Habakkuk 2 (BOYCB)
1 Èmi yóò dúró lórí ibusọ́ mi láti máa wòye,èmi yóò sì gbé ara mi ka orí alóre,èmi yóò si ṣọ́ láti gbọ́ ohun tí yóò sọ fún miàti èsì ti èmi yóò fún ẹ̀sùn yìí nígbà tó bá ń bá mi wí. 2 Nígbà náà ni OLÚWA dáhùn pé,“Kọ ìṣípayá náà sílẹ̀kí o sì fi hàn ketekete lórí wàláàkí ẹni tí ń kà á, lè máa sáré. 3 Nítorí ìṣípayá náà jẹ́ tí ìgbà kan tí a múra sílẹ̀ dè;yóò máa yára sí ìgbẹ̀yìnkí yóò sìsọ èké.Bí o tilẹ̀ lọ́ra, dúró dè é;nítorí, dájúdájú, yóò dé, kí yóò sí pẹ́.” 4 “Kíyèsi, ọkàn rẹ tí ó gbéga,ìfẹ́ rẹ̀ kò dúró ṣinṣin nínú rẹ̀,ṣùgbọ́n olódodo yóò wa nípa ìgbàgbọ́ rẹ̀. 5 Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lú, nítorí tí ọtí wáìnì ni ẹ̀tàn,agbéraga ènìyàn òun, kò sì ní sinmiẹni tí ó sọ ìwọra rẹ di gbígbòòrò bí isà òkú,ó sì dàbí ikú, a kò sì le tẹ́ ẹ lọ́rùn,ó kó gbogbo orílẹ̀-èdè jọ sí ọ̀dọ̀ó sì gba gbogbo ènìyàn jọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀. 6 “Gbogbo àwọn wọ̀nyí kì yóò máa pa òwe sí i tí wọn yóò sì máa kọ orin òwe sí i wí pé,“ ‘Ègbé ni fún ẹni tí ń mu ohun tí kì í ṣe tirẹ̀ pọ̀ sí i!Tí ó sì sọ ara rẹ̀ di ọlọ́rọ̀ nípasẹ̀ ìlọ́nilọ́wọ́gbà!Eléyìí yóò ha ti pẹ́ tó?’ 7 Ǹjẹ́ ẹni ti ó yọ ọ́ lẹ́nu, kí yóò ha dìde ní òjijì?Àti àwọn tí ó wàhálà rẹ kì yóò jí, kí wọn ó sì dẹ́rùbà ọ́?Nígbà náà ni ìwọ yóò wa dí ìkógun fún wọn. 8 Nítorí ìwọ ti kó Orílẹ̀-èdè púpọ̀,àwọn ènìyàn tókù yóò sì kó ọnítorí ìwọ tí ta ẹ̀jẹ̀ ènìyàn sílẹ̀; nítorí ẹ̀jẹ̀,ìwọ tí pa ilẹ̀ àti ìlú ńlá runàti gbogbo ènìyàn to ń gbé inú rẹ̀. 9 “Ègbé ni fún ẹni tí ń jẹ èrè ìjẹkújẹ sí ilé rẹ̀,tí o sí gbé ìtẹ́ rẹ̀ lórí ibi gíga,kí a ba le gbà á sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ibi! 10 Ìwọ ti gbìmọ̀ ìtìjú sí ilé rẹnípa kíké ènìyàn púpọ̀ kúrò;ìwọ sì ti pàdánù ẹ̀mí rẹ. 11 Nítorí tí òkúta yóò kígbe jáde láti inú ògiri wá,àti ìtí igi láti inú igi rírẹ́ wá yóò sì dá a lóhùn. 12 “Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ẹ̀jẹ̀ kọ́ ìlú,tí o sì fi àìṣedéédéé tẹ ìlú ńlá dó? 13 OLÚWA àwọn ọmọ-ogun kò ha ti ṣètò rẹ̀ pélàálàá àwọn ènìyàn jẹ́ epo fún inákí àwọn orílẹ̀-èdè náà sì máa ṣe wàhálà fún asán? 14 Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo OLÚWA,bí omi ti bo Òkun. 15 “Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ohun mímu fún aládùúgbò rẹ̀,tí ó sì fi ọtí-lílé rẹ̀ fún un, tí o sì jẹ́ kó mu àmupara,kí ìwọ kí ó ba lè wo ìhòhò wọn.” 16 Ìtìjú yóò bò ọ́ dípò ògo, ìwọ náà mu pẹ̀lúkí ìhòhò rẹ kí ó lè hàn,ago ọwọ́ ọ̀tún OLÚWA, yóò yípadà sí ọ,ìtìjú yóò sì bo ògo rẹ. 17 Nítorí ìwà ipá tí ó tí hù sí Lebanoni yóò bò ọ́,àti ìparun àwọn ẹranko yóò dẹ́rùbà ọ́ mọ́lẹ̀.Nítorí ìwọ tí ta ẹ̀jẹ̀ ènìyàn sílẹ̀;ìwọ tí pa ilẹ̀ náà àti ìlú ńlá run àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀. 