Jeremiah 12 (BOYCB)

1 OLÚWA, olódodo ni ọ́ nígbàkígbà,nígbà tí mo mú ẹjọ́ kan tọ̀ ọ́ wá.Síbẹ̀ èmi yóò bá ọ sọ̀rọ̀ nípa òdodo rẹ.Èéṣe tí ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú fi ń ṣe déédé?Èéṣe tí gbogbo àwọn aláìṣòdodo sì ń gbé ní ìrọ̀rùn? 2 Ó ti gbìn wọ́n, wọ́n sì ti fi egbò múlẹ̀,wọ́n dàgbà wọ́n sì so èso.Gbogbo ìgbà ni ó wà ní ètè wọn,o jìnnà sí ọkàn wọn. 3 Síbẹ̀ o mọ̀ mí ní OLÚWA,o ti rí mi o sì ti dán èrò mi nípa rẹ wò.Wọ, wọ́n lọ bí àgùntàn tí a fẹ́ pa.Yà wọ́n sọ́tọ̀ fún ọjọ́ pípa. 4 Yóò ti pẹ́ tó tí ọ̀gbẹlẹ̀ yóò fi wà,tí gbogbo ewéko igbó sì ń rọ?Nítorí àwọn ènìyàn búburú ni ó ń gbé ibẹ̀.Àwọn ẹranko àti àwọn ẹyẹ ti ṣègbé,pẹ̀lúpẹ̀lú àwọn ènìyàn ń sọ pé,“Kò lè rí ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wa.” 5 Bí ìwọ bá ń bá ẹlẹ́ṣẹ̀ sáré,tí àárẹ̀ sì mú ọ,báwo ni ìwọ yóò ṣe bá ẹṣin díje?Bí ìwọ bá kọsẹ̀ ní ilẹ̀ àlàáfíà,bí ìwọ bá ní ìgbẹ́kẹ̀lé,kí ni ìwọ ó ṣe nínú ẹkùn odò Jordani? 6 Àwọn arákùnrin rẹ àti àwọnìdíléti dà ọ́, kódà wọ́n ti kẹ̀yìn sí ọ,wọ́n ti hó lé ọ lórí.Má ṣe gbà wọ́n gbọ́bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ń sọ̀rọ̀ rẹ dáradára. 7 Èmi yóò kọ ilé mi sílẹ̀,èmi yóò fi ìní mi sílẹ̀.Èmi yóò fi ẹni tí mo fẹ́lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ lọ́wọ́. 8 Ogún mi ti rí sí mibí i kìnnìún nínú igbó.Ó ń bú ramúramù mọ́ mi;nítorí náà mo kórìíra rẹ̀. 9 Ogún mi kò ha ti rí sí mibí ẹyẹ kannakánnátí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ dòyì ka, tí wọ́n sì kọjú ìjà sí i?Ẹ lọ, kí ẹ sì kó gbogbo ẹranko igbó jọ,ẹ mú wọn wá jẹ. 10 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùṣọ́-àgùntàn ni yóò sì ba ọgbà àjàrà mi jẹ́,tí wọn yóò sì tẹ oko mi mọ́lẹ̀;wọ́n ó sọ oko dídára mi diibi tí a ń da ìdọ̀tí sí. 11 A ó sọ ọ́ di aṣálẹ̀ ilẹ̀tí kò wúlò níwájú mi,gbogbo ilẹ̀ ni yóò di ahoronítorí kò sí ẹnìkankan tí yóò náání. 12 Gbogbo ibi gíga tí ó wà nínú aṣálẹ̀ni àwọn apanirun ti gorí,nítorí idà OLÚWA yóò paláti ìkangun kìn-ín-ní dé ìkangun èkejì ilẹ̀ náà;kò sí àlàáfíà fún gbogbo alààyè. 13 Àlìkámà ni wọn yóò gbìn, ṣùgbọ́n ẹ̀gún ni wọn yóò ká,wọn yóò fi ara wọn ṣe wàhálà, ṣùgbọ́n òfo ni èrè wọn.Kí ojú kí ó tì yín nítorí èrè yín,nítorí ìbínú gbígbóná OLÚWA. 14 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí: “Ní ti gbogbo àwọn aládùúgbò mi búburú tí wọ́n gbẹ́sẹ̀ lé ogún tí mo fún àwọn ènìyàn Israẹli mi, Èmi yóò fà wọ́n tu kúrò lórí ilẹ̀ wọn, èmi yóò fa ìdílé Juda tu kúrò ní àárín wọn. 15 Ṣùgbọ́n tí mo bá fà wọ́n tu tán, Èmi yóò padà yọ́nú sí wọn. Èmi yóò sì padà fún oníkálùkù ní ogún ìní rẹ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ ìní oníkálùkù. 16 Bí wọ́n bá sì kọ ìwà àwọn ènìyàn mi, tí wọ́n sì fi orúkọ mi búra wí pé, ‘Níwọ̀n bí OLÚWA ń bẹ láààyè,’ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti kọ́ àwọn ènìyàn mi láti fi Baali búra, nígbà náà ni a ó gbé wọn ró láàrín àwọn ènìyàn mi. 17 Ṣùgbọ́n bí orílẹ̀-èdè kan kò bá gbọ́, Èmi yóò fà á tu pátápátá, èmi yóò sì pa wọ́n run,” ni OLÚWA wí.

