Numbers 27 (BOYCB)

1 Ọmọbìnrin Selofehadi ọmọ Heferi, ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri ọmọ Manase tó jẹ́ ìdílé Manase, ọmọ Josẹfu wá. Orúkọ àwọn ọmọbìnrin náà ni Mahila, Noa, Hogla, Milka àti Tirsa. 2 Wọ́n súnmọ́ ẹnu-ọ̀nà àgọ́ ìpàdé wọ́n sì dúró níwájú Mose, àti Eleasari àlùfáà, àti níwájú àwọn olórí àti ìjọ, wọ́n sì wí pé, 3 “Baba wa kú sí aginjù. Kò sí lára àwọn ẹgbẹ́ Kora tí wọ́n kó ara wọn pọ̀ lòdì sí OLÚWA, ṣùgbọ́n ó kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kò sì fi ọmọkùnrin sílẹ̀. 4 Kín ni ó dé tí orúkọ baba wa yóò parẹ́ nínú ìdílé rẹ̀ nítorí pé kò ní ọmọkùnrin? Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrín àwọn arákùnrin baba wa.” 5 Nígbà náà Mose mú ọ̀rọ̀ wọn wá síwájú OLÚWA. 6 OLÚWA sì wí fún un pé, 7 “Ohun tí àwọn ọmọbìnrin Selofehadi ń sọ tọ̀nà. O gbọdọ̀ fún wọn ní ogún ìní ti baba wọn. 8 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli, ‘Tí ọkùnrin kan bá kú tí kò sì fi ọmọkùnrin sáyé, ẹ fún àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ ní ogún ìní rẹ̀. 9 Tí kò bá ní ọmọbìnrin, fi ohun ìní rẹ́ fún àwọn arákùnrin rẹ̀. 10 Tí kò bá ní arákùnrin, fi ogún ìní rẹ̀ fún arákùnrin baba rẹ̀. 11 Tí baba rẹ̀ kò bá ní arákùnrin, fún ará ilé rẹ̀ tí ó bá súnmọ́ jù ní ìdílé rẹ̀ ní ogún ìní rẹ̀, kí ó lè jogún rẹ̀. Èyí gbọdọ̀ jẹ́ ìlànà ìdájọ́ fún àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mose.’ ” 12 Nígbà náà OLÚWA sọ fún Mose pé, “Lọ sì orí òkè Abarimu yìí, kí o sì lọ wo ilẹ̀ tí mo fún àwọn ọmọ Israẹli. 13 Lẹ́yìn ìgbà tí o bá sì ti rí i, ìwọ náà yóò darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn rẹ gẹ́gẹ́ bí Aaroni arákùnrin rẹ ṣe ṣe, 14 nítorí nígbà tí ìlú ṣọ̀tẹ̀ níbi omi ní aginjù Sini, tí gbogbo yín ṣe àìgbọ́ràn sí mi láti yà mí sí mímọ́ níwájú wọn.” (Èyí ni omi Meriba ní Kadeṣi ní aginjù Sini.) 15 Mose sọ fún OLÚWA wí pé, 16 “Jẹ́ kí OLÚWA, Ọlọ́run ẹ̀mí gbogbo ènìyàn, kí ó yan ọkùnrin kan sí orí ìjọ ènìyàn yìí, 17 láti máa darí wọn, ẹni tí yóò mú wọn jáde, tí yóò sì mú wọn wọlé, gbogbo ènìyàn OLÚWA kí yóò dàbí àgùntàn tí kò ní olùṣọ́.” 18 Nígbà náà ní OLÚWA sọ fún Mose pé, “Mú Joṣua ọmọ Nuni, ọkùnrin nínú ẹni tí èmi wà, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e. 19 Jẹ́ kí ó dúró níwájú Eleasari àlùfáà àti ojú gbogbo àwọn ìjọ ènìyàn Israẹli kí o sì fi àṣẹ fún un ní ojú wọn. 20 Kí ìwọ kí ó sì fi nínú ọláńlá rẹ sí i lára, kí gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli kí ó lè gbọ́rọ̀ sí i lẹ́nu. 21 Kí ó dúró níwájú Eleasari àlùfáà, tí yóò gba ìpinnu fún láti béèrè Urimu níwájú OLÚWA. Gẹ́gẹ́ bí òfin yìí ni òun pẹ̀lú gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli yóò jáde lọ, pẹ̀lú òfin rẹ̀ sì ni wọn ó wọlé.” 22 Mose sì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti sọ fún un. Ó mú Joṣua ó sì mú kí ó dúró níwájú Eleasari àlùfáà àti níwájú gbogbo ìjọ. 23 Nígbà náà ni ó gbé ọwọ́ rẹ̀ le e, ó sì fi àṣẹ fún un gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mose.

