Amos 8 (BOYCB)

1 Èyí ni ohun tí OLÚWA Olódùmarè fihàn mi: agbọ̀n èso pípọ́n. 2 Ó béèrè pé, “Amosi kí ni ìwọ rí.”Mo sì dáhùn pé, “Agbọ̀n èso pípọ́n.”Nígbà náà ni OLÚWA wí fún mi pé, “Àsìkò náà pọ́n tó fún àwọn ènìyàn mi Israẹli; Èmi kì yóò dá wọn sí mọ́.” 3 OLÚWA Olódùmarè wí pé, “Ní ọjọ́ náà, àwọn orin tẹmpili yóò yí padà sí ohùn réré ẹkún. Ọ̀pọ̀, àní ọ̀pọ̀ ara òkú ni yóò wà ni ibi gbogbo! Àní ni ìdákẹ́ jẹ́ẹ́!” 4 Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí ń tẹ aláìní lórí ba,tí ẹ sì ń sọ tálákà di ilẹ̀. 5 Tí ẹ ń wí pé,“Nígbà wo ni oṣù tuntun yóò paríkí àwa bá à lè ta ọkàkí ọjọ́ ìsinmi kí ó lè dópinkí àwa bá à le ta jéró?”Kí a sì dín ìwọ̀n wa kùkí a gbéraga lórí iye tí a ó tà ákí a sì fi òsùwọ̀n èké yàn wọ́n jẹ, 6 kí àwa lè fi fàdákà ra àwọn tálákà,kí a sì fi bàtà ẹsẹ̀ méjèèjì ra aláìní,kí a sì ta jéró tí a kó mọ́ ilẹ̀. 7 OLÚWA ti fi ìgbéraga Jakọbu búra pé, “Èmi kì yóò gbàgbé ọ̀kan nínú ohun tí wọ́n ṣe. 8 “Ǹjẹ́ ilẹ̀ náà kì yóò ha wárìrì fún èyí?Àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ kì yóò ha ṣọ̀fọ̀?Gbogbo ilẹ̀ yóò ru sókè bí omi Naili,yóò sì ru ú sókè pátápátá bí ìkún omia ó sì tì í jáde, a ó sì tẹ̀ ẹ́ rì gẹ́gẹ́ bí odò Ejibiti. 9 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,” ni OLÚWA Olódùmarè wí,“Èmi yóò mú oòrùn wọ̀ ní ọ̀sán,Èmi yóò mú kí ayé ṣókùnkùn ní ọ̀sán gangan. 10 Èmí yóò yí àsè ẹ̀sìn yín padà sí ọ̀fọ̀,gbogbo orin yín ni èmi yóò sọ di ẹkún.Èmi yóò mú kí gbogbo yín wọ aṣọ ọ̀fọ̀,kí a sì fá orí yín.Èmi yóò mú kí ìgbà náà rí bí ìṣọ̀fọ̀ fún ọmọkùnrinkan ṣoṣo tí a bí àti òpin rẹ̀ bí ọjọ́ kíkorò. 11 “Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLÚWA Olódùmarè wí,“nígbà tí èmi yóò rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí òǹgbẹ fún omi.Ṣùgbọ́n ìyàn gbígbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA. 12 Àwọn ènìyàn yóò rìn kiri láti Òkun dé Òkunwọn yóò sì máa rìn ká láti gúúsù sí àríwá,wọn yóò máa wá ọ̀rọ̀ OLÚWAṣùgbọ́n wọn kì yóò rí i. 13 “Ní ọjọ́ náà“àwọn arẹwà wúńdíá àti àwọn alágbára ọ̀dọ́mọkùnrinyóò dákú fún òǹgbẹ omi. 14 Àwọn tí ó fi ẹ̀ṣẹ̀ Samaria búra,tí wọ́n sì wí pé, ‘Bí ó ti dájú pé ọlọ́run rẹ ń bẹ láààyè, ìwọ Dani,’bí ó ti dájú pè ọlọ́run rẹ ń bẹ láààyè, ìwọ Beerṣeba,wọ́n yóò ṣubú,wọn kì yóò si tún dìde mọ.”

