Isaiah 47 (BOYCB)
1 “Sọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku,wúńdíá ọmọbìnrin Babeli;jókòó ní ilẹ̀ láìsí ìtẹ́,ọmọbìnrin àwọn ará Babeli.A kì yóò pè ọ́ ní aláìlókun àti ẹlẹgẹ́ mọ́. 2 Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun;mú ìbòjú rẹ kúrò.Ká aṣọ ẹsẹ̀ rẹ sókè, ká aṣọ itan,kí o sì la odò wọ̀n-ọn-nì kọjá. 3 Ìhòhò rẹ ni a ó sí sítaàti ìtìjú rẹ ni a ó ṣí sílẹ̀.Èmi yóò sì gba ẹ̀san,Èmi kì yóò sì dá ẹnìkan sí.” 4 Olùràpadà wa OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀òun ni Ẹni Mímọ́ Israẹli. 5 “Jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, lọ sínú òkùnkùn,ọmọbìnrin àwọn ará Babeli;a kì yóò pè ọ́ ní ọbabìnrinàwọn ilẹ̀ ọba mọ́. 6 Inú bí mi sí àwọn ènìyàn mití mo sì ba ogún mi jẹ́,mo fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́,Ìwọ kò sì síjú àánú wò wọ́n.Lórí àwọn arúgbó pẹ̀lúní o gbé àjàgà tí ó wúwo lé. 7 Ìwọ wí pé, ‘Èmi yóò tẹ̀síwájú títí láé—ọbabìnrin ayérayé!’Ṣùgbọ́n ìwọ kò kíyèsi nǹkan wọ̀nyítàbí kí o ronú nípa ohun tí ó lè ṣẹlẹ̀. 8 “Nísinsin yìí, tẹ́tí sílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dátí o kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ nínú ààbò rẹtí o sì ń sọ fún ara rẹ pé,‘Èmi ni, kò sì ṣí ẹlòmíràn lẹ́yìn mi.Èmi kì yóò di opótàbí kí n pàdánù àwọn ọmọ.’ 9 Méjèèjì yìí ni yóò wá sórí rẹláìpẹ́ jọjọ, ní ọjọ́ kan náà:pípàdánù ọmọ àti dídi opó.Wọn yóò wá sórí rẹ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,pẹ̀lúpẹ̀lú àwọn ìṣe oṣó rẹàti àwọn èpè rẹ tí ko lágbára. 10 Ìwọ ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ìwà ìkà rẹó sì ti wí pé, ‘Kò sí ẹni tí ó rí mi?’Ọgbọ́n àti òye rẹ ti ṣì ọ́ lọ́nànígbà tí o wí fún ara rẹ pé,‘Èmi ni, kò sí ẹlòmíràn lẹ́yìn mi.’ 11 Ìparun yóò dé bá ọbẹ́ẹ̀ ni ìwọ kì yóò mọ ọ̀nà láti ré e kúrò.Àjálù kan yóò ṣubú lù ọ́tí o kì yóò le è fi ètùtù ré kúrò;òfò kan tí o kò le faradà niyóò wá lójijì sí oríì rẹ. 12 “Tẹ̀síwájú nígbà náà, pẹ̀lú àfọ̀ṣẹ rẹàti pẹ̀lú ìwà oṣó rẹ gbogbo,tí o ti ń ṣiṣẹ́ fún láti ìgbà èwe rẹ wá.Bóyá o le è ṣàṣeyọrí,bóyá o le è dá rúgúdù sílẹ̀. 13 Gbogbo ìmọ̀ràn tí o ti gbà nió ti sọ ọ́ di akúrẹtẹ̀!Jẹ́ kí àwọn awòràwọ̀ rẹ bọ́ síwájú,àwọn awòràwọ̀ tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀láti oṣù dé oṣù,jẹ́ kí wọ́n gbà ọ́ lọ́wọ́ ohun tí ó ń bọ̀ wá bá ọ. 14 Lóòótọ́ wọ́n dàbí ìṣẹ́pẹ́ igi;iná ni yóò jó wọn dànù.Wọn kò kúkú lè gba ara wọn làlọ́wọ́ agbára iná náà.Kò sí èédú láti mú ara ẹnikẹ́ni gbónáníhìn-ín kò sí iná tí ènìyàn le jókòó tì. 15 Gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe fún ọ nìyìígbogbo èyí ní o tí ṣíṣẹ́ pẹ̀lú u rẹ̀tí o sì ti ń rù kiri láti ìgbà èwe.Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ń lọ nínú àṣìṣe rẹ̀;kò sí ẹyọ ẹnìkan tí ó lè gbà ọ́.
