Proverbs 11 (BOYCB)

1 OLÚWA kórìíra òsùwọ̀n èké,ṣùgbọ́n òsùwọ̀n òtítọ́ jẹ́ inú dídùn un rẹ̀. 2 Nígbà tí ìgbéraga bá dé, nígbà náà ni ìdójútì dé,ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ ni ọgbọ́n ń wá. 3 Òtítọ́ inú ẹni dídúró ṣinṣin ń ṣe amọ̀nà rẹ̀,ṣùgbọ́n aláìṣòótọ́ yóò parun nípasẹ̀ àìṣòótọ́ wọn. 4 Ọ̀rọ̀ kò níláárí ní ọjọ́ ìbínú,ṣùgbọ́n òdodo a máa gbani lọ́wọ́ ikú. 5 Òdodo aláìlẹ́gàn ṣe ọ̀nà tààrà fún wọn,ṣùgbọ́n ìwà búburú ènìyàn búburú yóò fà á lulẹ̀. 6 Òdodo ẹni ìdúró ṣinṣin gbà wọ́n là,ṣùgbọ́n ìdẹ̀kùn ètè búburú mú aláìṣòótọ́. 7 Nígbà tí ènìyàn búburú bá kú, ìrètí rẹ̀ a parun;gbogbo ohun tó ń fojú ṣọ́nà fún nípa agbára rẹ̀ já ṣófo. 8 A gba olódodo kúrò lọ́wọ́ ibi dípò o rẹ̀,ibi wá sórí ènìyàn búburú. 9 Aláìmọ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba aládùúgbò rẹ̀ jẹ́,ṣùgbọ́n nípasẹ̀ ìmọ̀ olódodo sá àsálà. 10 Nígbà tí olódodo ń gbèrú, ìlú a yọ̀;nígbà tí ènìyàn búburú parun, ariwo ayọ̀ gba ìlú kan. 11 Nípasẹ̀ ìbùkún, olódodo a gbé ìlú ga:ṣùgbọ́n nípasẹ̀ ẹnu ènìyàn búburú, a pa ìlú run. 12 Ẹni tí kò gbọ́n fojú kékeré wo aládùúgbò rẹ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ó ní òye pa ẹnu rẹ̀ mọ́. 13 Olófòófó tú àṣírí ìkọ̀kọ̀ṣùgbọ́n ẹni tó ṣe é gbẹ́kẹ̀lé a pa àṣírí mọ́. 14 Nítorí àìní ìtọ́sọ́nà orílẹ̀-èdè ṣubúṣùgbọ́n nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùbádámọ̀ràn ìṣẹ́gun dájú. 15 Ẹni tí ó ṣe onígbọ̀wọ́ fún àlejò yóò rí ìyọnu,ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó kọ̀ láti ṣe onígbọ̀wọ́ yóò wà láìléwu. 16 Obìnrin oníwà rere gba ìyìnṣùgbọ́n alágbára aláìbìkítà ènìyàn gba ọrọ̀ nìkan. 17 Ènìyàn rere ń ṣe ara rẹ̀ lóoreṣùgbọ́n ènìyàn ìkà ń mú ìyọnu wá sórí ara rẹ̀. 18 Ènìyàn búburú gba èrè ìtànjẹṣùgbọ́n ẹni tó fúnrúgbìn òdodo yóò gba èrè tó dájú. 19 Olódodo tòótọ́ rí ìyèṣùgbọ́n ẹni tí ń lépa ibi lé e sí ibi ikú ara rẹ̀. 20 OLÚWA kórìíra àwọn ènìyàn ọlọ́kàn búburúṣùgbọ́n ó ní inú dídùn sí àwọn tí ọ̀nà wọn kò lábùkù. 21 Mọ èyí dájú pé, ènìyàn búburú kì yóò lọ láìjìyà,ṣùgbọ́n àwọn olódodo yóò lọ láìjìyà. 22 Bí òrùka wúrà ní imú ẹlẹ́dẹ̀ni arẹwà obìnrin tí kò lọ́gbọ́n. 23 Ìfẹ́ inú olódodo yóò yọrí sí ohun rereṣùgbọ́n ìrètí ènìyàn búburú yóò yọrí sí ìbínú. 24 Ènìyàn kan ń fún ni lọ́fẹ̀ẹ́, síbẹ̀ ó ń ní sí i;òmíràn ń háwọ́ ju bí ó ti yẹ ṣùgbọ́n ó di aláìní. 25 Ẹni tí ń ṣoore yóò máa gbèrú sí i;ẹni tí ó tu ẹlòmíràn lára yóò ní ìtura. 26 Àwọn ènìyàn a ṣẹ́ èpè lé ènìyàn tí ń kó oúnjẹ pamọ́ṣùgbọ́n ìbùkún a máa wá sórí ẹni tí ó ṣetán láti tà. 27 Ẹni tí ń lépa ohun rere yóò rí ohun rereṣùgbọ́n ibi yóò dé bá ẹni tí ń lépa ibi. 28 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ rẹ̀ yóò ṣubú;ṣùgbọ́n olódodo yóò gbilẹ̀ bí i koríko tútù. 29 Ẹni tí ó ń mú ìdààmú dé bá ìdílé rẹ̀ yóò jogún afẹ́fẹ́ lásánaláìgbọ́n yóò sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọlọ́gbọ́n. 30 Èso òdodo ni igi ìyèẹni tí ó sì jèrè ọkàn jẹ́ ọlọ́gbọ́n. 31 Bí àwọn olódodo bá gba ìpín wọn lórí ilẹ̀ ayémélòó mélòó ni ènìyàn búburú àti àwọn tó dẹ́ṣẹ̀!