In Other Versions

Amos 8 in the ANGEFD

Amos 8 in the ANTPNG2D

Amos 8 in the AS21

Amos 8 in the BAGH

Amos 8 in the BBPNG

Amos 8 in the BBT1E

Amos 8 in the BDS

Amos 8 in the BEV

Amos 8 in the BHAD

Amos 8 in the BIB

Amos 8 in the BLPT

Amos 8 in the BNT

Amos 8 in the BNTABOOT

Amos 8 in the BNTLV

Amos 8 in the BOATCB

Amos 8 in the BOATCB2

Amos 8 in the BOBCV

Amos 8 in the BOCNT

Amos 8 in the BOECS

Amos 8 in the BOGWICC

Amos 8 in the BOHCB

Amos 8 in the BOHCV

Amos 8 in the BOHLNT

Amos 8 in the BOHNTLTAL

Amos 8 in the BOICB

Amos 8 in the BOILNTAP

Amos 8 in the BOITCV

Amos 8 in the BOKCV

Amos 8 in the BOKCV2

Amos 8 in the BOKHWOG

Amos 8 in the BOKSSV

Amos 8 in the BOLCB

Amos 8 in the BOLCB2

Amos 8 in the BOMCV

Amos 8 in the BONAV

Amos 8 in the BONCB

Amos 8 in the BONLT

Amos 8 in the BONUT2

Amos 8 in the BOPLNT

Amos 8 in the BOSCB

Amos 8 in the BOSNC

Amos 8 in the BOTLNT

Amos 8 in the BOVCB

Amos 8 in the BPBB

Amos 8 in the BPH

Amos 8 in the BSB

Amos 8 in the CCB

Amos 8 in the CUV

Amos 8 in the CUVS

Amos 8 in the DBT

Amos 8 in the DGDNT

Amos 8 in the DHNT

Amos 8 in the DNT

Amos 8 in the ELBE

Amos 8 in the EMTV

Amos 8 in the ESV

Amos 8 in the FBV

Amos 8 in the FEB

Amos 8 in the GGMNT

Amos 8 in the GNT

Amos 8 in the HARY

Amos 8 in the HNT

Amos 8 in the IRVA

Amos 8 in the IRVB

Amos 8 in the IRVG

Amos 8 in the IRVH

Amos 8 in the IRVK

Amos 8 in the IRVM

Amos 8 in the IRVM2

Amos 8 in the IRVO

Amos 8 in the IRVP

Amos 8 in the IRVT

Amos 8 in the IRVT2

Amos 8 in the IRVU

Amos 8 in the ISVN

Amos 8 in the JSNT

Amos 8 in the KAPI

Amos 8 in the KBT1ETNIK

Amos 8 in the KBV

Amos 8 in the KJV

Amos 8 in the KNFD

Amos 8 in the LBA

Amos 8 in the LBLA

Amos 8 in the LNT

Amos 8 in the LSV

Amos 8 in the MAAL

Amos 8 in the MBV

Amos 8 in the MBV2

Amos 8 in the MHNT

Amos 8 in the MKNFD

Amos 8 in the MNG

Amos 8 in the MNT

Amos 8 in the MNT2

Amos 8 in the MRS1T

Amos 8 in the NAA

Amos 8 in the NASB

Amos 8 in the NBLA

Amos 8 in the NBS

Amos 8 in the NBVTP

Amos 8 in the NET2

Amos 8 in the NIV11

Amos 8 in the NNT

Amos 8 in the NNT2

Amos 8 in the NNT3

Amos 8 in the PDDPT

Amos 8 in the PFNT

Amos 8 in the RMNT

Amos 8 in the SBIAS

Amos 8 in the SBIBS

Amos 8 in the SBIBS2

Amos 8 in the SBICS

Amos 8 in the SBIDS

Amos 8 in the SBIGS

Amos 8 in the SBIHS

Amos 8 in the SBIIS

Amos 8 in the SBIIS2

Amos 8 in the SBIIS3

Amos 8 in the SBIKS

Amos 8 in the SBIKS2

Amos 8 in the SBIMS

Amos 8 in the SBIOS

Amos 8 in the SBIPS

Amos 8 in the SBISS

Amos 8 in the SBITS

Amos 8 in the SBITS2

Amos 8 in the SBITS3

Amos 8 in the SBITS4

Amos 8 in the SBIUS

Amos 8 in the SBIVS

Amos 8 in the SBT

Amos 8 in the SBT1E

Amos 8 in the SCHL

Amos 8 in the SNT

Amos 8 in the SUSU

Amos 8 in the SUSU2

Amos 8 in the SYNO

Amos 8 in the TBIAOTANT

Amos 8 in the TBT1E

Amos 8 in the TBT1E2

Amos 8 in the TFTIP

Amos 8 in the TFTU

Amos 8 in the TGNTATF3T

Amos 8 in the THAI

Amos 8 in the TNFD

Amos 8 in the TNT

Amos 8 in the TNTIK

Amos 8 in the TNTIL

Amos 8 in the TNTIN

Amos 8 in the TNTIP

Amos 8 in the TNTIZ

Amos 8 in the TOMA

Amos 8 in the TTENT

Amos 8 in the UBG

Amos 8 in the UGV

Amos 8 in the UGV2

Amos 8 in the UGV3

Amos 8 in the VBL

Amos 8 in the VDCC

Amos 8 in the YALU

Amos 8 in the YAPE

Amos 8 in the YBVTP

Amos 8 in the ZBP