS
Amos 3 in the SBIVS
Amos 3 in the SBT
Amos 3 in the SBT1E
Amos 3 in the SCHL
Amos 3 in the SNT
Amos 3 in the SUSU
Amos 3 in the SUSU2
Amos 3 in the SYNO
Amos 3 in the TBIAOTANT
Amos 3 in the TBT1E
Amos 3 in the TBT1E2
Amos 3 in the TFTIP
Amos 3 in the TFTU
Amos 3 in the TGNTATF3T
Amos 3 in the THAI
Amos 3 in the TNFD
Amos 3 in the TNT
Amos 3 in the TNTIK
Amos 3 in the TNTIL
Amos 3 in the TNTIN
Amos 3 in the TNTIP
Amos 3 in the TNTIZ
Amos 3 in the TOMA
Amos 3 in the TTENT
Amos 3 in the UBG
Amos 3 in the UGV
Amos 3 in the UGV2
Amos 3 in the UGV3
Amos 3 in the VBL
Amos 3 in the VDCC
Amos 3 in the YALU
Amos 3 in the YAPE
Amos 3 in the YBVTP
Amos 3 in the ZBP