Ecclesiastes 6 (BOYCB)

1 Mo ti rí ibi mìíràn lábẹ́ oòrùn. 2 Ọlọ́run fún ọkùnrin kan ní ọrọ̀, ọlá àti ọlà kí ó má ba à ṣe aláìní ohunkóhun tí ọkàn rẹ̀ ń fẹ́. Ṣùgbọ́n, Ọlọ́run kò fún un ní àǹfààní láti gbádùn wọn, dípò èyí, àlejò ni ó ń gbádùn wọn. Asán ni èyí, ààrùn búburú gbá à ni. 3 Ọkùnrin kan le è ní ọgọ́rùn-ún ọmọ kí ó sì wà láààyè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, síbẹ̀ kò sí bí ó ti le wà láààyè pẹ́ tó, bí kò bá le è gbádùn ohun ìní rẹ̀ kí ó sì gba ìsìnkú tí ó tọ́, mo sọ wí pé ọlẹ̀ ọmọ tí a sin sàn jù ú lọ. 4 Ó wà láìní ìtumọ̀, ó lọ nínú òkùnkùn, nínú òkùnkùn sì ni orúkọ rẹ̀ fi ara pamọ́ sí. 5 Bí ó ti jẹ́ wí pé kò rí oòrùn tàbí mọ ohunkóhun, ó ní ọ̀pọ̀ ìsinmi ju ti ọkùnrin náà lọ. 6 Kódà, bí ó wà láààyè fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún méjì yípo ṣùgbọ́n tí ó kùnà láti gbádùn ohun ìní rẹ̀. Kì í ṣe ibìkan ni gbogbo wọn ń lọ? 7 Gbogbo wàhálà tí ènìyàn ń ṣe nítorí àtijẹ nisíbẹ̀ ikùn rẹ̀ kò yó rí. 8 Kí ni àǹfààní tí ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní lórí aṣiwèrè?Kí ni èrè tálákà ènìyànnípa mímọ bí yóò ṣe hùwà níwájú àwọn tókù? 9 Ohun tí ojú rí sànju ìfẹnuwákiri lọ.Asán ni eléyìí pẹ̀lúó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́. 10 Ohunkóhun tí ó bá ti wà ti ní orúkọ,ohun tí ènìyàn jẹ́ sì ti di mí mọ̀;kò sí ènìyàn tí ó le è ja ìjàkadìpẹ̀lú ẹni tí ó lágbára jù ú lọ. 11 Ọ̀rọ̀ púpọ̀,kì í ní ìtumọ̀èrè wo ni ènìyàn ń rí nínú rẹ̀? 12 Àbí, ta ni ó mọ ohun tí ó dára fún ènìyàn ní ayé fún ọjọ́ ayé kúkúrú àti asán tí ó ń là kọjá gẹ́gẹ́ bí òjìji? Ta ni ó le è sọ fún mi, ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lábẹ́ oòrùn lẹ́yìn tí ó bá lọ tán? Kò sí!

