3 John 1 (BOYCB)
1 Alàgbà, Sì Gaiusi, olùfẹ́, ẹni tí mo fẹ́ nínú òtítọ́. 2 Olùfẹ́, èmi ń gbàdúrà pé nínú ohun gbogbo kí o lè máa dára fún ọ, kí o sì máa wà ni ìlera, àní bí o tí dára fún ọkàn rẹ. 3 Nítorí mo yọ̀ gidigidi, nígbà tí àwọn arákùnrin dé tí wọn sì jẹ́rìí sí ìwà òtítọ́ inú rẹ̀, àní bí ìwọ tí ń rìn nínú òtítọ́. 4 Èmi ni ayọ̀ tí ó tayọ, láti máa gbọ́ pé, àwọn ọmọ mi ń rìn nínú òtítọ́. 5 Olùfẹ́, ìwọ ń ṣe olóòtítọ́ nínú iṣẹ́ tí ìwọ ń ṣe fún àwọn tí ń ṣe ará, àti pàápàá fún àwọn tí ń ṣe àlejò. 6 Tí wọn ń jẹ́rìí sí ìfẹ́ rẹ̀ níwájú ìjọ, bí ìwọ bá ń pèsè fún wọn ní ọ̀nà àjò wọn gẹ́gẹ́ bí ó tí yẹ nínú Ọlọ́run. 7 Nítorí pé, nítorí iṣẹ́ Kristi ni wọ́n ṣe jáde lọ, láìgba ohunkóhun lọ́wọ́ àwọn aláìkọlà. 8 Nítorí náà, ó yẹ kí àwa fi inú rere gba irú àwọn wọ̀nyí, kí àwa lè jẹ́ alábáṣiṣẹ́pọ̀ pẹ̀lú òtítọ́. 9 Èmi kọ̀wé sí ìjọ ṣùgbọ́n Diotirefe, ẹni tí ó fẹ́ láti jẹ́ ẹni pàtàkì jùlọ, kò gbà wá. 10 Nítorí náà bí mo bá dé, èmi yóò mú iṣẹ́ rẹ̀ tí ó ṣe wá sì ìrántí rẹ, tí ó ń sọ ọ̀rọ̀ búburú àti ìsọkúsọ sí wa, èyí kò sì tún tẹ́ ẹ lọ́rùn, síbẹ̀ òun fúnra rẹ̀ kọ̀ láti gba àwọn ará, àwọn tí ó sì ń fẹ́ gbà wọ́n, ó ń dá wọn lẹ́kun, ó sì ń lé wọn kúrò nínú ìjọ. 11 Olùfẹ́, má ṣe ṣe àfarawé ohun tí í ṣe ibi bí kò ṣe ohun tí ṣe rere. Ẹni tí ó bá ń ṣe rere ti Ọlọ́run ni; ẹni tí ó ba ń ṣe búburú kò rí Ọlọ́run. 12 Demetriusi ní ẹ̀rí rere lọ́dọ̀ gbogbo ènìyàn àti ní ti òtítọ́ fúnra rẹ̀ pẹ̀lú; nítòótọ́, àwa pẹ̀lú sì gba ẹ̀rí rẹ̀ jẹ́; ẹ̀yin sì mọ̀ pé, òtítọ́ ni ẹ̀rí wa. 13 Èmí ní ohun púpọ̀ láti kọ sínú ìwé sí ọ, ṣùgbọ́n èmi kò fẹ́ fi kálàmù àti tawada kọ wọ́n sínú ìwé. 14 Mo ni ìrètí láti rí ọ láìpẹ́, tí àwa yóò sì sọ̀rọ̀ lójúkojú. 15 Àlàáfíà fún ọ. Àwọn ọ̀rẹ́ wa tó wà níbí kí ọ. Kí àwọn ọ̀rẹ́ wa tó wà lọ́dọ̀ rẹ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.