18 “Èrè kí ni òrìṣà ni, tí oníṣọ̀nà rẹ̀ fi gbẹ́ ẹ,ère dídá ti ń kọ ni èké?Nítorí ti ẹni ti ó dá a gbẹ́kẹ̀ rẹ̀ lé ohun tí ó fúnra rẹ̀ dá;ó sì mọ ère tí kò le fọhùn. 19 Ègbé ni fún ẹni ti ń sọ fún igi pé, ‘Di alààyè?’Fún òkúta tí kò lè fọhùn pé, ‘Dìde.’Ǹjẹ́ òun lè tọ́ ni sí ọ̀nà?Wúrà àti fàdákà ni a fi bò ó yíká;kò sì sí èémí kan nínú rẹ.” 20 Ṣùgbọ́n OLÚWA wà nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀;ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé parọ́rọ́ níwájú rẹ.
In Other Versions
Habakkuk 2 in the ANGEFD
Habakkuk 2 in the ANTPNG2D
Habakkuk 2 in the AS21
Habakkuk 2 in the BAGH
Habakkuk 2 in the BBPNG
Habakkuk 2 in the BBT1E
Habakkuk 2 in the BDS
Habakkuk 2 in the BEV
Habakkuk 2 in the BHAD
Habakkuk 2 in the BIB
Habakkuk 2 in the BLPT
Habakkuk 2 in the BNT
Habakkuk 2 in the BNTABOOT
Habakkuk 2 in the BNTLV
Habakkuk 2 in the BOATCB
Habakkuk 2 in the BOATCB2
Habakkuk 2 in the BOBCV
Habakkuk 2 in the BOCNT
Habakkuk 2 in the BOECS
Habakkuk 2 in the BOGWICC
Habakkuk 2 in the BOHCB
Habakkuk 2 in the BOHCV
Habakkuk 2 in the BOHLNT
Habakkuk 2 in the BOHNTLTAL
Habakkuk 2 in the BOICB
Habakkuk 2 in the BOILNTAP
Habakkuk 2 in the BOITCV
Habakkuk 2 in the BOKCV
Habakkuk 2 in the BOKCV2
Habakkuk 2 in the BOKHWOG
Habakkuk 2 in the BOKSSV
Habakkuk 2 in the BOLCB
Habakkuk 2 in the BOLCB2
Habakkuk 2 in the BOMCV
Habakkuk 2 in the BONAV
Habakkuk 2 in the BONCB
Habakkuk 2 in the BONLT
Habakkuk 2 in the BONUT2
Habakkuk 2 in the BOPLNT
Habakkuk 2 in the BOSCB
Habakkuk 2 in the BOSNC
Habakkuk 2 in the BOTLNT
Habakkuk 2 in the BOVCB
Habakkuk 2 in the BPBB
Habakkuk 2 in the BPH
Habakkuk 2 in the BSB
Habakkuk 2 in the CCB
Habakkuk 2 in the CUV
Habakkuk 2 in the CUVS
Habakkuk 2 in the DBT
Habakkuk 2 in the DGDNT
Habakkuk 2 in the DHNT
Habakkuk 2 in the DNT
Habakkuk 2 in the ELBE
Habakkuk 2 in the EMTV
Habakkuk 2 in the ESV
Habakkuk 2 in the FBV
Habakkuk 2 in the FEB
Habakkuk 2 in the GGMNT
Habakkuk 2 in the GNT
Habakkuk 2 in the HARY
Habakkuk 2 in the HNT
Habakkuk 2 in the IRVA
