Micah 1 (BOYCB)

1 Ọ̀rọ̀ OLÚWA tí ó tọ Mika ará Moreṣeti wá ní àkókò ìjọba Jotamu, Ahasi, àti Hesekiah, àwọn ọba Juda nìwọ̀nyí, ìran tí ó rí nípa Samaria àti Jerusalẹmu. 2 Ẹ gbọ́, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn,fetísílẹ̀, ìwọ ayé àti gbogbo ohun tó wà níbẹ̀,kí OLÚWA Olódùmarè lè ṣe ẹlẹ́rìí sí yín,Olúwa láti inú tẹmpili mímọ́ rẹ̀ wá. 3 Wò ó! OLÚWA ń bọ̀ wá láti ibùgbé rẹ̀;yóò sọ̀kalẹ̀, yóò sì tẹ ibi gíga ayé mọ́lẹ̀. 4 Àwọn òkè ńlá yóò sí yọ́ lábẹ́ rẹ̀,àwọn àfonífojì yóò sì pínyà,bí idà níwájú iná,bí omi tí ó ń sàn lọ ni ibi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́. 5 Nítorí ìré-òfin-kọjá Jakọbu ni gbogbo èyí,àti nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli.Kí ni ìré-òfin-kọjá Jakọbu?Ǹjẹ́ Samaria ha kọ?Kí ni àwọn ibi gíga Juda?Ǹjẹ́ Jerusalẹmu ha kọ? 6 “Nítorí náà, èmi yóò ṣe Samaria bí òkìtì lórí pápá,bí ibi ti à ń lò fún gbígbin ọgbà àjàrà.Èmi yóò gbá àwọn òkúta rẹ̀ dànù sínú àfonífojì.Èmi yóò sí tú ìpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ palẹ̀. 7 Gbogbo àwọn ère fínfín rẹ̀ ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́gbogbo àwọn ẹ̀bùn tẹmpili rẹ̀ ni a ó fi iná sun,Èmi yóò sì pa gbogbo àwọn òrìṣà rẹ̀ run.Nítorí tí ó ti kó àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ jọ láti inú owó èrè panṣágà,gẹ́gẹ́ bí owó èrè panṣágà, wọn yóò sì tún padà sí owó iṣẹ́ panṣágà.” 8 Nítorí èyí, èmi yóò sì sọkún,èmi yóò sì pohùnréré ẹkún:èmi yóò máa lọ ní ẹsẹ̀ lásán àti ní ìhòhò.Èmi yóò ké bí akátá,èmi yóò sì máa dárò bí àwọn ọmọ ògòǹgò. 9 Nítorí tí ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ aláìlèwòtán;ó sì ti wá sí Juda.Ó sì ti dé ẹnu-bodè àwọn ènìyàn mi,àní sí Jerusalẹmu. 10 Ẹ má ṣe sọ ní Gatiẹ má ṣe sọkún rárá.Ní ilẹ̀ Beti-Oframo yí ara mi nínú eruku. 11 Ẹ kọjá lọ ni ìhòhò àti ni ìtìjú,ìwọ tí ó ń gbé ni Ṣafiri.Àwọn tí ó ń gbé ni Saananikì yóò sì jáde wá.Beti-Eseli wà nínú ọ̀fọ̀;a ó sì gba ààbò rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ yin. 12 Nítorí àwọn tí ó ń gbé ni Marati ń retí ìre,ṣùgbọ́n ibi sọ̀kalẹ̀ ti ọ̀dọ̀ OLÚWA wá sí ẹnu-bodè Jerusalẹmu. 13 Ìwọ olùgbé Lakiṣi,dì kẹ̀kẹ́ mọ́ ẹranko tí ó yára.Òun sì ni ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀sí àwọn ọmọbìnrin Sioni,nítorí a rí àìṣedéédéé Israẹli nínú rẹ̀. 14 Nítorí náà ni ìwọ ó ṣe fi ìwé ìkọ̀sílẹ̀fún Moreṣeti Gati.Àwọn ilé Aksibu yóò jẹ́ ẹlẹ́tàn sí àwọn ọba Israẹli. 15 Èmi yóò sì mú àrólé kan wá sórí rẹ ìwọ olùgbé Meraṣa.Ẹni tí ó jẹ́ ògo Israẹliyóò sì wá sí Adullamu. 16 Fá irun orí rẹ nínú ọ̀fọ̀nítorí àwọn ọmọ rẹ aláìlágbára,sọ ra rẹ̀ di apárí bí ẹyẹ igún,nítorí wọn yóò kúrò lọ́dọ̀ rẹ lọ sí ìgbèkùn.