In Other Versions
3 John 1 in the ANGEFD
3 John 1 in the ANTPNG2D
3 John 1 in the AS21
3 John 1 in the BAGH
3 John 1 in the BBPNG
3 John 1 in the BBT1E
3 John 1 in the BDS
3 John 1 in the BEV
3 John 1 in the BHAD
3 John 1 in the BIB
3 John 1 in the BLPT
3 John 1 in the BNT
3 John 1 in the BNTABOOT
3 John 1 in the BNTLV
3 John 1 in the BOATCB
3 John 1 in the BOATCB2
3 John 1 in the BOBCV
3 John 1 in the BOCNT
3 John 1 in the BOECS
3 John 1 in the BOGWICC
3 John 1 in the BOHCB
3 John 1 in the BOHCV
3 John 1 in the BOHLNT
3 John 1 in the BOHNTLTAL
3 John 1 in the BOICB
3 John 1 in the BOILNTAP
3 John 1 in the BOITCV
3 John 1 in the BOKCV
3 John 1 in the BOKCV2
3 John 1 in the BOKHWOG
3 John 1 in the BOKSSV
3 John 1 in the BOLCB
3 John 1 in the BOLCB2
3 John 1 in the BOMCV
3 John 1 in the BONAV
3 John 1 in the BONCB
3 John 1 in the BONLT
3 John 1 in the BONUT2
3 John 1 in the BOPLNT
3 John 1 in the BOSCB
3 John 1 in the BOSNC
3 John 1 in the BOTLNT
3 John 1 in the BOVCB
3 John 1 in the BPBB
3 John 1 in the BPH
3 John 1 in the BSB
3 John 1 in the CCB
3 John 1 in the CUV
3 John 1 in the CUVS
3 John 1 in the DBT
3 John 1 in the DGDNT
3 John 1 in the DHNT
3 John 1 in the DNT
3 John 1 in the ELBE
3 John 1 in the EMTV
3 John 1 in the ESV
3 John 1 in the FBV
3 John 1 in the FEB
3 John 1 in the GGMNT
3 John 1 in the GNT
3 John 1 in the HARY
3 John 1 in the HNT
3 John 1 in the IRVA
3 John 1 in the IRVB
3 John 1 in the IRVG
3 John 1 in the IRVH
3 John 1 in the IRVK
3 John 1 in the IRVM
3 John 1 in the IRVM2
3 John 1 in the IRVO
3 John 1 in the IRVP
3 John 1 in the IRVT
3 John 1 in the IRVT2
3 John 1 in the IRVU
3 John 1 in the ISVN
3 John 1 in the JSNT
3 John 1 in the KAPI
3 John 1 in the KBT1ETNIK
3 John 1 in the KBV
3 John 1 in the KJV
3 John 1 in the KNFD
3 John 1 in the LBA
3 John 1 in the LBLA
3 John 1 in the LNT
3 John 1 in the LSV
3 John 1 in the MAAL
3 John 1 in the MBV
3 John 1 in the MBV2
3 John 1 in the MHNT
3 John 1 in the MKNFD
3 John 1 in the MNG
3 John 1 in the MNT
3 John 1 in the MNT2
3 John 1 in the MRS1T
3 John 1 in the NAA
3 John 1 in the NASB
3 John 1 in the NBLA
3 John 1 in the NBS
3 John 1 in the NBVTP
3 John 1 in the NET2
3 John 1 in the NIV11
3 John 1 in the NNT
3 John 1 in the NNT2
3 John 1 in the NNT3
3 John 1 in the PDDPT
3 John 1 in the PFNT
3 John 1 in the RMNT
3 John 1 in the SBIAS
3 John 1 in the SBIBS
3 John 1 in the SBIBS2
3 John 1 in the SBICS
3 John 1 in the SBIDS
3 John 1 in the SBIGS
3 John 1 in the SBIHS
3 John 1 in the SBIIS
3 John 1 in the SBIIS2
3 John 1 in the SBIIS3
3 John 1 in the SBIKS
3 John 1 in the SBIKS2
3 John 1 in the SBIMS
3 John 1 in the SBIOS
3 John 1 in the SBIPS
3 John 1 in the SBISS
3 John 1 in the SBITS
3 John 1 in the SBITS2
3 John 1 in the SBITS3
3 John 1 in the SBITS4
3 John 1 in the SBIUS
3 John 1 in the SBIVS
3 John 1 in the SBT
3 John 1 in the SBT1E
3 John 1 in the SCHL
3 John 1 in the SNT
3 John 1 in the SUSU
3 John 1 in the SUSU2
3 John 1 in the SYNO
3 John 1 in the TBIAOTANT
3 John 1 in the TBT1E
3 John 1 in the TBT1E2
3 John 1 in the TFTIP
3 John 1 in the TFTU
3 John 1 in the TGNTATF3T
3 John 1 in the THAI
3 John 1 in the TNFD
3 John 1 in the TNT
3 John 1 in the TNTIK
3 John 1 in the TNTIL
3 John 1 in the TNTIN
3 John 1 in the TNTIP
3 John 1 in the TNTIZ
3 John 1 in the TOMA
3 John 1 in the TTENT
3 John 1 in the UBG
3 John 1 in the UGV
3 John 1 in the UGV2
3 John 1 in the UGV3
3 John 1 in the VBL
3 John 1 in the VDCC
3 John 1 in the YALU
3 John 1 in the YAPE
3 John 1 in the YBVTP
3 John 1 in the ZBP