In Other Versions

Proverbs 11 in the ANGEFD

Proverbs 11 in the ANTPNG2D

Proverbs 11 in the AS21

Proverbs 11 in the BAGH

Proverbs 11 in the BBPNG

Proverbs 11 in the BBT1E

Proverbs 11 in the BDS

Proverbs 11 in the BEV

Proverbs 11 in the BHAD

Proverbs 11 in the BIB

Proverbs 11 in the BLPT

Proverbs 11 in the BNT

Proverbs 11 in the BNTABOOT

Proverbs 11 in the BNTLV

Proverbs 11 in the BOATCB

Proverbs 11 in the BOATCB2

Proverbs 11 in the BOBCV

Proverbs 11 in the BOCNT

Proverbs 11 in the BOECS

Proverbs 11 in the BOGWICC

Proverbs 11 in the BOHCB

Proverbs 11 in the BOHCV

Proverbs 11 in the BOHLNT

Proverbs 11 in the BOHNTLTAL

Proverbs 11 in the BOICB

Proverbs 11 in the BOILNTAP

Proverbs 11 in the BOITCV

Proverbs 11 in the BOKCV

Proverbs 11 in the BOKCV2

Proverbs 11 in the BOKHWOG

Proverbs 11 in the BOKSSV

Proverbs 11 in the BOLCB

Proverbs 11 in the BOLCB2

Proverbs 11 in the BOMCV

Proverbs 11 in the BONAV

Proverbs 11 in the BONCB

Proverbs 11 in the BONLT

Proverbs 11 in the BONUT2

Proverbs 11 in the BOPLNT

Proverbs 11 in the BOSCB

Proverbs 11 in the BOSNC

Proverbs 11 in the BOTLNT

Proverbs 11 in the BOVCB

Proverbs 11 in the BPBB

Proverbs 11 in the BPH

Proverbs 11 in the BSB

Proverbs 11 in the CCB

Proverbs 11 in the CUV

Proverbs 11 in the CUVS

Proverbs 11 in the DBT

Proverbs 11 in the DGDNT

Proverbs 11 in the DHNT

Proverbs 11 in the DNT

Proverbs 11 in the ELBE

Proverbs 11 in the EMTV

Proverbs 11 in the ESV

Proverbs 11 in the FBV

Proverbs 11 in the FEB

Proverbs 11 in the GGMNT

Proverbs 11 in the GNT

Proverbs 11 in the HARY

Proverbs 11 in the HNT

Proverbs 11 in the IRVA

Proverbs 11 in the IRVB

Proverbs 11 in the IRVG

Proverbs 11 in the IRVH

Proverbs 11 in the IRVK

Proverbs 11 in the IRVM

Proverbs 11 in the IRVM2

Proverbs 11 in the IRVO

Proverbs 11 in the IRVP

Proverbs 11 in the IRVT

Proverbs 11 in the IRVT2

Proverbs 11 in the IRVU

Proverbs 11 in the ISVN

Proverbs 11 in the JSNT

Proverbs 11 in the KAPI

Proverbs 11 in the KBT1ETNIK

Proverbs 11 in the KBV

Proverbs 11 in the KJV

