Lamentations 2 (BOYCB)
1 Báwo ni Olúwa ṣe bo ọmọbìnrin Sionipẹ̀lú àwọsánmọ̀ ìbínú rẹ̀!Ó sọ ògo Israẹli kalẹ̀,láti ọ̀run sí ayé;kò rántí àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀. 2 Láìní àánú ni Olúwa gbéibùgbé Jakọbu mì;nínú ìrunú rẹ̀, ni ó wóibi gíga ọmọbìnrin Juda lulẹ̀.Ó ti mú ìjọba àti àwọn ọmọ-aládé ọkùnrinlọ sínú ilẹ̀ ní àìlọ́wọ̀. 3 Ní ìbínú gbígbóná rẹ̀ ni ó kégbogbo ìwo Israẹli.Ó ti mú ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ kúrònígbà tí àwọn ọ̀tá dé.Ó run ní Jakọbu bí ọ̀wọ́-inání àgọ́ àwọn ọmọbìnrin Sioni. 4 Ó na ọfà rẹ̀ bí ọ̀tá;ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ sì múra.Bí ti ọ̀tá tí ó ti parunó tú ìbínú rẹ̀ jáde bí inásórí àgọ́ ọmọbìnrin Sioni. 5 Olúwa dàbí ọ̀tá;ó gbé Israẹli mì.Ó ti gbé gbogbo ààfin rẹ̀ mìó pa ibi gíga rẹ̀ run.Ó sọ ìmí ẹ̀dùn àti ìbànújẹ́ di púpọ̀fún àwọn ọmọbìnrin Juda. 6 Ó mú ìparun bá ibi mímọ́,ó pa ibi ìpàdé rẹ̀ run. OLÚWA ti mú Sioni gbàgbéàjọ̀dún tí a yàn àti ọ̀sẹ̀ tí ó yàn;nínú ìbínú gbígbóná rẹ̀ ni ó runọba àti olórí àlùfáà. 7 Olúwa ti kọ̀ pẹpẹ rẹ̀ sílẹ̀ó sì ti kọ̀ ibi mímọ́ rẹ̀.Ó sì fi lé ọ̀tá lọ́wọ́àwọn odi ààfin rẹ̀;wọ́n sì kígbe ní ilé OLÚWAgẹ́gẹ́ bí ọjọ́ àpèjẹ tí a yàn. 8 OLÚWA pinnu láti faògiri tí ó yí ọmọbìnrin Sioni ya.Ó gbé wọn sórí òsùwọ̀n,kò sì fa ọwọ́ rẹ̀ padà kúrò nínú ìparun wọn.Ó mú kí ilé ìṣọ́ àti odi rẹ̀ ṣọ̀fọ̀wọ́n ṣòfò papọ̀. 9 Ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ ti wọ inú ilẹ̀;òpó rẹ̀ ni ó wó tí ó sì ti bàjẹ́.Ọba àti ọmọ ọbakùnrin rẹ̀ wà ní ìgbèkùn láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,kò sí òfin mọ́,àwọn wòlíì rẹ̀ kò ríìran láti ọ̀dọ̀ OLÚWA mọ́. 10 Àwọn àgbàgbà ọmọbìnrin Sionijókòó sílẹ̀ ní ìdákẹ́rọ́rọ́;wọ́n da eruku sí orí wọnwọ́n sì wọ aṣọ àkísà.Àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin Jerusalẹmuti tẹrí wọn ba sí ilẹ̀. 11 Ojú mi kọ̀ láti sọkún,mo ń jẹ ìrora nínú mi,mo tú ọkàn mi jáde sí ilẹ̀nítorí a pa àwọn ènìyàn mí run,nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ ọwọ́ ń kúní òpópó ìlú. 12 Wọ́n wí fún àwọn ìyá wọn,“Níbo ni ọkà àti wáìnì wà?” Wò óbí wọ́n ṣe ń kú lọ bí àwọn ọkùnrin tí a ṣe léṣení àwọn òpópónà ìlú,bí ayé wọn ṣe ń ṣòfòláti ọwọ́ ìyá wọn. 13 Kí ni mo le sọ fún ọ?Pẹ̀lú kí ni mo lè fi ọ́ wé,ìwọ ọmọbìnrin Jerusalẹmu?Kí sì ni mo lè fi ọ́ wé,kí n lè tù ọ́ nínú,ìwọ wúńdíá obìnrin Sioni?Ọgbẹ́ rẹ jì bí Òkun.Ta ni yóò wò ọ́ sàn? 14 Ìran àwọn wòlíì rẹjẹ́ kìkì ẹ̀tàn láìní ìwọ̀n;wọn kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ hàntí yóò mú ìgbèkùn kúrò fún ọ.Àwọn òrìṣà tí wọ́n fún ọjẹ́ èké àti ìmúniṣìnà. 15 Àwọn tí ó gba ọ̀nà ọ̀dọ̀ rẹpàtẹ́wọ́ lé ọ lórí;wọ́n kẹ́gàn wọ́n ju orí wọnsí ọmọbìnrin Jerusalẹmu:“Èyí ha ni ìlú tí à ń pèní àṣepé ẹwà,ìdùnnú gbogbo ayé?” 16 Gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ la ẹnu wọngbòòrò sí ọ;wọ́n kẹ́gàn, wọ́n sì payínkekewọ́n wí pé, “A ti gbé e mì tán.