Numbers 34 (BOYCB)
1 OLÚWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Tí ẹ bá wọ Kenaani, ilẹ̀ tí a ó fi fún yín, gẹ́gẹ́ bí ogún yín yóò ní ààlà wọn yí: 3 “ ‘Ìhà gúúsù yín yóò bọ́ sí ara aginjù Sini lẹ́bàá Edomu, àti ìlà-oòrùn, ààlà ìhà gúúsù yóò bẹ̀rẹ̀ láti òpin Òkun Iyọ̀, 4 kọjá lọ sí gúúsù Akrabbimu, tẹ̀síwájú lọ si Sini, kó bọ́ si gúúsù Kadeṣi-Barnea, kí o sì dé Hasari-Addari, kí o sì kọjá sí Asmoni. 5 Kí òpin ilẹ̀ rẹ̀ kí ó sì yíká láti Asmoni lọ dé odò Ejibiti, Òkun Ńlá ni yóò sì jẹ òpin rẹ. 6 Ìhà ìwọ̀-oòrùn yín yóò jẹ́ òpin lórí Òkun Ńlá. Èyí yóò jẹ́ ààlà yín lórí ìhà ìwọ̀-oòrùn. 7 Fún ààlà ìhà àríwá, fa ìlà láti Òkun Ńlá lọ sí orí òkè Hori, 8 àti láti orí òkè Hori sí Lebo-Hamati. Nígbà náà ààlà náà yóò lọ sí Sedadi, 9 tẹ̀síwájú lọ sí Sifroni, kí o sì fò pín si ní Hasari-Enani, èyí yóò jẹ́ ààlà tìrẹ ní ìhà àríwá. 10 Kí ẹ sì sàmì sí ilẹ̀ tiyín ní ìhà ìlà-oòrùn láti Hasari-Enani lọ dé Ṣefamu. 11 Ààlà náà yóò ti Ṣefamu sọ̀kalẹ̀ wá lọ sí Ribla ní ìhà ìlà-oòrùn Aini, kí o sì sọ̀kalẹ̀ lọ dé ìhà Òkun Kinnereti ní ìhà ìlà-oòrùn. 12 Nígbà náà, ààlà náà yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sí apá Jordani, yóò sì dópin nínú Òkun Iyọ̀. “ ‘Èyí yóò jẹ́ ilẹ̀ yín, pẹ̀lú ààlà tirẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà.’ ” 13 Mose pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Yan ilẹ̀ yìí pẹ̀lú kèké gẹ́gẹ́ bí ìní ogún: OLÚWA ti pàṣẹ láti fi fún ẹ̀yà mẹ́sàn-án, àti ààbọ̀. 14 Nítorí ará ilẹ̀ ẹ̀yà ti Reubeni, ẹ̀yà Gadi àti ẹ̀yà ààbọ̀ ti Manase ti gba ogún tiwọn. 15 Ẹ̀yà méjèèjì àti ààbọ̀ yìí ti gba ogún tiwọn ní ìhà ìhín Jordani létí i Jeriko, ní ìhà ìlà-oòrùn, ní ìdojúkọ Jordani.” 16 OLÚWA sọ fún Mose pé, 17 “Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin náà tí yóò pín ilẹ̀, náà fún yín gẹ́gẹ́ bí ogún: Eleasari àlùfáà àti Joṣua ọmọ Nuni. 18 Kí o sì yan olórí kan nínú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti pín ilẹ̀ náà. 19 “Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ Jefunne, láti ẹ̀yà Juda; 20 Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni; 21 Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini; 22 Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani; 23 Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu, 24 Kemueli ọmọ Ṣiftani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Efraimu, ọmọ Josẹfu; 25 Elisafani ọmọ Parnaki, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Sebuluni; 26 Paltieli ọmọ Assani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Isakari; 27 Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri; 28 Pedaheli ọmọ Ammihudu, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Naftali.” 29 Èyí ni àwọn ẹni tí OLÚWA yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ Israẹli ní ilẹ̀ Kenaani.
