Jeremiah 39 (BOYCB)

1 Ó sì ṣe, nígbà tí a kó Jerusalẹmu, ní ọdún kẹsànán Sedekiah, ọba Juda, nínú oṣù kẹwàá, Nebukadnessari ọba Babeli gbógun ti Jerusalẹmu pẹ̀lú gbogbo ogun rẹ̀, wọ́n sì dó tì í. 2 Ní ọjọ́ kẹsànán, oṣù kẹrin ọdún kọkànlá Sedekiah, ni a wó odi ìlú náà. 3 Nígbà náà ni gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli wá, wọ́n sì jókòó ní àárín ẹnu ibodè, àní Nergali-Ṣareseri ti Samgari, Nebo-Sarsikimu olórí ìwẹ̀fà, Nergali-Ṣareseri, olórí amòye, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli yóò kú. 4 Nígbà tí Sedekiah ọba Juda àti àwọn ọmọ-ogun rí wọn, wọ́n sá, wọ́n kúrò ní ìlú ní alẹ́, wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba lọ láàrín ẹnu ibodè pẹ̀lú odi méjì, wọ́n dojúkọ aginjù. 5 Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ọmọ-ogun Babeli lé wọn, wọ́n bá Sedekiah láàrín aginjù Jeriko. Wọ́n mú un ní ìgbèkùn, wọ́n sì mú u tọ Nebukadnessari ọba Babeli àti Ribla ní ilẹ̀ Hamati, níbi tí wọ́n ti ṣe ìdájọ́ rẹ̀. 6 Níbẹ̀ ní Ribla, ni ọba Babeli ti dúńbú àwọn ọmọ Sedekiah lójú rẹ̀, tí ó sì tún pa gbogbo àwọn ọlọ́lá ilẹ̀ Juda. 7 Nígbà náà ni ó fọ́ ojú Sedekiah, ó sì dè é pẹ̀lú ẹ̀wọ̀n láti gbé e lọ sí ilẹ̀ Babeli. 8 Àwọn Babeli dáná sun ààfin ọba àti ilé àwọn ènìyàn, wọ́n sì wó odi Jerusalẹmu. 9 Nebusaradani olórí àwọn ọmọ-ogun mú lọ sí ìgbèkùn Babeli pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó ṣẹ́kù nínú ìlú. 10 Ṣùgbọ́n Nebusaradani olórí ogun fi àwọn aláìní sílẹ̀ ní Juda, àwọn tí kò ní ohun kankan ní àkókò náà, ó fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko. 11 Nísinsin yìí, Nebukadnessari ọba àwọn Babeli pàṣẹ lórí Jeremiah, láti ọ̀dọ̀ Nebusaradani olórí ogun wá wí pé: 12 “Ẹ gbé e, kí ẹ sì bojútó o. Ẹ má ṣe ṣe ohun búburú fún un, ṣùgbọ́n ohunkóhun tó bá béèrè ni kí ẹ fi fún un.” 13 Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ pẹ̀lú, Nebusaradani balógun ìṣọ́, àti Nebusaradani olórí ìwẹ̀fà, àti Nergali-Ṣareseri, olórí amòye àti gbogbo àwọn ìjòyè ọba Babeli, 14 ránṣẹ́ láti mú Jeremiah kúrò nínú túbú. Wọ́n gbé e lọ fún Gedaliah ọmọ Ahikamu ọmọ Ṣafani láti mú padà lọ sí ilé àti máa wà pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀. 15 Nígbà tí Jeremiah wà nínú túbú, ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ̀ ọ́ wá wí pé: 16 “Lọ sọ fún Ebedimeleki ará Kuṣi, ‘Èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí: Èmi ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ mi ṣẹ lórí ìlú yìí nípa àjálù kì í ṣe àlàáfíà. Ní àkókò náà ni yóò ṣẹ lójú rẹ. 17 Ṣùgbọ́n, Èmi yóò gbà ọ́ lọ́jọ́ náà ni OLÚWA wí. A kò ní fi ọ́ lé ọwọ́ àwọn tí o bẹ̀rù. 18 Èmi yóò gbà ọ́ là; o kò ní ṣubú láti ipa idà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ, nítorí pé ìwọ ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú mi, ni OLÚWA wí.’ ”

