Deuteronomy 25 (BOYCB)
        
        
          1 Nígbà tí àwọn ènìyàn méjì bá ń jà, kí wọn kó ẹjọ́ lọ sí ilé ìdájọ́, kí àwọn onídàájọ́ dá ẹjọ́ náà, kí wọn dá àre fún aláre àti ẹ̀bi fún ẹlẹ́bi. 2 Bí ó bá tọ́ láti na ẹlẹ́bi, kí onídàájọ́ dá a dọ̀bálẹ̀ kí a sì nà án ní ojú u rẹ̀ ní iye pàṣán tí ó tọ́ sí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó sẹ̀. 3 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ fún un ju ogójì pàṣán lọ. Bí ó bá nà án ju bẹ́ẹ̀ lọ, arákùnrin rẹ̀ yóò di ẹni ìrẹ̀sílẹ̀ ní ojú rẹ̀.  4 Ìwọ kò gbọdọ̀ di màlúù ti ń tẹ ọkà lẹ́nu.  5 Bí àwọn arákùnrin bá ń gbé pọ̀, tí ọ̀kan nínú wọn bá sì kú, tí kò sí ní ọmọkùnrin, kí aya òkú má ṣe ní àlejò ará òde ní ọkọ rẹ̀. Arákùnrin ọkọ rẹ̀ ni kí ó wọlé tọ̀ ọ́, kí ó fi ṣe aya, kí ó sì ṣe iṣẹ́ arákùnrin ọkọ fún un. 6 Ọmọkùnrin tí ó bá kọ́ bí ni yóò máa jẹ́ orúkọ arákùnrin rẹ̀ tí ó kú náà, kí orúkọ rẹ̀ má ba á parẹ́ ní Israẹli.  7 Ṣùgbọ́n bí ọkùnrin náà kò bá fẹ́ fi aya arákùnrin rẹ̀ ṣe aya rẹ̀, obìnrin náà yóò lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn àgbàgbà ní ẹnu-bodè ìlú láti sọ pé, “Arákùnrin ọkọ ọ̀ mi kọ̀ láti gbé orúkọ arákùnrin rẹ̀ ró ní Israẹli. Kò ní ṣe ojúṣe rẹ̀ bí arákùnrin ọkọ mi sí mi.” 8 Nígbà náà ni àwọn àgbàgbà ìlú rẹ̀ yóò pè é, wọn yóò sì bá sọ̀rọ̀. Bí ó bá sì kọ̀ jálẹ̀ tí ó bá sọ pé, “Èmi kò fẹ́ láti fẹ́ ẹ,” 9 opó arákùnrin rẹ̀ yìí yóò lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ ní ojú àwọn àgbàgbà ìlú rẹ̀, yóò yọ bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀ kan, yóò sì tu itọ́ sí ọkùnrin náà lójú, yóò sì wí pé, “Èyí ni ohun tí a ṣe sí ọkùnrin tí kò jẹ́ kí ìdílé arákùnrin rẹ̀ wà títí ayé.” 10 A ó sì mọ ìdílé arákùnrin yìí ní Israẹli gẹ́gẹ́ bí “Ìdílé tí a yọ bàtà rẹ̀.”  11 Bí ọkùnrin méjì bá ń jà, tí ìyàwó ọ̀kan nínú wọn bá sì wá láti gbèjà ọkọ rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ọkùnrin tí ń lù ú, tí ó sì nawọ́ di nǹkan ọkùnrin abẹ́ ẹ rẹ̀ mú. 12 Ìwọ yóò gé ọwọ́ rẹ̀ náà kúrò. Má ṣe ṣàánú fún un.  13 Má ṣe ní oríṣìí ìtẹ̀wọ̀n méjì tó yàtọ̀ sí ara wọn nínú àpò rẹ, ọ̀kan wúwo àti ọ̀kan fífúyẹ́. 14 Má ṣe ní oríṣìí ìwọ̀n méjì tí ó yàtọ̀ sí ara wọn ní ilé è rẹ: ọ̀kan fífẹ̀, ọ̀kan kékeré. 15 O gbọdọ̀ ní ìtẹ̀wọ̀n àti òsùwọ̀n pípé àti ti òtítọ́ nítorí náà kí ìwọ kí ó lè pẹ́ ní ilẹ̀ tí OLÚWA Ọlọ́run rẹ fún ọ. 16 Nítorí OLÚWA Ọlọ́run kórìíra ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe nǹkan wọ̀nyí, àní ẹnikẹ́ni tí ń ṣe àìṣòdodo.  17 Rántí ohun tí àwọn ará Amaleki ṣe sí i yín ní ọ̀nà nígbà tí ẹ̀ ń jáde láti ilẹ̀ Ejibiti wá. 18 Nígbà tí àárẹ̀ mú un yín tí agara sì dá a yín, wọ́n pàdé e yín ní ọ̀nà àjò o yín, wọ́n gé àwọn tí ó rẹ̀yìn kúrò, wọn kò ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run. 19 Nígbà tí OLÚWA Ọlọ́run yín bá fún un yín ní ìsinmi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá yín tí ó yí i yín ká ní ilẹ̀ tí OLÚWA Ọlọ́run ń fi fún yín láti ni ní ìní, ẹ̀yin yóò sì pa ìrántí Amaleki rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run. Má ṣe gbàgbé.
        