In Other Versions

Ecclesiastes 6 in the ANGEFD

Ecclesiastes 6 in the ANTPNG2D

Ecclesiastes 6 in the AS21

Ecclesiastes 6 in the BAGH

Ecclesiastes 6 in the BBPNG

Ecclesiastes 6 in the BBT1E

Ecclesiastes 6 in the BDS

Ecclesiastes 6 in the BEV

Ecclesiastes 6 in the BHAD

Ecclesiastes 6 in the BIB

Ecclesiastes 6 in the BLPT

Ecclesiastes 6 in the BNT

Ecclesiastes 6 in the BNTABOOT

Ecclesiastes 6 in the BNTLV

Ecclesiastes 6 in the BOATCB

Ecclesiastes 6 in the BOATCB2

Ecclesiastes 6 in the BOBCV

Ecclesiastes 6 in the BOCNT

Ecclesiastes 6 in the BOECS

Ecclesiastes 6 in the BOGWICC

Ecclesiastes 6 in the BOHCB

Ecclesiastes 6 in the BOHCV

Ecclesiastes 6 in the BOHLNT

Ecclesiastes 6 in the BOHNTLTAL

Ecclesiastes 6 in the BOICB

Ecclesiastes 6 in the BOILNTAP

Ecclesiastes 6 in the BOITCV

Ecclesiastes 6 in the BOKCV

Ecclesiastes 6 in the BOKCV2

Ecclesiastes 6 in the BOKHWOG

Ecclesiastes 6 in the BOKSSV

Ecclesiastes 6 in the BOLCB

Ecclesiastes 6 in the BOLCB2

Ecclesiastes 6 in the BOMCV

Ecclesiastes 6 in the BONAV

Ecclesiastes 6 in the BONCB

Ecclesiastes 6 in the BONLT

Ecclesiastes 6 in the BONUT2

Ecclesiastes 6 in the BOPLNT

Ecclesiastes 6 in the BOSCB

Ecclesiastes 6 in the BOSNC

Ecclesiastes 6 in the BOTLNT

Ecclesiastes 6 in the BOVCB

Ecclesiastes 6 in the BPBB

Ecclesiastes 6 in the BPH

Ecclesiastes 6 in the BSB

Ecclesiastes 6 in the CCB

Ecclesiastes 6 in the CUV

Ecclesiastes 6 in the CUVS

Ecclesiastes 6 in the DBT

Ecclesiastes 6 in the DGDNT

Ecclesiastes 6 in the DHNT

Ecclesiastes 6 in the DNT

Ecclesiastes 6 in the ELBE

Ecclesiastes 6 in the EMTV

Ecclesiastes 6 in the ESV

Ecclesiastes 6 in the FBV

Ecclesiastes 6 in the FEB

Ecclesiastes 6 in the GGMNT

Ecclesiastes 6 in the GNT

Ecclesiastes 6 in the HARY

Ecclesiastes 6 in the HNT

Ecclesiastes 6 in the IRVA

Ecclesiastes 6 in the IRVB

Ecclesiastes 6 in the IRVG

Ecclesiastes 6 in the IRVH

Ecclesiastes 6 in the IRVK

Ecclesiastes 6 in the IRVM

Ecclesiastes 6 in the IRVM2

Ecclesiastes 6 in the IRVO

Ecclesiastes 6 in the IRVP

Ecclesiastes 6 in the IRVT

Ecclesiastes 6 in the IRVT2

Ecclesiastes 6 in the IRVU

Ecclesiastes 6 in the ISVN

Ecclesiastes 6 in the JSNT

Ecclesiastes 6 in the KAPI

Ecclesiastes 6 in the KBT1ETNIK

Ecclesiastes 6 in the KBV

Ecclesiastes 6 in the KJV

Ecclesiastes 6 in the KNFD

Ecclesiastes 6 in the LBA

Ecclesiastes 6 in the LBLA

Ecclesiastes 6 in the LNT

Ecclesiastes 6 in the LSV

Ecclesiastes 6 in the MAAL

Ecclesiastes 6 in the MBV

Ecclesiastes 6 in the MBV2

Ecclesiastes 6 in the MHNT

Ecclesiastes 6 in the MKNFD

Ecclesiastes 6 in the MNG

Ecclesiastes 6 in the MNT

Ecclesiastes 6 in the MNT2

Ecclesiastes 6 in the MRS1T

Ecclesiastes 6 in the NAA

Ecclesiastes 6 in the NASB

Ecclesiastes 6 in the NBLA

Ecclesiastes 6 in the NBS

Ecclesiastes 6 in the NBVTP

Ecclesiastes 6 in the NET2

Ecclesiastes 6 in the NIV11

Ecclesiastes 6 in the NNT

Ecclesiastes 6 in the NNT2

Ecclesiastes 6 in the NNT3

Ecclesiastes 6 in the PDDPT

Ecclesiastes 6 in the PFNT

Ecclesiastes 6 in the RMNT

Ecclesiastes 6 in the SBIAS

Ecclesiastes 6 in the SBIBS

Ecclesiastes 6 in the SBIBS2

Ecclesiastes 6 in the SBICS

Ecclesiastes 6 in the SBIDS

Ecclesiastes 6 in the SBIGS

Ecclesiastes 6 in the SBIHS

Ecclesiastes 6 in the SBIIS

Ecclesiastes 6 in the SBIIS2

Ecclesiastes 6 in the SBIIS3

Ecclesiastes 6 in the SBIKS

Ecclesiastes 6 in the SBIKS2

Ecclesiastes 6 in the SBIMS

Ecclesiastes 6 in the SBIOS

Ecclesiastes 6 in the SBIPS

Ecclesiastes 6 in the SBISS

Ecclesiastes 6 in the SBITS

Ecclesiastes 6 in the SBITS2

Ecclesiastes 6 in the SBITS3

Ecclesiastes 6 in the SBITS4

Ecclesiastes 6 in the SBIUS

Ecclesiastes 6 in the SBIVS

Ecclesiastes 6 in the SBT

Ecclesiastes 6 in the SBT1E

Ecclesiastes 6 in the SCHL

Ecclesiastes 6 in the SNT

Ecclesiastes 6 in the SUSU

Ecclesiastes 6 in the SUSU2

Ecclesiastes 6 in the SYNO

Ecclesiastes 6 in the TBIAOTANT

Ecclesiastes 6 in the TBT1E

Ecclesiastes 6 in the TBT1E2

Ecclesiastes 6 in the TFTIP

Ecclesiastes 6 in the TFTU

Ecclesiastes 6 in the TGNTATF3T

Ecclesiastes 6 in the THAI

Ecclesiastes 6 in the TNFD

Ecclesiastes 6 in the TNT

Ecclesiastes 6 in the TNTIK

Ecclesiastes 6 in the TNTIL

Ecclesiastes 6 in the TNTIN

Ecclesiastes 6 in the TNTIP

Ecclesiastes 6 in the TNTIZ

Ecclesiastes 6 in the TOMA

Ecclesiastes 6 in the TTENT

Ecclesiastes 6 in the UBG

Ecclesiastes 6 in the UGV

Ecclesiastes 6 in the UGV2

Ecclesiastes 6 in the UGV3

Ecclesiastes 6 in the VBL

Ecclesiastes 6 in the VDCC

Ecclesiastes 6 in the YALU

Ecclesiastes 6 in the YAPE

Ecclesiastes 6 in the YBVTP

Ecclesiastes 6 in the ZBP