1 Kings 4 (BOYCB)
1 Solomoni ọba sì jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli. 2 Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè rẹ̀: Asariah ọmọ Sadoku àlùfáà: 3 Elihorefu àti Ahijah àwọn ọmọ Ṣisa akọ̀wé;Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni akọ̀wé ìlú; 4 Benaiah ọmọ Jehoiada ni olórí ogun;Sadoku àti Abiatari ni àwọn àlùfáà; 5 Asariah ọmọ Natani ni olórí àwọn agbègbè;Sabudu ọmọ Natani, àlùfáà àti olùgba ọba ní ìmọ̀ràn; 6 Ahiṣari ni olùtọ́jú ààfin;Adoniramu ọmọ Abida ni ó ń ṣe olórí iṣẹ́-ìlú. 7 Solomoni sì tún ní ìjòyè méjìlá lórí gbogbo agbègbè Israẹli, tí wọ́n ń pèsè oúnjẹ fún ọba àti agbo ilé rẹ̀. Olúkúlùkù ní láti pèsè fún oṣù kan ní ọdún. 8 Orúkọ wọn ni wọ̀nyí: Bene-Huri ní ìlú olókè Efraimu. 9 Bene-Dekeri ní Makasi, Ṣaalbimu, Beti-Ṣemeṣi, àti Eloni Beti-Hanani; 10 Bene-Hesedi, ní Aruboti (tirẹ̀ ni Soko àti gbogbo ilẹ̀ Heferi ń ṣe); 11 Bene-Abinadabu, ní Napoti (Dori; òun ni ó fẹ́ Tafati ọmọbìnrin Solomoni ní aya). 12 Baana ọmọ Ahiludi, ní Taanaki àti Megido, àti ní gbogbo Beti-Ṣeani tí ń bẹ níhà Saretani ní ìsàlẹ̀ Jesreeli, láti Beti-Ṣeani dé Abeli-Mehola títí dé ibi tí ń bẹ ní ìkọjá Jokimeamu. 13 Ọmọ Geberi ní Ramoti Gileadi (tirẹ̀ ni àwọn ìletò Jairi ọmọ Manase tí ń bẹ ní Gileadi, tirẹ̀ sì ni agbègbè Argobu, tí ń bẹ ní Baṣani, ọgọ́ta ìlú tí ó tóbi pẹ̀lú odi tí ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ irin). 14 Ahinadabu ọmọ Iddo ní Mahanaimu 15 Ahimasi ní Naftali (ó fẹ́ Basemati ọmọbìnrin Solomoni ní aya). 16 Baana ọmọ Huṣai ní Aṣeri àti ní Aloti; 17 Jehoṣafati ọmọ Parua ni ó wà ní Isakari; 18 Ṣimei ọmọ Ela ni Benjamini; 19 Geberi ọmọ Uri ní Gileadi (orílẹ̀-èdè Sihoni ọba àwọn ará Amori àti orílẹ̀-èdè Ogu ọba Baṣani). Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà. 20 Àwọn ènìyàn Juda àti ti Israẹli pọ̀ gẹ́gẹ́ bí iyanrìn tí ń bẹ ní etí Òkun; wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu, wọ́n sì ń yọ ayọ̀. 21 Solomoni sì ń ṣàkóso lórí gbogbo àwọn ìjọba láti odò Eufurate títí dé ilẹ̀ àwọn ará Filistini, àti títí dé etí ilẹ̀ Ejibiti. Àwọn orílẹ̀-èdè yìí ń mú owó òde wá, wọ́n sì ń sin Solomoni ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀. 22 Oúnjẹ Solomoni fún ọjọ́ kan jásí ọgbọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná àti ọgọ́ta òsùwọ̀n ìyẹ̀fun, 23 Màlúù mẹ́wàá tí ó sanra, àti ogún màlúù láti inú pápá wá, àti ọgọ́rùn-ún àgùntàn àti ewúrẹ́, láìka àgbọ̀nrín àti èsúró, àti ogbúgbu, àti ẹyẹ tí ó sanra. 24 Nítorí òun ni ó ṣàkóso lórí gbogbo agbègbè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn odò Eufurate, láti Tifisa títí dé Gasa, lórí gbogbo àwọn ọba ní ìhà ìhín odò, ó sì ní àlàáfíà ní gbogbo ìlú tí ó yí i káàkiri. 