Ezekiel 42 (BOYCB)

1 Lẹ́yìn náà ó mú mi lọ sí ìta gbangba ni ìhà àríwá ó sì mú mi wọ àwọn yàrá ni òdìkejì ìta gbangba ilé Ọlọ́run àti ni òdìkejì ògiri ìta ní apá ìhà àríwá. 2 Ilé tí ìlẹ̀kùn rẹ̀ kọjú sí àríwá jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó sì jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ ní ìbú. 3 Méjèèjì ní ogún ìgbọ̀nwọ́ ìpín láti inú ilé ìdájọ́ àti ni ìpín tí ó dojúkọ iwájú ìta ìdájọ́, ọ̀dẹ̀dẹ̀ lókè kọjú sì ọ̀dẹ̀dẹ̀ lókè ní ìdọ́gba mẹ́ta. 4 Ní iwájú àwọn ọ̀nà, yàrá wà nínú tí ó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní ìbú tí ó sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn. Àwọn ìlẹ̀kùn wọn wà ní apá ìhà àríwá. 5 Nísinsin yìí àwọn yàrá òkè ṣe tóóró, nítorí ọ̀dẹ̀dẹ̀ lókè dàbí ẹni pé ó ní ààyè láti ara wọn ju láti ara àwọn yàrá ti ó wà ní ìsàlẹ̀ tàbí àárín ilé. 6 Àwọn yàrá tí ó wà ní àgbékà kẹta kò ni àwọn òpó gẹ́gẹ́ bí ilé ìdájọ́ ṣe ní; nítorí náà wọ́n kéré ní ààyè ju àwọn tí ó wà ní ìsàlẹ̀ àti àwọn àgbékà ti àárín. 7 Ògiri kan wà ní ìta tí ó ṣe déédé pẹ̀lú àwọn yàrá àti ìta ilé ìdájọ́; a fà á gùn ní iwájú àwọn yàrá ní àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́. 8 Nígbà tí ọ̀wọ́ yàrá ní ẹ̀gbẹ́ tí ó kángun sí ìta ilé ìdájọ́ jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn, ọ̀wọ́ ti ó wà ní ẹ̀gbẹ́ tí ó súnmọ́ ibi mímọ́ jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn. 9 Yàrá ìsàlẹ̀ ni ẹnu-ọ̀nà ní ìhà ìlà-oòrùn gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan ṣe wọ inú rẹ̀ láti ìta ilé ìdájọ́. 10 Ní ìhà gúúsù lọ sí ìbú ògiri ìta ilé ìdájọ́ tí o ṣe déédé pẹ̀lú àgbàlá ilé Ọlọ́run, ní òdìkejì ògiri ìta ni àwọn yàrá náà wà. 11 Àti ọ̀nà ni iwájú wọn rí gẹ́gẹ́ bí ti ìrí àwọn yàrá tí ó wà ní ọ̀nà àríwá bí wọ́n ti gùn mọ bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbòòrò mọ àti gbogbo ìjáde wọn sì dàbí ìṣe wọn àti bí ìlẹ̀kùn wọn 12 bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ní yàrá tí òun ti ìlẹ̀kùn wọn ní ọ̀nà gúúsù, ìlẹ̀kùn kan wà ní ìbẹ̀rẹ̀ ojú ọ̀nà tí ó ṣe déédé pẹ̀lú ògiri tí ó gùn dé ìhà ìlà-oòrùn tí ènìyàn ń gba wọ inú àwọn yàrá. 13 Ó sì wí fún mi pé, “Àwọn yàrá àríwá àti àwọn yàrá gúúsù, tí ó wà níwájú ibi tí a yà sọ́tọ̀ àwọn ni yàrá mímọ́, níbi tí àwọn àlùfáà ti ń súnmọ́ OLÚWA yó máa jẹ́ ohun mímọ́ jùlọ; níbẹ̀ ní wọn o máa gbé ohun mímọ́ jùlọ kà, àti ọrẹ ẹbọ jíjẹ, àti ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àti ọrẹ ẹbọ ìrékọjá; nítorí ibẹ̀ jẹ́ mímọ́. 14 Níwọ̀n ìgbà tí àwọn àlùfáà bá ti wọ aṣọ funfun ibi mímọ́, wọn kò gbọdọ̀ lọ sí ìta ilé ìdájọ́ àfi tí wọ́n bá bọ àwọn aṣọ tí wọ́n fi ṣiṣẹ́ ìsin sílẹ̀ ní ibi tí wọn tí lò ó, nítorí wọ́n jẹ́ mímọ́. Wọn gbọdọ̀ wọ aṣọ mìíràn kí wọn tó súnmọ́ ibi tí àwọn ènìyàn yòókù máa ń wà.” 15 Nígbà tí o parí nǹkan tí ó wà nínú ilé Ọlọ́run tán, o mú mi jáde lọ sí ọ̀nà tí ó wà ní ìhà ìlà-oòrùn, ó sì wọn agbègbè náà yípo: 16 Ó wọn ìhà ìlà-oòrùn pẹ̀lú ọ̀pá-ìwọ̀n nǹkan; ó jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ìgbọ̀nwọ́. 17 Ó wọn ìhà àríwá; ó jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ìgbọ̀nwọ́ pẹ̀lú ọ̀pá-ìwọ̀n nǹkan. 18 O wọn ìhà gúúsù; ó jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ìgbọ̀nwọ́ pẹ̀lú ọ̀pá wíwọ̀n nǹkan. 19 Lẹ́yìn èyí ni ó wà yí padà sí ìhà ìwọ̀-oòrùn o sì wọ̀n-ọ́n: ó sì jẹ́ ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ìgbọ̀nwọ́ pẹ̀lú ọ̀pá wíwọ̀n. 20 Báyìí ní ó wọ̀n-ọ́n ní ẹ̀gbẹ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin. Ó ní ògiri kan yípo rẹ̀, ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ìgbọ̀nwọ́ ní ìbú, àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, láti ya ibi mímọ́ sọ́tọ̀ kúrò ní ibi àìmọ́.