In Other Versions

Jeremiah 12 in the ANGEFD

Jeremiah 12 in the ANTPNG2D

Jeremiah 12 in the AS21

Jeremiah 12 in the BAGH

Jeremiah 12 in the BBPNG

Jeremiah 12 in the BBT1E

Jeremiah 12 in the BDS

Jeremiah 12 in the BEV

Jeremiah 12 in the BHAD

Jeremiah 12 in the BIB

Jeremiah 12 in the BLPT

Jeremiah 12 in the BNT

Jeremiah 12 in the BNTABOOT

Jeremiah 12 in the BNTLV

Jeremiah 12 in the BOATCB

Jeremiah 12 in the BOATCB2

Jeremiah 12 in the BOBCV

Jeremiah 12 in the BOCNT

Jeremiah 12 in the BOECS

Jeremiah 12 in the BOGWICC

Jeremiah 12 in the BOHCB

Jeremiah 12 in the BOHCV

Jeremiah 12 in the BOHLNT

Jeremiah 12 in the BOHNTLTAL

Jeremiah 12 in the BOICB

Jeremiah 12 in the BOILNTAP

Jeremiah 12 in the BOITCV

Jeremiah 12 in the BOKCV

Jeremiah 12 in the BOKCV2

Jeremiah 12 in the BOKHWOG

Jeremiah 12 in the BOKSSV

Jeremiah 12 in the BOLCB

Jeremiah 12 in the BOLCB2

Jeremiah 12 in the BOMCV

Jeremiah 12 in the BONAV

Jeremiah 12 in the BONCB

Jeremiah 12 in the BONLT

Jeremiah 12 in the BONUT2

Jeremiah 12 in the BOPLNT

Jeremiah 12 in the BOSCB

Jeremiah 12 in the BOSNC

Jeremiah 12 in the BOTLNT

Jeremiah 12 in the BOVCB

Jeremiah 12 in the BPBB

Jeremiah 12 in the BPH

Jeremiah 12 in the BSB

Jeremiah 12 in the CCB

Jeremiah 12 in the CUV

Jeremiah 12 in the CUVS

Jeremiah 12 in the DBT

Jeremiah 12 in the DGDNT

Jeremiah 12 in the DHNT

Jeremiah 12 in the DNT

Jeremiah 12 in the ELBE

Jeremiah 12 in the EMTV

Jeremiah 12 in the ESV

Jeremiah 12 in the FBV

Jeremiah 12 in the FEB

Jeremiah 12 in the GGMNT

Jeremiah 12 in the GNT

Jeremiah 12 in the HARY

Jeremiah 12 in the HNT

Jeremiah 12 in the IRVA

Jeremiah 12 in the IRVB

Jeremiah 12 in the IRVG

Jeremiah 12 in the IRVH

Jeremiah 12 in the IRVK

Jeremiah 12 in the IRVM

Jeremiah 12 in the IRVM2

Jeremiah 12 in the IRVO

Jeremiah 12 in the IRVP

Jeremiah 12 in the IRVT

Jeremiah 12 in the IRVT2

Jeremiah 12 in the IRVU

Jeremiah 12 in the ISVN

Jeremiah 12 in the JSNT

Jeremiah 12 in the KAPI

Jeremiah 12 in the KBT1ETNIK

Jeremiah 12 in the KBV

Jeremiah 12 in the KJV