In Other Versions
Isaiah 47 in the ANGEFD
Isaiah 47 in the ANTPNG2D
Isaiah 47 in the AS21
Isaiah 47 in the BAGH
Isaiah 47 in the BBPNG
Isaiah 47 in the BBT1E
Isaiah 47 in the BDS
Isaiah 47 in the BEV
Isaiah 47 in the BHAD
Isaiah 47 in the BIB
Isaiah 47 in the BLPT
Isaiah 47 in the BNT
Isaiah 47 in the BNTABOOT
Isaiah 47 in the BNTLV
Isaiah 47 in the BOATCB
Isaiah 47 in the BOATCB2
Isaiah 47 in the BOBCV
Isaiah 47 in the BOCNT
Isaiah 47 in the BOECS
Isaiah 47 in the BOGWICC
Isaiah 47 in the BOHCB
Isaiah 47 in the BOHCV
Isaiah 47 in the BOHLNT
Isaiah 47 in the BOHNTLTAL
Isaiah 47 in the BOICB
Isaiah 47 in the BOILNTAP
Isaiah 47 in the BOITCV
Isaiah 47 in the BOKCV
Isaiah 47 in the BOKCV2
Isaiah 47 in the BOKHWOG
Isaiah 47 in the BOKSSV
Isaiah 47 in the BOLCB
Isaiah 47 in the BOLCB2
Isaiah 47 in the BOMCV
Isaiah 47 in the BONAV
Isaiah 47 in the BONCB
Isaiah 47 in the BONLT
Isaiah 47 in the BONUT2
Isaiah 47 in the BOPLNT
Isaiah 47 in the BOSCB
Isaiah 47 in the BOSNC
Isaiah 47 in the BOTLNT
Isaiah 47 in the BOVCB
Isaiah 47 in the BPBB
Isaiah 47 in the BPH
Isaiah 47 in the BSB
Isaiah 47 in the CCB
Isaiah 47 in the CUV
Isaiah 47 in the CUVS
Isaiah 47 in the DBT
Isaiah 47 in the DGDNT
Isaiah 47 in the DHNT
Isaiah 47 in the DNT
Isaiah 47 in the ELBE
Isaiah 47 in the EMTV
Isaiah 47 in the ESV
Isaiah 47 in the FBV
Isaiah 47 in the FEB
Isaiah 47 in the GGMNT
Isaiah 47 in the GNT
Isaiah 47 in the HARY
Isaiah 47 in the HNT
Isaiah 47 in the IRVA
Isaiah 47 in the IRVB
Isaiah 47 in the IRVG
Isaiah 47 in the IRVH
Isaiah 47 in the IRVK
Isaiah 47 in the IRVM
Isaiah 47 in the IRVM2
Isaiah 47 in the IRVO
Isaiah 47 in the IRVP
Isaiah 47 in the IRVT
Isaiah 47 in the IRVT2
Isaiah 47 in the IRVU
Isaiah 47 in the ISVN
Isaiah 47 in the JSNT
Isaiah 47 in the KAPI
Isaiah 47 in the KBT1ETNIK
Isaiah 47 in the KBV
Isaiah 47 in the KJV
Isaiah 47 in the KNFD
Isaiah 47 in the LBA
Isaiah 47 in the LBLA
Isaiah 47 in the LNT
Isaiah 47 in the LSV
Isaiah 47 in the MAAL
Isaiah 47 in the MBV
Isaiah 47 in the MBV2
Isaiah 47 in the MHNT
Isaiah 47 in the MKNFD
Isaiah 47 in the MNG
Isaiah 47 in the MNT
Isaiah 47 in the MNT2
Isaiah 47 in the MRS1T
Isaiah 47 in the NAA
Isaiah 47 in the NASB
Isaiah 47 in the NBLA
Isaiah 47 in the NBS
Isaiah 47 in the NBVTP
Isaiah 47 in the NET2
Isaiah 47 in the NIV11
Isaiah 47 in the NNT
Isaiah 47 in the NNT2
Isaiah 47 in the NNT3
Isaiah 47 in the PDDPT
Isaiah 47 in the PFNT
Isaiah 47 in the RMNT
Isaiah 47 in the SBIAS
Isaiah 47 in the SBIBS
Isaiah 47 in the SBIBS2
Isaiah 47 in the SBICS
Isaiah 47 in the SBIDS
Isaiah 47 in the SBIGS
Isaiah 47 in the SBIHS
Isaiah 47 in the SBIIS
Isaiah 47 in the SBIIS2
Isaiah 47 in the SBIIS3
Isaiah 47 in the SBIKS
Isaiah 47 in the SBIKS2
Isaiah 47 in the SBIMS
Isaiah 47 in the SBIOS
Isaiah 47 in the SBIPS
Isaiah 47 in the SBISS
Isaiah 47 in the SBITS
Isaiah 47 in the SBITS2
Isaiah 47 in the SBITS3
Isaiah 47 in the SBITS4
Isaiah 47 in the SBIUS
Isaiah 47 in the SBIVS
Isaiah 47 in the SBT
Isaiah 47 in the SBT1E
Isaiah 47 in the SCHL
Isaiah 47 in the SNT
Isaiah 47 in the SUSU
Isaiah 47 in the SUSU2
Isaiah 47 in the SYNO
Isaiah 47 in the TBIAOTANT
Isaiah 47 in the TBT1E
Isaiah 47 in the TBT1E2
Isaiah 47 in the TFTIP
Isaiah 47 in the TFTU
Isaiah 47 in the TGNTATF3T
Isaiah 47 in the THAI
Isaiah 47 in the TNFD
Isaiah 47 in the TNT
Isaiah 47 in the TNTIK
Isaiah 47 in the TNTIL
Isaiah 47 in the TNTIN
Isaiah 47 in the TNTIP
Isaiah 47 in the TNTIZ
Isaiah 47 in the TOMA
Isaiah 47 in the TTENT
Isaiah 47 in the UBG
Isaiah 47 in the UGV
Isaiah 47 in the UGV2
Isaiah 47 in the UGV3
Isaiah 47 in the VBL
Isaiah 47 in the VDCC
Isaiah 47 in the YALU
Isaiah 47 in the YAPE
Isaiah 47 in the YBVTP
Isaiah 47 in the ZBP