In Other Versions

Ezekiel 42 in the ANGEFD

Ezekiel 42 in the ANTPNG2D

Ezekiel 42 in the AS21

Ezekiel 42 in the BAGH

Ezekiel 42 in the BBPNG

Ezekiel 42 in the BBT1E

Ezekiel 42 in the BDS

Ezekiel 42 in the BEV

Ezekiel 42 in the BHAD

Ezekiel 42 in the BIB

Ezekiel 42 in the BLPT

Ezekiel 42 in the BNT

Ezekiel 42 in the BNTABOOT

Ezekiel 42 in the BNTLV

Ezekiel 42 in the BOATCB

Ezekiel 42 in the BOATCB2

Ezekiel 42 in the BOBCV

Ezekiel 42 in the BOCNT

Ezekiel 42 in the BOECS

Ezekiel 42 in the BOGWICC

Ezekiel 42 in the BOHCB

Ezekiel 42 in the BOHCV

Ezekiel 42 in the BOHLNT

Ezekiel 42 in the BOHNTLTAL

Ezekiel 42 in the BOICB

Ezekiel 42 in the BOILNTAP

Ezekiel 42 in the BOITCV

Ezekiel 42 in the BOKCV

Ezekiel 42 in the BOKCV2

Ezekiel 42 in the BOKHWOG

Ezekiel 42 in the BOKSSV

Ezekiel 42 in the BOLCB

Ezekiel 42 in the BOLCB2

Ezekiel 42 in the BOMCV

Ezekiel 42 in the BONAV

Ezekiel 42 in the BONCB

Ezekiel 42 in the BONLT

Ezekiel 42 in the BONUT2

Ezekiel 42 in the BOPLNT

Ezekiel 42 in the BOSCB

Ezekiel 42 in the BOSNC

Ezekiel 42 in the BOTLNT

Ezekiel 42 in the BOVCB

Ezekiel 42 in the BPBB

Ezekiel 42 in the BPH

Ezekiel 42 in the BSB

Ezekiel 42 in the CCB

Ezekiel 42 in the CUV

Ezekiel 42 in the CUVS

Ezekiel 42 in the DBT

Ezekiel 42 in the DGDNT

Ezekiel 42 in the DHNT

Ezekiel 42 in the DNT

Ezekiel 42 in the ELBE

Ezekiel 42 in the EMTV

Ezekiel 42 in the ESV

Ezekiel 42 in the FBV

Ezekiel 42 in the FEB

Ezekiel 42 in the GGMNT

Ezekiel 42 in the GNT

Ezekiel 42 in the HARY

Ezekiel 42 in the HNT

Ezekiel 42 in the IRVA

Ezekiel 42 in the IRVB

Ezekiel 42 in the IRVG

Ezekiel 42 in the IRVH

Ezekiel 42 in the IRVK

Ezekiel 42 in the IRVM

Ezekiel 42 in the IRVM2

Ezekiel 42 in the IRVO

Ezekiel 42 in the IRVP

Ezekiel 42 in the IRVT

Ezekiel 42 in the IRVT2

Ezekiel 42 in the IRVU

Ezekiel 42 in the ISVN

Ezekiel 42 in the JSNT

Ezekiel 42 in the KAPI

Ezekiel 42 in the KBT1ETNIK

Ezekiel 42 in the KBV

Ezekiel 42 in the KJV