Jeremiah 12 in the KNFD

Jeremiah 12 in the LBA

Jeremiah 12 in the LBLA

Jeremiah 12 in the LNT

Jeremiah 12 in the LSV

Jeremiah 12 in the MAAL

Jeremiah 12 in the MBV

Jeremiah 12 in the MBV2

Jeremiah 12 in the MHNT

Jeremiah 12 in the MKNFD

Jeremiah 12 in the MNG

Jeremiah 12 in the MNT

Jeremiah 12 in the MNT2

Jeremiah 12 in the MRS1T

Jeremiah 12 in the NAA

Jeremiah 12 in the NASB

Jeremiah 12 in the NBLA

Jeremiah 12 in the NBS

Jeremiah 12 in the NBVTP

Jeremiah 12 in the NET2

Jeremiah 12 in the NIV11

Jeremiah 12 in the NNT

Jeremiah 12 in the NNT2

Jeremiah 12 in the NNT3

Jeremiah 12 in the PDDPT

Jeremiah 12 in the PFNT

Jeremiah 12 in the RMNT

Jeremiah 12 in the SBIAS

Jeremiah 12 in the SBIBS

Jeremiah 12 in the SBIBS2

Jeremiah 12 in the SBICS

Jeremiah 12 in the SBIDS

Jeremiah 12 in the SBIGS

Jeremiah 12 in the SBIHS

Jeremiah 12 in the SBIIS

Jeremiah 12 in the SBIIS2

Jeremiah 12 in the SBIIS3

Jeremiah 12 in the SBIKS

Jeremiah 12 in the SBIKS2

Jeremiah 12 in the SBIMS

Jeremiah 12 in the SBIOS

Jeremiah 12 in the SBIPS

Jeremiah 12 in the SBISS

Jeremiah 12 in the SBITS

Jeremiah 12 in the SBITS2

Jeremiah 12 in the SBITS3

Jeremiah 12 in the SBITS4

Jeremiah 12 in the SBIUS

Jeremiah 12 in the SBIVS

Jeremiah 12 in the SBT

Jeremiah 12 in the SBT1E

Jeremiah 12 in the SCHL

Jeremiah 12 in the SNT

Jeremiah 12 in the SUSU

Jeremiah 12 in the SUSU2

Jeremiah 12 in the SYNO

Jeremiah 12 in the TBIAOTANT

Jeremiah 12 in the TBT1E

Jeremiah 12 in the TBT1E2

Jeremiah 12 in the TFTIP

Jeremiah 12 in the TFTU

Jeremiah 12 in the TGNTATF3T

Jeremiah 12 in the THAI

Jeremiah 12 in the TNFD

Jeremiah 12 in the TNT

Jeremiah 12 in the TNTIK

Jeremiah 12 in the TNTIL

Jeremiah 12 in the TNTIN

Jeremiah 12 in the TNTIP

Jeremiah 12 in the TNTIZ

Jeremiah 12 in the TOMA

Jeremiah 12 in the TTENT

Jeremiah 12 in the UBG

Jeremiah 12 in the UGV

Jeremiah 12 in the UGV2

Jeremiah 12 in the UGV3

Jeremiah 12 in the VBL

Jeremiah 12 in the VDCC

Jeremiah 12 in the YALU

Jeremiah 12 in the YAPE

Jeremiah 12 in the YBVTP

Jeremiah 12 in the ZBP