Hosea 4 (BOYCB)

1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA ẹ̀yin ọmọ Israẹli,nítorí pé OLÚWA fi ẹ̀sùnkan ẹ̀yin tí ń gbé ní ilẹ̀ náà.“Kò sí ìwà òtítọ́, kò sí ìfẹ́,Kò sí ìmọ̀ Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà, 2 àfi èpè, irọ́ pípa àti ìpànìyànolè jíjà àti panṣágà.Wọ́n rú gbogbo òfin,ìtàjẹ̀ sílẹ̀ sì ń gorí ìtàjẹ̀ sílẹ̀. 3 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀,gbogbo olùgbé ibẹ̀ sì ń ṣòfò dànù.Ẹranko igbó àti ẹyẹ ojú ọ̀runàti ẹja inú omi ló ń kú. 4 “Ṣùgbọ́n kí ẹnikẹ́ni má ṣe mú ẹ̀sùn wá,kí ẹnìkan má sì ṣe fi ẹ̀sùn kan ẹnìkejìnítorí àwọn ènìyàn rẹ̀ dàbíàwọn ti ń fi ẹ̀sùn kan àlùfáà. 5 Ẹ ń ṣubú lọ́sàn án àti lóruàwọn wòlíì yín sì ń ṣubú pẹ̀lú yín.Èmi ó pa ìyá rẹ run, 6 àwọn ènìyàn mi ń ṣègbé nítorí pé wọn kò ní ìmọ̀. “Nítorí pé ẹ ti kọ ìmọ̀ sílẹ̀.Èmi náà kọ̀ yín ní àlùfáà mi;nítorí pé ẹ ti kọ òfin Ọlọ́run yín sílẹ̀,Èmi náà yóò gbàgbé àwọn ọmọ yín. 7 Bí àwọn àlùfáà ṣe ń pọ̀ sí ibẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ń dẹ́ṣẹ̀ sí mi.Wọ́n yí ògo mi padà sí ohun ìtìjú 8 wọ́n ń jẹun nípa ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn mi,wọ́n sì ń gbádùn nínú ìwà búburú wọn. 9 Yóò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ṣe rí náà ni àwọn àlùfáà rí.Èmi ó jẹ gbogbo wọn ní yà nítorí ọ̀nà wọn.Èmi ó sì san án fún wọn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn. 10 “Wọn ó máa jẹun ṣùgbọ́n wọn kò ní yó;wọn ó ṣe àgbèrè ṣùgbọ́n, wọn kò ni pọ̀ sí i,nítorí pé wọ́n ti kọ OLÚWA sílẹ̀,wọ́n sì ti fi ara wọn 11 fún àgbèrè;wọ́n fi ara wọn fún wáìnì àtijọ́,àti tuntun èyí tó gba òye àwọn ènìyàn mi sọnù. 12 Wọ́n ń gba ìmọ̀ràn lọ́wọ́ ère igiọ̀pá igi sì ń dá wọn lóhùn.Ẹ̀mí àgbèrè ti mú wọn ṣìnàwọ́n sì jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wọn. 13 Wọ́n ń rú ẹbọ lórí àwọn òkè ńlá,wọ́n sì ń sun ọrẹ tùràrí lórí àwọn òkè kékeré,lábẹ́ igi óákù, àti igi Poplariàti igi ẹlimuati onírúurú igi tí ìbòjú rẹ̀ dára.Nítorí náà àwọn ọmọbìnrin yín yóò ṣe àgbèrèàti àwọn àfẹ́sọ́nà yín yóò ṣe àgbèrè. 14 “Èmi kò ní jẹ àwọn ọmọbìnrin yínní yà nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrètàbí àwọn àfẹ́sọ́nà ọmọ yín,nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrènítorí pé àwọn ọkùnrin pàápàá ń bá alágbèrè kẹ́gbẹ́.Wọ́n sì ń rú ẹbọ pẹ̀lú àwọn alágbèrè ojúbọ òrìṣà.Nítorí náà, ènìyàn tí kò bá ní òye yóò parun! 15 “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o ṣe àgbèrè ìwọ Israẹli,ìdájọ́ yìí wà fún un yín. Ẹ má ṣe jẹ́ kí Juda di ẹlẹ́bi. “Ẹ má ṣe lọ sí Gilgali.Ẹ má sì ṣe gòkè lọ sí Beti-Afeniẹ má sì búra pé, ‘Bí OLÚWA ti wà láààyè nítòótọ́!’ 16 Àwọn ọmọ Israẹli ṣe agídíbí alágídí ọmọ màlúù.Báwo wá ni OLÚWA ṣe fẹ́ bọ́ wọnbí àgùntàn ní pápá oko tútù? 17 Efraimu ti darapọ̀ mọ́òrìṣà, ẹ fi sílẹ̀! 18 Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán,wọ́n tún tẹ̀síwájú nínú àgbèrè.Àwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ. 19 Ìjì ni yóò gbá wọn lọ.Gbogbo ìrúbọ wọn yóò sì kó ìtìjú bá wọn.