In Other Versions
Numbers 34 in the ANGEFD
Numbers 34 in the ANTPNG2D
Numbers 34 in the AS21
Numbers 34 in the BAGH
Numbers 34 in the BBPNG
Numbers 34 in the BBT1E
Numbers 34 in the BDS
Numbers 34 in the BEV
Numbers 34 in the BHAD
Numbers 34 in the BIB
Numbers 34 in the BLPT
Numbers 34 in the BNT
Numbers 34 in the BNTABOOT
Numbers 34 in the BNTLV
Numbers 34 in the BOATCB
Numbers 34 in the BOATCB2
Numbers 34 in the BOBCV
Numbers 34 in the BOCNT
Numbers 34 in the BOECS
Numbers 34 in the BOGWICC
Numbers 34 in the BOHCB
Numbers 34 in the BOHCV
Numbers 34 in the BOHLNT
Numbers 34 in the BOHNTLTAL
Numbers 34 in the BOICB
Numbers 34 in the BOILNTAP
Numbers 34 in the BOITCV
Numbers 34 in the BOKCV
Numbers 34 in the BOKCV2
Numbers 34 in the BOKHWOG
Numbers 34 in the BOKSSV
Numbers 34 in the BOLCB
Numbers 34 in the BOLCB2
Numbers 34 in the BOMCV
Numbers 34 in the BONAV
Numbers 34 in the BONCB
Numbers 34 in the BONLT
Numbers 34 in the BONUT2
Numbers 34 in the BOPLNT
Numbers 34 in the BOSCB
Numbers 34 in the BOSNC
Numbers 34 in the BOTLNT
Numbers 34 in the BOVCB
Numbers 34 in the BPBB
Numbers 34 in the BPH
Numbers 34 in the BSB
Numbers 34 in the CCB
Numbers 34 in the CUV
Numbers 34 in the CUVS
Numbers 34 in the DBT
Numbers 34 in the DGDNT
Numbers 34 in the DHNT
Numbers 34 in the DNT
Numbers 34 in the ELBE
Numbers 34 in the EMTV
Numbers 34 in the ESV
Numbers 34 in the FBV
Numbers 34 in the FEB
Numbers 34 in the GGMNT
Numbers 34 in the GNT
Numbers 34 in the HARY
Numbers 34 in the HNT
Numbers 34 in the IRVA
Numbers 34 in the IRVB
Numbers 34 in the IRVG
Numbers 34 in the IRVH
Numbers 34 in the IRVK
Numbers 34 in the IRVM
Numbers 34 in the IRVM2
Numbers 34 in the IRVO
Numbers 34 in the IRVP
Numbers 34 in the IRVT
Numbers 34 in the IRVT2
Numbers 34 in the IRVU
Numbers 34 in the ISVN
Numbers 34 in the JSNT
Numbers 34 in the KAPI
Numbers 34 in the KBT1ETNIK
Numbers 34 in the KBV
Numbers 34 in the KJV
Numbers 34 in the KNFD
Numbers 34 in the LBA
Numbers 34 in the LBLA
Numbers 34 in the LNT
Numbers 34 in the LSV
Numbers 34 in the MAAL
Numbers 34 in the MBV
Numbers 34 in the MBV2
Numbers 34 in the MHNT
Numbers 34 in the MKNFD
Numbers 34 in the MNG
Numbers 34 in the MNT
Numbers 34 in the MNT2
Numbers 34 in the MRS1T
Numbers 34 in the NAA
Numbers 34 in the NASB
Numbers 34 in the NBLA
Numbers 34 in the NBS
Numbers 34 in the NBVTP
Numbers 34 in the NET2
Numbers 34 in the NIV11
Numbers 34 in the NNT
Numbers 34 in the NNT2
Numbers 34 in the NNT3
Numbers 34 in the PDDPT
Numbers 34 in the PFNT
Numbers 34 in the RMNT
Numbers 34 in the SBIAS
Numbers 34 in the SBIBS
Numbers 34 in the SBIBS2
Numbers 34 in the SBICS
Numbers 34 in the SBIDS
Numbers 34 in the SBIGS
Numbers 34 in the SBIHS
Numbers 34 in the SBIIS
Numbers 34 in the SBIIS2
Numbers 34 in the SBIIS3
Numbers 34 in the SBIKS
Numbers 34 in the SBIKS2
Numbers 34 in the SBIMS
Numbers 34 in the SBIOS
Numbers 34 in the SBIPS
Numbers 34 in the SBISS
Numbers 34 in the SBITS
Numbers 34 in the SBITS2
Numbers 34 in the SBITS3
Numbers 34 in the SBITS4
Numbers 34 in the SBIUS
Numbers 34 in the SBIVS
Numbers 34 in the SBT
Numbers 34 in the SBT1E
Numbers 34 in the SCHL
Numbers 34 in the SNT
Numbers 34 in the SUSU
Numbers 34 in the SUSU2
Numbers 34 in the SYNO
Numbers 34 in the TBIAOTANT
Numbers 34 in the TBT1E
Numbers 34 in the TBT1E2
Numbers 34 in the TFTIP
Numbers 34 in the TFTU
Numbers 34 in the TGNTATF3T
Numbers 34 in the THAI
Numbers 34 in the TNFD
Numbers 34 in the TNT
Numbers 34 in the TNTIK
Numbers 34 in the TNTIL
Numbers 34 in the TNTIN
Numbers 34 in the TNTIP
Numbers 34 in the TNTIZ
Numbers 34 in the TOMA
Numbers 34 in the TTENT
Numbers 34 in the UBG
Numbers 34 in the UGV
Numbers 34 in the UGV2
Numbers 34 in the UGV3
Numbers 34 in the VBL
Numbers 34 in the VDCC
Numbers 34 in the YALU
Numbers 34 in the YAPE
Numbers 34 in the YBVTP
Numbers 34 in the ZBP