Habakkuk 2 in the IRVB
Habakkuk 2 in the IRVG
Habakkuk 2 in the IRVH
Habakkuk 2 in the IRVK
Habakkuk 2 in the IRVM
Habakkuk 2 in the IRVM2
Habakkuk 2 in the IRVO
Habakkuk 2 in the IRVP
Habakkuk 2 in the IRVT
Habakkuk 2 in the IRVT2
Habakkuk 2 in the IRVU
Habakkuk 2 in the ISVN
Habakkuk 2 in the JSNT
Habakkuk 2 in the KAPI
Habakkuk 2 in the KBT1ETNIK
Habakkuk 2 in the KBV
Habakkuk 2 in the KJV
Habakkuk 2 in the KNFD
Habakkuk 2 in the LBA
Habakkuk 2 in the LBLA
Habakkuk 2 in the LNT
Habakkuk 2 in the LSV
Habakkuk 2 in the MAAL
Habakkuk 2 in the MBV
Habakkuk 2 in the MBV2
Habakkuk 2 in the MHNT
Habakkuk 2 in the MKNFD
Habakkuk 2 in the MNG
Habakkuk 2 in the MNT
Habakkuk 2 in the MNT2
Habakkuk 2 in the MRS1T
Habakkuk 2 in the NAA
Habakkuk 2 in the NASB
Habakkuk 2 in the NBLA
Habakkuk 2 in the NBS
Habakkuk 2 in the NBVTP
Habakkuk 2 in the NET2
Habakkuk 2 in the NIV11
Habakkuk 2 in the NNT
Habakkuk 2 in the NNT2
Habakkuk 2 in the NNT3
Habakkuk 2 in the PDDPT
Habakkuk 2 in the PFNT
Habakkuk 2 in the RMNT
Habakkuk 2 in the SBIAS
Habakkuk 2 in the SBIBS
Habakkuk 2 in the SBIBS2
Habakkuk 2 in the SBICS
Habakkuk 2 in the SBIDS
Habakkuk 2 in the SBIGS
Habakkuk 2 in the SBIHS
Habakkuk 2 in the SBIIS
Habakkuk 2 in the SBIIS2
Habakkuk 2 in the SBIIS3
Habakkuk 2 in the SBIKS
Habakkuk 2 in the SBIKS2
Habakkuk 2 in the SBIMS
Habakkuk 2 in the SBIOS
Habakkuk 2 in the SBIPS
Habakkuk 2 in the SBISS
Habakkuk 2 in the SBITS
Habakkuk 2 in the SBITS2
Habakkuk 2 in the SBITS3
Habakkuk 2 in the SBITS4
Habakkuk 2 in the SBIUS
Habakkuk 2 in the SBIVS
Habakkuk 2 in the SBT
Habakkuk 2 in the SBT1E
Habakkuk 2 in the SCHL
Habakkuk 2 in the SNT
Habakkuk 2 in the SUSU
Habakkuk 2 in the SUSU2
Habakkuk 2 in the SYNO
Habakkuk 2 in the TBIAOTANT
Habakkuk 2 in the TBT1E
Habakkuk 2 in the TBT1E2
Habakkuk 2 in the TFTIP
Habakkuk 2 in the TFTU
Habakkuk 2 in the TGNTATF3T
Habakkuk 2 in the THAI
Habakkuk 2 in the TNFD
Habakkuk 2 in the TNT
Habakkuk 2 in the TNTIK
Habakkuk 2 in the TNTIL
Habakkuk 2 in the TNTIN
Habakkuk 2 in the TNTIP
Habakkuk 2 in the TNTIZ
Habakkuk 2 in the TOMA
Habakkuk 2 in the TTENT
Habakkuk 2 in the UBG
Habakkuk 2 in the UGV
Habakkuk 2 in the UGV2
Habakkuk 2 in the UGV3
Habakkuk 2 in the VBL
Habakkuk 2 in the VDCC
Habakkuk 2 in the YALU
Habakkuk 2 in the YAPE
Habakkuk 2 in the YBVTP
Habakkuk 2 in the ZBP