In Other Versions

Hosea 4 in the ANGEFD

Hosea 4 in the ANTPNG2D

Hosea 4 in the AS21

Hosea 4 in the BAGH

Hosea 4 in the BBPNG

Hosea 4 in the BBT1E

Hosea 4 in the BDS

Hosea 4 in the BEV

Hosea 4 in the BHAD

Hosea 4 in the BIB

Hosea 4 in the BLPT

Hosea 4 in the BNT

Hosea 4 in the BNTABOOT

Hosea 4 in the BNTLV

Hosea 4 in the BOATCB

Hosea 4 in the BOATCB2

Hosea 4 in the BOBCV

Hosea 4 in the BOCNT

Hosea 4 in the BOECS

Hosea 4 in the BOGWICC

Hosea 4 in the BOHCB

Hosea 4 in the BOHCV

Hosea 4 in the BOHLNT

Hosea 4 in the BOHNTLTAL

Hosea 4 in the BOICB

Hosea 4 in the BOILNTAP

Hosea 4 in the BOITCV

Hosea 4 in the BOKCV

Hosea 4 in the BOKCV2

Hosea 4 in the BOKHWOG

Hosea 4 in the BOKSSV

Hosea 4 in the BOLCB

Hosea 4 in the BOLCB2

Hosea 4 in the BOMCV

Hosea 4 in the BONAV

Hosea 4 in the BONCB

Hosea 4 in the BONLT

Hosea 4 in the BONUT2

Hosea 4 in the BOPLNT

Hosea 4 in the BOSCB

Hosea 4 in the BOSNC

Hosea 4 in the BOTLNT

Hosea 4 in the BOVCB

Hosea 4 in the BPBB

Hosea 4 in the BPH

Hosea 4 in the BSB

Hosea 4 in the CCB

Hosea 4 in the CUV

Hosea 4 in the CUVS

Hosea 4 in the DBT

Hosea 4 in the DGDNT

Hosea 4 in the DHNT

Hosea 4 in the DNT

Hosea 4 in the ELBE

Hosea 4 in the EMTV

Hosea 4 in the ESV

Hosea 4 in the FBV

Hosea 4 in the FEB

Hosea 4 in the GGMNT

Hosea 4 in the GNT

Hosea 4 in the HARY

Hosea 4 in the HNT

Hosea 4 in the IRVA

Hosea 4 in the IRVB

Hosea 4 in the IRVG

Hosea 4 in the IRVH

Hosea 4 in the IRVK

Hosea 4 in the IRVM

Hosea 4 in the IRVM2

Hosea 4 in the IRVO

Hosea 4 in the IRVP

Hosea 4 in the IRVT

Hosea 4 in the IRVT2

Hosea 4 in the IRVU

Hosea 4 in the ISVN

Hosea 4 in the JSNT

Hosea 4 in the KAPI

Hosea 4 in the KBT1ETNIK

Hosea 4 in the KBV

Hosea 4 in the KJV

Hosea 4 in the KNFD

Hosea 4 in the LBA

Hosea 4 in the LBLA

Hosea 4 in the LNT

Hosea 4 in the LSV

Hosea 4 in the MAAL

Hosea 4 in the MBV

Hosea 4 in the MBV2

Hosea 4 in the MHNT

Hosea 4 in the MKNFD

Hosea 4 in the MNG

Hosea 4 in the MNT

Hosea 4 in the MNT2

Hosea 4 in the MRS1T

Hosea 4 in the NAA

Hosea 4 in the NASB

Hosea 4 in the NBLA

Hosea 4 in the NBS

Hosea 4 in the NBVTP

Hosea 4 in the NET2

Hosea 4 in the NIV11

Hosea 4 in the NNT

Hosea 4 in the NNT2

Hosea 4 in the NNT3

Hosea 4 in the PDDPT

Hosea 4 in the PFNT

Hosea 4 in the RMNT

Hosea 4 in the SBIAS

Hosea 4 in the SBIBS

Hosea 4 in the SBIBS2

Hosea 4 in the SBICS

Hosea 4 in the SBIDS

Hosea 4 in the SBIGS

Hosea 4 in the SBIHS

Hosea 4 in the SBIIS

Hosea 4 in the SBIIS2

Hosea 4 in the SBIIS3

Hosea 4 in the SBIKS

Hosea 4 in the SBIKS2

Hosea 4 in the SBIMS

Hosea 4 in the SBIOS

Hosea 4 in the SBIPS

Hosea 4 in the SBISS

Hosea 4 in the SBITS

Hosea 4 in the SBITS2

Hosea 4 in the SBITS3

Hosea 4 in the SBITS4

Hosea 4 in the SBIUS

Hosea 4 in the SBIVS

Hosea 4 in the SBT

Hosea 4 in the SBT1E

Hosea 4 in the SCHL

Hosea 4 in the SNT

Hosea 4 in the SUSU

Hosea 4 in the SUSU2

Hosea 4 in the SYNO

Hosea 4 in the TBIAOTANT

Hosea 4 in the TBT1E

Hosea 4 in the TBT1E2

Hosea 4 in the TFTIP

Hosea 4 in the TFTU

Hosea 4 in the TGNTATF3T

Hosea 4 in the THAI

Hosea 4 in the TNFD

Hosea 4 in the TNT

Hosea 4 in the TNTIK

Hosea 4 in the TNTIL

Hosea 4 in the TNTIN

Hosea 4 in the TNTIP

Hosea 4 in the TNTIZ

Hosea 4 in the TOMA

Hosea 4 in the TTENT

Hosea 4 in the UBG

Hosea 4 in the UGV

Hosea 4 in the UGV2

Hosea 4 in the UGV3

Hosea 4 in the VBL

Hosea 4 in the VDCC

Hosea 4 in the YALU

Hosea 4 in the YAPE

Hosea 4 in the YBVTP

Hosea 4 in the ZBP