Isaiah 53 (BOYCB)
1 Ta ni ó ti gba ìròyìn in wa gbọ́àti ta ni a ti fi apá OLÚWA hàn fún? 2 Òun dàgbàsókè níwájú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ irúgbìn,àti gẹ́gẹ́ bí i gbòǹgbò tí ó jáde láti inú ìyàngbẹ ilẹ̀.Òun kò ní ẹwà tàbí ògo láti fà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀,kò sí ohun kankan nínú àbùdá rẹ̀tí ó fi yẹ kí a ṣàfẹ́rí i rẹ̀. 3 A kẹ́gàn rẹ̀ àwọn ènìyàn sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,ẹni ìbànújẹ́, tí ó sì mọ bí ìpọ́njú ti rí.Gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan tí àwọn ènìyàn ń fojú pamọ́ fúna kẹ́gàn rẹ, a kò sì bu ọlá fún un rárá. 4 Lóòtítọ́ ó ti ru àìlera wa lọó sì ti ru ìbànújẹ́ wa pẹ̀lú,síbẹ̀ a kà á sí ẹni tí Ọlọ́run lù,tí ó lù, tí a sì pọ́n lójú. 5 Ṣùgbọ́n a sá a lọ́gbẹ́ nítorí àìṣedéédéé waa pa á lára nítorí àìṣòdodo wa;ìjìyà tí ó mú àlàáfíà wá fún wa wà lórí i rẹ̀,àti nípa ọgbẹ́ rẹ̀ ni a fi mú wa láradá. 6 Gbogbo wa bí àgùntàn, ti ṣìnà lọ,ẹnìkọ̀ọ̀kan wa ti yà sí ọ̀nà ara rẹ̀; OLÚWA sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀gbogbo àìṣedéédéé wa. 7 A jẹ ẹ́ ní yà, a sì pọ́n ọn lójú,síbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀;a mú un wá gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́-àgùntàn sọ́dọ̀ alápatà,àti gẹ́gẹ́ bí àgùntàn tí ó dákẹ́ níwájú olùrẹ́run rẹ̀,síbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀. 8 Pẹ̀lú ìpọ́nlójú àti ìdánilẹ́jọ́ ni a mú un jáde lọ,ta ni ó sì le sọ nípa ìrànlọ́wọ́ rẹ̀?Nítorí a ké e kúrò ní ilẹ̀ àwọn alààyè;nítorí àìṣedéédéé àwọn ènìyàn mi ni a ṣe lù ú. 9 A fún un ní ibojì pẹ̀lú àwọn ìkà,àti pẹ̀lú àwọn ọlọ́rọ̀ ní ikú rẹ̀,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò hùwà jàgídíjàgan kan,tàbí kí a rí ẹ̀tàn kan ní ẹnu rẹ̀. 10 Síbẹ̀, ó wu OLÚWA láti pa á láraàti láti mú kí ó jìyà,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLÚWA fi ayé rẹ̀fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,Òun yóò rí àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ àti ọjọ́ ayérẹ̀ yóò pẹ́ títí,àti ète OLÚWA ni yóò gbèrú ní ọwọ́ rẹ̀. 11 Lẹ́yìn ìpọ́njú ẹ̀mí rẹ̀,òun yóò rí ìmọ́lẹ̀, ààyè yóò sì tẹ́ ẹ lọ́rùn;nípa ìmọ̀ rẹ̀ ìránṣẹ́ mi olódodo yóò dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ láre,Òun ni yóò sì ru àìṣedéédéé wọn. 12 Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńláòun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára,nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ fún ikú,tí a sì kà á mọ́ àwọn alárékọjá.Nítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀,ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárékọjá.