25 Nígbà ayé Solomoni, Juda àti Israẹli, láti Dani títí dé Beerṣeba, wọ́n ń gbé ní àlàáfíà, olúkúlùkù lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀. 26 Solomoni sì ní ẹgbàajì (4,000) ilé ẹṣin fún kẹ̀kẹ́ rẹ̀, àti ẹgbàá mẹ́fà (12,000) ẹlẹ́ṣin. 27 Àwọn ìjòyè agbègbè, olúkúlùkù ní oṣù rẹ̀, ń pèsè oúnjẹ fún Solomoni ọba àti gbogbo àwọn tí ń wá sí ibi tábìlì ọba, wọ́n sì rí i pé ohun kankan kò ṣẹ́kù. 28 Wọ́n tún máa ń mú ọkà barle àti koríko fún ẹṣin àti fún ẹṣin sísáré wá pẹ̀lú sí ibi tí ó yẹ, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí ìlànà tirẹ̀. 29 Ọlọ́run sì fún Solomoni ní ọgbọ́n, àti òye ní ọ̀pọ̀lọpọ̀, àti ìmọ̀ gbígbòòrò òye tí a kò le è fiwé iyanrìn tí ó wà létí Òkun. 30 Ọgbọ́n Solomoni sì pọ̀ ju ọgbọ́n ọkùnrin ìlà-oòrùn lọ, ó sì pọ̀ ju gbogbo ọgbọ́n Ejibiti lọ. 31 Ó sì ní òye ju gbogbo ènìyàn lọ, ju Etani, ará Esra, àti Hemani àti Kalkoli, àti Darda àwọn ọmọ Maholi lọ. Òkìkí rẹ̀ sì kàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè yíká. 32 Ó sì pa ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) òwe, àwọn orin rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé márùn-ún (1,005). 33 Ó sì sọ̀rọ̀ ti igi, láti kedari tí ń bẹ ní Lebanoni dé Hísópù tí ń dàgbà lára ògiri. Ó sì tún sọ ti àwọn ẹranko àti ti àwọn ẹyẹ, àti ohun tí ń rákò àti ti ẹja. 34 Àwọn ènìyàn sì ń wá láti gbogbo orílẹ̀-èdè láti gbọ́ ọgbọ́n Solomoni, láti ọ̀dọ̀ àwọn ọba ayé láti wá gbọ́ nípa ọgbọ́n rẹ̀.
In Other Versions
1 Kings 4 in the ANGEFD
1 Kings 4 in the ANTPNG2D
1 Kings 4 in the AS21
1 Kings 4 in the BAGH
1 Kings 4 in the BBPNG
1 Kings 4 in the BBT1E
1 Kings 4 in the BDS
1 Kings 4 in the BEV
1 Kings 4 in the BHAD
1 Kings 4 in the BIB
1 Kings 4 in the BLPT
1 Kings 4 in the BNT
1 Kings 4 in the BNTABOOT
1 Kings 4 in the BNTLV
1 Kings 4 in the BOATCB
1 Kings 4 in the BOATCB2
1 Kings 4 in the BOBCV
1 Kings 4 in the BOCNT
1 Kings 4 in the BOECS
1 Kings 4 in the BOGWICC
1 Kings 4 in the BOHCB
1 Kings 4 in the BOHCV
1 Kings 4 in the BOHLNT
1 Kings 4 in the BOHNTLTAL
1 Kings 4 in the BOICB
1 Kings 4 in the BOILNTAP
1 Kings 4 in the BOITCV
1 Kings 4 in the BOKCV
1 Kings 4 in the BOKCV2
1 Kings 4 in the BOKHWOG
1 Kings 4 in the BOKSSV
1 Kings 4 in the BOLCB
1 Kings 4 in the BOLCB2
1 Kings 4 in the BOMCV
1 Kings 4 in the BONAV
1 Kings 4 in the BONCB
1 Kings 4 in the BONLT
1 Kings 4 in the BONUT2
1 Kings 4 in the BOPLNT
1 Kings 4 in the BOSCB
1 Kings 4 in the BOSNC
1 Kings 4 in the BOTLNT
1 Kings 4 in the BOVCB
1 Kings 4 in the BPBB
1 Kings 4 in the BPH
1 Kings 4 in the BSB