        
          In Other Versions
        
        
  
    Deuteronomy 25 in the ANGEFD
  
  
    Deuteronomy 25 in the ANTPNG2D
  
  
    Deuteronomy 25 in the AS21
  
  
    Deuteronomy 25 in the BAGH
  
  
    Deuteronomy 25 in the BBPNG
  
  
    Deuteronomy 25 in the BBT1E
  
  
    Deuteronomy 25 in the BDS
  
  
    Deuteronomy 25 in the BEV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BHAD
  
  
    Deuteronomy 25 in the BIB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BLPT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BNTABOOT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BNTLV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOATCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOATCB2
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOBCV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOCNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOECS
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOGWICC
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOHCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOHCV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOHLNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOHNTLTAL
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOICB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOILNTAP
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOITCV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOKCV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOKCV2
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOKHWOG
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOKSSV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOLCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOLCB2
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOMCV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BONAV
  
  
    Deuteronomy 25 in the BONCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BONLT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BONUT2
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOPLNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOSCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOSNC
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOTLNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the BOVCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BPBB
  
  
    Deuteronomy 25 in the BPH
  
  
    Deuteronomy 25 in the BSB
  
  
    Deuteronomy 25 in the CCB
  
  
    Deuteronomy 25 in the CUV
  
  
    Deuteronomy 25 in the CUVS
  
  
    Deuteronomy 25 in the DBT
  
  
    Deuteronomy 25 in the DGDNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the DHNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the DNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the ELBE
  
  
    Deuteronomy 25 in the EMTV
  
  
    Deuteronomy 25 in the ESV
  
  
    Deuteronomy 25 in the FBV
  
  
    Deuteronomy 25 in the FEB
  
  
    Deuteronomy 25 in the GGMNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the GNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the HARY
  
  
    Deuteronomy 25 in the HNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVA
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVB
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVG
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVH
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVK
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVM
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVM2
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVO
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVP
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVT
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVT2
  
  
    Deuteronomy 25 in the IRVU
  
  
    Deuteronomy 25 in the ISVN
  
  
    Deuteronomy 25 in the JSNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the KAPI
  
  
    Deuteronomy 25 in the KBT1ETNIK
  
  
    Deuteronomy 25 in the KBV
  
  
    Deuteronomy 25 in the KJV
  
  
    Deuteronomy 25 in the KNFD
  
  
    Deuteronomy 25 in the LBA
  
  
    Deuteronomy 25 in the LBLA
  
  
    Deuteronomy 25 in the LNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the LSV
  
  
    Deuteronomy 25 in the MAAL
  
  
    Deuteronomy 25 in the MBV
  
  
    Deuteronomy 25 in the MBV2
  
  
    Deuteronomy 25 in the MHNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the MKNFD
  
  
    Deuteronomy 25 in the MNG
  
  
    Deuteronomy 25 in the MNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the MNT2
  
  
    Deuteronomy 25 in the MRS1T
  
  
    Deuteronomy 25 in the NAA
  
  
    Deuteronomy 25 in the NASB
  
  
    Deuteronomy 25 in the NBLA
  
  
    Deuteronomy 25 in the NBS
  
  
    Deuteronomy 25 in the NBVTP
  
  
    Deuteronomy 25 in the NET2
  
  
    Deuteronomy 25 in the NIV11
  
  
    Deuteronomy 25 in the NNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the NNT2
  
  
    Deuteronomy 25 in the NNT3
  
  
    Deuteronomy 25 in the PDDPT
  
  
    Deuteronomy 25 in the PFNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the RMNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIAS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIBS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIBS2
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBICS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIDS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIGS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIHS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIIS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIIS2
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIIS3
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIKS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIKS2
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIMS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIOS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIPS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBISS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBITS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBITS2
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBITS3
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBITS4
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIUS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBIVS
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBT
  
  
    Deuteronomy 25 in the SBT1E
  
  
    Deuteronomy 25 in the SCHL
  
  
    Deuteronomy 25 in the SNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the SUSU
  
  
    Deuteronomy 25 in the SUSU2
  
  
    Deuteronomy 25 in the SYNO
  
  
    Deuteronomy 25 in the TBIAOTANT
  
  
    Deuteronomy 25 in the TBT1E
  
  
    Deuteronomy 25 in the TBT1E2
  
  
    Deuteronomy 25 in the TFTIP
  
  
    Deuteronomy 25 in the TFTU
  
  
    Deuteronomy 25 in the TGNTATF3T
  
  
    Deuteronomy 25 in the THAI
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNFD
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNT
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNTIK
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNTIL
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNTIN
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNTIP
  
  
    Deuteronomy 25 in the TNTIZ
  
  
    Deuteronomy 25 in the TOMA
  
  
    Deuteronomy 25 in the TTENT
  
  
    Deuteronomy 25 in the UBG
  
  
    Deuteronomy 25 in the UGV
  
  
    Deuteronomy 25 in the UGV2
  
  
    Deuteronomy 25 in the UGV3
  
  
    Deuteronomy 25 in the VBL
  
  
    Deuteronomy 25 in the VDCC
  
  
    Deuteronomy 25 in the YALU
  
  
    Deuteronomy 25 in the YAPE
  
  
    Deuteronomy 25 in the YBVTP
  
  
    Deuteronomy 25 in the ZBP