Èyí ni ọjọ́ tí a ti ń retí;tí a sì wá láti rí.” 17 OLÚWA ti ṣe ohun tí ó pinnu;ó ti mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ,tí ó sì pàṣẹ ní ọjọ́ pípẹ́.Ó ti ṣí ọ ní ipò láì láàánú,ó fún ọ̀tá ní ìṣẹ́gun lórí rẹ,ó ti gbé ìwo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ga. 18 Ọkàn àwọn ènìyànkígbe jáde sí OLÚWA.Odi ọmọbìnrin Sioni,jẹ́ kí ẹkún rẹ̀ sàn bí odòní ọ̀sán àti òru;má ṣe fi ara rẹ fún ìtura,ojú rẹ fún ìsinmi. 19 Dìde, kígbe sókè ní àṣálẹ́,bí ìṣọ́ òru ti bẹ̀rẹ̀tú ọkàn rẹ̀ jáde bí ominíwájú OLÚWA.Gbé ọwọ́ yín sókè sí inítorí ẹ̀mí àwọn èwe rẹ̀tí ó ń kú lọ nítorí ebiní gbogbo oríta òpópó. 20 “Wò ó, OLÚWA, kí o sì rò ó.Ta ni ìwọ ti fìyà jẹ bí èyí.Ǹjẹ́ àwọn obìnrin yóò ha jẹ ọmọ wọn,àwọn ọmọ tí wọn ń ṣe ìtọ́jú fún?Ǹjẹ́ kí a pa olórí àlùfáà àti àwọn wòlíìní ibi mímọ́ OLÚWA? 21 “Ọmọdé àti àgbà ń sùn papọ̀sínú eruku àwọn òpópó;àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrin miti ṣègbé nípa idà.Ìwọ pa wọ́n run ní ọjọ́ ìbínú rẹ,Ìwọ pa wọ́n láìní àánú. 22 “Bí ó ti ṣe ní ọjọ́ àsè,bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe fi ẹ̀rù sí ẹ̀gbẹ́ mi.Ní ọjọ́ ìbínú OLÚWAkò sí ẹni tí ó sálà tí ó sì yè;àwọn tí mo ti tọ́jú tí mo sì fẹ́ràn,ni ọ̀tá mi parun.”
In Other Versions
Lamentations 2 in the ANGEFD
Lamentations 2 in the ANTPNG2D
Lamentations 2 in the AS21
Lamentations 2 in the BAGH
Lamentations 2 in the BBPNG
Lamentations 2 in the BBT1E
Lamentations 2 in the BDS
Lamentations 2 in the BEV
Lamentations 2 in the BHAD
Lamentations 2 in the BIB
Lamentations 2 in the BLPT
Lamentations 2 in the BNT
Lamentations 2 in the BNTABOOT
Lamentations 2 in the BNTLV
Lamentations 2 in the BOATCB
Lamentations 2 in the BOATCB2
Lamentations 2 in the BOBCV
Lamentations 2 in the BOCNT
Lamentations 2 in the BOECS
Lamentations 2 in the BOGWICC
Lamentations 2 in the BOHCB
Lamentations 2 in the BOHCV
Lamentations 2 in the BOHLNT
Lamentations 2 in the BOHNTLTAL
Lamentations 2 in the BOICB
Lamentations 2 in the BOILNTAP
Lamentations 2 in the BOITCV
Lamentations 2 in the BOKCV
Lamentations 2 in the BOKCV2
Lamentations 2 in the BOKHWOG
Lamentations 2 in the BOKSSV
Lamentations 2 in the BOLCB
Lamentations 2 in the BOLCB2
Lamentations 2 in the BOMCV
Lamentations 2 in the BONAV
Lamentations 2 in the BONCB
Lamentations 2 in the BONLT
Lamentations 2 in the BONUT2
Lamentations 2 in the BOPLNT
Lamentations 2 in the BOSCB
Lamentations 2 in the BOSNC
Lamentations 2 in the BOTLNT
Lamentations 2 in the BOVCB
Lamentations 2 in the BPBB
Lamentations 2 in the BPH
Lamentations 2 in the BSB
Lamentations 2 in the CCB
Lamentations 2 in the CUV
Lamentations 2 in the CUVS
Lamentations 2 in the DBT
Lamentations 2 in the DGDNT
Lamentations 2 in the DHNT
Lamentations 2 in the DNT
Lamentations 2 in the ELBE
Lamentations 2 in the EMTV
Lamentations 2 in the ESV
Lamentations 2 in the FBV
Lamentations 2 in the FEB
Lamentations 2 in the GGMNT