1 Kings 4 in the CCB
1 Kings 4 in the CUV
1 Kings 4 in the CUVS
1 Kings 4 in the DBT
1 Kings 4 in the DGDNT
1 Kings 4 in the DHNT
1 Kings 4 in the DNT
1 Kings 4 in the ELBE
1 Kings 4 in the EMTV
1 Kings 4 in the ESV
1 Kings 4 in the FBV
1 Kings 4 in the FEB
1 Kings 4 in the GGMNT
1 Kings 4 in the GNT
1 Kings 4 in the HARY
1 Kings 4 in the HNT
1 Kings 4 in the IRVA
1 Kings 4 in the IRVB
1 Kings 4 in the IRVG
1 Kings 4 in the IRVH
1 Kings 4 in the IRVK
1 Kings 4 in the IRVM
1 Kings 4 in the IRVM2
1 Kings 4 in the IRVO
1 Kings 4 in the IRVP
1 Kings 4 in the IRVT
1 Kings 4 in the IRVT2
1 Kings 4 in the IRVU
1 Kings 4 in the ISVN
1 Kings 4 in the JSNT
1 Kings 4 in the KAPI
1 Kings 4 in the KBT1ETNIK
1 Kings 4 in the KBV
1 Kings 4 in the KJV
1 Kings 4 in the KNFD
1 Kings 4 in the LBA
1 Kings 4 in the LBLA
1 Kings 4 in the LNT
1 Kings 4 in the LSV
1 Kings 4 in the MAAL
1 Kings 4 in the MBV
1 Kings 4 in the MBV2
1 Kings 4 in the MHNT
1 Kings 4 in the MKNFD
1 Kings 4 in the MNG
1 Kings 4 in the MNT
1 Kings 4 in the MNT2
1 Kings 4 in the MRS1T
1 Kings 4 in the NAA
1 Kings 4 in the NASB
1 Kings 4 in the NBLA
1 Kings 4 in the NBS
1 Kings 4 in the NBVTP
1 Kings 4 in the NET2
1 Kings 4 in the NIV11
1 Kings 4 in the NNT
1 Kings 4 in the NNT2
1 Kings 4 in the NNT3
1 Kings 4 in the PDDPT
1 Kings 4 in the PFNT
1 Kings 4 in the RMNT
1 Kings 4 in the SBIAS
1 Kings 4 in the SBIBS
1 Kings 4 in the SBIBS2
1 Kings 4 in the SBICS
1 Kings 4 in the SBIDS
1 Kings 4 in the SBIGS
1 Kings 4 in the SBIHS
1 Kings 4 in the SBIIS
1 Kings 4 in the SBIIS2
1 Kings 4 in the SBIIS3
1 Kings 4 in the SBIKS
1 Kings 4 in the SBIKS2
1 Kings 4 in the SBIMS
1 Kings 4 in the SBIOS
1 Kings 4 in the SBIPS
1 Kings 4 in the SBISS
1 Kings 4 in the SBITS
1 Kings 4 in the SBITS2
1 Kings 4 in the SBITS3
1 Kings 4 in the SBITS4
1 Kings 4 in the SBIUS
1 Kings 4 in the SBIVS
1 Kings 4 in the SBT
1 Kings 4 in the SBT1E
1 Kings 4 in the SCHL
1 Kings 4 in the SNT
1 Kings 4 in the SUSU
1 Kings 4 in the SUSU2
1 Kings 4 in the SYNO
1 Kings 4 in the TBIAOTANT
1 Kings 4 in the TBT1E
1 Kings 4 in the TBT1E2
1 Kings 4 in the TFTIP
1 Kings 4 in the TFTU
1 Kings 4 in the TGNTATF3T
1 Kings 4 in the THAI
1 Kings 4 in the TNFD
1 Kings 4 in the TNT
1 Kings 4 in the TNTIK
1 Kings 4 in the TNTIL
1 Kings 4 in the TNTIN
1 Kings 4 in the TNTIP
1 Kings 4 in the TNTIZ
1 Kings 4 in the TOMA
1 Kings 4 in the TTENT
1 Kings 4 in the UBG
1 Kings 4 in the UGV
1 Kings 4 in the UGV2
1 Kings 4 in the UGV3
1 Kings 4 in the VBL
1 Kings 4 in the VDCC
1 Kings 4 in the YALU
1 Kings 4 in the YAPE
1 Kings 4 in the YBVTP
1 Kings 4 in the ZBP