Ezekiel 42 in the KNFD

Ezekiel 42 in the LBA

Ezekiel 42 in the LBLA

Ezekiel 42 in the LNT

Ezekiel 42 in the LSV

Ezekiel 42 in the MAAL

Ezekiel 42 in the MBV

Ezekiel 42 in the MBV2

Ezekiel 42 in the MHNT

Ezekiel 42 in the MKNFD

Ezekiel 42 in the MNG

Ezekiel 42 in the MNT

Ezekiel 42 in the MNT2

Ezekiel 42 in the MRS1T

Ezekiel 42 in the NAA

Ezekiel 42 in the NASB

Ezekiel 42 in the NBLA

Ezekiel 42 in the NBS

Ezekiel 42 in the NBVTP

Ezekiel 42 in the NET2

Ezekiel 42 in the NIV11

Ezekiel 42 in the NNT

Ezekiel 42 in the NNT2

Ezekiel 42 in the NNT3

Ezekiel 42 in the PDDPT

Ezekiel 42 in the PFNT

Ezekiel 42 in the RMNT

Ezekiel 42 in the SBIAS

Ezekiel 42 in the SBIBS

Ezekiel 42 in the SBIBS2

Ezekiel 42 in the SBICS

Ezekiel 42 in the SBIDS

Ezekiel 42 in the SBIGS

Ezekiel 42 in the SBIHS

Ezekiel 42 in the SBIIS

Ezekiel 42 in the SBIIS2

Ezekiel 42 in the SBIIS3

Ezekiel 42 in the SBIKS

Ezekiel 42 in the SBIKS2

Ezekiel 42 in the SBIMS

Ezekiel 42 in the SBIOS

Ezekiel 42 in the SBIPS

Ezekiel 42 in the SBISS

Ezekiel 42 in the SBITS

Ezekiel 42 in the SBITS2

Ezekiel 42 in the SBITS3

Ezekiel 42 in the SBITS4

Ezekiel 42 in the SBIUS

Ezekiel 42 in the SBIVS

Ezekiel 42 in the SBT

Ezekiel 42 in the SBT1E

Ezekiel 42 in the SCHL

Ezekiel 42 in the SNT

Ezekiel 42 in the SUSU

Ezekiel 42 in the SUSU2

Ezekiel 42 in the SYNO

Ezekiel 42 in the TBIAOTANT

Ezekiel 42 in the TBT1E

Ezekiel 42 in the TBT1E2

Ezekiel 42 in the TFTIP

Ezekiel 42 in the TFTU

Ezekiel 42 in the TGNTATF3T

Ezekiel 42 in the THAI

Ezekiel 42 in the TNFD

Ezekiel 42 in the TNT

Ezekiel 42 in the TNTIK

Ezekiel 42 in the TNTIL

Ezekiel 42 in the TNTIN

Ezekiel 42 in the TNTIP

Ezekiel 42 in the TNTIZ

Ezekiel 42 in the TOMA

Ezekiel 42 in the TTENT

Ezekiel 42 in the UBG

Ezekiel 42 in the UGV

Ezekiel 42 in the UGV2

Ezekiel 42 in the UGV3

Ezekiel 42 in the VBL

Ezekiel 42 in the VDCC

Ezekiel 42 in the YALU

Ezekiel 42 in the YAPE

Ezekiel 42 in the YBVTP

Ezekiel 42 in the ZBP