In Other Versions

Jeremiah 39 in the ANGEFD

Jeremiah 39 in the ANTPNG2D

Jeremiah 39 in the AS21

Jeremiah 39 in the BAGH

Jeremiah 39 in the BBPNG

Jeremiah 39 in the BBT1E

Jeremiah 39 in the BDS

Jeremiah 39 in the BEV

Jeremiah 39 in the BHAD

Jeremiah 39 in the BIB

Jeremiah 39 in the BLPT

Jeremiah 39 in the BNT

Jeremiah 39 in the BNTABOOT

Jeremiah 39 in the BNTLV

Jeremiah 39 in the BOATCB

Jeremiah 39 in the BOATCB2

Jeremiah 39 in the BOBCV

Jeremiah 39 in the BOCNT

Jeremiah 39 in the BOECS

Jeremiah 39 in the BOGWICC

Jeremiah 39 in the BOHCB

Jeremiah 39 in the BOHCV

Jeremiah 39 in the BOHLNT

Jeremiah 39 in the BOHNTLTAL

Jeremiah 39 in the BOICB

Jeremiah 39 in the BOILNTAP

Jeremiah 39 in the BOITCV

Jeremiah 39 in the BOKCV

Jeremiah 39 in the BOKCV2

Jeremiah 39 in the BOKHWOG

Jeremiah 39 in the BOKSSV

Jeremiah 39 in the BOLCB

Jeremiah 39 in the BOLCB2

Jeremiah 39 in the BOMCV

Jeremiah 39 in the BONAV

Jeremiah 39 in the BONCB

Jeremiah 39 in the BONLT

Jeremiah 39 in the BONUT2

Jeremiah 39 in the BOPLNT

Jeremiah 39 in the BOSCB

Jeremiah 39 in the BOSNC

Jeremiah 39 in the BOTLNT

Jeremiah 39 in the BOVCB

Jeremiah 39 in the BPBB

Jeremiah 39 in the BPH

Jeremiah 39 in the BSB

Jeremiah 39 in the CCB

Jeremiah 39 in the CUV

Jeremiah 39 in the CUVS

Jeremiah 39 in the DBT

Jeremiah 39 in the DGDNT

Jeremiah 39 in the DHNT

Jeremiah 39 in the DNT

Jeremiah 39 in the ELBE

Jeremiah 39 in the EMTV

Jeremiah 39 in the ESV

Jeremiah 39 in the FBV

Jeremiah 39 in the FEB

Jeremiah 39 in the GGMNT

Jeremiah 39 in the GNT

Jeremiah 39 in the HARY

Jeremiah 39 in the HNT

Jeremiah 39 in the IRVA

Jeremiah 39 in the IRVB

Jeremiah 39 in the IRVG

Jeremiah 39 in the IRVH

Jeremiah 39 in the IRVK

Jeremiah 39 in the IRVM

Jeremiah 39 in the IRVM2

Jeremiah 39 in the IRVO

Jeremiah 39 in the IRVP

Jeremiah 39 in the IRVT

Jeremiah 39 in the IRVT2

Jeremiah 39 in the IRVU

Jeremiah 39 in the ISVN

Jeremiah 39 in the JSNT

Jeremiah 39 in the KAPI

Jeremiah 39 in the KBT1ETNIK

Jeremiah 39 in the KBV

Jeremiah 39 in the KJV

Jeremiah 39 in the KNFD

Jeremiah 39 in the LBA

Jeremiah 39 in the LBLA

Jeremiah 39 in the LNT

Jeremiah 39 in the LSV

Jeremiah 39 in the MAAL

Jeremiah 39 in the MBV

Jeremiah 39 in the MBV2

Jeremiah 39 in the MHNT

Jeremiah 39 in the MKNFD

Jeremiah 39 in the MNG

Jeremiah 39 in the MNT

Jeremiah 39 in the MNT2

Jeremiah 39 in the MRS1T

Jeremiah 39 in the NAA

Jeremiah 39 in the NASB

Jeremiah 39 in the NBLA

Jeremiah 39 in the NBS

Jeremiah 39 in the NBVTP

Jeremiah 39 in the NET2

Jeremiah 39 in the NIV11

Jeremiah 39 in the NNT

Jeremiah 39 in the NNT2

Jeremiah 39 in the NNT3

Jeremiah 39 in the PDDPT

Jeremiah 39 in the PFNT

Jeremiah 39 in the RMNT

Jeremiah 39 in the SBIAS

Jeremiah 39 in the SBIBS

Jeremiah 39 in the SBIBS2

Jeremiah 39 in the SBICS

Jeremiah 39 in the SBIDS

Jeremiah 39 in the SBIGS

Jeremiah 39 in the SBIHS

Jeremiah 39 in the SBIIS

Jeremiah 39 in the SBIIS2

Jeremiah 39 in the SBIIS3

Jeremiah 39 in the SBIKS

Jeremiah 39 in the SBIKS2

Jeremiah 39 in the SBIMS

Jeremiah 39 in the SBIOS

Jeremiah 39 in the SBIPS

Jeremiah 39 in the SBISS

Jeremiah 39 in the SBITS

Jeremiah 39 in the SBITS2

Jeremiah 39 in the SBITS3

Jeremiah 39 in the SBITS4

Jeremiah 39 in the SBIUS

Jeremiah 39 in the SBIVS

Jeremiah 39 in the SBT

Jeremiah 39 in the SBT1E

Jeremiah 39 in the SCHL

Jeremiah 39 in the SNT

Jeremiah 39 in the SUSU

Jeremiah 39 in the SUSU2

Jeremiah 39 in the SYNO

Jeremiah 39 in the TBIAOTANT

Jeremiah 39 in the TBT1E

Jeremiah 39 in the TBT1E2

Jeremiah 39 in the TFTIP

Jeremiah 39 in the TFTU

Jeremiah 39 in the TGNTATF3T

Jeremiah 39 in the THAI

Jeremiah 39 in the TNFD

Jeremiah 39 in the TNT

Jeremiah 39 in the TNTIK

Jeremiah 39 in the TNTIL

Jeremiah 39 in the TNTIN

Jeremiah 39 in the TNTIP

Jeremiah 39 in the TNTIZ

Jeremiah 39 in the TOMA

Jeremiah 39 in the TTENT

Jeremiah 39 in the UBG

Jeremiah 39 in the UGV

Jeremiah 39 in the UGV2

Jeremiah 39 in the UGV3

Jeremiah 39 in the VBL

Jeremiah 39 in the VDCC

Jeremiah 39 in the YALU

Jeremiah 39 in the YAPE

Jeremiah 39 in the YBVTP

Jeremiah 39 in the ZBP