Lamentations 2 in the GNT
Lamentations 2 in the HARY
Lamentations 2 in the HNT
Lamentations 2 in the IRVA
Lamentations 2 in the IRVB
Lamentations 2 in the IRVG
Lamentations 2 in the IRVH
Lamentations 2 in the IRVK
Lamentations 2 in the IRVM
Lamentations 2 in the IRVM2
Lamentations 2 in the IRVO
Lamentations 2 in the IRVP
Lamentations 2 in the IRVT
Lamentations 2 in the IRVT2
Lamentations 2 in the IRVU
Lamentations 2 in the ISVN
Lamentations 2 in the JSNT
Lamentations 2 in the KAPI
Lamentations 2 in the KBT1ETNIK
Lamentations 2 in the KBV
Lamentations 2 in the KJV
Lamentations 2 in the KNFD
Lamentations 2 in the LBA
Lamentations 2 in the LBLA
Lamentations 2 in the LNT
Lamentations 2 in the LSV
Lamentations 2 in the MAAL
Lamentations 2 in the MBV
Lamentations 2 in the MBV2
Lamentations 2 in the MHNT
Lamentations 2 in the MKNFD
Lamentations 2 in the MNG
Lamentations 2 in the MNT
Lamentations 2 in the MNT2
Lamentations 2 in the MRS1T
Lamentations 2 in the NAA
Lamentations 2 in the NASB
Lamentations 2 in the NBLA
Lamentations 2 in the NBS
Lamentations 2 in the NBVTP
Lamentations 2 in the NET2
Lamentations 2 in the NIV11
Lamentations 2 in the NNT
Lamentations 2 in the NNT2
Lamentations 2 in the NNT3
Lamentations 2 in the PDDPT
Lamentations 2 in the PFNT
Lamentations 2 in the RMNT
Lamentations 2 in the SBIAS
Lamentations 2 in the SBIBS
Lamentations 2 in the SBIBS2
Lamentations 2 in the SBICS
Lamentations 2 in the SBIDS
Lamentations 2 in the SBIGS
Lamentations 2 in the SBIHS
Lamentations 2 in the SBIIS
Lamentations 2 in the SBIIS2
Lamentations 2 in the SBIIS3
Lamentations 2 in the SBIKS
Lamentations 2 in the SBIKS2
Lamentations 2 in the SBIMS
Lamentations 2 in the SBIOS
Lamentations 2 in the SBIPS
Lamentations 2 in the SBISS
Lamentations 2 in the SBITS
Lamentations 2 in the SBITS2
Lamentations 2 in the SBITS3
Lamentations 2 in the SBITS4
Lamentations 2 in the SBIUS
Lamentations 2 in the SBIVS
Lamentations 2 in the SBT
Lamentations 2 in the SBT1E
Lamentations 2 in the SCHL
Lamentations 2 in the SNT
Lamentations 2 in the SUSU
Lamentations 2 in the SUSU2
Lamentations 2 in the SYNO
Lamentations 2 in the TBIAOTANT
Lamentations 2 in the TBT1E
Lamentations 2 in the TBT1E2
Lamentations 2 in the TFTIP
Lamentations 2 in the TFTU
Lamentations 2 in the TGNTATF3T
Lamentations 2 in the THAI
Lamentations 2 in the TNFD
Lamentations 2 in the TNT
Lamentations 2 in the TNTIK
Lamentations 2 in the TNTIL
Lamentations 2 in the TNTIN
Lamentations 2 in the TNTIP
Lamentations 2 in the TNTIZ
Lamentations 2 in the TOMA
Lamentations 2 in the TTENT
Lamentations 2 in the UBG
Lamentations 2 in the UGV
Lamentations 2 in the UGV2
Lamentations 2 in the UGV3
Lamentations 2 in the VBL
Lamentations 2 in the VDCC
Lamentations 2 in the YALU
Lamentations 2 in the YAPE
Lamentations 2 in the YBVTP
Lamentations 2 in the ZBP