In Other Versions

Numbers 27 in the ANGEFD

Numbers 27 in the ANTPNG2D

Numbers 27 in the AS21

Numbers 27 in the BAGH

Numbers 27 in the BBPNG

Numbers 27 in the BBT1E

Numbers 27 in the BDS

Numbers 27 in the BEV

Numbers 27 in the BHAD

Numbers 27 in the BIB

Numbers 27 in the BLPT

Numbers 27 in the BNT

Numbers 27 in the BNTABOOT

Numbers 27 in the BNTLV

Numbers 27 in the BOATCB

Numbers 27 in the BOATCB2

Numbers 27 in the BOBCV

Numbers 27 in the BOCNT

Numbers 27 in the BOECS

Numbers 27 in the BOGWICC

Numbers 27 in the BOHCB

Numbers 27 in the BOHCV

Numbers 27 in the BOHLNT

Numbers 27 in the BOHNTLTAL

Numbers 27 in the BOICB

Numbers 27 in the BOILNTAP

Numbers 27 in the BOITCV

Numbers 27 in the BOKCV

Numbers 27 in the BOKCV2

Numbers 27 in the BOKHWOG

Numbers 27 in the BOKSSV

Numbers 27 in the BOLCB

Numbers 27 in the BOLCB2

Numbers 27 in the BOMCV

Numbers 27 in the BONAV

Numbers 27 in the BONCB

Numbers 27 in the BONLT

Numbers 27 in the BONUT2

Numbers 27 in the BOPLNT

Numbers 27 in the BOSCB

Numbers 27 in the BOSNC

Numbers 27 in the BOTLNT

Numbers 27 in the BOVCB

Numbers 27 in the BPBB

Numbers 27 in the BPH

Numbers 27 in the BSB

Numbers 27 in the CCB

Numbers 27 in the CUV

Numbers 27 in the CUVS

Numbers 27 in the DBT

Numbers 27 in the DGDNT

Numbers 27 in the DHNT

Numbers 27 in the DNT

Numbers 27 in the ELBE

Numbers 27 in the EMTV

Numbers 27 in the ESV

Numbers 27 in the FBV

Numbers 27 in the FEB

Numbers 27 in the GGMNT

Numbers 27 in the GNT

Numbers 27 in the HARY

Numbers 27 in the HNT

Numbers 27 in the IRVA

Numbers 27 in the IRVB

Numbers 27 in the IRVG

Numbers 27 in the IRVH

Numbers 27 in the IRVK

Numbers 27 in the IRVM

Numbers 27 in the IRVM2

Numbers 27 in the IRVO

Numbers 27 in the IRVP

Numbers 27 in the IRVT

Numbers 27 in the IRVT2

Numbers 27 in the IRVU

Numbers 27 in the ISVN

Numbers 27 in the JSNT

Numbers 27 in the KAPI

Numbers 27 in the KBT1ETNIK

Numbers 27 in the KBV

Numbers 27 in the KJV

Numbers 27 in the KNFD

Numbers 27 in the LBA

Numbers 27 in the LBLA

Numbers 27 in the LNT

Numbers 27 in the LSV

Numbers 27 in the MAAL

Numbers 27 in the MBV

Numbers 27 in the MBV2

Numbers 27 in the MHNT

Numbers 27 in the MKNFD

Numbers 27 in the MNG

Numbers 27 in the MNT

Numbers 27 in the MNT2

Numbers 27 in the MRS1T

Numbers 27 in the NAA

Numbers 27 in the NASB

Numbers 27 in the NBLA

Numbers 27 in the NBS

Numbers 27 in the NBVTP

Numbers 27 in the NET2

Numbers 27 in the NIV11

Numbers 27 in the NNT

Numbers 27 in the NNT2

Numbers 27 in the NNT3

Numbers 27 in the PDDPT

Numbers 27 in the PFNT

Numbers 27 in the RMNT

Numbers 27 in the SBIAS

Numbers 27 in the SBIBS

Numbers 27 in the SBIBS2

Numbers 27 in the SBICS

Numbers 27 in the SBIDS

Numbers 27 in the SBIGS

Numbers 27 in the SBIHS

Numbers 27 in the SBIIS

Numbers 27 in the SBIIS2

Numbers 27 in the SBIIS3

Numbers 27 in the SBIKS

Numbers 27 in the SBIKS2

Numbers 27 in the SBIMS

Numbers 27 in the SBIOS

Numbers 27 in the SBIPS

Numbers 27 in the SBISS

Numbers 27 in the SBITS

Numbers 27 in the SBITS2

Numbers 27 in the SBITS3

Numbers 27 in the SBITS4

Numbers 27 in the SBIUS

Numbers 27 in the SBIVS

Numbers 27 in the SBT

Numbers 27 in the SBT1E

Numbers 27 in the SCHL

Numbers 27 in the SNT

Numbers 27 in the SUSU

Numbers 27 in the SUSU2

Numbers 27 in the SYNO

Numbers 27 in the TBIAOTANT

Numbers 27 in the TBT1E

Numbers 27 in the TBT1E2

Numbers 27 in the TFTIP

Numbers 27 in the TFTU

Numbers 27 in the TGNTATF3T

Numbers 27 in the THAI

Numbers 27 in the TNFD

Numbers 27 in the TNT

Numbers 27 in the TNTIK

Numbers 27 in the TNTIL

Numbers 27 in the TNTIN

Numbers 27 in the TNTIP

Numbers 27 in the TNTIZ

Numbers 27 in the TOMA

Numbers 27 in the TTENT

Numbers 27 in the UBG

Numbers 27 in the UGV

Numbers 27 in the UGV2

Numbers 27 in the UGV3

Numbers 27 in the VBL

Numbers 27 in the VDCC

Numbers 27 in the YALU

Numbers 27 in the YAPE

Numbers 27 in the YBVTP

Numbers 27 in the ZBP