Proverbs 11 in the KNFD

Proverbs 11 in the LBA

Proverbs 11 in the LBLA

Proverbs 11 in the LNT

Proverbs 11 in the LSV

Proverbs 11 in the MAAL

Proverbs 11 in the MBV

Proverbs 11 in the MBV2

Proverbs 11 in the MHNT

Proverbs 11 in the MKNFD

Proverbs 11 in the MNG

Proverbs 11 in the MNT

Proverbs 11 in the MNT2

Proverbs 11 in the MRS1T

Proverbs 11 in the NAA

Proverbs 11 in the NASB

Proverbs 11 in the NBLA

Proverbs 11 in the NBS

Proverbs 11 in the NBVTP

Proverbs 11 in the NET2

Proverbs 11 in the NIV11

Proverbs 11 in the NNT

Proverbs 11 in the NNT2

Proverbs 11 in the NNT3

Proverbs 11 in the PDDPT

Proverbs 11 in the PFNT

Proverbs 11 in the RMNT

Proverbs 11 in the SBIAS

Proverbs 11 in the SBIBS

Proverbs 11 in the SBIBS2

Proverbs 11 in the SBICS

Proverbs 11 in the SBIDS

Proverbs 11 in the SBIGS

Proverbs 11 in the SBIHS

Proverbs 11 in the SBIIS

Proverbs 11 in the SBIIS2

Proverbs 11 in the SBIIS3

Proverbs 11 in the SBIKS

Proverbs 11 in the SBIKS2

Proverbs 11 in the SBIMS

Proverbs 11 in the SBIOS

Proverbs 11 in the SBIPS

Proverbs 11 in the SBISS

Proverbs 11 in the SBITS

Proverbs 11 in the SBITS2

Proverbs 11 in the SBITS3

Proverbs 11 in the SBITS4

Proverbs 11 in the SBIUS

Proverbs 11 in the SBIVS

Proverbs 11 in the SBT

Proverbs 11 in the SBT1E

Proverbs 11 in the SCHL

Proverbs 11 in the SNT

Proverbs 11 in the SUSU

Proverbs 11 in the SUSU2

Proverbs 11 in the SYNO

Proverbs 11 in the TBIAOTANT

Proverbs 11 in the TBT1E

Proverbs 11 in the TBT1E2

Proverbs 11 in the TFTIP

Proverbs 11 in the TFTU

Proverbs 11 in the TGNTATF3T

Proverbs 11 in the THAI

Proverbs 11 in the TNFD

Proverbs 11 in the TNT

Proverbs 11 in the TNTIK

Proverbs 11 in the TNTIL

Proverbs 11 in the TNTIN

Proverbs 11 in the TNTIP

Proverbs 11 in the TNTIZ

Proverbs 11 in the TOMA

Proverbs 11 in the TTENT

Proverbs 11 in the UBG

Proverbs 11 in the UGV

Proverbs 11 in the UGV2

Proverbs 11 in the UGV3

Proverbs 11 in the VBL

Proverbs 11 in the VDCC

Proverbs 11 in the YALU

Proverbs 11 in the YAPE

Proverbs 11 in the YBVTP

Proverbs 11 in the ZBP