In Other Versions
Isaiah 53 in the ANGEFD
Isaiah 53 in the ANTPNG2D
Isaiah 53 in the AS21
Isaiah 53 in the BAGH
Isaiah 53 in the BBPNG
Isaiah 53 in the BBT1E
Isaiah 53 in the BDS
Isaiah 53 in the BEV
Isaiah 53 in the BHAD
Isaiah 53 in the BIB
Isaiah 53 in the BLPT
Isaiah 53 in the BNT
Isaiah 53 in the BNTABOOT
Isaiah 53 in the BNTLV
Isaiah 53 in the BOATCB
Isaiah 53 in the BOATCB2
Isaiah 53 in the BOBCV
Isaiah 53 in the BOCNT
Isaiah 53 in the BOECS
Isaiah 53 in the BOGWICC
Isaiah 53 in the BOHCB
Isaiah 53 in the BOHCV
Isaiah 53 in the BOHLNT
Isaiah 53 in the BOHNTLTAL
Isaiah 53 in the BOICB
Isaiah 53 in the BOILNTAP
Isaiah 53 in the BOITCV
Isaiah 53 in the BOKCV
Isaiah 53 in the BOKCV2
Isaiah 53 in the BOKHWOG
Isaiah 53 in the BOKSSV
Isaiah 53 in the BOLCB
Isaiah 53 in the BOLCB2
Isaiah 53 in the BOMCV
Isaiah 53 in the BONAV
Isaiah 53 in the BONCB
Isaiah 53 in the BONLT
Isaiah 53 in the BONUT2
Isaiah 53 in the BOPLNT
Isaiah 53 in the BOSCB
Isaiah 53 in the BOSNC
Isaiah 53 in the BOTLNT
Isaiah 53 in the BOVCB
Isaiah 53 in the BPBB
Isaiah 53 in the BPH
Isaiah 53 in the BSB
Isaiah 53 in the CCB
Isaiah 53 in the CUV
Isaiah 53 in the CUVS
Isaiah 53 in the DBT
Isaiah 53 in the DGDNT
Isaiah 53 in the DHNT
Isaiah 53 in the DNT
Isaiah 53 in the ELBE
Isaiah 53 in the EMTV
Isaiah 53 in the ESV
Isaiah 53 in the FBV
Isaiah 53 in the FEB
Isaiah 53 in the GGMNT
Isaiah 53 in the GNT
Isaiah 53 in the HARY
Isaiah 53 in the HNT
Isaiah 53 in the IRVA
Isaiah 53 in the IRVB
Isaiah 53 in the IRVG
Isaiah 53 in the IRVH
Isaiah 53 in the IRVK
Isaiah 53 in the IRVM
Isaiah 53 in the IRVM2
Isaiah 53 in the IRVO
Isaiah 53 in the IRVP
Isaiah 53 in the IRVT
Isaiah 53 in the IRVT2
Isaiah 53 in the IRVU
Isaiah 53 in the ISVN
Isaiah 53 in the JSNT
Isaiah 53 in the KAPI
Isaiah 53 in the KBT1ETNIK
Isaiah 53 in the KBV
Isaiah 53 in the KJV
Isaiah 53 in the KNFD
Isaiah 53 in the LBA
Isaiah 53 in the LBLA
Isaiah 53 in the LNT
Isaiah 53 in the LSV
Isaiah 53 in the MAAL
Isaiah 53 in the MBV
Isaiah 53 in the MBV2
Isaiah 53 in the MHNT
Isaiah 53 in the MKNFD
Isaiah 53 in the MNG
Isaiah 53 in the MNT
Isaiah 53 in the MNT2
Isaiah 53 in the MRS1T
Isaiah 53 in the NAA
Isaiah 53 in the NASB
Isaiah 53 in the NBLA
Isaiah 53 in the NBS
Isaiah 53 in the NBVTP
Isaiah 53 in the NET2
Isaiah 53 in the NIV11
Isaiah 53 in the NNT
Isaiah 53 in the NNT2
Isaiah 53 in the NNT3
Isaiah 53 in the PDDPT
Isaiah 53 in the PFNT
Isaiah 53 in the RMNT
Isaiah 53 in the SBIAS
Isaiah 53 in the SBIBS
Isaiah 53 in the SBIBS2
Isaiah 53 in the SBICS
Isaiah 53 in the SBIDS
Isaiah 53 in the SBIGS
Isaiah 53 in the SBIHS
Isaiah 53 in the SBIIS
Isaiah 53 in the SBIIS2
Isaiah 53 in the SBIIS3
Isaiah 53 in the SBIKS
Isaiah 53 in the SBIKS2
Isaiah 53 in the SBIMS
Isaiah 53 in the SBIOS
Isaiah 53 in the SBIPS
Isaiah 53 in the SBISS
Isaiah 53 in the SBITS
Isaiah 53 in the SBITS2
Isaiah 53 in the SBITS3
Isaiah 53 in the SBITS4
Isaiah 53 in the SBIUS
Isaiah 53 in the SBIVS
Isaiah 53 in the SBT
Isaiah 53 in the SBT1E
Isaiah 53 in the SCHL
Isaiah 53 in the SNT
Isaiah 53 in the SUSU
Isaiah 53 in the SUSU2
Isaiah 53 in the SYNO
Isaiah 53 in the TBIAOTANT
Isaiah 53 in the TBT1E
Isaiah 53 in the TBT1E2
Isaiah 53 in the TFTIP
Isaiah 53 in the TFTU
Isaiah 53 in the TGNTATF3T
Isaiah 53 in the THAI
Isaiah 53 in the TNFD
Isaiah 53 in the TNT
Isaiah 53 in the TNTIK
Isaiah 53 in the TNTIL
Isaiah 53 in the TNTIN
Isaiah 53 in the TNTIP
Isaiah 53 in the TNTIZ
Isaiah 53 in the TOMA
Isaiah 53 in the TTENT
Isaiah 53 in the UBG
Isaiah 53 in the UGV
Isaiah 53 in the UGV2
Isaiah 53 in the UGV3
Isaiah 53 in the VBL
Isaiah 53 in the VDCC
Isaiah 53 in the YALU
Isaiah 53 in the YAPE
Isaiah 53 in the YBVTP
Isaiah 53 in the ZBP