In Other Versions

Micah 1 in the ANGEFD

Micah 1 in the ANTPNG2D

Micah 1 in the AS21

Micah 1 in the BAGH

Micah 1 in the BBPNG

Micah 1 in the BBT1E

Micah 1 in the BDS

Micah 1 in the BEV

Micah 1 in the BHAD

Micah 1 in the BIB

Micah 1 in the BLPT

Micah 1 in the BNT

Micah 1 in the BNTABOOT

Micah 1 in the BNTLV

Micah 1 in the BOATCB

Micah 1 in the BOATCB2

Micah 1 in the BOBCV

Micah 1 in the BOCNT

Micah 1 in the BOECS

Micah 1 in the BOGWICC

Micah 1 in the BOHCB

Micah 1 in the BOHCV

Micah 1 in the BOHLNT

Micah 1 in the BOHNTLTAL

Micah 1 in the BOICB

Micah 1 in the BOILNTAP

Micah 1 in the BOITCV

Micah 1 in the BOKCV

Micah 1 in the BOKCV2

Micah 1 in the BOKHWOG

Micah 1 in the BOKSSV

Micah 1 in the BOLCB

Micah 1 in the BOLCB2

Micah 1 in the BOMCV

Micah 1 in the BONAV

Micah 1 in the BONCB

Micah 1 in the BONLT

Micah 1 in the BONUT2

Micah 1 in the BOPLNT

Micah 1 in the BOSCB

Micah 1 in the BOSNC

Micah 1 in the BOTLNT

Micah 1 in the BOVCB

Micah 1 in the BPBB

Micah 1 in the BPH

Micah 1 in the BSB

Micah 1 in the CCB

Micah 1 in the CUV

Micah 1 in the CUVS

Micah 1 in the DBT

Micah 1 in the DGDNT

Micah 1 in the DHNT

Micah 1 in the DNT

Micah 1 in the ELBE

Micah 1 in the EMTV

Micah 1 in the ESV

Micah 1 in the FBV

Micah 1 in the FEB

Micah 1 in the GGMNT

Micah 1 in the GNT

Micah 1 in the HARY

Micah 1 in the HNT

Micah 1 in the IRVA

Micah 1 in the IRVB

Micah 1 in the IRVG

Micah 1 in the IRVH

Micah 1 in the IRVK

Micah 1 in the IRVM

Micah 1 in the IRVM2

Micah 1 in the IRVO

Micah 1 in the IRVP

Micah 1 in the IRVT

Micah 1 in the IRVT2

Micah 1 in the IRVU

Micah 1 in the ISVN

Micah 1 in the JSNT

Micah 1 in the KAPI

Micah 1 in the KBT1ETNIK

Micah 1 in the KBV

Micah 1 in the KJV

Micah 1 in the KNFD

Micah 1 in the LBA

Micah 1 in the LBLA

Micah 1 in the LNT

Micah 1 in the LSV

Micah 1 in the MAAL

Micah 1 in the MBV

Micah 1 in the MBV2

Micah 1 in the MHNT

Micah 1 in the MKNFD

Micah 1 in the MNG

Micah 1 in the MNT

Micah 1 in the MNT2

Micah 1 in the MRS1T

Micah 1 in the NAA

Micah 1 in the NASB

Micah 1 in the NBLA

Micah 1 in the NBS

Micah 1 in the NBVTP

Micah 1 in the NET2

Micah 1 in the NIV11

Micah 1 in the NNT

Micah 1 in the NNT2

Micah 1 in the NNT3

Micah 1 in the PDDPT

Micah 1 in the PFNT

Micah 1 in the RMNT

Micah 1 in the SBIAS

Micah 1 in the SBIBS

Micah 1 in the SBIBS2

Micah 1 in the SBICS

Micah 1 in the SBIDS

Micah 1 in the SBIGS

Micah 1 in the SBIHS

Micah 1 in the SBIIS

Micah 1 in the SBIIS2

Micah 1 in the SBIIS3

Micah 1 in the SBIKS

Micah 1 in the SBIKS2

Micah 1 in the SBIMS

Micah 1 in the SBIOS

Micah 1 in the SBIPS

Micah 1 in the SBISS

Micah 1 in the SBITS

Micah 1 in the SBITS2

Micah 1 in the SBITS3

Micah 1 in the SBITS4

Micah 1 in the SBIUS

Micah 1 in the SBIVS

Micah 1 in the SBT

Micah 1 in the SBT1E

Micah 1 in the SCHL

Micah 1 in the SNT

Micah 1 in the SUSU

Micah 1 in the SUSU2

Micah 1 in the SYNO

Micah 1 in the TBIAOTANT

Micah 1 in the TBT1E

Micah 1 in the TBT1E2

Micah 1 in the TFTIP

Micah 1 in the TFTU

Micah 1 in the TGNTATF3T

Micah 1 in the THAI

Micah 1 in the TNFD

Micah 1 in the TNT

Micah 1 in the TNTIK

Micah 1 in the TNTIL

Micah 1 in the TNTIN

Micah 1 in the TNTIP

Micah 1 in the TNTIZ

Micah 1 in the TOMA

Micah 1 in the TTENT

Micah 1 in the UBG

Micah 1 in the UGV

Micah 1 in the UGV2

Micah 1 in the UGV3

Micah 1 in the VBL

Micah 1 in the VDCC

Micah 1 in the YALU

Micah 1 in the YAPE

Micah 1 in the YBVTP

Micah 1 in the ZBP